Isaiah 35 (BOYCB)
1 Aginjù àti ìyàngbẹ ilẹ̀ yóò yọ̀ fún wọn;aginjù yóò ṣe àjọyọ̀ yóò sì kún fún ìtànná.Gẹ́gẹ́ bí ewéko, 2 ní títanná yóò tanná;yóò yọ ayọ̀ ńlá ńlá yóò sì kọrin.Ògo Lebanoni ni a ó fi fún un,ẹwà Karmeli àti Ṣaroni;wọn yóò rí ògo OLÚWA,àti ẹwà Ọlọ́run wa. 3 Fún ọwọ́ àìlera lókun,mú orúnkún tí ń yẹ̀ lókun. 4 Sọ fún àwọn oníbẹ̀rù ọkàn pé,“Ẹ ṣe gírí, ẹ má bẹ̀rù;Ọlọ́run yín yóò wá,òun yóò wá pẹ̀lú ìgbẹ̀san;pẹ̀lú ìgbẹ̀san mímọ́òun yóò wá láti gbà yín là.” 5 Nígbà náà ni a ó la ojú àwọn afọ́júàti etí àwọn odi kì yóò dákẹ́. 6 Nígbà náà ni àwọn arọ yóò máa fò bí àgbọ̀nrín,àti ahọ́n odi yóò ké fún ayọ̀.Odò yóò tú jáde nínú aginjùàti àwọn odò nínú aṣálẹ̀. 7 Ilẹ̀ iyanrìn yíyan yóò di àbàtà,ilẹ̀ tí ń pòǹgbẹ yóò di orísun omi.Ní ibùgbé àwọn dragoni,níbi tí olúkúlùkù dùbúlẹ̀,ni ó jẹ́ ọgbà fún eèsún àti papirusi. 8 Àti òpópónà kan yóò wà níbẹ̀:a ó sì máa pè é ní ọ̀nà ìwà mímọ́.Àwọn aláìmọ́ kì yóò tọ ọ̀nà náà;yóò sì wà fún àwọn tí ń rìn ní ọ̀nà náà,àwọn ìkà búburú kì yóò gba ibẹ̀ kọjá. 9 Kì yóò sí kìnnìún níbẹ̀,tàbí kí ẹranko búburú kí ó dìde lórí i rẹ̀;a kì yóò rí wọn níbẹ̀.Ṣùgbọ́n àwọn ẹni ìràpadà nìkan ni yóò rìn níbẹ̀, 10 àwọn ẹni ìràpadà OLÚWA yóò padà wá.Wọn yóò wọ Sioni wá pẹ̀lú orin;ayọ̀ ayérayé ni yóò dé wọn ní orí.Ìdùnnú àti ayọ̀ ni yóò borí i wọn,ìkorò àti ìtìjú yóò sì sá kúrò lọ́dọ̀ wọn.
In Other Versions
Isaiah 35 in the ANGEFD
Isaiah 35 in the ANTPNG2D
Isaiah 35 in the AS21
Isaiah 35 in the BAGH
Isaiah 35 in the BBPNG
Isaiah 35 in the BBT1E
Isaiah 35 in the BDS
Isaiah 35 in the BEV
Isaiah 35 in the BHAD
Isaiah 35 in the BIB
Isaiah 35 in the BLPT
Isaiah 35 in the BNT
Isaiah 35 in the BNTABOOT
Isaiah 35 in the BNTLV
Isaiah 35 in the BOATCB
Isaiah 35 in the BOATCB2
Isaiah 35 in the BOBCV
Isaiah 35 in the BOCNT
Isaiah 35 in the BOECS
Isaiah 35 in the BOGWICC
Isaiah 35 in the BOHCB
Isaiah 35 in the BOHCV
Isaiah 35 in the BOHLNT
Isaiah 35 in the BOHNTLTAL
Isaiah 35 in the BOICB
Isaiah 35 in the BOILNTAP
Isaiah 35 in the BOITCV
Isaiah 35 in the BOKCV
Isaiah 35 in the BOKCV2
Isaiah 35 in the BOKHWOG
Isaiah 35 in the BOKSSV
Isaiah 35 in the BOLCB
Isaiah 35 in the BOLCB2
Isaiah 35 in the BOMCV
Isaiah 35 in the BONAV
Isaiah 35 in the BONCB
Isaiah 35 in the BONLT
Isaiah 35 in the BONUT2
Isaiah 35 in the BOPLNT
Isaiah 35 in the BOSCB
Isaiah 35 in the BOSNC
Isaiah 35 in the BOTLNT
Isaiah 35 in the BOVCB
Isaiah 35 in the BPBB
Isaiah 35 in the BPH
Isaiah 35 in the BSB
Isaiah 35 in the CCB
Isaiah 35 in the CUV
Isaiah 35 in the CUVS
Isaiah 35 in the DBT
