1 Chronicles 14 (BOYCB)
1 Nísinsin yìí Hiramu àti ọba Tire rán oníṣẹ́ sí Dafidi, àti pẹ̀lú igi kedari pẹ̀lú àwọn ọ̀mọ̀lé àti gbẹ́nàgbẹ́nà láti kọ́ ààfin fún un. 2 Dafidi sì mọ Israẹli àti pé OLÚWA ti fi òun ṣe ọba lórí Israẹli àti pé ìjọba rẹ̀ ga jùlọ nítorí ti àwọn ènìyàn rẹ̀. 3 Ní Jerusalẹmu Dafidi mú ọ̀pọ̀ ìyàwó ó sì di baba àwọn ọmọ ọkùnrin púpọ̀ àti ọmọbìnrin. 4 Èyí ni orúkọ àwọn ọmọ náà tí wọ́n bí fún un níbẹ̀: Ṣammua, Ṣobabu, Natani, Solomoni, 5 Ibhari, Eliṣua, Elifeleti, 6 Noga, Nefegi, Jafia, 7 Eliṣama, Beeliada, àti Elifeleti. 8 Nígbà tí àwọn ará Filistini gbọ́ pé a ti fi àmì òróró yàn Dafidi ní ọba lórí gbogbo Israẹli, wọ́n sì lọ sókè pẹ̀lú ipá láti wá a rí, ṣùgbọ́n Dafidi gbọ́ nípa rẹ̀ ó sì jáde lọ láti pàdé wọn. 9 Nísinsin yìí àwọn ará Filistini ti wá láti gbógun ti àfonífojì Refaimu; 10 Dafidi sì béèrè lọ́dọ̀ Ọlọ́run wí pé, “Kí èmi kí ó gòkè tọ àwọn ará Filistini lọ bí? Ìwọ ó ha fi wọ́n lé mi lọ́wọ́?” OLÚWA sì wí fún un pé, “Gòkè lọ èmi ó sì fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́.” 11 Bẹ́ẹ̀ ni Dafidi àti àwọn ènìyàn rẹ̀ gòkè lọ sí Baali-Perasimu, níbẹ̀ ó sì kọlù wọ́n. Ó sí wí pé, “Gẹ́gẹ́ bí omi tí ya jáde, Ọlọ́run ti ya Dafidi lórí àwọn ọ̀tá mi pẹ̀lú ọwọ́ mi.” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì ń pè ibẹ̀ ní Baali-Perasimu. 12 Àwọn ará Filistini sì ti fi àwọn òrìṣà wọn sílẹ̀ níbẹ̀. Dafidi sì pa á láṣẹ láti jó wọn nínú iná. 13 Lẹ́ẹ̀kan sí i àwọn ará Filistini gbógun wọ́n sì fọ́nká àfonífojì, 14 Bẹ́ẹ̀ ni Dafidi sì tún béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run, Ọlọ́run sì dalóhùn pé, “Má ṣe gòkè tààrà, ṣùgbọ́n ẹ yí wọn ká, kí ẹ sì mú wọn níwájú igi muliberi. 15 Tí ó bá sì ṣe, tí ẹ̀yin bá ti gbọ́ ìró ẹsẹ̀ ní orí òkè igi muliberi, ẹ jáde fún ogun, nítorí èyí yóò fihàn pé Ọlọ́run ti jáde níwájú rẹ láti kọlu àwọn ọmọ-ogun Filistini.” 16 Bẹ́ẹ̀ ni Dafidi ṣe ohun tí Ọlọ́run ti pàṣẹ fún wọn, wọ́n sì kọlu àwọn ọmọ-ogun Filistini láti gbogbo ọ̀nà Gibeoni lọ sí Geseri. 17 Bẹ́ẹ̀ ni òkìkí Dafidi tàn ká gbogbo ilẹ̀ káàkiri, OLÚWA sì mú kí gbogbo orílẹ̀-èdè bẹ̀rù rẹ̀.
