1 Chronicles 8 (BOYCB)

1 Benjamini jẹ́ baba:Bela àkọ́bí rẹ̀,Aṣbeli ọmọkùnrin ni ẹ̀ẹ̀kejì, Ahara ẹ̀ẹ̀kẹ́ta, 2 Noha ẹ̀ẹ̀kẹrin àti Rafa ẹ̀karùnún. 3 Àwọn ọmọ Bela ni,Adari, Gera, Abihudi, 4 Abiṣua, Naamani, Ahoa, 5 Gera, Ṣefufani àti Huramu. 6 Wọ̀nyí ni àwọn ìran ọmọ Ehudu, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé tí ó ń gbé ní Geba tí a sì lé kúrò lọ sí Manahati: 7 Naamani Ahijah àti Gera, tí ó lé wọn kúrò ní ìlú, àti tí ó sì jẹ́ baba Ussa àti Ahihudu. 8 A bí àwọn ọmọkùnrin fún Ṣaharaimu ní Moabu lẹ́yìn tí ó ti kọ àwọn ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, Huṣimu àti Baara. 9 Nípasẹ̀ ìyàwó rẹ̀ Hodeṣi ó ní Jobabu Sibia, Meṣa, Malkamu, 10 Jeusi, Sakia àti Mirma. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin rẹ̀, olórí àwọn ìdílé. 11 Nípasẹ̀ Huṣimu ó ní Abitubu àti Elipali. 12 Àwọn ọmọ Elipali:Eberi, Miṣamu, Ṣemedu (ẹni tí ó kọ́ Ono àti Lodi pẹ̀lú àwọn ìletò àyíká rẹ̀.) 13 Pẹ̀lú Beriah àti Ṣema, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Aijaloni àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gati kúrò. 14 Ahio, Ṣasaki, Jeremoti, 15 Sebadiah, Aradi, Ederi 16 Mikaeli, Iṣifa àti Joha jẹ́ àwọn ọmọ Beriah. 17 Sebadiah, Meṣullamu, Hiski, Heberi 18 Iṣimerai, Isiliahi àti Jobabu jẹ́ àwọn ọmọ Elipali. 19 Jakimu, Sikri, Sabdi, 20 Elienai, Siletai, Elieli, 21 Adaiah, Beraiah àti Ṣimrati jẹ́ àwọn ọmọ, Ṣimei. 22 Iṣipani Eberi, Elieli, 23 Abdoni, Sikri, Hanani, 24 Hananiah, Elamu, Anitotijah, 25 Ifediah àti Penueli jẹ́ àwọn ọmọ Ṣasaki. 26 Ṣamṣerai, Ṣeharaiah, Ataliah 27 Jareṣiah, Elijah àti Sikri jẹ́ àwọn ọmọ Jerohamu. 28 Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn ìdílé, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìran wọn, wọ́n sì ń gbé ní Jerusalẹmu. 29 Jeieli, baba Gibeoni ń gbé ní Gibeoni.Ìyàwó o rẹ̀ a má jẹ́ Maaka, 30 àkọ́bí rẹ̀ a sì máa jẹ́ Abdoni wọ̀nyí sì ń tẹ̀lé Suri, Kiṣi, Baali, Neri, Nadabu, 31 Gedori Ahio, Sekeri 32 pẹ̀lú Mikiloti, tí ó jẹ́ baba Ṣimea. Wọ́n ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní Jerusalẹmu. 33 Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba Saulu àti Saulu baba Jonatani, Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-Baali. 34 Ọmọ Jonatani:Meribu-Baali tí ó jẹ́ baba Mika. 35 Àwọn ọmọ Mika:Pitoni, Meleki, Tarea, àti Ahasi. 36 Ahasi jẹ́ baba a Jeheada, Jeheada jẹ́ baba a Alemeti, Asmafeti àti Simri, Simri sì jẹ́ baba Mosa. 37 Mosa jẹ́ baba Binea; Rafa sì jẹ́ ọmọ rẹ̀, Eleasa ọmọ rẹ̀ àti Aseli ọmọ rẹ̀. 38 Aseli ní ọmọ mẹ́fà pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn:Asrikamu, Bokeru, Iṣmaeli, Ṣeariah, Obadiah àti Hanani. Gbogbo wọ̀nyí ni ọmọ Aseli. 39 Àwọn ọmọ arákùnrin rẹ̀ Eseki:Ulamu àkọ́bí rẹ̀, Jeuṣi ọmọkùnrin ẹ̀ẹ̀kejì àti Elifeleti ẹ̀ẹ̀kẹ́ta. 40 Àwọn ọmọ Ulamu jẹ́ ògboyà jagunjagun tí ó lè gbá orin mú. Wọ́n ní ọ̀pọ̀ ọmọkùnrin àti ọmọ ọmọkùnrin áàdọ́jọ ní gbogbo rẹ̀.Gbogbo wọ̀nyí ni àwọn ìdílé ìran ọmọ Benjamini.

