1 Chronicles 9 (BOYCB)

1 Gbogbo Israẹli ni a kọ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ àwọn baba ńlá nínú ìwé àwọn ọba Israẹli. Àwọn ènìyàn Juda ni a kó ní ìgbèkùn lọ sí Babeli nítorí àìṣòótọ́ wọn. 2 Nísinsin yìí, àwọn tí ó kọ́kọ́ tún tẹ̀dó lórí ohun ìní wọn ní ìlú wọn ni díẹ̀ nínú àwọn ọmọ Israẹli, àwọn àlùfáà, àwọn ará Lefi àti àwọn ìránṣẹ́ ilé OLÚWA. 3 Àwọn tí ó wá láti Juda láti Benjamini àti láti Efraimu àti Manase tí ó ń gbé ní Jerusalẹmu jẹ́: 4 Uttai ọmọ Ammihudu, ọmọ Omri, ọmọ Imri, ọmọ Bani, ìran ọmọ Peresi ọmọ Juda. 5 Àti nínú ará Ṣilo:Asaiah àkọ́bí àti àwọn ọmọ rẹ̀. 6 Ní ti ará Sera:Jeueli.Àwọn ènìyàn láti Juda sì jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin ó dín mẹ́wàá (690). 7 Àti nínú àwọn ọmọ Benjamini ni:Sallu ọmọ Meṣullamu, ọmọ Hodafiah; ọmọ Hasenuah; 8 Ibinaiah ọmọ Jerohamu;Ela ọmọ Ussi, ọmọ Mikri;àti Meṣullamu ọmọ Ṣefatia; ọmọ Reueli, ọmọ Ibinijah. 9 Àwọn ènìyàn láti Benjamini gẹ́gẹ́ bí a ti ṣe kọ ọ́ nínú ìran wọn nínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn, tí ó jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó dín mẹ́rìnlélógójì (956). Gbogbo àwọn ọkùnrin yí jẹ́ àwọn olórí àwọn ìdílé. 10 Ní ti àwọn àlùfáà:Jedaiah; Jehoiaribi; Jakini; 11 Asariah ọmọ Hilkiah, ọmọ Meṣullamu, ọmọ Sadoku, ọmọ Meraioti, ọmọ Ahitubu, olórí tí ó ń bojútó ilé Ọlọ́run; 12 Adaiah ọmọ Jerohamu, ọmọ Paṣuri, ọmọ Malkiah;àti Masai ọmọ Adieli, ọmọ Jahisera, ọmọ Meṣullamu ọmọ Meṣilemiti, ọmọ Immeri. 13 Àwọn àlùfáà, tí wọ́n jẹ́ àwọn olórí àwọn ìdílé, tí ó jẹ́ ẹgbẹ̀sán ó dín méjì (1,760). Wọ́n jẹ́ alágbára ọkùnrin, tí wọ́n lè dúró fún iṣẹ́ ìránṣẹ́ nínú ilé Ọlọ́run. 14 Ní ti àwọn ará Lefi:Ṣemaiah ọmọ Haṣubu, ọmọ Asrikamu, ọmọ Haṣabiah ará Merari; 15 Bakibakari, Hereṣi, Galali àti Mattaniah, ọmọ Mika, ọmọ Sikri, ọmọ Asafu; 16 Obadiah ọmọ Ṣemaiah, ọmọ Galali, ọmọ Jedutuni;àti Berekiah ọmọ Asa, ọmọ Elkana, tí ó ń gbé nínú àwọn ìlú àwọn ará Netofa. 17 Àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà:Ṣallumu, Akkubu, Talmoni, Ahimani àti arákùnrin wọn, Ṣalumu olóyè wọn, 18 ti wà ní ipò ìdúró ní ẹnu-ọ̀nà ọba ní apá ìhà ìlà-oòrùn títí di àkókò yí. Wọ̀nyí ni àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà tí ó jẹ́ ti ìpàgọ́ àwọn ará Lefi. 19 Ṣallumu ọmọ Kore ọmọ Ebiasafi, ọmọ Kora, àti àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà ẹlẹgbẹ́ rẹ̀. Láti ìdílé rẹ̀ (àwọn ará Korati) ni ó dúró fún ṣíṣọ́ ìloro ẹnu-ọ̀nà àgọ́ gẹ́gẹ́ bí baba wọn ti ń dúró fún ṣíṣọ́ àbáwọlé ibùgbé OLÚWA. 20 Ní ìgbà àkọ́kọ́ Finehasi ọmọ Eleasari jẹ́ olórí fún àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà, OLÚWA sì wà pẹ̀lú rẹ̀. 21 Sekariah, ọmọ Meṣelemiah jẹ́ olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà ní àbáwọlé sí àgọ́ ibi ìpàdé. 