In Other Versions
1 Chronicles 14 in the ANGEFD
1 Chronicles 14 in the ANTPNG2D
1 Chronicles 14 in the AS21
1 Chronicles 14 in the BAGH
1 Chronicles 14 in the BBPNG
1 Chronicles 14 in the BBT1E
1 Chronicles 14 in the BDS
1 Chronicles 14 in the BEV
1 Chronicles 14 in the BHAD
1 Chronicles 14 in the BIB
1 Chronicles 14 in the BLPT
1 Chronicles 14 in the BNT
1 Chronicles 14 in the BNTABOOT
1 Chronicles 14 in the BNTLV
1 Chronicles 14 in the BOATCB
1 Chronicles 14 in the BOATCB2
1 Chronicles 14 in the BOBCV
1 Chronicles 14 in the BOCNT
1 Chronicles 14 in the BOECS
1 Chronicles 14 in the BOGWICC
1 Chronicles 14 in the BOHCB
1 Chronicles 14 in the BOHCV
1 Chronicles 14 in the BOHLNT
1 Chronicles 14 in the BOHNTLTAL
1 Chronicles 14 in the BOICB
1 Chronicles 14 in the BOILNTAP
1 Chronicles 14 in the BOITCV
1 Chronicles 14 in the BOKCV
1 Chronicles 14 in the BOKCV2
1 Chronicles 14 in the BOKHWOG
1 Chronicles 14 in the BOKSSV
1 Chronicles 14 in the BOLCB
1 Chronicles 14 in the BOLCB2
1 Chronicles 14 in the BOMCV
1 Chronicles 14 in the BONAV
1 Chronicles 14 in the BONCB
1 Chronicles 14 in the BONLT
1 Chronicles 14 in the BONUT2
1 Chronicles 14 in the BOPLNT
1 Chronicles 14 in the BOSCB
1 Chronicles 14 in the BOSNC
1 Chronicles 14 in the BOTLNT
1 Chronicles 14 in the BOVCB
1 Chronicles 14 in the BPBB
1 Chronicles 14 in the BPH
1 Chronicles 14 in the BSB
1 Chronicles 14 in the CCB
1 Chronicles 14 in the CUV
1 Chronicles 14 in the CUVS
1 Chronicles 14 in the DBT
1 Chronicles 14 in the DGDNT
1 Chronicles 14 in the DHNT
1 Chronicles 14 in the DNT
1 Chronicles 14 in the ELBE
1 Chronicles 14 in the EMTV
1 Chronicles 14 in the ESV
1 Chronicles 14 in the FBV
1 Chronicles 14 in the FEB
1 Chronicles 14 in the GGMNT
1 Chronicles 14 in the GNT
1 Chronicles 14 in the HARY
1 Chronicles 14 in the HNT
1 Chronicles 14 in the IRVA
1 Chronicles 14 in the IRVB
1 Chronicles 14 in the IRVG
1 Chronicles 14 in the IRVH
1 Chronicles 14 in the IRVK
1 Chronicles 14 in the IRVM
1 Chronicles 14 in the IRVM2
1 Chronicles 14 in the IRVO
1 Chronicles 14 in the IRVP
1 Chronicles 14 in the IRVT
1 Chronicles 14 in the IRVT2
1 Chronicles 14 in the IRVU
1 Chronicles 14 in the ISVN
1 Chronicles 14 in the JSNT
1 Chronicles 14 in the KAPI
1 Chronicles 14 in the KBT1ETNIK
1 Chronicles 14 in the KBV
1 Chronicles 14 in the KJV
1 Chronicles 14 in the KNFD
1 Chronicles 14 in the LBA
1 Chronicles 14 in the LBLA
1 Chronicles 14 in the LNT
1 Chronicles 14 in the LSV
1 Chronicles 14 in the MAAL
1 Chronicles 14 in the MBV
1 Chronicles 14 in the MBV2
1 Chronicles 14 in the MHNT
1 Chronicles 14 in the MKNFD
1 Chronicles 14 in the MNG
1 Chronicles 14 in the MNT
1 Chronicles 14 in the MNT2
1 Chronicles 14 in the MRS1T
1 Chronicles 14 in the NAA
1 Chronicles 14 in the NASB
1 Chronicles 14 in the NBLA
1 Chronicles 14 in the NBS
1 Chronicles 14 in the NBVTP
1 Chronicles 14 in the NET2
1 Chronicles 14 in the NIV11
1 Chronicles 14 in the NNT
1 Chronicles 14 in the NNT2
1 Chronicles 14 in the NNT3
1 Chronicles 14 in the PDDPT
1 Chronicles 14 in the PFNT
1 Chronicles 14 in the RMNT
1 Chronicles 14 in the SBIAS
1 Chronicles 14 in the SBIBS
1 Chronicles 14 in the SBIBS2
1 Chronicles 14 in the SBICS
1 Chronicles 14 in the SBIDS
1 Chronicles 14 in the SBIGS
1 Chronicles 14 in the SBIHS
1 Chronicles 14 in the SBIIS
1 Chronicles 14 in the SBIIS2
1 Chronicles 14 in the SBIIS3
1 Chronicles 14 in the SBIKS
1 Chronicles 14 in the SBIKS2
1 Chronicles 14 in the SBIMS
1 Chronicles 14 in the SBIOS
1 Chronicles 14 in the SBIPS
1 Chronicles 14 in the SBISS
1 Chronicles 14 in the SBITS
1 Chronicles 14 in the SBITS2
1 Chronicles 14 in the SBITS3
1 Chronicles 14 in the SBITS4
1 Chronicles 14 in the SBIUS
1 Chronicles 14 in the SBIVS
1 Chronicles 14 in the SBT
1 Chronicles 14 in the SBT1E
1 Chronicles 14 in the SCHL
1 Chronicles 14 in the SNT
1 Chronicles 14 in the SUSU
1 Chronicles 14 in the SUSU2
1 Chronicles 14 in the SYNO
1 Chronicles 14 in the TBIAOTANT
1 Chronicles 14 in the TBT1E
1 Chronicles 14 in the TBT1E2
1 Chronicles 14 in the TFTIP
1 Chronicles 14 in the TFTU
1 Chronicles 14 in the TGNTATF3T
1 Chronicles 14 in the THAI
1 Chronicles 14 in the TNFD
1 Chronicles 14 in the TNT
1 Chronicles 14 in the TNTIK
1 Chronicles 14 in the TNTIL
1 Chronicles 14 in the TNTIN
1 Chronicles 14 in the TNTIP
1 Chronicles 14 in the TNTIZ
1 Chronicles 14 in the TOMA
1 Chronicles 14 in the TTENT
1 Chronicles 14 in the UBG
1 Chronicles 14 in the UGV
1 Chronicles 14 in the UGV2
1 Chronicles 14 in the UGV3
1 Chronicles 14 in the VBL
1 Chronicles 14 in the VDCC
1 Chronicles 14 in the YALU
1 Chronicles 14 in the YAPE
1 Chronicles 14 in the YBVTP
1 Chronicles 14 in the ZBP