1 Samuel 27 (BOYCB)
1 Dafidi sì wí ní ọkàn ara rẹ̀ pé, “Ǹjẹ́ ni ìjọ kan ni èmi yóò ti ọwọ́ Saulu ṣègbé, kò sì sí ohun tí ó yẹ mí jù kí èmi yára sá àsálà lọ sórí ilẹ̀ àwọn Filistini, yóò sú Saulu láti máa tún wa mi kiri ní gbogbo agbègbè Israẹli, èmi a sì bọ́ lọ́wọ́ rẹ̀.” 2 Dafidi sì dìde, ó sì rékọjá, òun pẹ̀lú ẹgbẹ̀ta (600) ọmọkùnrin tí o ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀ sí Akiṣi, ọmọ Maoki, ọba Gati. 3 Dafidi sì bá Akiṣi jókòó ní Gati, òun, àti àwọn ọmọkùnrin rẹ, olúkúlùkù wọn pẹ̀lú ará ilé rẹ̀; Dafidi pẹ̀lú àwọn aya rẹ̀ méjèèjì, Ahinoamu ará Jesreeli, àti Abigaili ará Karmeli aya Nabali. 4 A sì sọ fún Saulu pé, Dafidi sálọ si Gati, òun kò sì tún wá á kiri mọ́. 5 Dafidi sì wí fún Akiṣi pé, “Bí ó bá jẹ́ pé èmi rí oore-ọ̀fẹ́ lójú rẹ̀, jẹ́ kí wọn ó fún mi ní ibìkan nínú àwọn ìletò wọ̀nyí; èmi yóò máa gbé ibẹ̀, èéṣe tí ìránṣẹ́ rẹ yóò sì máa bá ọ gbé ní ìlú ọba.” 6 Akiṣi sí fi Siklagi fún un ní ọjọ́ náà nítorí náà ni Siklagi fi dí ọba Juda títí ó fi dì òní yìí. 7 Iye ọjọ́ tí Dafidi fi jókòó ní ìlú àwọn Filistini sì jẹ́ ọdún kan àti oṣù mẹ́rin. 8 Dafidi àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì gòkè lọ, wọ́n sì gbé ogun ti àwọn ará Geṣuri, àti àwọn ará Gesri, àti àwọn ará Amaleki àwọn wọ̀nyí ni ó sì tí ń gbé ní ilẹ̀ náà, láti ìgbà àtijọ́, bí ó ti fẹ̀ lọ sí Ṣuri títí ó fi dé ilẹ̀ Ejibiti. 9 Dafidi sì kọlu ilẹ̀ náà kò sì fi ọkùnrin tàbí obìnrin sílẹ̀ láààyè, ó sì kó àgùntàn, àti màlúù, àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àti ìbákasẹ, àti aṣọ, ó sì yípadà ó tọ Akiṣi wá. 10 Akiṣi sì bi í pé, “Níbo ni ẹ̀yin gbé rìn sí lónìí?” Dafidi sì dáhùn pé, “Sí ìhà gúúsù ti Juda ni, tàbí sí ìhà gúúsù ti Jerahmeeli,” tàbí “Sí ìhà gúúsù ti àwọn ará Keni.” 11 Dafidi kò sì dá ọkùnrin tàbí obìnrin sí láààyè, láti mú ìròyìn wá sí Gati, wí pé, “Ki wọn máa bá à sọ ọ̀rọ̀ wa níbẹ̀, pé, ‘Báyìí ni Dafidi ṣe,’ ” àti bẹ́ẹ̀ ni ìṣe rẹ̀, yóò sì rí ni gbogbo ọjọ́ ti yóò fi jókòó ni ìlú àwọn Filistini. 12 Akiṣi sì gba ti Dafidi gbọ́, wí pé, “Òun ti mú kí Israẹli àti àwọn ènìyàn rẹ̀ kórìíra rẹ̀ pátápátá, yóò si jẹ́ ìránṣẹ́ mi títí láé.”
