2 Chronicles 27 (BOYCB)
1 Jotamu sì jẹ́ ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n nígbà tí ó jẹ ọba, ó sì di ọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹ́rìndínlógún. Orúkọ ìyá rẹ̀ sì ni Jeruṣa ọmọbìnrin Sadoku. 2 Ó sì ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú OLÚWA, gẹ́gẹ́ bí baba rẹ̀ Ussiah ti ṣe, ṣùgbọ́n kìkì wí pé kò wọ ilé OLÚWA. Àwọn ènìyàn síbẹ̀síbẹ̀ wọ́n ń ṣe iṣẹ́ ibi wọn. 3 Jotamu sì kọ́ ẹnu-ọ̀nà gíga ilé OLÚWA ó sì ṣe iṣẹ́ lórí odi ni pẹ̀tẹ́lẹ̀ Ofeli. 4 Ó sì kọ́ àwọn ìlú ní Juda òkè àti nínú igbó àti ilé ìṣọ́, ó mọ ilé odi. 5 Jotamu sì ṣẹ́ ogun lórí ọba àwọn ará Ammoni ó sì borí wọn. Ní ọdún náà àwọn ará Ammoni wọ́n sì san fún ọgọ́rùn-ún tálẹ́ǹtì fàdákà àti ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) òsùwọ̀n alikama àti ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) barle. Àwọn ará Ammoni gbé e wá ní iye kan náà àti pẹ̀lú ní ọdún kejì àti ní ọdún kẹta. 6 Jotamu sì di alágbára nítorí ó rìn ní ọ̀nà tó tọ́ níwájú OLÚWA Ọlọ́run rẹ̀. 7 Ìyókù iṣẹ́ ìjọba Jotamu, pẹ̀lú gbogbo àwọn ogun rẹ̀ pẹ̀lú ohun mìíràn tí ó ṣe, ni a kọ sínú ìwé àwọn ọba Israẹli àti ti Juda. 8 Ó sì jẹ́ ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n nígbà tí ó jẹ ọba, ó sì jẹ ọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹ́rìndínlógún. 9 Jotamu sì sùn pẹ̀lú àwọn baba a rẹ̀ a sì sin ín ní ìlú Dafidi, Ahasi ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.
In Other Versions
2 Chronicles 27 in the ANGEFD
2 Chronicles 27 in the ANTPNG2D
2 Chronicles 27 in the AS21
2 Chronicles 27 in the BAGH
2 Chronicles 27 in the BBPNG
2 Chronicles 27 in the BBT1E
2 Chronicles 27 in the BDS
2 Chronicles 27 in the BEV
2 Chronicles 27 in the BHAD
2 Chronicles 27 in the BIB
2 Chronicles 27 in the BLPT
2 Chronicles 27 in the BNT
2 Chronicles 27 in the BNTABOOT
2 Chronicles 27 in the BNTLV
2 Chronicles 27 in the BOATCB
2 Chronicles 27 in the BOATCB2
2 Chronicles 27 in the BOBCV
2 Chronicles 27 in the BOCNT
2 Chronicles 27 in the BOECS
2 Chronicles 27 in the BOGWICC
2 Chronicles 27 in the BOHCB
2 Chronicles 27 in the BOHCV
2 Chronicles 27 in the BOHLNT
2 Chronicles 27 in the BOHNTLTAL
2 Chronicles 27 in the BOICB
2 Chronicles 27 in the BOILNTAP
2 Chronicles 27 in the BOITCV
2 Chronicles 27 in the BOKCV
2 Chronicles 27 in the BOKCV2
2 Chronicles 27 in the BOKHWOG
2 Chronicles 27 in the BOKSSV
2 Chronicles 27 in the BOLCB
2 Chronicles 27 in the BOLCB2
2 Chronicles 27 in the BOMCV
2 Chronicles 27 in the BONAV
2 Chronicles 27 in the BONCB
2 Chronicles 27 in the BONLT
2 Chronicles 27 in the BONUT2
2 Chronicles 27 in the BOPLNT
2 Chronicles 27 in the BOSCB
2 Chronicles 27 in the BOSNC
2 Chronicles 27 in the BOTLNT
2 Chronicles 27 in the BOVCB
2 Chronicles 27 in the BPBB
2 Chronicles 27 in the BPH
2 Chronicles 27 in the BSB
2 Chronicles 27 in the CCB
2 Chronicles 27 in the CUV
2 Chronicles 27 in the CUVS
2 Chronicles 27 in the DBT
2 Chronicles 27 in the DGDNT
2 Chronicles 27 in the DHNT
2 Chronicles 27 in the DNT
2 Chronicles 27 in the ELBE
2 Chronicles 27 in the EMTV
