1 Samuel 29 (BOYCB)
1 Àwọn Filistini sì kó gbogbo ogun wọn jọ sí Afeki: Israẹli sì dó ni ibi ìsun omi tí ó wà ní Jesreeli. 2 Àwọn ìjòyè Filistini sì kọjá ní ọ̀rọ̀ọ̀rún àti lẹgbẹẹgbẹ̀rún; Dafidi àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ pẹ̀lú Akiṣi sì kẹ́yìn. 3 Àwọn ìjòyè Filistini sì béèrè wí pé, “Kín ni àwọn Heberu ń ṣe níhìn-ín yìí?”Akiṣi sì wí fún àwọn ìjòyè Filistini pé “Dafidi kọ yìí, ìránṣẹ́ Saulu ọba Israẹli, tí ó wà lọ́dọ̀ mi láti ọjọ́ wọ̀nyí tàbí láti ọdún wọ̀nyí, èmi kò ì tì í rí àṣìṣe kan ni ọwọ́ rẹ̀ láti ọjọ́ tí ó ti dé ọ̀dọ̀ mi títí di òní yìí.” 4 Àwọn ìjòyè Filistini sì bínú sí i; àwọn ìjòyè Filistini sì wí fún un pé, “Jẹ́ kí ọkùnrin yìí padà kí ó sì lọ sí ipò rẹ̀ tí ó fi fún un, kí ó má sì jẹ́ kí ó bá wa sọ̀kalẹ̀ lọ sí ogun, kí ó má ba à jásí ọ̀tá fún wa ni ogun, kín ni òun ó fi ba olúwa rẹ̀ làjà, orí àwọn ènìyàn wọ̀nyí kọ́? 5 Ṣé èyí ni Dafidi tiwọn torí rẹ̀ gberin ara wọn nínú ijó wí pé,“ ‘Saulu pa ẹgbẹ̀rún rẹ̀,Dafidi si pa ẹgbẹgbàarùn-ún tirẹ̀.’ ” 6 Akiṣi sì pe Dafidi, ó sì wí fún un pé, “Bí OLÚWA ti ń bẹ láààyè, ìwọ jẹ́ olóòótọ́ àti ẹni ìwà rere lójú mi, ní àlọ rẹ àti ààbọ̀ rẹ pẹ̀lú mi ní ogun: nítorí pé èmi ko tí ì ri búburú kan lọ́wọ́ rẹ́ láti ọjọ́ ti ìwọ ti tọ̀ mí wá, títí o fi dì òní yìí ṣùgbọ́n lójú àwọn ìjòyè, ìwọ kò ṣe ẹni tí ó tọ́. 7 Ǹjẹ́ yípadà kí o sì máa lọ ní àlàáfíà, kí ìwọ má ṣe bà àwọn Filistini nínú jẹ́.” 8 Dafidi sì wí fún Akiṣi pé, “Kín ni èmi ṣe? Kín ni ìwọ sì rí lọ́wọ́ ìránṣẹ́ rẹ láti ọjọ́ ti èmi ti ń gbé níwájú rẹ títí di òní yìí, tí èmi kì yóò fi lọ bá àwọn ọ̀tá ọba jà.” 9 Akiṣi sì dáhùn, ó sì wí fún Dafidi pé, “Èmi mọ̀ pé ìwọ ṣe ẹni rere lójú mi, bi angẹli Ọlọ́run; ṣùgbọ́n àwọn ìjòyè Filistini wí pé, ‘Òun kì yóò bá wa lọ sí ogun.’ 10 Ǹjẹ́, nísinsin yìí dìde ní òwúrọ̀ pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́ olúwa rẹ tí ó bá ọ wá, ki ẹ si dìde ní òwúrọ̀ nígbà tí ilẹ̀ bá mọ́ kí ẹ sì máa lọ.” 11 Dafidi àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì dìde ní òwúrọ̀ láti padà lọ sí ilẹ̀ àwọn Filistini. Àwọn Filistini sì gòkè lọ sí Jesreeli.
