Isaiah 46 (BOYCB)
1 Beli tẹrí i rẹ̀ ba, Nebo bẹ̀rẹ̀ mọ́lẹ̀;àwọn ère wọn ni àwọn ẹranko rù.Àwọn ère tí wọ́n ń rù káàkiri ti diàjàgà sí wọn lọ́rùn,ẹrù fún àwọn tí àárẹ̀ mú. 2 Wọ́n bẹ̀rẹ̀ wọ́n sì foríbalẹ̀ papọ̀;wọn kò lè gba ẹrù náà,àwọn pẹ̀lú ni a kó lọ ní ìgbèkùn. 3 “Tẹ́tí sí mi, ìwọ ilé Jakọbu,gbogbo ẹ̀yin tí ó ṣẹ́kù nínú ilé Israẹli,ìwọ tí mo ti gbéró láti ìgbà tí o ti wà nínú oyún,tí mo sì ti ń pọ̀n láti ìgbà tí a ti bí ọ. 4 Pẹ̀lúpẹ̀lú sí àwọn arúgbó àti ewú orí yín,Èmi ni ẹni náà, Èmi ni ẹni tí yóò gbé ọ ró.Èmi ti mọ ọ́, èmi yóò sì gbé ọ;Èmi yóò dì ọ́ mú èmi ó sì gbà ọ́ sílẹ̀. 5 “Ta ni ìwọ yóò fi mí wé tàbí ta ni èmi yóò bá dọ́gba?Ta ni ìwọ yóò fi ṣe àkàwé mití àwa yóò jọ fi ara wé ara? 6 Ọ̀pọ̀ da wúrà sílẹ̀ nínú àpò wọnwọ́n sì wọn fàdákà lórí òsùwọ̀n;wọ́n bẹ alágbẹ̀dẹ lọ́wẹ̀ láti fi wọ́n ṣe òrìṣà,wọn sì tẹríba láti sìn ín. 7 Wọ́n gbé e lé èjìká wọn, wọ́n rù wọ́n,wọ́n sì gbé e sí ààyè rẹ̀ níbẹ̀ ni ó sì dúró sí.Láti ibẹ̀ náà kò le è paradà.Bí ènìyàn tilẹ̀ pariwo lé e lórí, òun kò le è dáhùn;òun kò lè gbà á nínú ìyọnu rẹ̀. 8 “Rántí èyí, fi í sí ọkàn rẹ,fi sí ọkàn rẹ, ẹ̀yin ọlọ̀tẹ̀. 9 Rántí àwọn nǹkan àtẹ̀yìnwá, àwọn ti àtijọ́-tijọ́;Èmi ni Ọlọ́run, kò sì sí ẹlòmíràn;Èmi ni Ọlọ́run, kò sí ẹlòmíràn bí ì mi. 10 Mo fi òpin hàn láti ìbẹ̀rẹ̀ wá,láti àtètèkọ́ṣe, ohun tí ó sì ń bọ̀ wá.Mo wí pé, Ète mi yóò dúró,àti pé èmi yóò ṣe ohun tí ó wù mí. 11 Láti ìlà-oòrùn wá ni mo ti pe ẹyẹ ajẹran wá;láti ọ̀nà jíjìn réré, ọkùnrin kan tí yóò mú ète mi ṣẹ.Ohun tí mo ti sọ, òun ni èmi yóò mú ṣẹ;èyí tí mo ti gbèrò, òun ni èmi yóò ṣe. 12 Gbọ́ tèmi, ẹ̀yin alágídí ọkàn,ìwọ tí ó jìnnà sí òdodo. 13 Èmi ń mú òdodo mi bọ̀ nítòsí,kò tilẹ̀ jìnnà rárá;àti ìgbàlà mi ni a kì yóò dádúró.Èmi yóò fún Sioni ní ìgbàlàògo mi fún Israẹli.
