Ecclesiastes 1 (BOYCB)
1 Ọ̀rọ̀ Oniwaasu, ọmọ Dafidi, ọba Jerusalẹmu: 2 “Asán inú asán!”Oníwàásù náà wí pé,“Asán inú asán!Gbogbo rẹ̀ asán ni.” 3 Kí ni ènìyàn rí jẹ ní èrè lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ̀,lórí èyí tí ó ń ṣe wàhálà sí lábẹ́ oòrùn? 4 Bí ìran kan ti wá ni ìran mìíràn ń kọjá lọ,síbẹ̀ ayé dúró títí láé. 5 Oòrùn ń ràn, oòrùn sì ń wọ̀,ó sì sáré padà sí ibi tí ó ti yọ. 6 Afẹ́fẹ́ ń fẹ́ lọ sí ìhà gúúsù,Ó sì ń fẹ́ yípo sí ìhà àríwá,a sì tún padà sí ọ̀nà rẹ̀. 7 Gbogbo odò ń sàn sí inú Òkun,síbẹ̀síbẹ̀ Òkun kò kún.Níbi tí àwọn odò ti wá,níbẹ̀ ni wọ́n tún padà sí. 8 Ohun gbogbo ni ó ń mú àárẹ̀ wá,ju èyí tí ẹnu le è sọ.Ojú kò tí ì rí ìrírí tí ó tẹ́ ẹ lọ́rùn,bẹ́ẹ̀ ni, etí kò tí ì kún fún gbígbọ́. 9 Ohun tí ó ti wà tẹ́lẹ̀ náà ni yóò sì máa wà, ohun tí a ti ṣe sẹ́yìnòun ni a ó tún máa ṣe padàkò sí ohun tuntun lábẹ́ oòrùn. 10 Ǹjẹ́ ohun kan wà tí ẹnìkan le è sọ wí pé,“Wò ó! Ohun tuntun ni èyí”?Ó ti wà tẹ́lẹ̀ rí ní ọjọ́ tó ti pẹ́,o ti wà ṣáájú tiwa. 11 Kò sí ìrántí ohun ìṣáájúbẹ́ẹ̀ ni ìrántí kì yóò sí fúnohun ìkẹyìn tí ń bọ̀lọ́dọ̀ àwọn tí ń bọ̀ ní ìgbà ìkẹyìn. 12 Èmi, Oniwaasu ti jẹ ọba lórí Israẹli ní Jerusalẹmu rí. 13 Mo fi àsìkò mi sílẹ̀ láti kọ́ àti láti ṣe àwárí pẹ̀lú ọgbọ́n, gbogbo ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ lábẹ́ ọ̀run. Háà! Ẹrù wúwo tí Ọlọ́run ti gbé lé àwọn ènìyàn. 14 Èmi ti rí ohun gbogbo tí ó ń ṣẹlẹ̀ lábẹ́ oòrùn, gbogbo rẹ̀ kò ní ìtumọ̀ bí ẹní gbìyànjú àti mú afẹ́fẹ́ ni. 15 Ohun tí ó ti wọ́ kò le è ṣe é tọ́ mọ́,ohun tí kò sí kò le è ṣe é kà. 16 Mo rò nínú ara mi, “Wò ó, mo ti dàgbà, ọgbọ́n mi sì ti pọ̀ ju ti ẹnikẹ́ni tí ó ti ṣe alákòóso Jerusalẹmu síwájú mi lọ, mo ti ní ìrírí púpọ̀ nípa ọgbọ́n àti ìmọ̀.” 17 Nígbà náà ni mo fi ara jì láti ní ìmọ̀ nípa ọgbọ́n, àti pàápàá àìgbọ́n àti òmùgọ̀, ṣùgbọ́n mo rí, wí pé èyí pẹ̀lú bí ẹni ń gbìyànjú àti mú afẹ́fẹ́ ni. 18 Nítorí pé ọgbọ́n púpọ̀ ìbànújẹ́ púpọ̀ ní ń mú wá,bí ìmọ̀ bá sì ṣe pọ̀ tó náà ni ìbànújẹ́ ń pọ̀ tó.