Isaiah 35 in the DGDNT
Isaiah 35 in the DHNT
Isaiah 35 in the DNT
Isaiah 35 in the ELBE
Isaiah 35 in the EMTV
Isaiah 35 in the ESV
Isaiah 35 in the FBV
Isaiah 35 in the FEB
Isaiah 35 in the GGMNT
Isaiah 35 in the GNT
Isaiah 35 in the HARY
Isaiah 35 in the HNT
Isaiah 35 in the IRVA
Isaiah 35 in the IRVB
Isaiah 35 in the IRVG
Isaiah 35 in the IRVH
Isaiah 35 in the IRVK
Isaiah 35 in the IRVM
Isaiah 35 in the IRVM2
Isaiah 35 in the IRVO
Isaiah 35 in the IRVP
Isaiah 35 in the IRVT
Isaiah 35 in the IRVT2
Isaiah 35 in the IRVU
Isaiah 35 in the ISVN
Isaiah 35 in the JSNT
Isaiah 35 in the KAPI
Isaiah 35 in the KBT1ETNIK
Isaiah 35 in the KBV
Isaiah 35 in the KJV
Isaiah 35 in the KNFD
Isaiah 35 in the LBA
Isaiah 35 in the LBLA
Isaiah 35 in the LNT
Isaiah 35 in the LSV
Isaiah 35 in the MAAL
Isaiah 35 in the MBV
Isaiah 35 in the MBV2
Isaiah 35 in the MHNT
Isaiah 35 in the MKNFD
Isaiah 35 in the MNG
Isaiah 35 in the MNT
Isaiah 35 in the MNT2
Isaiah 35 in the MRS1T
Isaiah 35 in the NAA
Isaiah 35 in the NASB
Isaiah 35 in the NBLA
Isaiah 35 in the NBS
Isaiah 35 in the NBVTP
Isaiah 35 in the NET2
Isaiah 35 in the NIV11
Isaiah 35 in the NNT
Isaiah 35 in the NNT2
Isaiah 35 in the NNT3
Isaiah 35 in the PDDPT
Isaiah 35 in the PFNT
Isaiah 35 in the RMNT
Isaiah 35 in the SBIAS
Isaiah 35 in the SBIBS
Isaiah 35 in the SBIBS2
Isaiah 35 in the SBICS
Isaiah 35 in the SBIDS
Isaiah 35 in the SBIGS
Isaiah 35 in the SBIHS
Isaiah 35 in the SBIIS
Isaiah 35 in the SBIIS2
Isaiah 35 in the SBIIS3
Isaiah 35 in the SBIKS
Isaiah 35 in the SBIKS2
Isaiah 35 in the SBIMS
Isaiah 35 in the SBIOS
Isaiah 35 in the SBIPS
Isaiah 35 in the SBISS
Isaiah 35 in the SBITS
Isaiah 35 in the SBITS2
Isaiah 35 in the SBITS3
Isaiah 35 in the SBITS4
Isaiah 35 in the SBIUS
Isaiah 35 in the SBIVS
Isaiah 35 in the SBT
Isaiah 35 in the SBT1E
Isaiah 35 in the SCHL
Isaiah 35 in the SNT
Isaiah 35 in the SUSU
Isaiah 35 in the SUSU2
Isaiah 35 in the SYNO
Isaiah 35 in the TBIAOTANT
Isaiah 35 in the TBT1E
Isaiah 35 in the TBT1E2
Isaiah 35 in the TFTIP
Isaiah 35 in the TFTU
Isaiah 35 in the TGNTATF3T
Isaiah 35 in the THAI
Isaiah 35 in the TNFD
Isaiah 35 in the TNT
Isaiah 35 in the TNTIK
Isaiah 35 in the TNTIL
Isaiah 35 in the TNTIN
Isaiah 35 in the TNTIP
Isaiah 35 in the TNTIZ
Isaiah 35 in the TOMA
Isaiah 35 in the TTENT
Isaiah 35 in the UBG
Isaiah 35 in the UGV
Isaiah 35 in the UGV2
Isaiah 35 in the UGV3
Isaiah 35 in the VBL
Isaiah 35 in the VDCC
Isaiah 35 in the YALU
Isaiah 35 in the YAPE
Isaiah 35 in the YBVTP
Isaiah 35 in the ZBP