Zechariah 2 (BOYCB)
1 Mó si tún gbé ojú mi, sókè, mo sì wò, sì kíyèsi i, ọkùnrin kan ti o mú okùn ìwọ̀n lọ́wọ́ rẹ̀. 2 Mo sí wí pé, “Níbo ni ìwọ ń lọ?”O sí wí fún mí pé, “Láti wọn Jerusalẹmu, láti rí iye ìbú rẹ̀, àti iye gígùn rẹ̀.” 3 Sì kíyèsi i, angẹli tí ó ń bá mi sọ̀rọ̀ jáde lọ, angẹli mìíràn si jáde lọ pàdé rẹ̀. 4 Ó si wí fún un pé, “Sáré, sọ fún ọ̀dọ́mọkùnrin yìí wí pé, ‘A ó gbé inú Jerusalẹmu bi ìlú ti kò ní odi, nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn àti ohun ọ̀sìn inú rẹ̀. 5 OLÚWA wí pé: Èmi ó sì jẹ́ odi iná fún un yíká, èmi ó sì jẹ́ ògo láàrín rẹ̀.’ 6 “Wá! Wá! Sá kúrò ni ilẹ̀ àríwá,” ni OLÚWA wí, “nítorí pé bí afẹ́fẹ́ mẹ́rin ọ̀run ni mo tú yín káàkiri,” ni OLÚWA wí. 7 “Gbà ara rẹ̀ sílẹ̀, ìwọ Sioni, ìwọ tí ó ń bà ọmọbìnrin Babeli gbé.” 8 Nítorí báyìí ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí: “Lẹ́yìn ògo rẹ̀ ni a ti rán mi sí àwọn orílẹ̀-èdè tí ń kó yin: nítorí ẹni tí ó tọ́ yin, ó tọ́ ọmọ ojú rẹ̀. 9 Nítorí kíyèsi i, èmi ó gbọn ọwọ́ mi sí orí wọn, wọn yóò sì jẹ́ ìkógun fún ìránṣẹ́ wọn: ẹ̀yin yóò sì mọ̀ pé, OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ni ó rán mi. 10 “Kọrin kí o sì yọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Sioni. Nítorí èmi ń bọ̀ àti pé èmi yóò sì gbé àárín rẹ,” ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí. 11 “Ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè ni yóò dàpọ̀ mọ́ OLÚWA ní ọjọ́ náà, wọn yóò sì di ènìyàn mi, èmi yóò sì gbé àárín rẹ, ìwọ yóò sì mọ̀ pé, OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ni ó rán mi sí ọ. 12 OLÚWA yóò sì jogún Juda ìní rẹ̀, ni ilẹ̀ mímọ́, yóò sì tún yan Jerusalẹmu. 13 Ẹ̀ dákẹ́, gbogbo ẹran-ara níwájú OLÚWA: nítorí a jí i láti ibùgbé mímọ́ rẹ̀ wá.”
In Other Versions
Zechariah 2 in the ANGEFD
Zechariah 2 in the ANTPNG2D
Zechariah 2 in the AS21
Zechariah 2 in the BAGH
Zechariah 2 in the BBPNG
Zechariah 2 in the BBT1E
Zechariah 2 in the BDS
Zechariah 2 in the BEV
Zechariah 2 in the BHAD
Zechariah 2 in the BIB
Zechariah 2 in the BLPT
Zechariah 2 in the BNT
Zechariah 2 in the BNTABOOT
Zechariah 2 in the BNTLV
Zechariah 2 in the BOATCB
Zechariah 2 in the BOATCB2
Zechariah 2 in the BOBCV
Zechariah 2 in the BOCNT
Zechariah 2 in the BOECS
Zechariah 2 in the BOGWICC
Zechariah 2 in the BOHCB
Zechariah 2 in the BOHCV
Zechariah 2 in the BOHLNT
Zechariah 2 in the BOHNTLTAL
Zechariah 2 in the BOICB
Zechariah 2 in the BOILNTAP
Zechariah 2 in the BOITCV
Zechariah 2 in the BOKCV
Zechariah 2 in the BOKCV2
Zechariah 2 in the BOKHWOG
Zechariah 2 in the BOKSSV
Zechariah 2 in the BOLCB
Zechariah 2 in the BOLCB2
Zechariah 2 in the BOMCV
Zechariah 2 in the BONAV
Zechariah 2 in the BONCB
Zechariah 2 in the BONLT
Zechariah 2 in the BONUT2
Zechariah 2 in the BOPLNT
Zechariah 2 in the BOSCB
Zechariah 2 in the BOSNC
Zechariah 2 in the BOTLNT
Zechariah 2 in the BOVCB
Zechariah 2 in the BPBB
Zechariah 2 in the BPH