In Other Versions
1 Samuel 29 in the ANGEFD
1 Samuel 29 in the ANTPNG2D
1 Samuel 29 in the AS21
1 Samuel 29 in the BAGH
1 Samuel 29 in the BBPNG
1 Samuel 29 in the BBT1E
1 Samuel 29 in the BDS
1 Samuel 29 in the BEV
1 Samuel 29 in the BHAD
1 Samuel 29 in the BIB
1 Samuel 29 in the BLPT
1 Samuel 29 in the BNT
1 Samuel 29 in the BNTABOOT
1 Samuel 29 in the BNTLV
1 Samuel 29 in the BOATCB
1 Samuel 29 in the BOATCB2
1 Samuel 29 in the BOBCV
1 Samuel 29 in the BOCNT
1 Samuel 29 in the BOECS
1 Samuel 29 in the BOGWICC
1 Samuel 29 in the BOHCB
1 Samuel 29 in the BOHCV
1 Samuel 29 in the BOHLNT
1 Samuel 29 in the BOHNTLTAL
1 Samuel 29 in the BOICB
1 Samuel 29 in the BOILNTAP
1 Samuel 29 in the BOITCV
1 Samuel 29 in the BOKCV
1 Samuel 29 in the BOKCV2
1 Samuel 29 in the BOKHWOG
1 Samuel 29 in the BOKSSV
1 Samuel 29 in the BOLCB
1 Samuel 29 in the BOLCB2
1 Samuel 29 in the BOMCV
1 Samuel 29 in the BONAV
1 Samuel 29 in the BONCB
1 Samuel 29 in the BONLT
1 Samuel 29 in the BONUT2
1 Samuel 29 in the BOPLNT
1 Samuel 29 in the BOSCB
1 Samuel 29 in the BOSNC
1 Samuel 29 in the BOTLNT
1 Samuel 29 in the BOVCB
1 Samuel 29 in the BPBB
1 Samuel 29 in the BPH
1 Samuel 29 in the BSB
1 Samuel 29 in the CCB
1 Samuel 29 in the CUV
1 Samuel 29 in the CUVS
1 Samuel 29 in the DBT
1 Samuel 29 in the DGDNT
1 Samuel 29 in the DHNT
1 Samuel 29 in the DNT
1 Samuel 29 in the ELBE
1 Samuel 29 in the EMTV
1 Samuel 29 in the ESV
1 Samuel 29 in the FBV
1 Samuel 29 in the FEB
1 Samuel 29 in the GGMNT
1 Samuel 29 in the GNT
1 Samuel 29 in the HARY
1 Samuel 29 in the HNT
1 Samuel 29 in the IRVA
1 Samuel 29 in the IRVB
1 Samuel 29 in the IRVG
1 Samuel 29 in the IRVH
1 Samuel 29 in the IRVK
1 Samuel 29 in the IRVM
1 Samuel 29 in the IRVM2
1 Samuel 29 in the IRVO
1 Samuel 29 in the IRVP
1 Samuel 29 in the IRVT
1 Samuel 29 in the IRVT2
1 Samuel 29 in the IRVU
1 Samuel 29 in the ISVN
1 Samuel 29 in the JSNT
1 Samuel 29 in the KAPI
1 Samuel 29 in the KBT1ETNIK
1 Samuel 29 in the KBV
1 Samuel 29 in the KJV
1 Samuel 29 in the KNFD
1 Samuel 29 in the LBA
1 Samuel 29 in the LBLA
1 Samuel 29 in the LNT
1 Samuel 29 in the LSV
1 Samuel 29 in the MAAL
1 Samuel 29 in the MBV
1 Samuel 29 in the MBV2
1 Samuel 29 in the MHNT
1 Samuel 29 in the MKNFD
1 Samuel 29 in the MNG
1 Samuel 29 in the MNT
1 Samuel 29 in the MNT2
1 Samuel 29 in the MRS1T
1 Samuel 29 in the NAA
1 Samuel 29 in the NASB
1 Samuel 29 in the NBLA
1 Samuel 29 in the NBS
1 Samuel 29 in the NBVTP
1 Samuel 29 in the NET2
1 Samuel 29 in the NIV11
1 Samuel 29 in the NNT
1 Samuel 29 in the NNT2
1 Samuel 29 in the NNT3
1 Samuel 29 in the PDDPT
1 Samuel 29 in the PFNT
1 Samuel 29 in the RMNT
1 Samuel 29 in the SBIAS
1 Samuel 29 in the SBIBS
1 Samuel 29 in the SBIBS2
1 Samuel 29 in the SBICS
1 Samuel 29 in the SBIDS
1 Samuel 29 in the SBIGS
1 Samuel 29 in the SBIHS
1 Samuel 29 in the SBIIS
1 Samuel 29 in the SBIIS2
1 Samuel 29 in the SBIIS3
1 Samuel 29 in the SBIKS
1 Samuel 29 in the SBIKS2
1 Samuel 29 in the SBIMS
1 Samuel 29 in the SBIOS
1 Samuel 29 in the SBIPS
1 Samuel 29 in the SBISS
1 Samuel 29 in the SBITS
1 Samuel 29 in the SBITS2
1 Samuel 29 in the SBITS3
1 Samuel 29 in the SBITS4
1 Samuel 29 in the SBIUS
1 Samuel 29 in the SBIVS
1 Samuel 29 in the SBT
1 Samuel 29 in the SBT1E
1 Samuel 29 in the SCHL
1 Samuel 29 in the SNT
1 Samuel 29 in the SUSU
1 Samuel 29 in the SUSU2
1 Samuel 29 in the SYNO
1 Samuel 29 in the TBIAOTANT
1 Samuel 29 in the TBT1E
1 Samuel 29 in the TBT1E2
1 Samuel 29 in the TFTIP
1 Samuel 29 in the TFTU
1 Samuel 29 in the TGNTATF3T
1 Samuel 29 in the THAI
1 Samuel 29 in the TNFD
1 Samuel 29 in the TNT
1 Samuel 29 in the TNTIK
1 Samuel 29 in the TNTIL
1 Samuel 29 in the TNTIN
1 Samuel 29 in the TNTIP
1 Samuel 29 in the TNTIZ
1 Samuel 29 in the TOMA
1 Samuel 29 in the TTENT
1 Samuel 29 in the UBG
1 Samuel 29 in the UGV
1 Samuel 29 in the UGV2
1 Samuel 29 in the UGV3
1 Samuel 29 in the VBL
1 Samuel 29 in the VDCC
1 Samuel 29 in the YALU
1 Samuel 29 in the YAPE
1 Samuel 29 in the YBVTP
1 Samuel 29 in the ZBP