Ezra 2 (BOYCB)

1 Lákòókò náà, wọ̀nyí ni àwọn ènìyàn agbègbè Juda tí ó gòkè wá láti ìgbèkùn láàrín àwọn tí a kó lọ, ẹni tí Nebukadnessari ọba Babeli ti fi agbára mú ní ìgbèkùn lọ sí Babeli (wọ́n padà sí Jerusalẹmu àti Juda, olúkúlùkù sí ìlú rẹ̀. 2 Àwọn wọ̀nyí bá Serubbabeli, Jeṣua, Nehemiah, Seraiah, Reelaiah, Mordekai, Bilṣani, Mispari, Bigfai, Rehumu àti Baanah wá). Iye àwọn ọkùnrin àwọn ènìyàn Israẹli. 3 Àwọn ọmọParoṣi jẹ́ ẹgbàá ó lé méjìléláàádọ́sàn-án (2,172) 4 Ṣefatia jẹ́ òjìdínnírinwó ó lé méjìlá (372) 5 Arah jẹ́ ẹgbẹ̀rin ó dín mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (775) 6 Pahati-Moabu (láti ipasẹ̀ àwọn ọmọ Jeṣua àti Joabu) jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì àti ẹgbẹ̀rin lé méjìlá (2,812) 7 Elamu jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀fà ó lé mẹ́rin (1,254) 8 Sattu jẹ́ ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rún ó lé márùn-ún (945) 9 Sakkai jẹ́ òjìdínlẹ́gbẹ̀rin (760) 10 Bani jẹ́ òjìlélẹ́gbẹ̀ta ó lé méjì (642) 11 Bebai jẹ́ ẹgbẹ̀ta ó lé mẹ́tàlélógún (623) 12 Asgadi jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé méjìlélógún (1,222) 13 Adonikami jẹ́ ọ̀tàlélẹ́gbẹ̀ta ó lé mẹ́fà (666) 14 Bigfai jẹ́ ẹgbàá ó lé mẹ́rìndínlọ́gọ́ta (2,056) 15 Adini jẹ́ àádọ́ta lé ní irinwó ó lé mẹ́rin (454) 16 Ateri (nípasẹ̀ Hesekiah) jẹ́ méjìdínlọ́gọ́run (98) 17 Besai jẹ́ ọrùndínnírinwó ó lé mẹ́ta (323) 18 Jora jẹ́ méjìléláàádọ́fà (112) 19 Haṣumu jẹ́ igba ó lé mẹ́tàlélógún (223) 20 Gibbari jẹ́ márùndínlọ́gọ́rùn (95). 21 Àwọn ọmọBẹtilẹhẹmu jẹ́ mẹ́tàlélọ́gọ́fà (123) 22 Netofa jẹ́ mẹ́rìndínlọ́gọ́ta (56) 23 Anatoti jẹ́ méjìdínláàádóje (128) 24 Asmafeti jẹ́ méjìlélógójì (42) 25 Kiriati-Jearimu, Kefira àti Beeroti jẹ́ ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rin ó lé mẹ́ta (743) 26 Rama àti Geba jẹ́ ẹgbẹ̀ta ó lé mọ́kànlélógún (621) 27 Mikmasi jẹ́ méjìlélọ́gọ́fà (122) 28 Beteli àti Ai jẹ́ igba ó lé mẹ́tàlélógún (223) 29 Nebo jẹ́ méjìléláàádọ́ta (52) 30 Magbiṣi jẹ́ mẹ́rìndínlọ́gọ́jọ (156) 31 Elamu mìíràn jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́rìnléláàádọ́ta (1,254) 32 Harimu jẹ́ ọ̀rìndínnírinwó (320). 33 Lodi, Hadidi àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé márùn-ún (725) 34 Jeriko jẹ́ ọ̀tàdínnírinwó ó lé márùn-ún (345) 35 Senaa jẹ́ egbèji dín lógún ó lé ọgbọ̀n (3,630). 36 Àwọn àlùfáà.Àwọn ọmọJedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973) 37 Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052) 38 Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247) 39 Harimu jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017). 40 Àwọn ọmọ Lefi.