Psalms 33 (BOYCB)
1 Ẹ yọ̀ nínú OLÚWA, ẹ̀yin olódodo;ìyìn si yẹ fún ẹni dídúró ṣinṣin. 2 Ẹ yin OLÚWA pẹ̀lú dùùrù;ẹ máa fi ohun èlò olókùn mẹ́wàá kọrin sí i. 3 Ẹ kọ orin tuntun sí i;ẹ máa fi ọgbọọgbọ́n lu ohun èlò orin sí i, pẹ̀lú ariwo. 4 Nítorí pé ọ̀rọ̀ OLÚWA dúró ṣinṣin,gbogbo iṣẹ́ rẹ̀ ni à ń ṣe nínú òtítọ́. 5 Ó fẹ́ òtítọ́ àti ìdájọ́;ilé ayé kún fún ìdúró ṣinṣin àti àánú OLÚWA. 6 Nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ OLÚWA ni a ṣe dá àwọn ọ̀run,àti gbogbo àwọn ẹgbẹ́ ogun wọn nípa ìmísí ẹnu rẹ̀. 7 Ó kó àwọn omi òkun jọ gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó wà nínú ìgò;ó sì fi ibú ṣe ilé ìṣúra gbogbo. 8 Jẹ́ kí gbogbo ayé kí ó bẹ̀rù OLÚWA:jẹ́ kí gbogbo àwọn olùgbé ayé kí ó wà nínú ìbẹ̀rù rẹ̀. 9 Nítorí tí ó sọ̀rọ̀, ó sì ti rí bẹ́ẹ̀;ó pàṣẹ ó sì dúró ṣinṣin. 10 OLÚWA ti mú ìmọ̀ràn àwọn orílẹ̀-èdè wá sí asán;ó sì mú àrékérekè àwọn ènìyàn di ṣíṣákì í. 11 Ìgbìmọ̀ OLÚWA dúró títí ayérayé,àní ìrò inú rẹ̀ láti ìrandíran ni. 12 Ìbùkún ni fún orílẹ̀-èdè náà, Ọlọ́run ẹni tí OLÚWA jẹ́ tirẹ̀,àti àwọn ènìyàn náà tí ó ti yàn ṣe ìní rẹ̀. 13 OLÚWA wò láti ọ̀run wá;Ó sì rí gbogbo ìran ènìyàn. 14 Níbi tí ó ti jókòó lórí ìtẹ́Ó wo gbogbo àwọn olùgbé ayé 15 ẹni tí ó ṣe àyà wọn bákan náà,ó sì kíyèsi ìṣe wọn. 16 A kò gba ọba kan là nípasẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ-ogun;kò sì sí jagunjagun tí a gbà sílẹ̀ nípa agbára ńlá rẹ̀. 17 Ohun asán ni ẹṣin fún ìṣẹ́gun;bẹ́ẹ̀ ni kì yóò fi agbára ńlá rẹ̀ gbani sílẹ̀. 18 Wò ó, ojú OLÚWA wà lára àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀,àti lára àwọn tí ó ní ìrètí nínú ìfẹ́ rẹ̀ tí ó dúró ṣinṣin. 19 Láti gba ọkàn wọn kúrò lọ́wọ́ ikúàti láti pa wọ́n mọ́ láààyè lọ́wọ́ ìyàn. 20 Ọkàn wa dúró de OLÚWA;òun ni ìrànlọ́wọ́ wa àti asà wa. 21 Ọkàn wa yọ̀ nínú rẹ̀,nítorí pé, àwa gbẹ́kẹ̀lé orúkọ rẹ mímọ́. 22 Kí àánú rẹ, OLÚWA, kí ó wà lára wa,àní gẹ́gẹ́ bí àwa ti ń ṣe ìrètí nínú rẹ.