2 Chronicles 27 in the ESV
2 Chronicles 27 in the FBV
2 Chronicles 27 in the FEB
2 Chronicles 27 in the GGMNT
2 Chronicles 27 in the GNT
2 Chronicles 27 in the HARY
2 Chronicles 27 in the HNT
2 Chronicles 27 in the IRVA
2 Chronicles 27 in the IRVB
2 Chronicles 27 in the IRVG
2 Chronicles 27 in the IRVH
2 Chronicles 27 in the IRVK
2 Chronicles 27 in the IRVM
2 Chronicles 27 in the IRVM2
2 Chronicles 27 in the IRVO
2 Chronicles 27 in the IRVP
2 Chronicles 27 in the IRVT
2 Chronicles 27 in the IRVT2
2 Chronicles 27 in the IRVU
2 Chronicles 27 in the ISVN
2 Chronicles 27 in the JSNT
2 Chronicles 27 in the KAPI
2 Chronicles 27 in the KBT1ETNIK
2 Chronicles 27 in the KBV
2 Chronicles 27 in the KJV
2 Chronicles 27 in the KNFD
2 Chronicles 27 in the LBA
2 Chronicles 27 in the LBLA
2 Chronicles 27 in the LNT
2 Chronicles 27 in the LSV
2 Chronicles 27 in the MAAL
2 Chronicles 27 in the MBV
2 Chronicles 27 in the MBV2
2 Chronicles 27 in the MHNT
2 Chronicles 27 in the MKNFD
2 Chronicles 27 in the MNG
2 Chronicles 27 in the MNT
2 Chronicles 27 in the MNT2
2 Chronicles 27 in the MRS1T
2 Chronicles 27 in the NAA
2 Chronicles 27 in the NASB
2 Chronicles 27 in the NBLA
2 Chronicles 27 in the NBS
2 Chronicles 27 in the NBVTP
2 Chronicles 27 in the NET2
2 Chronicles 27 in the NIV11
2 Chronicles 27 in the NNT
2 Chronicles 27 in the NNT2
2 Chronicles 27 in the NNT3
2 Chronicles 27 in the PDDPT
2 Chronicles 27 in the PFNT
2 Chronicles 27 in the RMNT
2 Chronicles 27 in the SBIAS
2 Chronicles 27 in the SBIBS
2 Chronicles 27 in the SBIBS2
2 Chronicles 27 in the SBICS
2 Chronicles 27 in the SBIDS
2 Chronicles 27 in the SBIGS
2 Chronicles 27 in the SBIHS
2 Chronicles 27 in the SBIIS
2 Chronicles 27 in the SBIIS2
2 Chronicles 27 in the SBIIS3
2 Chronicles 27 in the SBIKS
2 Chronicles 27 in the SBIKS2
2 Chronicles 27 in the SBIMS
2 Chronicles 27 in the SBIOS
2 Chronicles 27 in the SBIPS
2 Chronicles 27 in the SBISS
2 Chronicles 27 in the SBITS
2 Chronicles 27 in the SBITS2
2 Chronicles 27 in the SBITS3
2 Chronicles 27 in the SBITS4
2 Chronicles 27 in the SBIUS
2 Chronicles 27 in the SBIVS
2 Chronicles 27 in the SBT
2 Chronicles 27 in the SBT1E
2 Chronicles 27 in the SCHL
2 Chronicles 27 in the SNT
2 Chronicles 27 in the SUSU
2 Chronicles 27 in the SUSU2
2 Chronicles 27 in the SYNO
2 Chronicles 27 in the TBIAOTANT
2 Chronicles 27 in the TBT1E
2 Chronicles 27 in the TBT1E2
2 Chronicles 27 in the TFTIP
2 Chronicles 27 in the TFTU
2 Chronicles 27 in the TGNTATF3T
2 Chronicles 27 in the THAI
2 Chronicles 27 in the TNFD
2 Chronicles 27 in the TNT
2 Chronicles 27 in the TNTIK
2 Chronicles 27 in the TNTIL
2 Chronicles 27 in the TNTIN
2 Chronicles 27 in the TNTIP
2 Chronicles 27 in the TNTIZ
2 Chronicles 27 in the TOMA
2 Chronicles 27 in the TTENT
2 Chronicles 27 in the UBG
2 Chronicles 27 in the UGV
2 Chronicles 27 in the UGV2
2 Chronicles 27 in the UGV3
2 Chronicles 27 in the VBL
2 Chronicles 27 in the VDCC
2 Chronicles 27 in the YALU
2 Chronicles 27 in the YAPE
2 Chronicles 27 in the YBVTP
2 Chronicles 27 in the ZBP