Ezekiel 2 (BOYCB)
1 Ó sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, dìde dúró lórí ẹsẹ̀ rẹ. Èmi yóò bá ọ sọ̀rọ̀.” 2 Bí ó ṣe ń sọ̀rọ̀, ẹ̀mí sì wọ inú mi ó mú mi dúró lórí ẹsẹ̀ mi, mo sì ń gbọ́ tí ó ń bá mi sọ̀rọ̀. 3 Ó sọ pé, “Ọmọ ènìyàn, mo ń rán ọ sí àwọn ọmọ Israẹli, sí ọlọ̀tẹ̀ orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi; àwọn àti baba ńlá wọn ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi títí di òní olónìí. 4 Àwọn ènìyàn tí mo ń rán ọ sí jẹ́ aláìgbọ́ràn àti ọlọ́kàn líle. Sọ fún wọn pé, ‘Èyí ni ohun tí OLÚWA Olódùmarè wí.’ 5 Bí wọn fetísílẹ̀ tàbí wọn kò fetísílẹ̀ nítorí pé wọ́n ọlọ̀tẹ̀ ilé ni wọ́n—wọn yóò mọ̀ pé wòlíì kan wà láàrín wọn. 6 Àti ìwọ, ọmọ ènìyàn, má ṣe bẹ̀rù wọn tàbí ọ̀rọ̀ ẹnu wọn. Má ṣe bẹ̀rù, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé òṣùṣú àti ẹ̀gún yí ọ ká, tí o sì ń gbé àárín àwọn àkéekèe. Má ṣe bẹ̀rù ohun tí wọ́n ń sọ tàbí bẹ̀rù wọn, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọlọ̀tẹ̀ ìdílé ni wọ́n. 7 Ìwọ gbọdọ̀ sọ ọ̀rọ̀ mi fún wọn, bí wọ́n gbọ́ bí wọn kọ̀ láti gbọ́ torí pé ọlọ̀tẹ̀ ni wọ́n. 8 Ṣùgbọ́n ìwọ, ọmọ ènìyàn, gbọ́ ohun tí mo ń sọ fún ọ. Má ṣe ṣọ̀tẹ̀ bí i ti ìdílé ọlọ́tẹ̀; la ẹnu rẹ kí o sì jẹ ohun tí mo fún ọ.” 9 Mo sì wò, mo sì rí ọwọ́ kan tí a nà sí mi. Ìwé kíká sì wà níbẹ̀, 10 ó sì tú ìwé náà fún mi. Ní ojú àti ẹ̀yìn ìwé náà ni a kọ ìpohùnréré ẹkún, ọ̀fọ̀ àti ègún sí.
In Other Versions
Ezekiel 2 in the ANGEFD
Ezekiel 2 in the ANTPNG2D
Ezekiel 2 in the AS21
Ezekiel 2 in the BAGH
Ezekiel 2 in the BBPNG
Ezekiel 2 in the BBT1E
Ezekiel 2 in the BDS
Ezekiel 2 in the BEV
Ezekiel 2 in the BHAD
Ezekiel 2 in the BIB
Ezekiel 2 in the BLPT
Ezekiel 2 in the BNT
Ezekiel 2 in the BNTABOOT
Ezekiel 2 in the BNTLV
Ezekiel 2 in the BOATCB
Ezekiel 2 in the BOATCB2
Ezekiel 2 in the BOBCV
Ezekiel 2 in the BOCNT
Ezekiel 2 in the BOECS
Ezekiel 2 in the BOGWICC
Ezekiel 2 in the BOHCB
Ezekiel 2 in the BOHCV
Ezekiel 2 in the BOHLNT
Ezekiel 2 in the BOHNTLTAL
Ezekiel 2 in the BOICB
Ezekiel 2 in the BOILNTAP
Ezekiel 2 in the BOITCV
Ezekiel 2 in the BOKCV
Ezekiel 2 in the BOKCV2
Ezekiel 2 in the BOKHWOG
Ezekiel 2 in the BOKSSV
Ezekiel 2 in the BOLCB
Ezekiel 2 in the BOLCB2
Ezekiel 2 in the BOMCV
Ezekiel 2 in the BONAV
Ezekiel 2 in the BONCB
Ezekiel 2 in the BONLT
Ezekiel 2 in the BONUT2
Ezekiel 2 in the BOPLNT
Ezekiel 2 in the BOSCB
Ezekiel 2 in the BOSNC
Ezekiel 2 in the BOTLNT
Ezekiel 2 in the BOVCB
Ezekiel 2 in the BPBB
Ezekiel 2 in the BPH
Ezekiel 2 in the BSB
Ezekiel 2 in the CCB
Ezekiel 2 in the CUV
Ezekiel 2 in the CUVS