Àwọn ọmọJeṣua àti Kadmieli (ti ìdílé Hodafiah) jẹ́ mẹ́rìnléláàádọ́rin (74). 41 Àwọn akọrin.Àwọn ọmọAsafu jẹ́ méjìdínláàádóje (128). 42 Àwọn aṣọ́bodè.Àwọn aráṢallumu, Ateri, Talmoni,Akkubu, Hatita àti Ṣobai jẹ́ mọ́kàndínlógóje (139). 43 Àwọn ìránṣẹ́ tẹmpili.Àwọn ọmọ.Siha, Hasufa, Tabboati, 44 Kerosi, Siaha, Padoni, 45 Lebana, Hagaba, Akkubu, 46 Hagabu, Ṣalmai, Hanani, 47 Giddeli, Gahari, Reaiah, 48 Resini, Nekoda, Gassamu, 49 Ussa, Pasea, Besai, 50 Asna, Mehuni, Nefisimu, 51 Bakbu, Hakufa, Harhuri. 52 Basluti, Mehida, Harṣa, 53 Barkosi, Sisera, Tema, 54 Nesia àti Hatifa. 55 Àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Solomoni.Àwọn ọmọSotai, Sofereti, Peruda, 56 Jaala, Darkoni, Giddeli, 57 Ṣefatia, àwọn ọmọ Hattili,Pokereti ti Haṣebaimu àti àwọn ọmọ Ami. 58 Àwọn ìránṣẹ́ tẹmpili àti àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Solomoni jẹ́ irinwó ó dín mẹ́jọ (392). 59 Àwọn wọ̀nyí gòkè wá láti àwọn ìlú ti Teli-Mela, Teli-Harṣa, Kerubu, Addoni àti Immeri, ṣùgbọ́n wọn kò lè sọ pẹ̀lú ìdánilójú pé ìdílé àwọn wá láti ara ìran ẹ̀yà Israẹli. 60 Àwọn ọmọDelaiah, Tobiah àti Nekoda jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀ta ó lé méjì (652). 61 Àti nínú àwọn ọmọ àwọn àlùfáà.Àwọn ọmọ:Hobaiah, Hakosi àti Barsillai (ọkùnrin tí ó fẹ́ ọmọbìnrin Barsillai ará Gileadi a sì ń fi orúkọ náà pè é). 62 Àwọn wọ̀nyí wá ìwé ìrántí ìdílé wọn, ṣùgbọ́n wọn kò rí i, bẹ́ẹ̀ ni a kò kà wọ́n kún ara àlùfáà nítorí, a kà wọ́n sí aláìmọ́. 63 Baálẹ̀ pa á láṣẹ fún wọn pé wọn kò gbọdọ̀ jẹ nínú oúnjẹ mímọ́ jùlọ títí tí àlùfáà kan yóò fi ṣiṣẹ́ ìránṣẹ́ pẹ̀lú Urimu àti Tumimu. 64 Gbogbo ìjọ ènìyàn náà jẹ́ ẹgbàá mọ́kànlélógún ó lé òjìdínnírinwó (42,360). 65 Yàtọ̀ sí ẹgbẹ̀rin dín lẹ́gbàárin ó dín mẹ́tàlélọ́gọ́ta (7,337) ìránṣẹ́ ọkùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin; wọ́n ní igba (200) akọrin ọkùnrin àti obìnrin. 66 Wọ́n ní ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rin ó dín mẹ́rin ẹṣin (736); ìbáaka òjìlélúgba ó lé márùn-ún (245), 67 ràkunmí jẹ́ irinwó ó lé márùndínlógójì (435) àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ẹgbẹ̀rin lé lọ́gbọ̀n ó dín ọgọ́rin (6,720). 68 Ní ìgbà tí wọ́n dé ilé OLÚWA ní Jerusalẹmu, díẹ̀ nínú àwọn olórí àwọn ìdílé fi ọrẹ àtinúwá sílẹ̀ fún ṣíṣe àtúnkọ́ ilé Ọlọ́run ní ààyè rẹ̀. 69 Gẹ́gẹ́ bí agbára wọn, wọ́n fún ilé ìṣúra fún iṣẹ́ yìí ní ọ̀kẹ́ mẹ́ta ó lé lẹ́gbẹ̀rún (61,000) ìwọ̀n dariki wúrà, ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) fàdákà àti ọgọ́rùn-ún ẹ̀wù àlùfáà. 70 Àwọn àlùfáà, àwọn ará Lefi, àwọn akọrin, àwọn aṣọ́bodè àti àwọn ìránṣẹ́ ilé OLÚWA ṣe àtìpó sínú àwọn ìlú wọn, pẹ̀lú àwọn ènìyàn mìíràn, àti ìyókù àwọn ọmọ Israẹli ṣe àtìpó sínú ìlú u wọn.

