Joshua 20 (BOYCB)

1 Nígbà náà ni OLÚWA sọ fún Joṣua pé, 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé kí wọn yan àwọn ìlú ààbò, gẹ́gẹ́ bí mo ti pàṣẹ fún ọ láti ẹnu Mose, 3 kí ẹni tí ó bá ṣèèṣì pa ènìyàn tàbí tí ó bá pa ènìyàn láìmọ̀-ọ́n-mọ̀ lè sálọ sí ibẹ̀, fún ààbò lọ́wọ́ olùgbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ ẹni tí ó pa. 4 Nígbà tí ó bá sálọ sí ọ̀kan nínú àwọn ìlú wọ̀nyí, yóò sì dúró ní ẹnu-ọ̀nà àtiwọ ibodè ìlú, kí ó sì ṣe àlàyé ara rẹ̀ ní iwájú àwọn àgbàgbà ìlú náà. Nígbà náà ni wọn yóò gbà á sí ìlú wọn, wọn yóò sì fun ní ibùgbé láàrín wọn. 5 Bí olùgbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ bá ń lépa rẹ̀, wọn kò gbọdọ̀ fi àwọn ọ̀daràn náà lé wọn lọ́wọ́, nítorí tí ó pa aládùúgbò rẹ̀ láìmọ̀, tí kò sì kórìíra rẹ̀ tẹ́lẹ̀ rí. 6 Òun ó sì máa gbé inú ìlú náà, títí yóò fi jẹ́jọ́ níwájú ìjọ ènìyàn àti títí ikú olórí àlùfáà tí ó ń ṣiṣẹ́ ìsìn nígbà náà. Nígbà náà ó lè padà sí ilé rẹ̀ ní ìlú tí ó ti sá wá.” 7 Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n yan Kedeṣi ní Galili ní ìlú òkè Naftali, Ṣekemu ní ìlú òkè Efraimu, àti Kiriati-Arba (tí í ṣe, Hebroni) ní ìlú òkè Juda. 8 Ní ìhà ìlà-oòrùn Jordani ti Jeriko, wọ́n ya Beseri ní aginjù ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ ní ẹ̀yà Reubeni, Ramoti ní Gileadi ní ẹ̀yà Gadi, àti Golani ní Baṣani ní ẹ̀yà Manase. 9 Ẹnikẹ́ni nínú àwọn ọmọ Israẹli tàbí àlejò tí ń gbé ní àárín wọn tí ó ṣèèṣì pa ẹnìkan lè sálọ sí àwọn ìlú tí a yà sọ́tọ̀ wọ̀nyí, kí olùgbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ má sì ṣe pa á kí ó to di àkókò tí yóò jẹ́jọ́ níwájú ìjọ ènìyàn.