In Other Versions

1 Chronicles 8 in the ANGEFD

1 Chronicles 8 in the ANTPNG2D

1 Chronicles 8 in the AS21

1 Chronicles 8 in the BAGH

1 Chronicles 8 in the BBPNG

1 Chronicles 8 in the BBT1E

1 Chronicles 8 in the BDS

1 Chronicles 8 in the BEV

1 Chronicles 8 in the BHAD

1 Chronicles 8 in the BIB

1 Chronicles 8 in the BLPT

1 Chronicles 8 in the BNT

1 Chronicles 8 in the BNTABOOT

1 Chronicles 8 in the BNTLV

1 Chronicles 8 in the BOATCB

1 Chronicles 8 in the BOATCB2

1 Chronicles 8 in the BOBCV

1 Chronicles 8 in the BOCNT

1 Chronicles 8 in the BOECS

1 Chronicles 8 in the BOGWICC

1 Chronicles 8 in the BOHCB

1 Chronicles 8 in the BOHCV

1 Chronicles 8 in the BOHLNT

1 Chronicles 8 in the BOHNTLTAL

1 Chronicles 8 in the BOICB

1 Chronicles 8 in the BOILNTAP

1 Chronicles 8 in the BOITCV

1 Chronicles 8 in the BOKCV

1 Chronicles 8 in the BOKCV2

1 Chronicles 8 in the BOKHWOG

1 Chronicles 8 in the BOKSSV

1 Chronicles 8 in the BOLCB

1 Chronicles 8 in the BOLCB2

1 Chronicles 8 in the BOMCV

1 Chronicles 8 in the BONAV

1 Chronicles 8 in the BONCB

1 Chronicles 8 in the BONLT

1 Chronicles 8 in the BONUT2

1 Chronicles 8 in the BOPLNT

1 Chronicles 8 in the BOSCB

1 Chronicles 8 in the BOSNC

1 Chronicles 8 in the BOTLNT

1 Chronicles 8 in the BOVCB

1 Chronicles 8 in the BPBB

1 Chronicles 8 in the BPH

1 Chronicles 8 in the BSB

1 Chronicles 8 in the CCB

1 Chronicles 8 in the CUV

1 Chronicles 8 in the CUVS

1 Chronicles 8 in the DBT

1 Chronicles 8 in the DGDNT

1 Chronicles 8 in the DHNT

1 Chronicles 8 in the DNT

1 Chronicles 8 in the ELBE

1 Chronicles 8 in the EMTV

1 Chronicles 8 in the ESV

1 Chronicles 8 in the FBV

1 Chronicles 8 in the FEB

1 Chronicles 8 in the GGMNT

1 Chronicles 8 in the GNT

1 Chronicles 8 in the HARY

1 Chronicles 8 in the HNT

1 Chronicles 8 in the IRVA

1 Chronicles 8 in the IRVB

1 Chronicles 8 in the IRVG

1 Chronicles 8 in the IRVH

1 Chronicles 8 in the IRVK

1 Chronicles 8 in the IRVM

1 Chronicles 8 in the IRVM2

1 Chronicles 8 in the IRVO

1 Chronicles 8 in the IRVP

1 Chronicles 8 in the IRVT

1 Chronicles 8 in the IRVT2

1 Chronicles 8 in the IRVU

1 Chronicles 8 in the ISVN

1 Chronicles 8 in the JSNT

1 Chronicles 8 in the KAPI

1 Chronicles 8 in the KBT1ETNIK

1 Chronicles 8 in the KBV

1 Chronicles 8 in the KJV

