Ezekiel 6 (BOYCB)
1 Ọ̀rọ̀ OLÚWA sì tọ̀ mí wá wí pé, 2 “Ọmọ ènìyàn, dojúkọ àwọn òkè Israẹli; kí o sì sọtẹ́lẹ̀ lòdì sí wọn 3 wí pé, ‘Ẹ̀yin òkè Israẹli, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ OLÚWA Olódùmarè. Báyìí ni OLÚWA Olódùmarè wí sí ẹ̀yin òkè ńlá àti àwọn òkè kéékèèké, sí àwọn odò ṣíṣàn àti sí àfonífojì, èmi yóò mú idà wa sórí yín, èmí yóò sì pa ibi gíga yín run. 4 Èmi yóò wó pẹpẹ yín lulẹ̀, èmi yóò sì fọ́ pẹpẹ tùràrí yín túútúú; èmi yóò sì pa àwọn ènìyàn yín síwájú àwọn òrìṣà wọn. 5 Èmi yóò tẹ́ òkú àwọn ará Israẹli síwájú òrìṣà wọn, èmi yóò sì fọ́n egungun wọn yí pẹpẹ wọn ká. 6 Gbogbo ibi tí ẹ ń gbé àti àwọn ibi gíga yín ni yóò di píparun, gbogbo pẹpẹ yín ni yóò di ahoro, àwọn òrìṣà yín yóò di fífọ́ túútúú, àwọn pẹpẹ tùràrí yín ni a ó gé lulẹ̀, gbogbo iṣẹ́ yín yóò parẹ́. 7 Àwọn ènìyàn yín yóò ṣubú láàrín yín, ẹ ó sì mọ̀ pé, Èmi ni OLÚWA. 8 “ ‘Ṣùgbọ́n èmi yóò dá àwọn kan sí nítorí pé díẹ̀ nínú yín ni yóò bọ́ lọ́wọ́ idà, nígbà tí a bá fọ́n yín ká sí gbogbo ilẹ̀ àti orílẹ̀-èdè. 9 Àwọn ti ó bọ́ nínú yin yóò sì rántí mi láàrín àwọn orílẹ̀-èdè níbi tí wọn yóò dìwọ́n ní ìgbèkùn lọ, nítorí wọ́n yóò máa rántí mi bí wọ́n ti bà mí lọ́kàn jẹ́ nípa àgbèrè wọn, tí ó yà wọ́n kúrò lọ́dọ̀ mi àti nípa ojú wọn tí ó ṣàfẹ́rí àwọn òrìṣà. Wọn yóò sì ṣú ara wọn nítorí ìwà ibi tí wọ́n ti hù nípa gbogbo ìríra wọn. 10 Wọn yóò sì mọ̀ pé, Èmi ni OLÚWA; àti pé kì í ṣe lásán ni mo ń lérí pé èmi yóò mú ìdààmú bá wọn. 11 “ ‘Èyí ni ohun tí OLÚWA Olódùmarè wí, Pàtẹ́wọ́ kí o tún fẹsẹ̀ janlẹ̀, kí o wá kígbe síta pé, “Ó ṣe!” Ilé Israẹli yóò ṣubú nípa idà, ìyàn àti àjàkálẹ̀-ààrùn nítorí gbogbo ìwà ìríra búburú tí wọ́n hù. Wọn yóò ṣubú nípa idà àti ìyàn. 12 Ẹni tó wà lókèèrè yóò kú pẹ̀lú àjàkálẹ̀-ààrùn, àti ẹni tó wà nítòsí yóò ṣubú pẹ̀lú idà, ìyàn ni yóò pa ẹni tó bá ṣẹ́kù sílẹ̀. Báyìí ni èmi yóò ṣe mú ìbínú gbígbóná mi wá sórí wọn. 13 Wọn yóò sì mọ̀ pé, Èmi ni OLÚWA, nígbà tí òkú àwọn ènìyàn wọn bá wà níbẹ̀ láàrín òrìṣà wọn yí pẹpẹ wọn ká, lórí àwọn òkè gíga gbogbo, àti lórí góńgó òkè àti lábẹ́ igi tútù àti lábẹ́ igi óákù, níbi tí wọ́n ti ń fi tùràrí olóòórùn dídùn rú ẹbọ sí gbogbo òrìṣà wọn. 14 Èmi yóò na ọwọ́ mi jáde sí wọn láti mú kí ilẹ̀ náà ṣòfò, kí ó sì dahoro dé aṣálẹ̀ ìhà Dibila—ní gbogbo ibùgbé wọn. Nígbà náà ni wọn yóò mọ̀ pé, Èmi ni OLÚWA.’ ”
In Other Versions
Ezekiel 6 in the ANGEFD
Ezekiel 6 in the ANTPNG2D
Ezekiel 6 in the AS21
Ezekiel 6 in the BAGH
Ezekiel 6 in the BBPNG
Ezekiel 6 in the BBT1E
Ezekiel 6 in the BDS
Ezekiel 6 in the BEV
Ezekiel 6 in the BHAD
Ezekiel 6 in the BIB
Ezekiel 6 in the BLPT
Ezekiel 6 in the BNT
Ezekiel 6 in the BNTABOOT
Ezekiel 6 in the BNTLV
Ezekiel 6 in the BOATCB
Ezekiel 6 in the BOATCB2
Ezekiel 6 in the BOBCV
Ezekiel 6 in the BOCNT
Ezekiel 6 in the BOECS
Ezekiel 6 in the BOGWICC
Ezekiel 6 in the BOHCB
Ezekiel 6 in the BOHCV
Ezekiel 6 in the BOHLNT
Ezekiel 6 in the BOHNTLTAL
Ezekiel 6 in the BOICB
Ezekiel 6 in the BOILNTAP
Ezekiel 6 in the BOITCV
Ezekiel 6 in the BOKCV
Ezekiel 6 in the BOKCV2