Zechariah 2 in the BSB
Zechariah 2 in the CCB
Zechariah 2 in the CUV
Zechariah 2 in the CUVS
Zechariah 2 in the DBT
Zechariah 2 in the DGDNT
Zechariah 2 in the DHNT
Zechariah 2 in the DNT
Zechariah 2 in the ELBE
Zechariah 2 in the EMTV
Zechariah 2 in the ESV
Zechariah 2 in the FBV
Zechariah 2 in the FEB
Zechariah 2 in the GGMNT
Zechariah 2 in the GNT
Zechariah 2 in the HARY
Zechariah 2 in the HNT
Zechariah 2 in the IRVA
Zechariah 2 in the IRVB
Zechariah 2 in the IRVG
Zechariah 2 in the IRVH
Zechariah 2 in the IRVK
Zechariah 2 in the IRVM
Zechariah 2 in the IRVM2
Zechariah 2 in the IRVO
Zechariah 2 in the IRVP
Zechariah 2 in the IRVT
Zechariah 2 in the IRVT2
Zechariah 2 in the IRVU
Zechariah 2 in the ISVN
Zechariah 2 in the JSNT
Zechariah 2 in the KAPI
Zechariah 2 in the KBT1ETNIK
Zechariah 2 in the KBV
Zechariah 2 in the KJV
Zechariah 2 in the KNFD
Zechariah 2 in the LBA
Zechariah 2 in the LBLA
Zechariah 2 in the LNT
Zechariah 2 in the LSV
Zechariah 2 in the MAAL
Zechariah 2 in the MBV
Zechariah 2 in the MBV2
Zechariah 2 in the MHNT
Zechariah 2 in the MKNFD
Zechariah 2 in the MNG
Zechariah 2 in the MNT
Zechariah 2 in the MNT2
Zechariah 2 in the MRS1T
Zechariah 2 in the NAA
Zechariah 2 in the NASB
Zechariah 2 in the NBLA
Zechariah 2 in the NBS
Zechariah 2 in the NBVTP
Zechariah 2 in the NET2
Zechariah 2 in the NIV11
Zechariah 2 in the NNT
Zechariah 2 in the NNT2
Zechariah 2 in the NNT3
Zechariah 2 in the PDDPT
Zechariah 2 in the PFNT
Zechariah 2 in the RMNT
Zechariah 2 in the SBIAS
Zechariah 2 in the SBIBS
Zechariah 2 in the SBIBS2
Zechariah 2 in the SBICS
Zechariah 2 in the SBIDS
Zechariah 2 in the SBIGS
Zechariah 2 in the SBIHS
Zechariah 2 in the SBIIS
Zechariah 2 in the SBIIS2
Zechariah 2 in the SBIIS3
Zechariah 2 in the SBIKS
Zechariah 2 in the SBIKS2
Zechariah 2 in the SBIMS
Zechariah 2 in the SBIOS
Zechariah 2 in the SBIPS
Zechariah 2 in the SBISS
Zechariah 2 in the SBITS
Zechariah 2 in the SBITS2
Zechariah 2 in the SBITS3
Zechariah 2 in the SBITS4
Zechariah 2 in the SBIUS
Zechariah 2 in the SBIVS
Zechariah 2 in the SBT
Zechariah 2 in the SBT1E
Zechariah 2 in the SCHL
Zechariah 2 in the SNT
Zechariah 2 in the SUSU
Zechariah 2 in the SUSU2
Zechariah 2 in the SYNO
Zechariah 2 in the TBIAOTANT
Zechariah 2 in the TBT1E
Zechariah 2 in the TBT1E2
Zechariah 2 in the TFTIP
Zechariah 2 in the TFTU
Zechariah 2 in the TGNTATF3T
Zechariah 2 in the THAI
Zechariah 2 in the TNFD
Zechariah 2 in the TNT
Zechariah 2 in the TNTIK
Zechariah 2 in the TNTIL
Zechariah 2 in the TNTIN
Zechariah 2 in the TNTIP
Zechariah 2 in the TNTIZ
Zechariah 2 in the TOMA
Zechariah 2 in the TTENT
Zechariah 2 in the UBG
Zechariah 2 in the UGV
Zechariah 2 in the UGV2
Zechariah 2 in the UGV3
Zechariah 2 in the VBL
Zechariah 2 in the VDCC
Zechariah 2 in the YALU
Zechariah 2 in the YAPE
Zechariah 2 in the YBVTP
Zechariah 2 in the ZBP