1 Chronicles 8 in the KNFD

1 Chronicles 8 in the LBA

1 Chronicles 8 in the LBLA

1 Chronicles 8 in the LNT

1 Chronicles 8 in the LSV

1 Chronicles 8 in the MAAL

1 Chronicles 8 in the MBV

1 Chronicles 8 in the MBV2

1 Chronicles 8 in the MHNT

1 Chronicles 8 in the MKNFD

1 Chronicles 8 in the MNG

1 Chronicles 8 in the MNT

1 Chronicles 8 in the MNT2

1 Chronicles 8 in the MRS1T

1 Chronicles 8 in the NAA

1 Chronicles 8 in the NASB

1 Chronicles 8 in the NBLA

1 Chronicles 8 in the NBS

1 Chronicles 8 in the NBVTP

1 Chronicles 8 in the NET2

1 Chronicles 8 in the NIV11

1 Chronicles 8 in the NNT

1 Chronicles 8 in the NNT2

1 Chronicles 8 in the NNT3

1 Chronicles 8 in the PDDPT

1 Chronicles 8 in the PFNT

1 Chronicles 8 in the RMNT

1 Chronicles 8 in the SBIAS

1 Chronicles 8 in the SBIBS

1 Chronicles 8 in the SBIBS2

1 Chronicles 8 in the SBICS

1 Chronicles 8 in the SBIDS

1 Chronicles 8 in the SBIGS

1 Chronicles 8 in the SBIHS

1 Chronicles 8 in the SBIIS

1 Chronicles 8 in the SBIIS2

1 Chronicles 8 in the SBIIS3

1 Chronicles 8 in the SBIKS

1 Chronicles 8 in the SBIKS2

1 Chronicles 8 in the SBIMS

1 Chronicles 8 in the SBIOS

1 Chronicles 8 in the SBIPS

1 Chronicles 8 in the SBISS

1 Chronicles 8 in the SBITS

1 Chronicles 8 in the SBITS2

1 Chronicles 8 in the SBITS3

1 Chronicles 8 in the SBITS4

1 Chronicles 8 in the SBIUS

1 Chronicles 8 in the SBIVS

1 Chronicles 8 in the SBT

1 Chronicles 8 in the SBT1E

1 Chronicles 8 in the SCHL

1 Chronicles 8 in the SNT

1 Chronicles 8 in the SUSU

1 Chronicles 8 in the SUSU2

1 Chronicles 8 in the SYNO

1 Chronicles 8 in the TBIAOTANT

1 Chronicles 8 in the TBT1E

1 Chronicles 8 in the TBT1E2

1 Chronicles 8 in the TFTIP

1 Chronicles 8 in the TFTU

1 Chronicles 8 in the TGNTATF3T

1 Chronicles 8 in the THAI

1 Chronicles 8 in the TNFD

1 Chronicles 8 in the TNT

1 Chronicles 8 in the TNTIK

1 Chronicles 8 in the TNTIL

1 Chronicles 8 in the TNTIN

1 Chronicles 8 in the TNTIP

1 Chronicles 8 in the TNTIZ

1 Chronicles 8 in the TOMA

1 Chronicles 8 in the TTENT

1 Chronicles 8 in the UBG

1 Chronicles 8 in the UGV

1 Chronicles 8 in the UGV2

1 Chronicles 8 in the UGV3

1 Chronicles 8 in the VBL

1 Chronicles 8 in the VDCC

1 Chronicles 8 in the YALU

1 Chronicles 8 in the YAPE

1 Chronicles 8 in the YBVTP

1 Chronicles 8 in the ZBP