In Other Versions

Ezra 2 in the ANGEFD

Ezra 2 in the ANTPNG2D

Ezra 2 in the AS21

Ezra 2 in the BAGH

Ezra 2 in the BBPNG

Ezra 2 in the BBT1E

Ezra 2 in the BDS

Ezra 2 in the BEV

Ezra 2 in the BHAD

Ezra 2 in the BIB

Ezra 2 in the BLPT

Ezra 2 in the BNT

Ezra 2 in the BNTABOOT

Ezra 2 in the BNTLV

Ezra 2 in the BOATCB

Ezra 2 in the BOATCB2

Ezra 2 in the BOBCV

Ezra 2 in the BOCNT

Ezra 2 in the BOECS

Ezra 2 in the BOGWICC

Ezra 2 in the BOHCB

Ezra 2 in the BOHCV

Ezra 2 in the BOHLNT

Ezra 2 in the BOHNTLTAL

Ezra 2 in the BOICB

Ezra 2 in the BOILNTAP

Ezra 2 in the BOITCV

Ezra 2 in the BOKCV

Ezra 2 in the BOKCV2

Ezra 2 in the BOKHWOG

Ezra 2 in the BOKSSV

Ezra 2 in the BOLCB

Ezra 2 in the BOLCB2

Ezra 2 in the BOMCV

Ezra 2 in the BONAV

Ezra 2 in the BONCB

Ezra 2 in the BONLT

Ezra 2 in the BONUT2

Ezra 2 in the BOPLNT

Ezra 2 in the BOSCB

Ezra 2 in the BOSNC

Ezra 2 in the BOTLNT

Ezra 2 in the BOVCB

Ezra 2 in the BPBB

Ezra 2 in the BPH

Ezra 2 in the BSB

Ezra 2 in the CCB

Ezra 2 in the CUV

Ezra 2 in the CUVS

Ezra 2 in the DBT

Ezra 2 in the DGDNT

Ezra 2 in the DHNT

Ezra 2 in the DNT

Ezra 2 in the ELBE

Ezra 2 in the EMTV

Ezra 2 in the ESV

Ezra 2 in the FBV

Ezra 2 in the FEB

Ezra 2 in the GGMNT

Ezra 2 in the GNT

Ezra 2 in the HARY

Ezra 2 in the HNT

Ezra 2 in the IRVA

Ezra 2 in the IRVB

Ezra 2 in the IRVG

Ezra 2 in the IRVH

Ezra 2 in the IRVK

Ezra 2 in the IRVM

Ezra 2 in the IRVM2

Ezra 2 in the IRVO

Ezra 2 in the IRVP

Ezra 2 in the IRVT

Ezra 2 in the IRVT2

Ezra 2 in the IRVU

Ezra 2 in the ISVN

Ezra 2 in the JSNT

Ezra 2 in the KAPI

Ezra 2 in the KBT1ETNIK

Ezra 2 in the KBV

Ezra 2 in the KJV

Ezra 2 in the KNFD

Ezra 2 in the LBA

Ezra 2 in the LBLA

Ezra 2 in the LNT

Ezra 2 in the LSV

Ezra 2 in the MAAL

Ezra 2 in the MBV

Ezra 2 in the MBV2

Ezra 2 in the MHNT

Ezra 2 in the MKNFD

Ezra 2 in the MNG

Ezra 2 in the MNT

Ezra 2 in the MNT2

Ezra 2 in the MRS1T

Ezra 2 in the NAA

Ezra 2 in the NASB

Ezra 2 in the NBLA

Ezra 2 in the NBS

Ezra 2 in the NBVTP

Ezra 2 in the NET2

Ezra 2 in the NIV11

Ezra 2 in the NNT

Ezra 2 in the NNT2

Ezra 2 in the NNT3

Ezra 2 in the PDDPT

Ezra 2 in the PFNT

Ezra 2 in the RMNT

Ezra 2 in the SBIAS

Ezra 2 in the SBIBS

Ezra 2 in the SBIBS2

Ezra 2 in the SBICS

Ezra 2 in the SBIDS

Ezra 2 in the SBIGS

Ezra 2 in the SBIHS

Ezra 2 in the SBIIS

Ezra 2 in the SBIIS2

Ezra 2 in the SBIIS3

Ezra 2 in the SBIKS

Ezra 2 in the SBIKS2

Ezra 2 in the SBIMS

Ezra 2 in the SBIOS

Ezra 2 in the SBIPS

Ezra 2 in the SBISS

Ezra 2 in the SBITS

Ezra 2 in the SBITS2

Ezra 2 in the SBITS3

Ezra 2 in the SBITS4

Ezra 2 in the SBIUS

Ezra 2 in the SBIVS

Ezra 2 in the SBT

Ezra 2 in the SBT1E

Ezra 2 in the SCHL

Ezra 2 in the SNT

Ezra 2 in the SUSU

Ezra 2 in the SUSU2

Ezra 2 in the SYNO

Ezra 2 in the TBIAOTANT

Ezra 2 in the TBT1E

Ezra 2 in the TBT1E2

Ezra 2 in the TFTIP

Ezra 2 in the TFTU

Ezra 2 in the TGNTATF3T

Ezra 2 in the THAI

Ezra 2 in the TNFD

Ezra 2 in the TNT

Ezra 2 in the TNTIK

Ezra 2 in the TNTIL

Ezra 2 in the TNTIN

Ezra 2 in the TNTIP

Ezra 2 in the TNTIZ

Ezra 2 in the TOMA

Ezra 2 in the TTENT

Ezra 2 in the UBG

Ezra 2 in the UGV

Ezra 2 in the UGV2

Ezra 2 in the UGV3

Ezra 2 in the VBL

Ezra 2 in the VDCC

Ezra 2 in the YALU

Ezra 2 in the YAPE

Ezra 2 in the YBVTP

Ezra 2 in the ZBP