Psalms 77 (BOYCB)
undefined Fún adarí orin. Fún Jedutuni. Ti Asafu. Saamu. 1 Mó kígbe sí Ọlọ́run fún ìrànlọ́wọ́;mo kígbe sí Ọlọ́run láti gbọ́ tèmi. 2 Nígbà tí mo wà nínú ìpọ́njú,mo wá OLÚWA;ní òru ni mo na ọwọ́ mi jáde ní àìkáárẹ̀ọkàn mí sì kọ̀ láti tù ú nínú. 3 Èmi rántí rẹ, Ọlọ́run,mo sì kẹ́dùn;mo ṣe àròyé, ẹ̀mí mi sì rẹ̀wẹ̀sì. Sela. 4 Ìwọ kò fẹ́ kí èmi fi ojú ba oorun,mo dààmú tó bẹ́ẹ̀ tí ń kò le sọ̀rọ̀. 5 Mo ronú nípa ọjọ́ ìgbàanì;ọdún pípẹ́ sẹ́yìn; 6 mo rántí orin mi ní òru.Èmi ń bá àyà mi sọ̀rọ̀,ọkàn mi sì ń ṣe àwárí jọjọ. 7 “Olúwa yóò ha kọ̀ títí láé?Ki yóò ha ṣe ojúrere rẹ̀ mọ́? 8 Ṣe ìfẹ́ rẹ̀ àti àánú rẹ̀ ti kú lọ láéláé?Ìlérí rẹ̀ ha kùnà títí ayé? 9 Ọlọ́run ha gbàgbé láti máa ṣàánú?Ní ìbínú rẹ̀, ó ha sé ojúrere rẹ̀ mọ́?” Sela. 10 Èmi wí pé, “Èyí ní ẹ̀dùn ọkàn mi,pé ọwọ́ ọ̀tún Ọ̀gá-ògo jùlọ ti yípadà”. 11 Èmi ó rántí iṣẹ́ OLÚWA:bẹ́ẹ̀ ni, èmi ó rántí iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ ọjọ́ pípẹ́. 12 Èmi ṣàṣàrò lórí iṣẹ́ rẹ gbogbo,pẹ̀lú, ènìyàn sì máa sọ̀rọ̀ gbogbo iṣẹ́ agbára rẹ. 13 Ọlọ́run, ọ̀nà rẹ jẹ́ mímọ́.Ọlọ́run wo ni ó sì tóbi bí Ọlọ́run wa? 14 Ìwọ ni Ọlọ́run tó ń ṣe ìyanu;ìwọ fi agbára rẹ hàn nínú àwọn ènìyàn. 15 Pẹ̀lú ọwọ́ agbára rẹ ni ìwọ ra àwọn ènìyàn padà,àwọn ọmọ Jakọbu àti Josẹfu. Sela. 16 Nígbà tí àwọn omi rí Ọlọ́run,nígbà tí àwọn omi rí ọ,ẹ̀rù bà wọ́n,nítòótọ́ ara ibú kò balẹ̀. 17 Àwọn ojú ọ̀run tú omi sílẹ̀,àwọsánmọ̀ fi àrá dáhùn;ọfà rẹ̀ ń tàn sẹ́yìn àti síwájú. 18 Àrá rẹ̀ ni a gbọ́ nínú ìjì,ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ sí gbogbo ayé;ayé bẹ̀rù, wọ́n sì wárìrì. 19 Ipa rẹ̀ gba Òkun, ọ̀nà rẹ̀ ń bẹ nínú Òkun,ọ̀nà la omi alágbára kọjá ipa rẹ̀ ń bẹ nínú líla omi alágbára kọjá,nítòótọ́ a kò rí ojú ẹsẹ̀ rẹ̀. 20 Ó tọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀wọ́ ẹrannípa ọwọ́ Mose àti Aaroni.
