1 Chronicles 3 (BOYCB)

1 Àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ Dafidi tí a bí fún un ní Hebroni. Àkọ́bí sì ni Amnoni ọmọ Ahinoamu ti Jesreeli;èkejì sì ni Daniẹli ọmọ Abigaili ará Karmeli; 2 ẹ̀kẹta sì ni Absalomu ọmọ Maaka ọmọbìnrin Talmai ọba Geṣuri bí fún un;ẹ̀kẹrin sì ni Adonijah ọmọ Haggiti; 3 ẹ̀karùnún ni Ṣefatia láti ọ̀dọ̀ Abitali;àti ẹ̀kẹfà, Itreamu, láti ọ̀dọ̀ Egla aya rẹ̀. 4 Àwọn mẹ́fà wọ̀nyí ni a bí fún Dafidi ni Hebroni, níbi tí ó ti jẹ ọba fún ọdún méje àti oṣù mẹ́fà. Dafidi sì jẹ ọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n. 5 Wọ̀nyí ni ọmọ wẹ́wẹ́ tí a bí fún un ní Jerusalẹmu: Ṣimea, Ṣobabu, Natani àti Solomoni. Àwọn mẹ́rin wọ̀nyí sì ni a bí láti ọ̀dọ̀ Bati-Ṣua ọmọbìnrin Ammieli. 6 Ibhari sì wà pẹ̀lú, Eliṣama, Elifeleti, 7 Noga, Nefegi, Jafia, 8 Eliṣama, Eliada àti Elifeleti mẹ́sàn-án ni wọ́n. 9 Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Dafidi yàtọ̀ sí àwọn ọmọ tí àlè bí fún un. Tamari sì ni arábìnrin wọn. 10 Ọmọ Solomoni ni Rehoboamu,Abijah ọmọ rẹ̀,Asa ọmọ rẹ̀,Jehoṣafati ọmọ rẹ̀, 11 Jehoramu ọmọ rẹ̀,Ahasiah ọmọ rẹ̀,Joaṣi ọmọ rẹ̀, 12 Amasiah ọmọ rẹ̀,Asariah ọmọ rẹ̀,Jotamu ọmọ rẹ̀, 13 Ahasi ọmọ rẹ̀,Hesekiah ọmọ rẹ̀,Manase ọmọ rẹ̀, 14 Amoni ọmọ rẹ̀,Josiah ọmọ rẹ̀. 15 Àwọn ọmọ Josiah:àkọ́bí ọmọ rẹ̀ ni Johanani,èkejì ọmọ rẹ̀ ni Jehoiakimu,ẹ̀kẹta ọmọ rẹ̀ ni Sedekiah,ẹ̀kẹrin ọmọ rẹ̀ ni Ṣallumu. 16 Àwọn ìran ọmọ Jehoiakimu:Jekoniah ọmọ rẹ̀,àti Sedekiah. 17 Àwọn ọmọ Jekoniah tí a mú ní ìgbèkùn:Ṣealitieli ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, 18 Malkiramu, Pedaiah, Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama àti Nedabiah. 19 Àwọn ọmọ Pedaiah:Serubbabeli àti Ṣimei.Àwọn ọmọ Serubbabeli:Meṣullamu àti Hananiah. Ṣelomiti ni arábìnrin wọn. 20 Àwọn márùn-ún mìíràn sì tún wà: Haṣuba, Oheli, Berekiah, Hasadiah àti Jusabhesedi. 21 Àwọn ọmọ Hananiah:Pelatiah àti Jeṣaiah, àti àwọn ọmọ Refaiah, ti Arnani, ti Obadiah àti ti Ṣekaniah. 22 Àwọn ọmọ Ṣekaniah:Ṣemaiah àti àwọn ọmọ rẹ̀: Hattusi, Igali, Bariah, Neariah àti Ṣafati, mẹ́fà ni gbogbo wọn. 23 Àwọn ọmọ Neariah:Elioenai; Hesekiah, àti Asrikamu, mẹ́ta ni gbogbo wọn. 24 Àwọn ọmọ Elioenai:Hodafiah, Eliaṣibu, Pelaiah, Akkubu, Johanani, Delaiah àti Anani, méje sì ni gbogbo wọn.