In Other Versions
Ecclesiastes 1 in the ANGEFD
Ecclesiastes 1 in the ANTPNG2D
Ecclesiastes 1 in the AS21
Ecclesiastes 1 in the BAGH
Ecclesiastes 1 in the BBPNG
Ecclesiastes 1 in the BBT1E
Ecclesiastes 1 in the BDS
Ecclesiastes 1 in the BEV
Ecclesiastes 1 in the BHAD
Ecclesiastes 1 in the BIB
Ecclesiastes 1 in the BLPT
Ecclesiastes 1 in the BNT
Ecclesiastes 1 in the BNTABOOT
Ecclesiastes 1 in the BNTLV
Ecclesiastes 1 in the BOATCB
Ecclesiastes 1 in the BOATCB2
Ecclesiastes 1 in the BOBCV
Ecclesiastes 1 in the BOCNT
Ecclesiastes 1 in the BOECS
Ecclesiastes 1 in the BOGWICC
Ecclesiastes 1 in the BOHCB
Ecclesiastes 1 in the BOHCV
Ecclesiastes 1 in the BOHLNT
Ecclesiastes 1 in the BOHNTLTAL
Ecclesiastes 1 in the BOICB
Ecclesiastes 1 in the BOILNTAP
Ecclesiastes 1 in the BOITCV
Ecclesiastes 1 in the BOKCV
Ecclesiastes 1 in the BOKCV2
Ecclesiastes 1 in the BOKHWOG
Ecclesiastes 1 in the BOKSSV
Ecclesiastes 1 in the BOLCB
Ecclesiastes 1 in the BOLCB2
Ecclesiastes 1 in the BOMCV
Ecclesiastes 1 in the BONAV
Ecclesiastes 1 in the BONCB
Ecclesiastes 1 in the BONLT
Ecclesiastes 1 in the BONUT2
Ecclesiastes 1 in the BOPLNT
Ecclesiastes 1 in the BOSCB
Ecclesiastes 1 in the BOSNC
Ecclesiastes 1 in the BOTLNT
Ecclesiastes 1 in the BOVCB
Ecclesiastes 1 in the BPBB
Ecclesiastes 1 in the BPH
Ecclesiastes 1 in the BSB
Ecclesiastes 1 in the CCB
Ecclesiastes 1 in the CUV
Ecclesiastes 1 in the CUVS
Ecclesiastes 1 in the DBT
Ecclesiastes 1 in the DGDNT
Ecclesiastes 1 in the DHNT
Ecclesiastes 1 in the DNT
Ecclesiastes 1 in the ELBE
Ecclesiastes 1 in the EMTV
Ecclesiastes 1 in the ESV
Ecclesiastes 1 in the FBV
Ecclesiastes 1 in the FEB
Ecclesiastes 1 in the GGMNT
Ecclesiastes 1 in the GNT
Ecclesiastes 1 in the HARY
Ecclesiastes 1 in the HNT
Ecclesiastes 1 in the IRVA
Ecclesiastes 1 in the IRVB
Ecclesiastes 1 in the IRVG
Ecclesiastes 1 in the IRVH
Ecclesiastes 1 in the IRVK
Ecclesiastes 1 in the IRVM
Ecclesiastes 1 in the IRVM2
Ecclesiastes 1 in the IRVO
Ecclesiastes 1 in the IRVP
Ecclesiastes 1 in the IRVT
Ecclesiastes 1 in the IRVT2
Ecclesiastes 1 in the IRVU
Ecclesiastes 1 in the ISVN
Ecclesiastes 1 in the JSNT
Ecclesiastes 1 in the KAPI
Ecclesiastes 1 in the KBT1ETNIK
Ecclesiastes 1 in the KBV
Ecclesiastes 1 in the KJV