22 Gbogbo rẹ̀ lápapọ̀, àwọn tí a yàn láti jẹ́ olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà ní àwọn ìloro jẹ́ igba ó lé méjìlá (212). A ka àwọn wọ̀nyí nípa ìdílé ní ìletò wọn. Àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà ni a ti yàn sí ipò láti ọ̀dọ̀ Dafidi àti Samuẹli, aríran, nítorí òtítọ́ wọn. 23 Àwọn àti àwọn ọmọ wọn ni ó wà fún ṣíṣọ́ ẹnu-ọ̀nà ilé OLÚWA ilé tí a pè ní àgọ́. 24 Àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà wà ní igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin: ìlà-oòrùn, ìwọ̀-oòrùn àríwá àti gúúsù. 25 Àwọn arákùnrin wọn ní àwọn ìletò wọn ní láti wá ní àkókò dé àkókò láti pín iṣẹ́ ìsìn wọn fún àkókò ọjọ́ méje. 26 Ṣùgbọ́n àwọn olórí alábojútó ẹnu-ọ̀nà mẹ́rẹ̀ẹ̀rin tí wọ́n jẹ́ ará Lefi ni a yàn fún àwọn iyàrá àti àwọn àpótí ìṣúra ní ilé Ọlọ́run. 27 Wọ́n á lo gbogbo òru ní dídúró yí ilé Ọlọ́run ká, nítorí wọ́n ní láti ṣọ́ ọ, wọ́n sì ní àṣẹ sí kọ́kọ́rọ́ fún ṣíṣí i ní àràárọ̀. 28 Díẹ̀ wà ní ìdí ohun èlò tí à ń lò fún ìsìn ilé Ọlọ́run; wọn a máa kà á nígbà tí wọ́n gbé e wọlé àti nígbà tí a kó wọn jáde. 29 Àwọn mìíràn ni a yàn láti bojútó ohun èlò àti gbogbo ohun èlò ilé tí a yà sọ́tọ̀ fún Ọlọ́run, àti ìyẹ̀fun àti ọtí èso àjàrà àti òróró náà, tùràrí àti tùràrí olóòórùn dídùn. 30 Ṣùgbọ́n díẹ̀ nínú àwọn àlùfáà ni ó ń bojútó pípò tùràrí olóòórùn dídùn papọ̀. 31 Ará Lefi tí a sọ ní Mattitiah àkọ́bí ọmọkùnrin Ṣallumu ará Kora ni a yàn, tí ń ṣe alábojútó ohun tí a dín. 32 Àti nínú àwọn arákùnrin wọn, nínú àwọn ọmọ Kohati tó ń ṣe ìtọ́jú àkàrà ìfihàn, láti máa pèsè rẹ̀ ní ọjọọjọ́ ìsinmi. 33 Àwọn tí wọ́n jẹ́ ọkùnrin, olórí àwọn ìdílé Lefi dúró nínú àgọ́ ilé OLÚWA, wọn kò sì ṣe lára iṣẹ́ ìsìn yòókù nítorí wọ́n ń ṣe iṣẹ́ náà lọ́sàn, lóru. 34 Gbogbo wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn Lefi, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti ṣe kọ lẹ́sẹẹsẹ sínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn, wọ́n sì ń gbé ní Jerusalẹmu. 35 Jeieli baba Gibeoni ń gbé ní Gibeoni.Orúkọ ìyàwó rẹ̀ a máa jẹ́ Maaka, 36 pẹ̀lú àkọ́bí ọmọkùnrin rẹ̀ jẹ́ Abdoni, tí wọ̀nyí sì ń tẹ̀lé Suri, Kiṣi, Baali, Neri, Nadabu. 37 Gedori, Ahio, Sekariah àti Mikiloti. 38 Mikiloti jẹ́ baba Ṣimeamu, àwọn náà ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní Jerusalẹmu. 39 Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba a Saulu, àti Saulu baba a Jonatani, àti Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-Baali. 40 Ọmọ Jonatani:Meribu-Baali, tí ó jẹ́ baba Mika. 41 Àwọn ọmọ Mika:Pitoni. Meleki, Tarea àti Ahasi. 42 Ahasi jẹ́ baba Jada, Jada jẹ́ baba Alemeti, Asmafeti, Simri, sì Simri jẹ́ baba Mosa. 43 Mosa jẹ́ baba Binea; Refaiah jẹ́ ọmọ rẹ̀, Eleasa ọmọ rẹ̀ àti Aseli ọmọ rẹ̀. 44 Aseli ní ọmọ mẹ́fà, pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn:Asrikamu, Bokeru, Iṣmaeli Ṣeariah, Obadiah àti Hanani, gbogbo wọ̀nyí ni ọmọ Aseli.

