1 Chronicles 13 (BOYCB)
1 Dafidi sì gbèrò pẹ̀lú olúkúlùkù àwọn ìjòyè rẹ̀, àwọn aláṣẹ ẹgbẹẹgbẹ̀rún àti àwọn aláṣẹ ọgọ́rùn-ún 2 Dafidi sì wí fún gbogbo àwọn ìjọ Israẹli pé, tí ó bá dára lójú yín àti tí ó bá ṣe jẹ́ àṣẹ OLÚWA Ọlọ́run wa, jẹ́ kí a ránṣẹ́ sí ọ̀nà jíjìn àti gbígbòòrò sí àwọn arákùnrin wa tókù ní gbogbo àwọn agbègbè ìlú Israẹli àti pẹ̀lú àwọn àlùfáà àti àwọn ará Lefi àwọn tí ó wà pẹ̀lú wọn nínú ìlú wọn àti pápá oko tútù, láti wá kó ara wọn jọ pọ̀ sọ́dọ̀ wa. 3 Ẹ jẹ́ kí a gbé àpótí ẹ̀rí OLÚWA padà sọ́dọ̀ wa, nítorí wí pé àwa kò ṣe ìwádìí nípa rẹ̀ ní àsìkò ìjọba Saulu. 4 Gbogbo ìjọ náà sì gbà láti ṣe èyí nítorí ó dàbí wí pé ó tọ lójú gbogbo àwọn ènìyàn. 5 Nígbà náà ni Dafidi pe gbogbo àwọn ọmọ Israẹli jọ, láti ọ̀dọ̀ Ṣihori ní Ejibiti lọ sí Lebo ní ọ̀nà à bá wọ Hamati, láti gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run padà láti Kiriati-Jearimu. 6 Dafidi àti gbogbo àwọn ọmọ Israẹli pẹ̀lú rẹ̀ lọ sí Baalahi ti Juda (Kiriati-Jearimu) láti gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run OLÚWA tí a fi orúkọ rẹ̀ pè, tí ó jókòó láàrín kérúbù gòkè wá. 7 Wọ́n sì gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run láti ilé Abinadabu lórí kẹ̀kẹ́ tuntun, Ussa àti Ahio ń ṣọ́ ọ. 8 Dafidi àti gbogbo àwọn ọmọ Israẹli ni wọ́n ṣe àjọyọ̀ pẹ̀lú gbogbo agbára wọn níwájú Ọlọ́run, pẹ̀lú orin àti pẹ̀lú dùùrù, ohun èlò orin olókùn, tambori, kimbali pẹ̀lú ìpè. 9 Nígbà tí wọ́n dé sí ilẹ̀ ìpakà Kidoni, Ussa sì na ọwọ́ rẹ̀ síta láti di àpótí ẹ̀rí OLÚWA mú, nítorí màlúù kọsẹ̀. 10 Ìbínú OLÚWA, sì ru sí Ussa, ó sì lù ú bolẹ̀ nítorí o ti fi ọwọ́ rẹ̀ lórí àpótí ẹ̀rí. Bẹ́ẹ̀ ni ó sì kú síbẹ̀ níwájú Ọlọ́run. 11 Nígbà náà Dafidi sì bínú nítorí ìbínú OLÚWA ké jáde lórí Ussa, àti títí di òní, wọ́n sì ń pe ibẹ̀ ní Peresi-Usa. 12 Dafidi sì bẹ̀rù Ọlọ́run ní ọjọ́ náà, ó sì béèrè pé, báwo ni èmi náà ó ṣe gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run sí ọ̀dọ̀ mi? 13 Kò gbé àpótí ẹ̀rí náà wá sí ọ̀dọ̀ ará rẹ̀ ní ìlú ti Dafidi dípò èyí, ó sì gbé e yà sí ilé Obedi-Edomu ará Gitti. 14 Àpótí ẹ̀rí OLÚWA sì wà lọ́dọ̀ àwọn ará ilé Obedi-Edomu ní ilé rẹ̀ fún oṣù mẹ́ta, OLÚWA sì bùkún agbo ilé àti gbogbo ohun tí ó ní.
