Zechariah 13 (BOYCB)

1 “Ní ọjọ́ náà ìsun kan yóò ṣí sílẹ̀ fún ilé Dafidi àti fún àwọn ará Jerusalẹmu, láti wẹ̀ wọ́n mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ àti àìmọ́ wọn. 2 “Yóò sì ṣe ní ọjọ́ náà ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí, ni èmi ó gé orúkọ àwọn òrìṣà kúrò ni ilẹ̀ náà, a kì yóò sì rántí wọn mọ́, àti pẹ̀lú èmi ó mú àwọn wòlíì èké àti àwọn ẹ̀mí àìmọ́ kúrò ni ilẹ̀ náà. 3 Yóò sì ṣe, nígbà tí ẹnìkan yóò sọtẹ́lẹ̀ síbẹ̀, ni baba rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ tí ó bí í yóò wí fún un pé, ‘Ìwọ ki yóò yè, nítorí ìwọ ń sọ ọ̀rọ̀ èké ni orúkọ OLÚWA.’ Àti baba rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ tí o bí í yóò gun un ni àgúnpa nígbà tí ó bá sọtẹ́lẹ̀. 4 “Yóò sì ṣe ní ọjọ́ náà, ojú yóò tí àwọn wòlíì èké olúkúlùkù nítorí ìran rẹ̀, nígbà tí òun ba tí sọtẹ́lẹ̀; bẹ́ẹ̀ ni wọn kì yóò sì wọ aṣọ wòlíì onírun rẹ̀ tí o fi ń tan ní jẹ. 5 Ṣùgbọ́n òun o wí pé, ‘Èmi kí í ṣe wòlíì, àgbẹ̀ ni èmi; nítorí tí a ti fi mí ṣe ìránṣẹ́ láti ìgbà èwe mi wá.’ 6 Ẹnìkan ó sì wí fún un pé, ‘Ọgbẹ́ kín ní wọ̀nyí ni ẹ̀yìn rẹ?’ Òun o sì dáhùn pé, ‘Wọ̀nyí ni ibi tí a ti sá mi ní ilé àwọn ọ̀rẹ́ mi.’ 7 “Dìde, ìwọ idà, sí Olùṣọ́-àgùntàn mi,àti sí ẹni tí í ṣe ẹnìkejì mi,”ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí:“Kọlu Olùṣọ́-àgùntàn,àwọn àgùntàn a sì túká:èmi o sì yí ọwọ́ mi sí àwọn kéékèèké. 8 Yóò sì ṣe, ni gbogbo ilẹ̀,” ni OLÚWA wí,“a ó gé apá méjì nínú rẹ̀ kúrò yóò sì kú;ṣùgbọ́n apá kẹta yóò kù nínú rẹ̀. 9 Èmi ó sì mú apá kẹta náà la àárín iná,èmi yóò sì yọ́ wọn bí a ti yọ́ fàdákà,èmi yóò sì dán wọn wò, bi a tí ń dán wúrà wò:wọn yóò sì pé orúkọ mi,èmi yóò sì dá wọn lóhùn:èmi yóò wí pé, ‘Àwọn ènìyàn mi ni,’àwọn yóò sì wí pé, ‘OLÚWA ni Ọlọ́run wa.’ ”