In Other Versions
Psalms 77 in the ANGEFD
Psalms 77 in the ANTPNG2D
Psalms 77 in the AS21
Psalms 77 in the BAGH
Psalms 77 in the BBPNG
Psalms 77 in the BBT1E
Psalms 77 in the BDS
Psalms 77 in the BEV
Psalms 77 in the BHAD
Psalms 77 in the BIB
Psalms 77 in the BLPT
Psalms 77 in the BNT
Psalms 77 in the BNTABOOT
Psalms 77 in the BNTLV
Psalms 77 in the BOATCB
Psalms 77 in the BOATCB2
Psalms 77 in the BOBCV
Psalms 77 in the BOCNT
Psalms 77 in the BOECS
Psalms 77 in the BOGWICC
Psalms 77 in the BOHCB
Psalms 77 in the BOHCV
Psalms 77 in the BOHLNT
Psalms 77 in the BOHNTLTAL
Psalms 77 in the BOICB
Psalms 77 in the BOILNTAP
Psalms 77 in the BOITCV
Psalms 77 in the BOKCV
Psalms 77 in the BOKCV2
Psalms 77 in the BOKHWOG
Psalms 77 in the BOKSSV
Psalms 77 in the BOLCB
Psalms 77 in the BOLCB2
Psalms 77 in the BOMCV
Psalms 77 in the BONAV
Psalms 77 in the BONCB
Psalms 77 in the BONLT
Psalms 77 in the BONUT2
Psalms 77 in the BOPLNT
Psalms 77 in the BOSCB
Psalms 77 in the BOSNC
Psalms 77 in the BOTLNT
Psalms 77 in the BOVCB
Psalms 77 in the BPBB
Psalms 77 in the BPH
Psalms 77 in the BSB
Psalms 77 in the CCB
Psalms 77 in the CUV
Psalms 77 in the CUVS
Psalms 77 in the DBT
Psalms 77 in the DGDNT
Psalms 77 in the DHNT
Psalms 77 in the DNT
Psalms 77 in the ELBE
Psalms 77 in the EMTV
Psalms 77 in the ESV
Psalms 77 in the FBV
Psalms 77 in the FEB
Psalms 77 in the GGMNT
Psalms 77 in the GNT
Psalms 77 in the HARY
Psalms 77 in the HNT
Psalms 77 in the IRVA
Psalms 77 in the IRVB
Psalms 77 in the IRVG
Psalms 77 in the IRVH
Psalms 77 in the IRVK
Psalms 77 in the IRVM
Psalms 77 in the IRVM2
Psalms 77 in the IRVO
Psalms 77 in the IRVP
Psalms 77 in the IRVT
Psalms 77 in the IRVT2
Psalms 77 in the IRVU
Psalms 77 in the ISVN
Psalms 77 in the JSNT
Psalms 77 in the KAPI
Psalms 77 in the KBT1ETNIK
Psalms 77 in the KBV
Psalms 77 in the KJV
Psalms 77 in the KNFD
Psalms 77 in the LBA
Psalms 77 in the LBLA
Psalms 77 in the LNT
Psalms 77 in the LSV
Psalms 77 in the MAAL
Psalms 77 in the MBV
Psalms 77 in the MBV2
Psalms 77 in the MHNT
Psalms 77 in the MKNFD
Psalms 77 in the MNG
Psalms 77 in the MNT
Psalms 77 in the MNT2
Psalms 77 in the MRS1T
Psalms 77 in the NAA
Psalms 77 in the NASB
Psalms 77 in the NBLA
Psalms 77 in the NBS
Psalms 77 in the NBVTP
Psalms 77 in the NET2
Psalms 77 in the NIV11
Psalms 77 in the NNT
Psalms 77 in the NNT2
Psalms 77 in the NNT3
Psalms 77 in the PDDPT
Psalms 77 in the PFNT
Psalms 77 in the RMNT
Psalms 77 in the SBIAS
Psalms 77 in the SBIBS
Psalms 77 in the SBIBS2
Psalms 77 in the SBICS
Psalms 77 in the SBIDS
Psalms 77 in the SBIGS
Psalms 77 in the SBIHS
Psalms 77 in the SBIIS
Psalms 77 in the SBIIS2
Psalms 77 in the SBIIS3
Psalms 77 in the SBIKS
Psalms 77 in the SBIKS2
Psalms 77 in the SBIMS
Psalms 77 in the SBIOS
Psalms 77 in the SBIPS
Psalms 77 in the SBISS
Psalms 77 in the SBITS
Psalms 77 in the SBITS2
Psalms 77 in the SBITS3
Psalms 77 in the SBITS4
Psalms 77 in the SBIUS
Psalms 77 in the SBIVS
Psalms 77 in the SBT
Psalms 77 in the SBT1E
Psalms 77 in the SCHL
Psalms 77 in the SNT
Psalms 77 in the SUSU
Psalms 77 in the SUSU2
Psalms 77 in the SYNO
Psalms 77 in the TBIAOTANT
Psalms 77 in the TBT1E
Psalms 77 in the TBT1E2
Psalms 77 in the TFTIP
Psalms 77 in the TFTU
Psalms 77 in the TGNTATF3T
Psalms 77 in the THAI
Psalms 77 in the TNFD
Psalms 77 in the TNT
Psalms 77 in the TNTIK
Psalms 77 in the TNTIL
Psalms 77 in the TNTIN
Psalms 77 in the TNTIP
Psalms 77 in the TNTIZ
Psalms 77 in the TOMA
Psalms 77 in the TTENT
Psalms 77 in the UBG
Psalms 77 in the UGV
Psalms 77 in the UGV2
Psalms 77 in the UGV3
Psalms 77 in the VBL
Psalms 77 in the VDCC
Psalms 77 in the YALU
Psalms 77 in the YAPE
Psalms 77 in the YBVTP
Psalms 77 in the ZBP