Micah 3 (BOYCB)
1 Nígbà náà, ni mo wí pé,“Ẹ gbọ́, ẹ̀yin olórí Jakọbu,ẹ̀yin alákòóso ilé Israẹli.Ǹjẹ́ ẹ̀yin kò ha ni í gba òdodo bí. 2 Ẹ̀yin tí ó kórìíra ìre, tí ẹ sì fẹ́ràn ibi;ẹ̀yin tí ẹ fa awọ ẹran-ara àwọn ènìyàn mi ya kúrò lára wọnàti ẹran-ara wọn kúrò ní egungun wọn; 3 àwọn tí ó jẹ ẹran-ara àwọn ènìyàn mi,wọn sì bọ́ awọ ara wọn kúrò lára wọn.Wọ́n sì fọ́ egungun wọn sí wẹ́wẹ́;wọn sì gé e sí wẹ́wẹ́ bí ẹran inú ìkòkò,bí ẹran inú agbada?” 4 Nígbà náà ni wọn yóò kígbe sí OLÚWA,ṣùgbọ́n òun kì yóò dá wọn lóhùn.Ní àkókò náà ni òun yóò fi ojú rẹ̀ pamọ́ kúrò lọ́dọ̀ wọn,nítorí ibi tí wọ́n ti ṣe. 5 Báyìí ni OLÚWA wí,“Ní ti àwọn Wòlíìtí ń ṣi àwọn ènìyàn mi lọ́nà,tí ẹnìkan bá fún wọn ní oúnjẹ,wọn yóò kéde àlàáfíà;ṣùgbọ́n tí kò bá fi nǹkan sí wọn ní ẹnu,wọn yóò múra ogun sí i. 6 Nítorí náà òru yóò wá sórí yín,tí ẹ̀yin kì yóò sì rí ìran kankan,òkùnkùn yóò sì kùn fún yín,tí ẹ̀yin kì yóò sì lè sọtẹ́lẹ̀.Oòrùn yóò sì wọ lórí àwọn wòlíìọjọ́ yóò sì ṣókùnkùn lórí wọn. 7 Ojú yóò sì ti àwọn wòlíìàwọn alásọtẹ́lẹ̀ pẹ̀lú yóò sì gba ìtìjú.Gbogbo wọn ni yóò bo ojú wọn,nítorí kò sí ìdáhùn láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run.” 8 Ṣùgbọ́n ní tèmi,èmi kún fún agbára pẹ̀lú ẹ̀mí OLÚWA,láti sọ ìré-òfin-kọjá Jakọbu fún un,àti láti sọ ẹ̀ṣẹ̀ Israẹli fún un. 9 Gbọ́ ẹ̀yin olórí ilé Jakọbu,àti ẹ̀yin alákòóso ilé Israẹli,tí ó kórìíra òdodotí ó sì yí òtítọ́ padà; 10 tí ó kọ́ Sioni pẹ̀lú ìtàjẹ̀ sílẹ̀,àti Jerusalẹmu pẹ̀lú ìwà búburú. 11 Àwọn olórí rẹ̀ ń ṣe ìdájọ́ nítorí àbẹ̀tẹ́lẹ̀,àwọn àlùfáà rẹ̀ sì ń kọ́ni nítorí owó ọ̀yààwọn wòlíì rẹ̀ pẹ̀lú sì ń sọtẹ́lẹ̀ nítorí owó.Síbẹ̀, wọn gbẹ́kẹ̀lé OLÚWA, wọ́n sì wí pé,“Nítòótọ́, OLÚWA wà pẹ̀lú wa!Ibi kan kì yóò bá wa.” 12 Nítorí náà, nítorí tiyín,ni a ó ṣe ro Sioni bí oko,Jerusalẹmu yóò sì di ebèàti òkè tẹmpili bí i ibi gíga igbó.
