Numbers 12 (BOYCB)

1 Miriamu àti Aaroni sọ̀rọ̀-òdì sí Mose nítorí pé ó fẹ́ obìnrin ará Etiopia. 2 Wọ́n sì wí pé, “Nípa Mose nìkan ni OLÚWA ti sọ̀rọ̀ bí, kò ha ti ipa wa sọ̀rọ̀ bí?” OLÚWA sì gbọ́ èyí. 3 (Mose sì jẹ́ ọlọ́kàn tútù ju gbogbo ènìyàn tó wà lórí ilẹ̀ ayé lọ). 4 Lẹ́ẹ̀kan náà ni OLÚWA sọ fún Mose, Aaroni àti Miriamu pé, “Ẹ̀yin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta, jáde wá sínú àgọ́ ìpàdé.” Àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta sì jáde síta. 5 Nígbà náà ni OLÚWA sọ̀kalẹ̀ nínú ọ̀wọ́n ìkùùkuu, ó sì dúró ní ẹnu-ọ̀nà àgọ́, ó ké sí Aaroni àti Miriamu. Àwọn méjèèjì sì bọ́ síwájú, 6 Ó wí pé, “Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi,“Bí wòlíì OLÚWA bá wà láàrín yín,Èmi OLÚWA a máa fi ara à mi hàn án ní ojúran,Èmi a máa bá a sọ̀rọ̀ nínú àlá. 7 Ṣùgbọ́n èyí kò rí bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú Mose ìránṣẹ́ mi;ó jẹ́ olóòtítọ́ nínú gbogbo ilé mi. 8 Mo sì ń bá a sọ̀rọ̀ ní ojúkojú,ọ̀rọ̀ yékéyéké tí kì í ṣe òwe,ó rí àwòrán OLÚWA.Kí ló wá dé tí ẹ̀yin kò ṣe bẹ̀rùláti sọ̀rọ̀-òdì sí Mose ìránṣẹ́ mi?” 9 Ìbínú OLÚWA sì ru sókè sí wọn OLÚWA sì fi wọ́n sílẹ̀. 10 Nígbà tí ìkùùkuu kúrò lórí àgọ́ lójijì ni Miriamu di adẹ́tẹ̀, ó funfun bí i yìnyín. Aaroni sì padà wo Miriamu ó sì rí i pé ó ti di adẹ́tẹ̀, 11 Aaroni sì wí fún Mose pé, “Jọ̀wọ́ olúwa mi, má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀, èyí tí a fi ìwà òmùgọ̀ dá sí wa lọ́rùn. 12 Má ṣe jẹ́ kí ó dàbí òkú ọmọ tí a bí, tí ìdajì ara rẹ̀ ti rà dànù.” 13 Torí èyí Mose sì kígbe sí OLÚWA, “Ọlọ́run, jọ̀wọ́, mú un láradá!” 14 OLÚWA sì dá Mose lóhùn, “Bí baba rẹ̀ bá tutọ́ sí i lójú, ojú kò wa ní í tì í fún ọjọ́ méje? Dá a dúró sí ẹ̀yìn ibùdó fún ọjọ́ méje, lẹ́yìn èyí ki a tó ó le mú wọlé.” 15 Miriamu sì dúró sí ẹ̀yìn ibùdó fún ọjọ́ méje, àwọn ènìyàn kò sì tẹ̀síwájú nínú ìrìnàjò wọn títí tí Miriamu fi wọ inú ibùdó padà. 16 Lẹ́yìn èyí, àwọn ènìyàn kúrò ní Haserotu, wọ́n sì pa ibùdó sí aginjù Parani.