In Other Versions

Joshua 20 in the ANGEFD

Joshua 20 in the ANTPNG2D

Joshua 20 in the AS21

Joshua 20 in the BAGH

Joshua 20 in the BBPNG

Joshua 20 in the BBT1E

Joshua 20 in the BDS

Joshua 20 in the BEV

Joshua 20 in the BHAD

Joshua 20 in the BIB

Joshua 20 in the BLPT

Joshua 20 in the BNT

Joshua 20 in the BNTABOOT

Joshua 20 in the BNTLV

Joshua 20 in the BOATCB

Joshua 20 in the BOATCB2

Joshua 20 in the BOBCV

Joshua 20 in the BOCNT

Joshua 20 in the BOECS

Joshua 20 in the BOGWICC

Joshua 20 in the BOHCB

Joshua 20 in the BOHCV

Joshua 20 in the BOHLNT

Joshua 20 in the BOHNTLTAL

Joshua 20 in the BOICB

Joshua 20 in the BOILNTAP

Joshua 20 in the BOITCV

Joshua 20 in the BOKCV

Joshua 20 in the BOKCV2

Joshua 20 in the BOKHWOG

Joshua 20 in the BOKSSV

Joshua 20 in the BOLCB

Joshua 20 in the BOLCB2

Joshua 20 in the BOMCV

Joshua 20 in the BONAV

Joshua 20 in the BONCB

Joshua 20 in the BONLT

Joshua 20 in the BONUT2

Joshua 20 in the BOPLNT

Joshua 20 in the BOSCB

Joshua 20 in the BOSNC

Joshua 20 in the BOTLNT

Joshua 20 in the BOVCB

Joshua 20 in the BPBB

Joshua 20 in the BPH

Joshua 20 in the BSB

Joshua 20 in the CCB

Joshua 20 in the CUV

Joshua 20 in the CUVS

Joshua 20 in the DBT

Joshua 20 in the DGDNT

Joshua 20 in the DHNT

Joshua 20 in the DNT

Joshua 20 in the ELBE

Joshua 20 in the EMTV

Joshua 20 in the ESV

Joshua 20 in the FBV

Joshua 20 in the FEB

Joshua 20 in the GGMNT

Joshua 20 in the GNT

Joshua 20 in the HARY

Joshua 20 in the HNT

Joshua 20 in the IRVA

Joshua 20 in the IRVB

Joshua 20 in the IRVG

Joshua 20 in the IRVH

Joshua 20 in the IRVK

Joshua 20 in the IRVM

Joshua 20 in the IRVM2

Joshua 20 in the IRVO

Joshua 20 in the IRVP

Joshua 20 in the IRVT

Joshua 20 in the IRVT2

Joshua 20 in the IRVU

Joshua 20 in the ISVN

Joshua 20 in the JSNT

Joshua 20 in the KAPI

Joshua 20 in the KBT1ETNIK

Joshua 20 in the KBV

Joshua 20 in the KJV

Joshua 20 in the KNFD

Joshua 20 in the LBA

Joshua 20 in the LBLA

Joshua 20 in the LNT

Joshua 20 in the LSV

Joshua 20 in the MAAL

Joshua 20 in the MBV

Joshua 20 in the MBV2

Joshua 20 in the MHNT

Joshua 20 in the MKNFD

Joshua 20 in the MNG

Joshua 20 in the MNT

Joshua 20 in the MNT2

Joshua 20 in the MRS1T

Joshua 20 in the NAA

Joshua 20 in the NASB

Joshua 20 in the NBLA

Joshua 20 in the NBS

Joshua 20 in the NBVTP

Joshua 20 in the NET2

Joshua 20 in the NIV11

Joshua 20 in the NNT

Joshua 20 in the NNT2

Joshua 20 in the NNT3

Joshua 20 in the PDDPT

Joshua 20 in the PFNT

Joshua 20 in the RMNT

Joshua 20 in the SBIAS

Joshua 20 in the SBIBS

Joshua 20 in the SBIBS2

Joshua 20 in the SBICS

Joshua 20 in the SBIDS

Joshua 20 in the SBIGS

Joshua 20 in the SBIHS

Joshua 20 in the SBIIS

Joshua 20 in the SBIIS2

Joshua 20 in the SBIIS3

Joshua 20 in the SBIKS

Joshua 20 in the SBIKS2

Joshua 20 in the SBIMS

Joshua 20 in the SBIOS

Joshua 20 in the SBIPS

Joshua 20 in the SBISS

Joshua 20 in the SBITS

Joshua 20 in the SBITS2

Joshua 20 in the SBITS3

Joshua 20 in the SBITS4

Joshua 20 in the SBIUS

Joshua 20 in the SBIVS

Joshua 20 in the SBT

Joshua 20 in the SBT1E

Joshua 20 in the SCHL

Joshua 20 in the SNT

Joshua 20 in the SUSU

Joshua 20 in the SUSU2

Joshua 20 in the SYNO

Joshua 20 in the TBIAOTANT

Joshua 20 in the TBT1E

Joshua 20 in the TBT1E2

Joshua 20 in the TFTIP

Joshua 20 in the TFTU

Joshua 20 in the TGNTATF3T

Joshua 20 in the THAI

Joshua 20 in the TNFD

Joshua 20 in the TNT

Joshua 20 in the TNTIK

Joshua 20 in the TNTIL

Joshua 20 in the TNTIN

Joshua 20 in the TNTIP

Joshua 20 in the TNTIZ

Joshua 20 in the TOMA

Joshua 20 in the TTENT

Joshua 20 in the UBG

Joshua 20 in the UGV

Joshua 20 in the UGV2

Joshua 20 in the UGV3

Joshua 20 in the VBL

Joshua 20 in the VDCC

Joshua 20 in the YALU

Joshua 20 in the YAPE

Joshua 20 in the YBVTP

Joshua 20 in the ZBP