In Other Versions
1 Samuel 27 in the ANGEFD
1 Samuel 27 in the ANTPNG2D
1 Samuel 27 in the AS21
1 Samuel 27 in the BAGH
1 Samuel 27 in the BBPNG
1 Samuel 27 in the BBT1E
1 Samuel 27 in the BDS
1 Samuel 27 in the BEV
1 Samuel 27 in the BHAD
1 Samuel 27 in the BIB
1 Samuel 27 in the BLPT
1 Samuel 27 in the BNT
1 Samuel 27 in the BNTABOOT
1 Samuel 27 in the BNTLV
1 Samuel 27 in the BOATCB
1 Samuel 27 in the BOATCB2
1 Samuel 27 in the BOBCV
1 Samuel 27 in the BOCNT
1 Samuel 27 in the BOECS
1 Samuel 27 in the BOGWICC
1 Samuel 27 in the BOHCB
1 Samuel 27 in the BOHCV
1 Samuel 27 in the BOHLNT
1 Samuel 27 in the BOHNTLTAL
1 Samuel 27 in the BOICB
1 Samuel 27 in the BOILNTAP
1 Samuel 27 in the BOITCV
1 Samuel 27 in the BOKCV
1 Samuel 27 in the BOKCV2
1 Samuel 27 in the BOKHWOG
1 Samuel 27 in the BOKSSV
1 Samuel 27 in the BOLCB
1 Samuel 27 in the BOLCB2
1 Samuel 27 in the BOMCV
1 Samuel 27 in the BONAV
1 Samuel 27 in the BONCB
1 Samuel 27 in the BONLT
1 Samuel 27 in the BONUT2
1 Samuel 27 in the BOPLNT
1 Samuel 27 in the BOSCB
1 Samuel 27 in the BOSNC
1 Samuel 27 in the BOTLNT
1 Samuel 27 in the BOVCB
1 Samuel 27 in the BPBB
1 Samuel 27 in the BPH
1 Samuel 27 in the BSB
1 Samuel 27 in the CCB
1 Samuel 27 in the CUV
1 Samuel 27 in the CUVS
1 Samuel 27 in the DBT
1 Samuel 27 in the DGDNT
1 Samuel 27 in the DHNT
1 Samuel 27 in the DNT
1 Samuel 27 in the ELBE
1 Samuel 27 in the EMTV
1 Samuel 27 in the ESV
1 Samuel 27 in the FBV
1 Samuel 27 in the FEB
1 Samuel 27 in the GGMNT
1 Samuel 27 in the GNT
1 Samuel 27 in the HARY
1 Samuel 27 in the HNT
1 Samuel 27 in the IRVA
1 Samuel 27 in the IRVB
1 Samuel 27 in the IRVG
1 Samuel 27 in the IRVH
1 Samuel 27 in the IRVK
1 Samuel 27 in the IRVM
1 Samuel 27 in the IRVM2
1 Samuel 27 in the IRVO
1 Samuel 27 in the IRVP
1 Samuel 27 in the IRVT
1 Samuel 27 in the IRVT2
1 Samuel 27 in the IRVU
1 Samuel 27 in the ISVN
1 Samuel 27 in the JSNT
1 Samuel 27 in the KAPI
1 Samuel 27 in the KBT1ETNIK
1 Samuel 27 in the KBV
1 Samuel 27 in the KJV
1 Samuel 27 in the KNFD
1 Samuel 27 in the LBA
1 Samuel 27 in the LBLA
1 Samuel 27 in the LNT
1 Samuel 27 in the LSV
1 Samuel 27 in the MAAL
1 Samuel 27 in the MBV
1 Samuel 27 in the MBV2
1 Samuel 27 in the MHNT
1 Samuel 27 in the MKNFD
1 Samuel 27 in the MNG
1 Samuel 27 in the MNT
1 Samuel 27 in the MNT2
1 Samuel 27 in the MRS1T
1 Samuel 27 in the NAA
1 Samuel 27 in the NASB
1 Samuel 27 in the NBLA
1 Samuel 27 in the NBS
1 Samuel 27 in the NBVTP
1 Samuel 27 in the NET2
1 Samuel 27 in the NIV11
1 Samuel 27 in the NNT
1 Samuel 27 in the NNT2
1 Samuel 27 in the NNT3
1 Samuel 27 in the PDDPT
1 Samuel 27 in the PFNT
1 Samuel 27 in the RMNT
1 Samuel 27 in the SBIAS
1 Samuel 27 in the SBIBS
1 Samuel 27 in the SBIBS2
1 Samuel 27 in the SBICS
1 Samuel 27 in the SBIDS
1 Samuel 27 in the SBIGS
1 Samuel 27 in the SBIHS
1 Samuel 27 in the SBIIS
1 Samuel 27 in the SBIIS2
1 Samuel 27 in the SBIIS3
1 Samuel 27 in the SBIKS
1 Samuel 27 in the SBIKS2
1 Samuel 27 in the SBIMS
1 Samuel 27 in the SBIOS
1 Samuel 27 in the SBIPS
1 Samuel 27 in the SBISS
1 Samuel 27 in the SBITS
1 Samuel 27 in the SBITS2
1 Samuel 27 in the SBITS3
1 Samuel 27 in the SBITS4
1 Samuel 27 in the SBIUS
1 Samuel 27 in the SBIVS
1 Samuel 27 in the SBT
1 Samuel 27 in the SBT1E
1 Samuel 27 in the SCHL
1 Samuel 27 in the SNT
1 Samuel 27 in the SUSU
1 Samuel 27 in the SUSU2
1 Samuel 27 in the SYNO
1 Samuel 27 in the TBIAOTANT
1 Samuel 27 in the TBT1E
1 Samuel 27 in the TBT1E2
1 Samuel 27 in the TFTIP
1 Samuel 27 in the TFTU
1 Samuel 27 in the TGNTATF3T
1 Samuel 27 in the THAI
1 Samuel 27 in the TNFD
1 Samuel 27 in the TNT
1 Samuel 27 in the TNTIK
1 Samuel 27 in the TNTIL
1 Samuel 27 in the TNTIN
1 Samuel 27 in the TNTIP
1 Samuel 27 in the TNTIZ
1 Samuel 27 in the TOMA
1 Samuel 27 in the TTENT
1 Samuel 27 in the UBG
1 Samuel 27 in the UGV
1 Samuel 27 in the UGV2
1 Samuel 27 in the UGV3
1 Samuel 27 in the VBL
1 Samuel 27 in the VDCC
1 Samuel 27 in the YALU
1 Samuel 27 in the YAPE
1 Samuel 27 in the YBVTP
1 Samuel 27 in the ZBP