In Other Versions
Isaiah 46 in the ANGEFD
Isaiah 46 in the ANTPNG2D
Isaiah 46 in the AS21
Isaiah 46 in the BAGH
Isaiah 46 in the BBPNG
Isaiah 46 in the BBT1E
Isaiah 46 in the BDS
Isaiah 46 in the BEV
Isaiah 46 in the BHAD
Isaiah 46 in the BIB
Isaiah 46 in the BLPT
Isaiah 46 in the BNT
Isaiah 46 in the BNTABOOT
Isaiah 46 in the BNTLV
Isaiah 46 in the BOATCB
Isaiah 46 in the BOATCB2
Isaiah 46 in the BOBCV
Isaiah 46 in the BOCNT
Isaiah 46 in the BOECS
Isaiah 46 in the BOGWICC
Isaiah 46 in the BOHCB
Isaiah 46 in the BOHCV
Isaiah 46 in the BOHLNT
Isaiah 46 in the BOHNTLTAL
Isaiah 46 in the BOICB
Isaiah 46 in the BOILNTAP
Isaiah 46 in the BOITCV
Isaiah 46 in the BOKCV
Isaiah 46 in the BOKCV2
Isaiah 46 in the BOKHWOG
Isaiah 46 in the BOKSSV
Isaiah 46 in the BOLCB
Isaiah 46 in the BOLCB2
Isaiah 46 in the BOMCV
Isaiah 46 in the BONAV
Isaiah 46 in the BONCB
Isaiah 46 in the BONLT
Isaiah 46 in the BONUT2
Isaiah 46 in the BOPLNT
Isaiah 46 in the BOSCB
Isaiah 46 in the BOSNC
Isaiah 46 in the BOTLNT
Isaiah 46 in the BOVCB
Isaiah 46 in the BPBB
Isaiah 46 in the BPH
Isaiah 46 in the BSB
Isaiah 46 in the CCB
Isaiah 46 in the CUV
Isaiah 46 in the CUVS
Isaiah 46 in the DBT
Isaiah 46 in the DGDNT
Isaiah 46 in the DHNT
Isaiah 46 in the DNT
Isaiah 46 in the ELBE
Isaiah 46 in the EMTV
Isaiah 46 in the ESV
Isaiah 46 in the FBV
Isaiah 46 in the FEB
Isaiah 46 in the GGMNT
Isaiah 46 in the GNT
Isaiah 46 in the HARY
Isaiah 46 in the HNT
Isaiah 46 in the IRVA
Isaiah 46 in the IRVB
Isaiah 46 in the IRVG
Isaiah 46 in the IRVH
Isaiah 46 in the IRVK
Isaiah 46 in the IRVM
Isaiah 46 in the IRVM2
Isaiah 46 in the IRVO
Isaiah 46 in the IRVP
Isaiah 46 in the IRVT
Isaiah 46 in the IRVT2
Isaiah 46 in the IRVU
Isaiah 46 in the ISVN
Isaiah 46 in the JSNT
Isaiah 46 in the KAPI
Isaiah 46 in the KBT1ETNIK
Isaiah 46 in the KBV
Isaiah 46 in the KJV
Isaiah 46 in the KNFD
Isaiah 46 in the LBA
Isaiah 46 in the LBLA
Isaiah 46 in the LNT
Isaiah 46 in the LSV
Isaiah 46 in the MAAL
Isaiah 46 in the MBV
Isaiah 46 in the MBV2
Isaiah 46 in the MHNT
Isaiah 46 in the MKNFD
Isaiah 46 in the MNG
Isaiah 46 in the MNT
Isaiah 46 in the MNT2
Isaiah 46 in the MRS1T
Isaiah 46 in the NAA
Isaiah 46 in the NASB
Isaiah 46 in the NBLA
Isaiah 46 in the NBS
Isaiah 46 in the NBVTP
Isaiah 46 in the NET2
Isaiah 46 in the NIV11
Isaiah 46 in the NNT
Isaiah 46 in the NNT2
Isaiah 46 in the NNT3
Isaiah 46 in the PDDPT
Isaiah 46 in the PFNT
Isaiah 46 in the RMNT
Isaiah 46 in the SBIAS
Isaiah 46 in the SBIBS
Isaiah 46 in the SBIBS2
Isaiah 46 in the SBICS
Isaiah 46 in the SBIDS
Isaiah 46 in the SBIGS
Isaiah 46 in the SBIHS
Isaiah 46 in the SBIIS
Isaiah 46 in the SBIIS2
Isaiah 46 in the SBIIS3
Isaiah 46 in the SBIKS
Isaiah 46 in the SBIKS2
Isaiah 46 in the SBIMS
Isaiah 46 in the SBIOS
Isaiah 46 in the SBIPS
Isaiah 46 in the SBISS
Isaiah 46 in the SBITS
Isaiah 46 in the SBITS2
Isaiah 46 in the SBITS3
Isaiah 46 in the SBITS4
Isaiah 46 in the SBIUS
Isaiah 46 in the SBIVS
Isaiah 46 in the SBT
Isaiah 46 in the SBT1E
Isaiah 46 in the SCHL
Isaiah 46 in the SNT
Isaiah 46 in the SUSU
Isaiah 46 in the SUSU2
Isaiah 46 in the SYNO
Isaiah 46 in the TBIAOTANT
Isaiah 46 in the TBT1E
Isaiah 46 in the TBT1E2
Isaiah 46 in the TFTIP
Isaiah 46 in the TFTU
Isaiah 46 in the TGNTATF3T
Isaiah 46 in the THAI
Isaiah 46 in the TNFD
Isaiah 46 in the TNT
Isaiah 46 in the TNTIK
Isaiah 46 in the TNTIL
Isaiah 46 in the TNTIN
Isaiah 46 in the TNTIP
Isaiah 46 in the TNTIZ
Isaiah 46 in the TOMA
Isaiah 46 in the TTENT
Isaiah 46 in the UBG
Isaiah 46 in the UGV
Isaiah 46 in the UGV2
Isaiah 46 in the UGV3
Isaiah 46 in the VBL
Isaiah 46 in the VDCC
Isaiah 46 in the YALU
Isaiah 46 in the YAPE
Isaiah 46 in the YBVTP
Isaiah 46 in the ZBP