In Other Versions

1 Chronicles 3 in the ANGEFD

1 Chronicles 3 in the ANTPNG2D

1 Chronicles 3 in the AS21

1 Chronicles 3 in the BAGH

1 Chronicles 3 in the BBPNG

1 Chronicles 3 in the BBT1E

1 Chronicles 3 in the BDS

1 Chronicles 3 in the BEV

1 Chronicles 3 in the BHAD

1 Chronicles 3 in the BIB

1 Chronicles 3 in the BLPT

1 Chronicles 3 in the BNT

1 Chronicles 3 in the BNTABOOT

1 Chronicles 3 in the BNTLV

1 Chronicles 3 in the BOATCB

1 Chronicles 3 in the BOATCB2

1 Chronicles 3 in the BOBCV

1 Chronicles 3 in the BOCNT

1 Chronicles 3 in the BOECS

1 Chronicles 3 in the BOGWICC

1 Chronicles 3 in the BOHCB

1 Chronicles 3 in the BOHCV

1 Chronicles 3 in the BOHLNT

1 Chronicles 3 in the BOHNTLTAL

1 Chronicles 3 in the BOICB

1 Chronicles 3 in the BOILNTAP

1 Chronicles 3 in the BOITCV

1 Chronicles 3 in the BOKCV

1 Chronicles 3 in the BOKCV2

1 Chronicles 3 in the BOKHWOG

1 Chronicles 3 in the BOKSSV

1 Chronicles 3 in the BOLCB

1 Chronicles 3 in the BOLCB2

1 Chronicles 3 in the BOMCV

1 Chronicles 3 in the BONAV

1 Chronicles 3 in the BONCB

1 Chronicles 3 in the BONLT

1 Chronicles 3 in the BONUT2

1 Chronicles 3 in the BOPLNT

1 Chronicles 3 in the BOSCB

1 Chronicles 3 in the BOSNC

1 Chronicles 3 in the BOTLNT

1 Chronicles 3 in the BOVCB

1 Chronicles 3 in the BPBB

1 Chronicles 3 in the BPH

1 Chronicles 3 in the BSB

1 Chronicles 3 in the CCB

1 Chronicles 3 in the CUV

1 Chronicles 3 in the CUVS

1 Chronicles 3 in the DBT

1 Chronicles 3 in the DGDNT

1 Chronicles 3 in the DHNT

1 Chronicles 3 in the DNT

1 Chronicles 3 in the ELBE

1 Chronicles 3 in the EMTV

1 Chronicles 3 in the ESV

1 Chronicles 3 in the FBV

1 Chronicles 3 in the FEB

1 Chronicles 3 in the GGMNT

1 Chronicles 3 in the GNT

1 Chronicles 3 in the HARY

1 Chronicles 3 in the HNT

1 Chronicles 3 in the IRVA

1 Chronicles 3 in the IRVB

1 Chronicles 3 in the IRVG

1 Chronicles 3 in the IRVH

1 Chronicles 3 in the IRVK

1 Chronicles 3 in the IRVM

1 Chronicles 3 in the IRVM2

1 Chronicles 3 in the IRVO

1 Chronicles 3 in the IRVP

1 Chronicles 3 in the IRVT

1 Chronicles 3 in the IRVT2

1 Chronicles 3 in the IRVU

1 Chronicles 3 in the ISVN

1 Chronicles 3 in the JSNT

1 Chronicles 3 in the KAPI

1 Chronicles 3 in the KBT1ETNIK

1 Chronicles 3 in the KBV

1 Chronicles 3 in the KJV

1 Chronicles 3 in the KNFD

1 Chronicles 3 in the LBA

1 Chronicles 3 in the LBLA

1 Chronicles 3 in the LNT

1 Chronicles 3 in the LSV

1 Chronicles 3 in the MAAL

1 Chronicles 3 in the MBV

1 Chronicles 3 in the MBV2

1 Chronicles 3 in the MHNT

1 Chronicles 3 in the MKNFD

1 Chronicles 3 in the MNG

1 Chronicles 3 in the MNT

1 Chronicles 3 in the MNT2

1 Chronicles 3 in the MRS1T

1 Chronicles 3 in the NAA

1 Chronicles 3 in the NASB

1 Chronicles 3 in the NBLA

1 Chronicles 3 in the NBS

1 Chronicles 3 in the NBVTP

1 Chronicles 3 in the NET2

1 Chronicles 3 in the NIV11

1 Chronicles 3 in the NNT

1 Chronicles 3 in the NNT2

1 Chronicles 3 in the NNT3

1 Chronicles 3 in the PDDPT

1 Chronicles 3 in the PFNT

1 Chronicles 3 in the RMNT

1 Chronicles 3 in the SBIAS

1 Chronicles 3 in the SBIBS

1 Chronicles 3 in the SBIBS2

1 Chronicles 3 in the SBICS

1 Chronicles 3 in the SBIDS

1 Chronicles 3 in the SBIGS

1 Chronicles 3 in the SBIHS

1 Chronicles 3 in the SBIIS

1 Chronicles 3 in the SBIIS2

1 Chronicles 3 in the SBIIS3

1 Chronicles 3 in the SBIKS

1 Chronicles 3 in the SBIKS2

1 Chronicles 3 in the SBIMS

1 Chronicles 3 in the SBIOS

1 Chronicles 3 in the SBIPS

1 Chronicles 3 in the SBISS

1 Chronicles 3 in the SBITS

1 Chronicles 3 in the SBITS2

1 Chronicles 3 in the SBITS3

1 Chronicles 3 in the SBITS4

1 Chronicles 3 in the SBIUS

1 Chronicles 3 in the SBIVS

1 Chronicles 3 in the SBT

1 Chronicles 3 in the SBT1E

1 Chronicles 3 in the SCHL

1 Chronicles 3 in the SNT

1 Chronicles 3 in the SUSU

1 Chronicles 3 in the SUSU2

1 Chronicles 3 in the SYNO

1 Chronicles 3 in the TBIAOTANT

1 Chronicles 3 in the TBT1E

1 Chronicles 3 in the TBT1E2

1 Chronicles 3 in the TFTIP

1 Chronicles 3 in the TFTU

1 Chronicles 3 in the TGNTATF3T

1 Chronicles 3 in the THAI

1 Chronicles 3 in the TNFD

1 Chronicles 3 in the TNT

1 Chronicles 3 in the TNTIK

1 Chronicles 3 in the TNTIL

1 Chronicles 3 in the TNTIN

1 Chronicles 3 in the TNTIP

1 Chronicles 3 in the TNTIZ

1 Chronicles 3 in the TOMA

1 Chronicles 3 in the TTENT

1 Chronicles 3 in the UBG

1 Chronicles 3 in the UGV

1 Chronicles 3 in the UGV2

1 Chronicles 3 in the UGV3

1 Chronicles 3 in the VBL

1 Chronicles 3 in the VDCC

1 Chronicles 3 in the YALU

1 Chronicles 3 in the YAPE

1 Chronicles 3 in the YBVTP

1 Chronicles 3 in the ZBP