Ezekiel 6 in the BOKHWOG
Ezekiel 6 in the BOKSSV
Ezekiel 6 in the BOLCB
Ezekiel 6 in the BOLCB2
Ezekiel 6 in the BOMCV
Ezekiel 6 in the BONAV
Ezekiel 6 in the BONCB
Ezekiel 6 in the BONLT
Ezekiel 6 in the BONUT2
Ezekiel 6 in the BOPLNT
Ezekiel 6 in the BOSCB
Ezekiel 6 in the BOSNC
Ezekiel 6 in the BOTLNT
Ezekiel 6 in the BOVCB
Ezekiel 6 in the BPBB
Ezekiel 6 in the BPH
Ezekiel 6 in the BSB
Ezekiel 6 in the CCB
Ezekiel 6 in the CUV
Ezekiel 6 in the CUVS
Ezekiel 6 in the DBT
Ezekiel 6 in the DGDNT
Ezekiel 6 in the DHNT
Ezekiel 6 in the DNT
Ezekiel 6 in the ELBE
Ezekiel 6 in the EMTV
Ezekiel 6 in the ESV
Ezekiel 6 in the FBV
Ezekiel 6 in the FEB
Ezekiel 6 in the GGMNT
Ezekiel 6 in the GNT
Ezekiel 6 in the HARY
Ezekiel 6 in the HNT
Ezekiel 6 in the IRVA
Ezekiel 6 in the IRVB
Ezekiel 6 in the IRVG
Ezekiel 6 in the IRVH
Ezekiel 6 in the IRVK
Ezekiel 6 in the IRVM
Ezekiel 6 in the IRVM2
Ezekiel 6 in the IRVO
Ezekiel 6 in the IRVP
Ezekiel 6 in the IRVT
Ezekiel 6 in the IRVT2
Ezekiel 6 in the IRVU
Ezekiel 6 in the ISVN
Ezekiel 6 in the JSNT
Ezekiel 6 in the KAPI
Ezekiel 6 in the KBT1ETNIK
Ezekiel 6 in the KBV
Ezekiel 6 in the KJV
Ezekiel 6 in the KNFD
Ezekiel 6 in the LBA
Ezekiel 6 in the LBLA
Ezekiel 6 in the LNT
Ezekiel 6 in the LSV
Ezekiel 6 in the MAAL
Ezekiel 6 in the MBV
Ezekiel 6 in the MBV2
Ezekiel 6 in the MHNT
Ezekiel 6 in the MKNFD
Ezekiel 6 in the MNG
Ezekiel 6 in the MNT
Ezekiel 6 in the MNT2
Ezekiel 6 in the MRS1T
Ezekiel 6 in the NAA
Ezekiel 6 in the NASB
Ezekiel 6 in the NBLA
Ezekiel 6 in the NBS
Ezekiel 6 in the NBVTP
Ezekiel 6 in the NET2
Ezekiel 6 in the NIV11
Ezekiel 6 in the NNT
Ezekiel 6 in the NNT2
Ezekiel 6 in the NNT3
Ezekiel 6 in the PDDPT
Ezekiel 6 in the PFNT
Ezekiel 6 in the RMNT
Ezekiel 6 in the SBIAS
Ezekiel 6 in the SBIBS
Ezekiel 6 in the SBIBS2
Ezekiel 6 in the SBICS
Ezekiel 6 in the SBIDS
Ezekiel 6 in the SBIGS
Ezekiel 6 in the SBIHS
Ezekiel 6 in the SBIIS
Ezekiel 6 in the SBIIS2
Ezekiel 6 in the SBIIS3
Ezekiel 6 in the SBIKS
Ezekiel 6 in the SBIKS2
Ezekiel 6 in the SBIMS
Ezekiel 6 in the SBIOS
Ezekiel 6 in the SBIPS
Ezekiel 6 in the SBISS
Ezekiel 6 in the SBITS
Ezekiel 6 in the SBITS2
Ezekiel 6 in the SBITS3
Ezekiel 6 in the SBITS4
Ezekiel 6 in the SBIUS
Ezekiel 6 in the SBIVS
Ezekiel 6 in the SBT
Ezekiel 6 in the SBT1E
Ezekiel 6 in the SCHL
Ezekiel 6 in the SNT
Ezekiel 6 in the SUSU
Ezekiel 6 in the SUSU2
Ezekiel 6 in the SYNO
Ezekiel 6 in the TBIAOTANT
Ezekiel 6 in the TBT1E
Ezekiel 6 in the TBT1E2
Ezekiel 6 in the TFTIP
Ezekiel 6 in the TFTU
Ezekiel 6 in the TGNTATF3T
Ezekiel 6 in the THAI
Ezekiel 6 in the TNFD
Ezekiel 6 in the TNT
Ezekiel 6 in the TNTIK
Ezekiel 6 in the TNTIL
Ezekiel 6 in the TNTIN
Ezekiel 6 in the TNTIP
Ezekiel 6 in the TNTIZ
Ezekiel 6 in the TOMA
Ezekiel 6 in the TTENT
Ezekiel 6 in the UBG
Ezekiel 6 in the UGV
Ezekiel 6 in the UGV2
Ezekiel 6 in the UGV3
Ezekiel 6 in the VBL
Ezekiel 6 in the VDCC
Ezekiel 6 in the YALU
Ezekiel 6 in the YAPE
Ezekiel 6 in the YBVTP
Ezekiel 6 in the ZBP