In Other Versions

1 Chronicles 9 in the ANGEFD

1 Chronicles 9 in the ANTPNG2D

1 Chronicles 9 in the AS21

1 Chronicles 9 in the BAGH

1 Chronicles 9 in the BBPNG

1 Chronicles 9 in the BBT1E

1 Chronicles 9 in the BDS

1 Chronicles 9 in the BEV

1 Chronicles 9 in the BHAD

1 Chronicles 9 in the BIB

1 Chronicles 9 in the BLPT

1 Chronicles 9 in the BNT

1 Chronicles 9 in the BNTABOOT

1 Chronicles 9 in the BNTLV

1 Chronicles 9 in the BOATCB

1 Chronicles 9 in the BOATCB2

1 Chronicles 9 in the BOBCV

1 Chronicles 9 in the BOCNT

1 Chronicles 9 in the BOECS

1 Chronicles 9 in the BOGWICC

1 Chronicles 9 in the BOHCB

1 Chronicles 9 in the BOHCV

1 Chronicles 9 in the BOHLNT

1 Chronicles 9 in the BOHNTLTAL

1 Chronicles 9 in the BOICB

1 Chronicles 9 in the BOILNTAP

1 Chronicles 9 in the BOITCV

1 Chronicles 9 in the BOKCV

1 Chronicles 9 in the BOKCV2

1 Chronicles 9 in the BOKHWOG

1 Chronicles 9 in the BOKSSV

1 Chronicles 9 in the BOLCB

1 Chronicles 9 in the BOLCB2

1 Chronicles 9 in the BOMCV

1 Chronicles 9 in the BONAV

1 Chronicles 9 in the BONCB

1 Chronicles 9 in the BONLT

1 Chronicles 9 in the BONUT2

1 Chronicles 9 in the BOPLNT

1 Chronicles 9 in the BOSCB

1 Chronicles 9 in the BOSNC

1 Chronicles 9 in the BOTLNT

1 Chronicles 9 in the BOVCB

1 Chronicles 9 in the BPBB

1 Chronicles 9 in the BPH

1 Chronicles 9 in the BSB

1 Chronicles 9 in the CCB

1 Chronicles 9 in the CUV

1 Chronicles 9 in the CUVS

1 Chronicles 9 in the DBT

1 Chronicles 9 in the DGDNT

1 Chronicles 9 in the DHNT

1 Chronicles 9 in the DNT

1 Chronicles 9 in the ELBE

1 Chronicles 9 in the EMTV

1 Chronicles 9 in the ESV

1 Chronicles 9 in the FBV

1 Chronicles 9 in the FEB

1 Chronicles 9 in the GGMNT

1 Chronicles 9 in the GNT

1 Chronicles 9 in the HARY

1 Chronicles 9 in the HNT

1 Chronicles 9 in the IRVA

1 Chronicles 9 in the IRVB

1 Chronicles 9 in the IRVG

1 Chronicles 9 in the IRVH

1 Chronicles 9 in the IRVK

1 Chronicles 9 in the IRVM

1 Chronicles 9 in the IRVM2

1 Chronicles 9 in the IRVO

1 Chronicles 9 in the IRVP

1 Chronicles 9 in the IRVT

1 Chronicles 9 in the IRVT2

1 Chronicles 9 in the IRVU

1 Chronicles 9 in the ISVN

1 Chronicles 9 in the JSNT

1 Chronicles 9 in the KAPI

1 Chronicles 9 in the KBT1ETNIK

1 Chronicles 9 in the KBV

1 Chronicles 9 in the KJV