In Other Versions
1 Chronicles 13 in the ANGEFD
1 Chronicles 13 in the ANTPNG2D
1 Chronicles 13 in the AS21
1 Chronicles 13 in the BAGH
1 Chronicles 13 in the BBPNG
1 Chronicles 13 in the BBT1E
1 Chronicles 13 in the BDS
1 Chronicles 13 in the BEV
1 Chronicles 13 in the BHAD
1 Chronicles 13 in the BIB
1 Chronicles 13 in the BLPT
1 Chronicles 13 in the BNT
1 Chronicles 13 in the BNTABOOT
1 Chronicles 13 in the BNTLV
1 Chronicles 13 in the BOATCB
1 Chronicles 13 in the BOATCB2
1 Chronicles 13 in the BOBCV
1 Chronicles 13 in the BOCNT
1 Chronicles 13 in the BOECS
1 Chronicles 13 in the BOGWICC
1 Chronicles 13 in the BOHCB
1 Chronicles 13 in the BOHCV
1 Chronicles 13 in the BOHLNT
1 Chronicles 13 in the BOHNTLTAL
1 Chronicles 13 in the BOICB
1 Chronicles 13 in the BOILNTAP
1 Chronicles 13 in the BOITCV
1 Chronicles 13 in the BOKCV
1 Chronicles 13 in the BOKCV2
1 Chronicles 13 in the BOKHWOG
1 Chronicles 13 in the BOKSSV
1 Chronicles 13 in the BOLCB
1 Chronicles 13 in the BOLCB2
1 Chronicles 13 in the BOMCV
1 Chronicles 13 in the BONAV
1 Chronicles 13 in the BONCB
1 Chronicles 13 in the BONLT
1 Chronicles 13 in the BONUT2
1 Chronicles 13 in the BOPLNT
1 Chronicles 13 in the BOSCB
1 Chronicles 13 in the BOSNC
1 Chronicles 13 in the BOTLNT
1 Chronicles 13 in the BOVCB
1 Chronicles 13 in the BPBB
1 Chronicles 13 in the BPH
1 Chronicles 13 in the BSB
1 Chronicles 13 in the CCB
1 Chronicles 13 in the CUV
1 Chronicles 13 in the CUVS
1 Chronicles 13 in the DBT
1 Chronicles 13 in the DGDNT
1 Chronicles 13 in the DHNT
1 Chronicles 13 in the DNT
1 Chronicles 13 in the ELBE
1 Chronicles 13 in the EMTV
1 Chronicles 13 in the ESV
1 Chronicles 13 in the FBV
1 Chronicles 13 in the FEB
1 Chronicles 13 in the GGMNT
1 Chronicles 13 in the GNT
1 Chronicles 13 in the HARY
1 Chronicles 13 in the HNT
1 Chronicles 13 in the IRVA
1 Chronicles 13 in the IRVB
1 Chronicles 13 in the IRVG
1 Chronicles 13 in the IRVH
1 Chronicles 13 in the IRVK
1 Chronicles 13 in the IRVM
1 Chronicles 13 in the IRVM2
1 Chronicles 13 in the IRVO
1 Chronicles 13 in the IRVP
1 Chronicles 13 in the IRVT
1 Chronicles 13 in the IRVT2
1 Chronicles 13 in the IRVU
1 Chronicles 13 in the ISVN
1 Chronicles 13 in the JSNT
1 Chronicles 13 in the KAPI
1 Chronicles 13 in the KBT1ETNIK
1 Chronicles 13 in the KBV
1 Chronicles 13 in the KJV
1 Chronicles 13 in the KNFD
1 Chronicles 13 in the LBA
1 Chronicles 13 in the LBLA
1 Chronicles 13 in the LNT
1 Chronicles 13 in the LSV
1 Chronicles 13 in the MAAL
1 Chronicles 13 in the MBV
1 Chronicles 13 in the MBV2
1 Chronicles 13 in the MHNT
1 Chronicles 13 in the MKNFD
1 Chronicles 13 in the MNG
1 Chronicles 13 in the MNT
1 Chronicles 13 in the MNT2
1 Chronicles 13 in the MRS1T
1 Chronicles 13 in the NAA
1 Chronicles 13 in the NASB
1 Chronicles 13 in the NBLA
1 Chronicles 13 in the NBS
1 Chronicles 13 in the NBVTP
1 Chronicles 13 in the NET2
1 Chronicles 13 in the NIV11
1 Chronicles 13 in the NNT
1 Chronicles 13 in the NNT2
1 Chronicles 13 in the NNT3
1 Chronicles 13 in the PDDPT
1 Chronicles 13 in the PFNT
1 Chronicles 13 in the RMNT
1 Chronicles 13 in the SBIAS
1 Chronicles 13 in the SBIBS
1 Chronicles 13 in the SBIBS2
1 Chronicles 13 in the SBICS
1 Chronicles 13 in the SBIDS
1 Chronicles 13 in the SBIGS
1 Chronicles 13 in the SBIHS
1 Chronicles 13 in the SBIIS
1 Chronicles 13 in the SBIIS2
1 Chronicles 13 in the SBIIS3
1 Chronicles 13 in the SBIKS
1 Chronicles 13 in the SBIKS2
1 Chronicles 13 in the SBIMS
1 Chronicles 13 in the SBIOS
1 Chronicles 13 in the SBIPS
1 Chronicles 13 in the SBISS
1 Chronicles 13 in the SBITS
1 Chronicles 13 in the SBITS2
1 Chronicles 13 in the SBITS3
1 Chronicles 13 in the SBITS4
1 Chronicles 13 in the SBIUS
1 Chronicles 13 in the SBIVS
1 Chronicles 13 in the SBT
1 Chronicles 13 in the SBT1E
1 Chronicles 13 in the SCHL
1 Chronicles 13 in the SNT
1 Chronicles 13 in the SUSU
1 Chronicles 13 in the SUSU2
1 Chronicles 13 in the SYNO
1 Chronicles 13 in the TBIAOTANT
1 Chronicles 13 in the TBT1E
1 Chronicles 13 in the TBT1E2
1 Chronicles 13 in the TFTIP
1 Chronicles 13 in the TFTU
1 Chronicles 13 in the TGNTATF3T
1 Chronicles 13 in the THAI
1 Chronicles 13 in the TNFD
1 Chronicles 13 in the TNT
1 Chronicles 13 in the TNTIK
1 Chronicles 13 in the TNTIL
1 Chronicles 13 in the TNTIN
1 Chronicles 13 in the TNTIP
1 Chronicles 13 in the TNTIZ
1 Chronicles 13 in the TOMA
1 Chronicles 13 in the TTENT
1 Chronicles 13 in the UBG
1 Chronicles 13 in the UGV
1 Chronicles 13 in the UGV2
1 Chronicles 13 in the UGV3
1 Chronicles 13 in the VBL
1 Chronicles 13 in the VDCC
1 Chronicles 13 in the YALU
1 Chronicles 13 in the YAPE
1 Chronicles 13 in the YBVTP
1 Chronicles 13 in the ZBP