Zechariah 3 (BOYCB)
1 Ó sì fi Joṣua olórí àlùfáà hàn mí, ó dúró níwájú angẹli OLÚWA, Satani sí dúró lọ́wọ́ ọ̀tún rẹ̀ láti kọjú ìjà sí i. 2 OLÚWA si wí fún Satani pé, “OLÚWA bá ọ wí ìwọ Satani; àní OLÚWA tí ó ti yan Jerusalẹmu, bá ọ wí, igi iná kọ́ ni èyí tí a mú kúrò nínú iná?” 3 A sì wọ Joṣua ni aṣọ èérí, ó sì dúró níwájú angẹli náà. 4 Ó sì dáhùn ó wí fún àwọn tí ó dúró níwájú rẹ̀ pé, “Bọ́ aṣọ èérí nì kúrò ní ara rẹ̀.”Ó sì wí fún Joṣua pé, “Wò ó, mo mú kí àìṣedéédéé rẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, èmi yóò sì wọ̀ ọ́ ní aṣọ ẹ̀yẹ.” 5 Mó sì wí pé, “Jẹ kí wọn fi gèlè mímọ́ wé e lórí.” Wọn sì fi gèlè mímọ́ wé e lórí, wọn sì fi aṣọ wọ̀ ọ́. Angẹli OLÚWA sì dúró tì í. 6 Angẹli OLÚWA sì tẹnumọ́ ọn fún Joṣua pé: 7 “Báyìí ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí: ‘Bí ìwọ ọ́ bá rìn ní ọ̀nà mi, bí ìwọ yóò bá sì pa àṣẹ mi mọ́, ìwọ yóò sì ṣe ìdájọ́ ilé mi pẹ̀lú, ìwọ yóò sì ṣe àkóso ààfin mi, èmi yóò fún ọ ní ààyè láti rìn láàrín àwọn tí ó dúró yìí. 8 “ ‘Gbọ́, ìwọ Joṣua olórí àlùfáà, ìwọ, àti àwọn ẹgbẹ́ rẹ tí ó jókòó níwájú rẹ: nítorí ẹni ìyanu ni wọ́n: nítorí kíyèsi i, èmi yóò mú ẹ̀ka náà wá fun ìránṣẹ́ mi. 9 Nítorí kíyèsi i, òkúta tí mo tí gbé kalẹ̀ níwájú Joṣua; lórí òkúta kan ni ojú méje wà: kíyèsi i, èmi yóò fín àkọlé rẹ̀,’ ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí, ‘Èmi yóò sì mú ẹ̀bi ilẹ̀ náà kúrò ní ọjọ́ kan. 10 “ ‘OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí pé, ní ọjọ́ náà ni olúkúlùkù yóò pe ẹnìkejì láti jókòó rẹ̀ sábẹ́ igi àjàrà àti sábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́.’ ”
In Other Versions
Zechariah 3 in the ANGEFD
Zechariah 3 in the ANTPNG2D
Zechariah 3 in the AS21
Zechariah 3 in the BAGH
Zechariah 3 in the BBPNG
Zechariah 3 in the BBT1E
Zechariah 3 in the BDS
Zechariah 3 in the BEV
Zechariah 3 in the BHAD
Zechariah 3 in the BIB
Zechariah 3 in the BLPT
Zechariah 3 in the BNT
Zechariah 3 in the BNTABOOT
Zechariah 3 in the BNTLV
Zechariah 3 in the BOATCB
Zechariah 3 in the BOATCB2
Zechariah 3 in the BOBCV
Zechariah 3 in the BOCNT
Zechariah 3 in the BOECS
Zechariah 3 in the BOGWICC
Zechariah 3 in the BOHCB
Zechariah 3 in the BOHCV
Zechariah 3 in the BOHLNT
Zechariah 3 in the BOHNTLTAL
Zechariah 3 in the BOICB
Zechariah 3 in the BOILNTAP
Zechariah 3 in the BOITCV
Zechariah 3 in the BOKCV
Zechariah 3 in the BOKCV2
Zechariah 3 in the BOKHWOG
Zechariah 3 in the BOKSSV
Zechariah 3 in the BOLCB
Zechariah 3 in the BOLCB2
Zechariah 3 in the BOMCV
Zechariah 3 in the BONAV
Zechariah 3 in the BONCB
Zechariah 3 in the BONLT
Zechariah 3 in the BONUT2
Zechariah 3 in the BOPLNT
Zechariah 3 in the BOSCB
Zechariah 3 in the BOSNC
Zechariah 3 in the BOTLNT
Zechariah 3 in the BOVCB
Zechariah 3 in the BPBB
Zechariah 3 in the BPH
Zechariah 3 in the BSB
Zechariah 3 in the CCB