1 Chronicles 9 in the KNFD

1 Chronicles 9 in the LBA

1 Chronicles 9 in the LBLA

1 Chronicles 9 in the LNT

1 Chronicles 9 in the LSV

1 Chronicles 9 in the MAAL

1 Chronicles 9 in the MBV

1 Chronicles 9 in the MBV2

1 Chronicles 9 in the MHNT

1 Chronicles 9 in the MKNFD

1 Chronicles 9 in the MNG

1 Chronicles 9 in the MNT

1 Chronicles 9 in the MNT2

1 Chronicles 9 in the MRS1T

1 Chronicles 9 in the NAA

1 Chronicles 9 in the NASB

1 Chronicles 9 in the NBLA

1 Chronicles 9 in the NBS

1 Chronicles 9 in the NBVTP

1 Chronicles 9 in the NET2

1 Chronicles 9 in the NIV11

1 Chronicles 9 in the NNT

1 Chronicles 9 in the NNT2

1 Chronicles 9 in the NNT3

1 Chronicles 9 in the PDDPT

1 Chronicles 9 in the PFNT

1 Chronicles 9 in the RMNT

1 Chronicles 9 in the SBIAS

1 Chronicles 9 in the SBIBS

1 Chronicles 9 in the SBIBS2

1 Chronicles 9 in the SBICS

1 Chronicles 9 in the SBIDS

1 Chronicles 9 in the SBIGS

1 Chronicles 9 in the SBIHS

1 Chronicles 9 in the SBIIS

1 Chronicles 9 in the SBIIS2

1 Chronicles 9 in the SBIIS3

1 Chronicles 9 in the SBIKS

1 Chronicles 9 in the SBIKS2

1 Chronicles 9 in the SBIMS

1 Chronicles 9 in the SBIOS

1 Chronicles 9 in the SBIPS

1 Chronicles 9 in the SBISS

1 Chronicles 9 in the SBITS

1 Chronicles 9 in the SBITS2

1 Chronicles 9 in the SBITS3

1 Chronicles 9 in the SBITS4

1 Chronicles 9 in the SBIUS

1 Chronicles 9 in the SBIVS

1 Chronicles 9 in the SBT

1 Chronicles 9 in the SBT1E

1 Chronicles 9 in the SCHL

1 Chronicles 9 in the SNT

1 Chronicles 9 in the SUSU

1 Chronicles 9 in the SUSU2

1 Chronicles 9 in the SYNO

1 Chronicles 9 in the TBIAOTANT

1 Chronicles 9 in the TBT1E

1 Chronicles 9 in the TBT1E2

1 Chronicles 9 in the TFTIP

1 Chronicles 9 in the TFTU

1 Chronicles 9 in the TGNTATF3T

1 Chronicles 9 in the THAI

1 Chronicles 9 in the TNFD

1 Chronicles 9 in the TNT

1 Chronicles 9 in the TNTIK

1 Chronicles 9 in the TNTIL

1 Chronicles 9 in the TNTIN

1 Chronicles 9 in the TNTIP

1 Chronicles 9 in the TNTIZ

1 Chronicles 9 in the TOMA

1 Chronicles 9 in the TTENT

1 Chronicles 9 in the UBG

1 Chronicles 9 in the UGV

1 Chronicles 9 in the UGV2

1 Chronicles 9 in the UGV3

1 Chronicles 9 in the VBL

1 Chronicles 9 in the VDCC

1 Chronicles 9 in the YALU

1 Chronicles 9 in the YAPE

1 Chronicles 9 in the YBVTP

1 Chronicles 9 in the ZBP