Ezekiel 2 in the DBT
Ezekiel 2 in the DGDNT
Ezekiel 2 in the DHNT
Ezekiel 2 in the DNT
Ezekiel 2 in the ELBE
Ezekiel 2 in the EMTV
Ezekiel 2 in the ESV
Ezekiel 2 in the FBV
Ezekiel 2 in the FEB
Ezekiel 2 in the GGMNT
Ezekiel 2 in the GNT
Ezekiel 2 in the HARY
Ezekiel 2 in the HNT
Ezekiel 2 in the IRVA
Ezekiel 2 in the IRVB
Ezekiel 2 in the IRVG
Ezekiel 2 in the IRVH
Ezekiel 2 in the IRVK
Ezekiel 2 in the IRVM
Ezekiel 2 in the IRVM2
Ezekiel 2 in the IRVO
Ezekiel 2 in the IRVP
Ezekiel 2 in the IRVT
Ezekiel 2 in the IRVT2
Ezekiel 2 in the IRVU
Ezekiel 2 in the ISVN
Ezekiel 2 in the JSNT
Ezekiel 2 in the KAPI
Ezekiel 2 in the KBT1ETNIK
Ezekiel 2 in the KBV
Ezekiel 2 in the KJV
Ezekiel 2 in the KNFD
Ezekiel 2 in the LBA
Ezekiel 2 in the LBLA
Ezekiel 2 in the LNT
Ezekiel 2 in the LSV
Ezekiel 2 in the MAAL
Ezekiel 2 in the MBV
Ezekiel 2 in the MBV2
Ezekiel 2 in the MHNT
Ezekiel 2 in the MKNFD
Ezekiel 2 in the MNG
Ezekiel 2 in the MNT
Ezekiel 2 in the MNT2
Ezekiel 2 in the MRS1T
Ezekiel 2 in the NAA
Ezekiel 2 in the NASB
Ezekiel 2 in the NBLA
Ezekiel 2 in the NBS
Ezekiel 2 in the NBVTP
Ezekiel 2 in the NET2
Ezekiel 2 in the NIV11
Ezekiel 2 in the NNT
Ezekiel 2 in the NNT2
Ezekiel 2 in the NNT3
Ezekiel 2 in the PDDPT
Ezekiel 2 in the PFNT
Ezekiel 2 in the RMNT
Ezekiel 2 in the SBIAS
Ezekiel 2 in the SBIBS
Ezekiel 2 in the SBIBS2
Ezekiel 2 in the SBICS
Ezekiel 2 in the SBIDS
Ezekiel 2 in the SBIGS
Ezekiel 2 in the SBIHS
Ezekiel 2 in the SBIIS
Ezekiel 2 in the SBIIS2
Ezekiel 2 in the SBIIS3
Ezekiel 2 in the SBIKS
Ezekiel 2 in the SBIKS2
Ezekiel 2 in the SBIMS
Ezekiel 2 in the SBIOS
Ezekiel 2 in the SBIPS
Ezekiel 2 in the SBISS
Ezekiel 2 in the SBITS
Ezekiel 2 in the SBITS2
Ezekiel 2 in the SBITS3
Ezekiel 2 in the SBITS4
Ezekiel 2 in the SBIUS
Ezekiel 2 in the SBIVS
Ezekiel 2 in the SBT
Ezekiel 2 in the SBT1E
Ezekiel 2 in the SCHL
Ezekiel 2 in the SNT
Ezekiel 2 in the SUSU
Ezekiel 2 in the SUSU2
Ezekiel 2 in the SYNO
Ezekiel 2 in the TBIAOTANT
Ezekiel 2 in the TBT1E
Ezekiel 2 in the TBT1E2
Ezekiel 2 in the TFTIP
Ezekiel 2 in the TFTU
Ezekiel 2 in the TGNTATF3T
Ezekiel 2 in the THAI
Ezekiel 2 in the TNFD
Ezekiel 2 in the TNT
Ezekiel 2 in the TNTIK
Ezekiel 2 in the TNTIL
Ezekiel 2 in the TNTIN
Ezekiel 2 in the TNTIP
Ezekiel 2 in the TNTIZ
Ezekiel 2 in the TOMA
Ezekiel 2 in the TTENT
Ezekiel 2 in the UBG
Ezekiel 2 in the UGV
Ezekiel 2 in the UGV2
Ezekiel 2 in the UGV3
Ezekiel 2 in the VBL
Ezekiel 2 in the VDCC
Ezekiel 2 in the YALU
Ezekiel 2 in the YAPE
Ezekiel 2 in the YBVTP
Ezekiel 2 in the ZBP