In Other Versions

Zechariah 13 in the ANGEFD

Zechariah 13 in the ANTPNG2D

Zechariah 13 in the AS21

Zechariah 13 in the BAGH

Zechariah 13 in the BBPNG

Zechariah 13 in the BBT1E

Zechariah 13 in the BDS

Zechariah 13 in the BEV

Zechariah 13 in the BHAD

Zechariah 13 in the BIB

Zechariah 13 in the BLPT

Zechariah 13 in the BNT

Zechariah 13 in the BNTABOOT

Zechariah 13 in the BNTLV

Zechariah 13 in the BOATCB

Zechariah 13 in the BOATCB2

Zechariah 13 in the BOBCV

Zechariah 13 in the BOCNT

Zechariah 13 in the BOECS

Zechariah 13 in the BOGWICC

Zechariah 13 in the BOHCB

Zechariah 13 in the BOHCV

Zechariah 13 in the BOHLNT

Zechariah 13 in the BOHNTLTAL

Zechariah 13 in the BOICB

Zechariah 13 in the BOILNTAP

Zechariah 13 in the BOITCV

Zechariah 13 in the BOKCV

Zechariah 13 in the BOKCV2

Zechariah 13 in the BOKHWOG

Zechariah 13 in the BOKSSV

Zechariah 13 in the BOLCB

Zechariah 13 in the BOLCB2

Zechariah 13 in the BOMCV

Zechariah 13 in the BONAV

Zechariah 13 in the BONCB

Zechariah 13 in the BONLT

Zechariah 13 in the BONUT2

Zechariah 13 in the BOPLNT

Zechariah 13 in the BOSCB

Zechariah 13 in the BOSNC

Zechariah 13 in the BOTLNT

Zechariah 13 in the BOVCB

Zechariah 13 in the BPBB

Zechariah 13 in the BPH

Zechariah 13 in the BSB

Zechariah 13 in the CCB

Zechariah 13 in the CUV

Zechariah 13 in the CUVS

Zechariah 13 in the DBT

Zechariah 13 in the DGDNT

Zechariah 13 in the DHNT

Zechariah 13 in the DNT

Zechariah 13 in the ELBE

Zechariah 13 in the EMTV

Zechariah 13 in the ESV

Zechariah 13 in the FBV

Zechariah 13 in the FEB

Zechariah 13 in the GGMNT

Zechariah 13 in the GNT

Zechariah 13 in the HARY

Zechariah 13 in the HNT

Zechariah 13 in the IRVA

Zechariah 13 in the IRVB

Zechariah 13 in the IRVG

Zechariah 13 in the IRVH

Zechariah 13 in the IRVK

Zechariah 13 in the IRVM

Zechariah 13 in the IRVM2

Zechariah 13 in the IRVO

Zechariah 13 in the IRVP

Zechariah 13 in the IRVT

Zechariah 13 in the IRVT2

Zechariah 13 in the IRVU

Zechariah 13 in the ISVN

Zechariah 13 in the JSNT

Zechariah 13 in the KAPI

Zechariah 13 in the KBT1ETNIK

Zechariah 13 in the KBV

Zechariah 13 in the KJV

Zechariah 13 in the KNFD

Zechariah 13 in the LBA

Zechariah 13 in the LBLA

Zechariah 13 in the LNT

Zechariah 13 in the LSV

Zechariah 13 in the MAAL

Zechariah 13 in the MBV

Zechariah 13 in the MBV2

Zechariah 13 in the MHNT

Zechariah 13 in the MKNFD

Zechariah 13 in the MNG

Zechariah 13 in the MNT

Zechariah 13 in the MNT2

Zechariah 13 in the MRS1T

Zechariah 13 in the NAA

Zechariah 13 in the NASB

Zechariah 13 in the NBLA

Zechariah 13 in the NBS

Zechariah 13 in the NBVTP

Zechariah 13 in the NET2

Zechariah 13 in the NIV11

Zechariah 13 in the NNT

Zechariah 13 in the NNT2

Zechariah 13 in the NNT3

Zechariah 13 in the PDDPT

Zechariah 13 in the PFNT

Zechariah 13 in the RMNT

Zechariah 13 in the SBIAS

Zechariah 13 in the SBIBS

Zechariah 13 in the SBIBS2

Zechariah 13 in the SBICS

Zechariah 13 in the SBIDS

Zechariah 13 in the SBIGS

Zechariah 13 in the SBIHS

Zechariah 13 in the SBIIS

Zechariah 13 in the SBIIS2

Zechariah 13 in the SBIIS3

Zechariah 13 in the SBIKS

Zechariah 13 in the SBIKS2

Zechariah 13 in the SBIMS

Zechariah 13 in the SBIOS

Zechariah 13 in the SBIPS

Zechariah 13 in the SBISS

Zechariah 13 in the SBITS

Zechariah 13 in the SBITS2

Zechariah 13 in the SBITS3

Zechariah 13 in the SBITS4

Zechariah 13 in the SBIUS

Zechariah 13 in the SBIVS

Zechariah 13 in the SBT

Zechariah 13 in the SBT1E

Zechariah 13 in the SCHL

Zechariah 13 in the SNT

Zechariah 13 in the SUSU

Zechariah 13 in the SUSU2

Zechariah 13 in the SYNO

Zechariah 13 in the TBIAOTANT

Zechariah 13 in the TBT1E

Zechariah 13 in the TBT1E2

Zechariah 13 in the TFTIP

Zechariah 13 in the TFTU

Zechariah 13 in the TGNTATF3T

Zechariah 13 in the THAI

Zechariah 13 in the TNFD

Zechariah 13 in the TNT

Zechariah 13 in the TNTIK

Zechariah 13 in the TNTIL

Zechariah 13 in the TNTIN

Zechariah 13 in the TNTIP

Zechariah 13 in the TNTIZ

Zechariah 13 in the TOMA

Zechariah 13 in the TTENT

Zechariah 13 in the UBG

Zechariah 13 in the UGV

Zechariah 13 in the UGV2

Zechariah 13 in the UGV3

Zechariah 13 in the VBL

Zechariah 13 in the VDCC

Zechariah 13 in the YALU

Zechariah 13 in the YAPE

Zechariah 13 in the YBVTP

Zechariah 13 in the ZBP