In Other Versions

Numbers 12 in the ANGEFD

Numbers 12 in the ANTPNG2D

Numbers 12 in the AS21

Numbers 12 in the BAGH

Numbers 12 in the BBPNG

Numbers 12 in the BBT1E

Numbers 12 in the BDS

Numbers 12 in the BEV

Numbers 12 in the BHAD

Numbers 12 in the BIB

Numbers 12 in the BLPT

Numbers 12 in the BNT

Numbers 12 in the BNTABOOT

Numbers 12 in the BNTLV

Numbers 12 in the BOATCB

Numbers 12 in the BOATCB2

Numbers 12 in the BOBCV

Numbers 12 in the BOCNT

Numbers 12 in the BOECS

Numbers 12 in the BOGWICC

Numbers 12 in the BOHCB

Numbers 12 in the BOHCV

Numbers 12 in the BOHLNT

Numbers 12 in the BOHNTLTAL

Numbers 12 in the BOICB

Numbers 12 in the BOILNTAP

Numbers 12 in the BOITCV

Numbers 12 in the BOKCV

Numbers 12 in the BOKCV2

Numbers 12 in the BOKHWOG

Numbers 12 in the BOKSSV

Numbers 12 in the BOLCB

Numbers 12 in the BOLCB2

Numbers 12 in the BOMCV

Numbers 12 in the BONAV

Numbers 12 in the BONCB

Numbers 12 in the BONLT

Numbers 12 in the BONUT2

Numbers 12 in the BOPLNT

Numbers 12 in the BOSCB

Numbers 12 in the BOSNC

Numbers 12 in the BOTLNT

Numbers 12 in the BOVCB

Numbers 12 in the BPBB

Numbers 12 in the BPH

Numbers 12 in the BSB

Numbers 12 in the CCB

Numbers 12 in the CUV

Numbers 12 in the CUVS

Numbers 12 in the DBT

Numbers 12 in the DGDNT

Numbers 12 in the DHNT

Numbers 12 in the DNT

Numbers 12 in the ELBE

Numbers 12 in the EMTV

Numbers 12 in the ESV

Numbers 12 in the FBV

Numbers 12 in the FEB

Numbers 12 in the GGMNT

Numbers 12 in the GNT

Numbers 12 in the HARY

Numbers 12 in the HNT

Numbers 12 in the IRVA

Numbers 12 in the IRVB

Numbers 12 in the IRVG

Numbers 12 in the IRVH

Numbers 12 in the IRVK

Numbers 12 in the IRVM

Numbers 12 in the IRVM2

Numbers 12 in the IRVO

Numbers 12 in the IRVP

Numbers 12 in the IRVT

Numbers 12 in the IRVT2

Numbers 12 in the IRVU

Numbers 12 in the ISVN

Numbers 12 in the JSNT

Numbers 12 in the KAPI

Numbers 12 in the KBT1ETNIK

Numbers 12 in the KBV

Numbers 12 in the KJV

Numbers 12 in the KNFD

Numbers 12 in the LBA

Numbers 12 in the LBLA

Numbers 12 in the LNT

Numbers 12 in the LSV

Numbers 12 in the MAAL

Numbers 12 in the MBV

Numbers 12 in the MBV2

Numbers 12 in the MHNT

Numbers 12 in the MKNFD

Numbers 12 in the MNG

Numbers 12 in the MNT

Numbers 12 in the MNT2

Numbers 12 in the MRS1T

Numbers 12 in the NAA

Numbers 12 in the NASB

Numbers 12 in the NBLA

Numbers 12 in the NBS

Numbers 12 in the NBVTP

Numbers 12 in the NET2

Numbers 12 in the NIV11

Numbers 12 in the NNT

Numbers 12 in the NNT2

Numbers 12 in the NNT3

Numbers 12 in the PDDPT

Numbers 12 in the PFNT

Numbers 12 in the RMNT

Numbers 12 in the SBIAS

Numbers 12 in the SBIBS

Numbers 12 in the SBIBS2

Numbers 12 in the SBICS

Numbers 12 in the SBIDS

Numbers 12 in the SBIGS

Numbers 12 in the SBIHS

Numbers 12 in the SBIIS

Numbers 12 in the SBIIS2

Numbers 12 in the SBIIS3

Numbers 12 in the SBIKS

Numbers 12 in the SBIKS2

Numbers 12 in the SBIMS

Numbers 12 in the SBIOS

Numbers 12 in the SBIPS

Numbers 12 in the SBISS

Numbers 12 in the SBITS

Numbers 12 in the SBITS2

Numbers 12 in the SBITS3

Numbers 12 in the SBITS4

Numbers 12 in the SBIUS

Numbers 12 in the SBIVS

Numbers 12 in the SBT

Numbers 12 in the SBT1E

Numbers 12 in the SCHL

Numbers 12 in the SNT

Numbers 12 in the SUSU

Numbers 12 in the SUSU2

Numbers 12 in the SYNO

Numbers 12 in the TBIAOTANT

Numbers 12 in the TBT1E

Numbers 12 in the TBT1E2

Numbers 12 in the TFTIP

Numbers 12 in the TFTU

Numbers 12 in the TGNTATF3T

Numbers 12 in the THAI

Numbers 12 in the TNFD

Numbers 12 in the TNT

Numbers 12 in the TNTIK

Numbers 12 in the TNTIL

Numbers 12 in the TNTIN

Numbers 12 in the TNTIP

Numbers 12 in the TNTIZ

Numbers 12 in the TOMA

Numbers 12 in the TTENT

Numbers 12 in the UBG

Numbers 12 in the UGV

Numbers 12 in the UGV2

Numbers 12 in the UGV3

Numbers 12 in the VBL

Numbers 12 in the VDCC

Numbers 12 in the YALU

Numbers 12 in the YAPE

Numbers 12 in the YBVTP

Numbers 12 in the ZBP