In Other Versions
Micah 3 in the ANGEFD
Micah 3 in the ANTPNG2D
Micah 3 in the AS21
Micah 3 in the BAGH
Micah 3 in the BBPNG
Micah 3 in the BBT1E
Micah 3 in the BDS
Micah 3 in the BEV
Micah 3 in the BHAD
Micah 3 in the BIB
Micah 3 in the BLPT
Micah 3 in the BNT
Micah 3 in the BNTABOOT
Micah 3 in the BNTLV
Micah 3 in the BOATCB
Micah 3 in the BOATCB2
Micah 3 in the BOBCV
Micah 3 in the BOCNT
Micah 3 in the BOECS
Micah 3 in the BOGWICC
Micah 3 in the BOHCB
Micah 3 in the BOHCV
Micah 3 in the BOHLNT
Micah 3 in the BOHNTLTAL
Micah 3 in the BOICB
Micah 3 in the BOILNTAP
Micah 3 in the BOITCV
Micah 3 in the BOKCV
Micah 3 in the BOKCV2
Micah 3 in the BOKHWOG
Micah 3 in the BOKSSV
Micah 3 in the BOLCB
Micah 3 in the BOLCB2
Micah 3 in the BOMCV
Micah 3 in the BONAV
Micah 3 in the BONCB
Micah 3 in the BONLT
Micah 3 in the BONUT2
Micah 3 in the BOPLNT
Micah 3 in the BOSCB
Micah 3 in the BOSNC
Micah 3 in the BOTLNT
Micah 3 in the BOVCB
Micah 3 in the BPBB
Micah 3 in the BPH
Micah 3 in the BSB
Micah 3 in the CCB
Micah 3 in the CUV
Micah 3 in the CUVS
Micah 3 in the DBT
Micah 3 in the DGDNT
Micah 3 in the DHNT
Micah 3 in the DNT
Micah 3 in the ELBE
Micah 3 in the EMTV
Micah 3 in the ESV
Micah 3 in the FBV
Micah 3 in the FEB
Micah 3 in the GGMNT
Micah 3 in the GNT
Micah 3 in the HARY
Micah 3 in the HNT
Micah 3 in the IRVA
Micah 3 in the IRVB
Micah 3 in the IRVG
Micah 3 in the IRVH
Micah 3 in the IRVK
Micah 3 in the IRVM
Micah 3 in the IRVM2
Micah 3 in the IRVO
Micah 3 in the IRVP
Micah 3 in the IRVT
Micah 3 in the IRVT2
Micah 3 in the IRVU
Micah 3 in the ISVN
Micah 3 in the JSNT
Micah 3 in the KAPI
Micah 3 in the KBT1ETNIK
Micah 3 in the KBV
Micah 3 in the KJV
Micah 3 in the KNFD
Micah 3 in the LBA
Micah 3 in the LBLA
Micah 3 in the LNT
Micah 3 in the LSV
Micah 3 in the MAAL
Micah 3 in the MBV
Micah 3 in the MBV2
Micah 3 in the MHNT
Micah 3 in the MKNFD
Micah 3 in the MNG
Micah 3 in the MNT
Micah 3 in the MNT2
Micah 3 in the MRS1T
Micah 3 in the NAA
Micah 3 in the NASB
Micah 3 in the NBLA
Micah 3 in the NBS
Micah 3 in the NBVTP
Micah 3 in the NET2
Micah 3 in the NIV11
Micah 3 in the NNT
Micah 3 in the NNT2
Micah 3 in the NNT3
Micah 3 in the PDDPT
Micah 3 in the PFNT
Micah 3 in the RMNT
Micah 3 in the SBIAS
Micah 3 in the SBIBS
Micah 3 in the SBIBS2
Micah 3 in the SBICS
Micah 3 in the SBIDS
Micah 3 in the SBIGS
Micah 3 in the SBIHS
Micah 3 in the SBIIS
Micah 3 in the SBIIS2
Micah 3 in the SBIIS3
Micah 3 in the SBIKS
Micah 3 in the SBIKS2
Micah 3 in the SBIMS
Micah 3 in the SBIOS
Micah 3 in the SBIPS
Micah 3 in the SBISS
Micah 3 in the SBITS
Micah 3 in the SBITS2
Micah 3 in the SBITS3
Micah 3 in the SBITS4
Micah 3 in the SBIUS
Micah 3 in the SBIVS
Micah 3 in the SBT
Micah 3 in the SBT1E
Micah 3 in the SCHL
Micah 3 in the SNT
Micah 3 in the SUSU
Micah 3 in the SUSU2
Micah 3 in the SYNO
Micah 3 in the TBIAOTANT
Micah 3 in the TBT1E
Micah 3 in the TBT1E2
Micah 3 in the TFTIP
Micah 3 in the TFTU
Micah 3 in the TGNTATF3T
Micah 3 in the THAI
Micah 3 in the TNFD
Micah 3 in the TNT
Micah 3 in the TNTIK
Micah 3 in the TNTIL
Micah 3 in the TNTIN
Micah 3 in the TNTIP
Micah 3 in the TNTIZ
Micah 3 in the TOMA
Micah 3 in the TTENT
Micah 3 in the UBG
Micah 3 in the UGV
Micah 3 in the UGV2
Micah 3 in the UGV3
Micah 3 in the VBL
Micah 3 in the VDCC
Micah 3 in the YALU
Micah 3 in the YAPE
Micah 3 in the YBVTP
Micah 3 in the ZBP