In Other Versions
Psalms 33 in the ANGEFD
Psalms 33 in the ANTPNG2D
Psalms 33 in the AS21
Psalms 33 in the BAGH
Psalms 33 in the BBPNG
Psalms 33 in the BBT1E
Psalms 33 in the BDS
Psalms 33 in the BEV
Psalms 33 in the BHAD
Psalms 33 in the BIB
Psalms 33 in the BLPT
Psalms 33 in the BNT
Psalms 33 in the BNTABOOT
Psalms 33 in the BNTLV
Psalms 33 in the BOATCB
Psalms 33 in the BOATCB2
Psalms 33 in the BOBCV
Psalms 33 in the BOCNT
Psalms 33 in the BOECS
Psalms 33 in the BOGWICC
Psalms 33 in the BOHCB
Psalms 33 in the BOHCV
Psalms 33 in the BOHLNT
Psalms 33 in the BOHNTLTAL
Psalms 33 in the BOICB
Psalms 33 in the BOILNTAP
Psalms 33 in the BOITCV
Psalms 33 in the BOKCV
Psalms 33 in the BOKCV2
Psalms 33 in the BOKHWOG
Psalms 33 in the BOKSSV
Psalms 33 in the BOLCB
Psalms 33 in the BOLCB2
Psalms 33 in the BOMCV
Psalms 33 in the BONAV
Psalms 33 in the BONCB
Psalms 33 in the BONLT
Psalms 33 in the BONUT2
Psalms 33 in the BOPLNT
Psalms 33 in the BOSCB
Psalms 33 in the BOSNC
Psalms 33 in the BOTLNT
Psalms 33 in the BOVCB
Psalms 33 in the BPBB
Psalms 33 in the BPH
Psalms 33 in the BSB
Psalms 33 in the CCB
Psalms 33 in the CUV
Psalms 33 in the CUVS
Psalms 33 in the DBT
Psalms 33 in the DGDNT
Psalms 33 in the DHNT
Psalms 33 in the DNT
Psalms 33 in the ELBE
Psalms 33 in the EMTV
Psalms 33 in the ESV
Psalms 33 in the FBV
Psalms 33 in the FEB
Psalms 33 in the GGMNT
Psalms 33 in the GNT
Psalms 33 in the HARY
Psalms 33 in the HNT
Psalms 33 in the IRVA
Psalms 33 in the IRVB
Psalms 33 in the IRVG
Psalms 33 in the IRVH
Psalms 33 in the IRVK
Psalms 33 in the IRVM
Psalms 33 in the IRVM2
Psalms 33 in the IRVO
Psalms 33 in the IRVP
Psalms 33 in the IRVT
Psalms 33 in the IRVT2
Psalms 33 in the IRVU
Psalms 33 in the ISVN
Psalms 33 in the JSNT
Psalms 33 in the KAPI
Psalms 33 in the KBT1ETNIK
Psalms 33 in the KBV
Psalms 33 in the KJV
Psalms 33 in the KNFD
Psalms 33 in the LBA
Psalms 33 in the LBLA
Psalms 33 in the LNT
Psalms 33 in the LSV
Psalms 33 in the MAAL
Psalms 33 in the MBV
Psalms 33 in the MBV2
Psalms 33 in the MHNT
Psalms 33 in the MKNFD
Psalms 33 in the MNG
Psalms 33 in the MNT
Psalms 33 in the MNT2
Psalms 33 in the MRS1T
Psalms 33 in the NAA
Psalms 33 in the NASB
Psalms 33 in the NBLA
Psalms 33 in the NBS
Psalms 33 in the NBVTP
Psalms 33 in the NET2
Psalms 33 in the NIV11
Psalms 33 in the NNT
Psalms 33 in the NNT2
Psalms 33 in the NNT3
Psalms 33 in the PDDPT
Psalms 33 in the PFNT
Psalms 33 in the RMNT
Psalms 33 in the SBIAS
Psalms 33 in the SBIBS
Psalms 33 in the SBIBS2
Psalms 33 in the SBICS
Psalms 33 in the SBIDS
Psalms 33 in the SBIGS
Psalms 33 in the SBIHS
Psalms 33 in the SBIIS
Psalms 33 in the SBIIS2
Psalms 33 in the SBIIS3
Psalms 33 in the SBIKS
Psalms 33 in the SBIKS2
Psalms 33 in the SBIMS
Psalms 33 in the SBIOS
Psalms 33 in the SBIPS
Psalms 33 in the SBISS
Psalms 33 in the SBITS
Psalms 33 in the SBITS2
Psalms 33 in the SBITS3
Psalms 33 in the SBITS4
Psalms 33 in the SBIUS
Psalms 33 in the SBIVS
Psalms 33 in the SBT
Psalms 33 in the SBT1E
Psalms 33 in the SCHL
Psalms 33 in the SNT
Psalms 33 in the SUSU
Psalms 33 in the SUSU2
Psalms 33 in the SYNO
Psalms 33 in the TBIAOTANT
Psalms 33 in the TBT1E
Psalms 33 in the TBT1E2
Psalms 33 in the TFTIP
Psalms 33 in the TFTU
Psalms 33 in the TGNTATF3T
Psalms 33 in the THAI
Psalms 33 in the TNFD
Psalms 33 in the TNT
Psalms 33 in the TNTIK
Psalms 33 in the TNTIL
Psalms 33 in the TNTIN
Psalms 33 in the TNTIP
Psalms 33 in the TNTIZ
Psalms 33 in the TOMA
Psalms 33 in the TTENT
Psalms 33 in the UBG
Psalms 33 in the UGV
Psalms 33 in the UGV2
Psalms 33 in the UGV3
Psalms 33 in the VBL
Psalms 33 in the VDCC
Psalms 33 in the YALU
Psalms 33 in the YAPE
Psalms 33 in the YBVTP
Psalms 33 in the ZBP