Zechariah 3 in the CUV
Zechariah 3 in the CUVS
Zechariah 3 in the DBT
Zechariah 3 in the DGDNT
Zechariah 3 in the DHNT
Zechariah 3 in the DNT
Zechariah 3 in the ELBE
Zechariah 3 in the EMTV
Zechariah 3 in the ESV
Zechariah 3 in the FBV
Zechariah 3 in the FEB
Zechariah 3 in the GGMNT
Zechariah 3 in the GNT
Zechariah 3 in the HARY
Zechariah 3 in the HNT
Zechariah 3 in the IRVA
Zechariah 3 in the IRVB
Zechariah 3 in the IRVG
Zechariah 3 in the IRVH
Zechariah 3 in the IRVK
Zechariah 3 in the IRVM
Zechariah 3 in the IRVM2
Zechariah 3 in the IRVO
Zechariah 3 in the IRVP
Zechariah 3 in the IRVT
Zechariah 3 in the IRVT2
Zechariah 3 in the IRVU
Zechariah 3 in the ISVN
Zechariah 3 in the JSNT
Zechariah 3 in the KAPI
Zechariah 3 in the KBT1ETNIK
Zechariah 3 in the KBV
Zechariah 3 in the KJV
Zechariah 3 in the KNFD
Zechariah 3 in the LBA
Zechariah 3 in the LBLA
Zechariah 3 in the LNT
Zechariah 3 in the LSV
Zechariah 3 in the MAAL
Zechariah 3 in the MBV
Zechariah 3 in the MBV2
Zechariah 3 in the MHNT
Zechariah 3 in the MKNFD
Zechariah 3 in the MNG
Zechariah 3 in the MNT
Zechariah 3 in the MNT2
Zechariah 3 in the MRS1T
Zechariah 3 in the NAA
Zechariah 3 in the NASB
Zechariah 3 in the NBLA
Zechariah 3 in the NBS
Zechariah 3 in the NBVTP
Zechariah 3 in the NET2
Zechariah 3 in the NIV11
Zechariah 3 in the NNT
Zechariah 3 in the NNT2
Zechariah 3 in the NNT3
Zechariah 3 in the PDDPT
Zechariah 3 in the PFNT
Zechariah 3 in the RMNT
Zechariah 3 in the SBIAS
Zechariah 3 in the SBIBS
Zechariah 3 in the SBIBS2
Zechariah 3 in the SBICS
Zechariah 3 in the SBIDS
Zechariah 3 in the SBIGS
Zechariah 3 in the SBIHS
Zechariah 3 in the SBIIS
Zechariah 3 in the SBIIS2
Zechariah 3 in the SBIIS3
Zechariah 3 in the SBIKS
Zechariah 3 in the SBIKS2
Zechariah 3 in the SBIMS
Zechariah 3 in the SBIOS
Zechariah 3 in the SBIPS
Zechariah 3 in the SBISS
Zechariah 3 in the SBITS
Zechariah 3 in the SBITS2
Zechariah 3 in the SBITS3
Zechariah 3 in the SBITS4
Zechariah 3 in the SBIUS
Zechariah 3 in the SBIVS
Zechariah 3 in the SBT
Zechariah 3 in the SBT1E
Zechariah 3 in the SCHL
Zechariah 3 in the SNT
Zechariah 3 in the SUSU
Zechariah 3 in the SUSU2
Zechariah 3 in the SYNO
Zechariah 3 in the TBIAOTANT
Zechariah 3 in the TBT1E
Zechariah 3 in the TBT1E2
Zechariah 3 in the TFTIP
Zechariah 3 in the TFTU
Zechariah 3 in the TGNTATF3T
Zechariah 3 in the THAI
Zechariah 3 in the TNFD
Zechariah 3 in the TNT
Zechariah 3 in the TNTIK
Zechariah 3 in the TNTIL
Zechariah 3 in the TNTIN
Zechariah 3 in the TNTIP
Zechariah 3 in the TNTIZ
Zechariah 3 in the TOMA
Zechariah 3 in the TTENT
Zechariah 3 in the UBG
Zechariah 3 in the UGV
Zechariah 3 in the UGV2
Zechariah 3 in the UGV3
Zechariah 3 in the VBL
Zechariah 3 in the VDCC
Zechariah 3 in the YALU
Zechariah 3 in the YAPE
Zechariah 3 in the YBVTP
Zechariah 3 in the ZBP