Ecclesiastes 1 in the KNFD
Ecclesiastes 1 in the LBA
Ecclesiastes 1 in the LBLA
Ecclesiastes 1 in the LNT
Ecclesiastes 1 in the LSV
Ecclesiastes 1 in the MAAL
Ecclesiastes 1 in the MBV
Ecclesiastes 1 in the MBV2
Ecclesiastes 1 in the MHNT
Ecclesiastes 1 in the MKNFD
Ecclesiastes 1 in the MNG
Ecclesiastes 1 in the MNT
Ecclesiastes 1 in the MNT2
Ecclesiastes 1 in the MRS1T
Ecclesiastes 1 in the NAA
Ecclesiastes 1 in the NASB
Ecclesiastes 1 in the NBLA
Ecclesiastes 1 in the NBS
Ecclesiastes 1 in the NBVTP
Ecclesiastes 1 in the NET2
Ecclesiastes 1 in the NIV11
Ecclesiastes 1 in the NNT
Ecclesiastes 1 in the NNT2
Ecclesiastes 1 in the NNT3
Ecclesiastes 1 in the PDDPT
Ecclesiastes 1 in the PFNT
Ecclesiastes 1 in the RMNT
Ecclesiastes 1 in the SBIAS
Ecclesiastes 1 in the SBIBS
Ecclesiastes 1 in the SBIBS2
Ecclesiastes 1 in the SBICS
Ecclesiastes 1 in the SBIDS
Ecclesiastes 1 in the SBIGS
Ecclesiastes 1 in the SBIHS
Ecclesiastes 1 in the SBIIS
Ecclesiastes 1 in the SBIIS2
Ecclesiastes 1 in the SBIIS3
Ecclesiastes 1 in the SBIKS
Ecclesiastes 1 in the SBIKS2
Ecclesiastes 1 in the SBIMS
Ecclesiastes 1 in the SBIOS
Ecclesiastes 1 in the SBIPS
Ecclesiastes 1 in the SBISS
Ecclesiastes 1 in the SBITS
Ecclesiastes 1 in the SBITS2
Ecclesiastes 1 in the SBITS3
Ecclesiastes 1 in the SBITS4
Ecclesiastes 1 in the SBIUS
Ecclesiastes 1 in the SBIVS
Ecclesiastes 1 in the SBT
Ecclesiastes 1 in the SBT1E
Ecclesiastes 1 in the SCHL
Ecclesiastes 1 in the SNT
Ecclesiastes 1 in the SUSU
Ecclesiastes 1 in the SUSU2
Ecclesiastes 1 in the SYNO
Ecclesiastes 1 in the TBIAOTANT
Ecclesiastes 1 in the TBT1E
Ecclesiastes 1 in the TBT1E2
Ecclesiastes 1 in the TFTIP
Ecclesiastes 1 in the TFTU
Ecclesiastes 1 in the TGNTATF3T
Ecclesiastes 1 in the THAI
Ecclesiastes 1 in the TNFD
Ecclesiastes 1 in the TNT
Ecclesiastes 1 in the TNTIK
Ecclesiastes 1 in the TNTIL
Ecclesiastes 1 in the TNTIN
Ecclesiastes 1 in the TNTIP
Ecclesiastes 1 in the TNTIZ
Ecclesiastes 1 in the TOMA
Ecclesiastes 1 in the TTENT
Ecclesiastes 1 in the UBG
Ecclesiastes 1 in the UGV
Ecclesiastes 1 in the UGV2
Ecclesiastes 1 in the UGV3
Ecclesiastes 1 in the VBL
Ecclesiastes 1 in the VDCC
Ecclesiastes 1 in the YALU
Ecclesiastes 1 in the YAPE
Ecclesiastes 1 in the YBVTP
Ecclesiastes 1 in the ZBP