Isaiah 32 (BOYCB)
1 Wò ó, ọba kan yóò jẹ nínú òdodoàwọn olórí yóò máa fi ìdájọ́ ṣe àkóso. 2 Ẹnìkọ̀ọ̀kan yóò jẹ́ bí ibi ìṣápamọ́ kúrò lọ́wọ́ afẹ́fẹ́àti ààbò kúrò lọ́wọ́ ìjì,gẹ́gẹ́ bí odò omi ní ilẹ̀ aṣálẹ̀,àti bí òjìji àpáta ńlá ní ilẹ̀ gbígbẹ. 3 Nígbà náà ni ojú àwọn tí ó rí kò ní padé mọ́,àti etí àwọn tí ó gbọ́ yóò tẹ́tí sílẹ̀. 4 Ọkàn àwọn oníwàdùwàdù ni yóò là tí yóò sì yè,àti ahọ́n tí ń kólòlò ni yóò là geerege. 5 A kò ní pe òmùgọ̀ ní ọlọ́lá mọ́tàbí kí a fi ọ̀wọ̀ tí ó ga jù fún aláìlóòótọ́ ènìyàn. 6 Nítorí òmùgọ̀ sọ̀rọ̀ òmùgọ̀,ọkàn rẹ̀ kún fún ìwà ibi:òun hùwà àìwà-bí-Ọlọ́runó sì ń tan àṣìṣe tí ó kan OLÚWA kalẹ̀;ẹni ebi ń pa ló fi sílẹ̀ lófoàti fún àwọn tí òǹgbẹ ń gbẹni ó mú omi kúrò. 7 Ibi ni gbogbo ọgbọ́n àwọn ìkà ènìyàn jẹ́,ó ń gba èrò búburúláti fi ọ̀rọ̀ èké pa tálákà run,bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀bẹ̀ aláìní sì tọ̀nà. 8 Ṣùgbọ́n ọlọ́lá ènìyàn a máa pète ohun ńláàti nípa èrò rere ni yóò dúró. 9 Ẹ̀yin obìnrin tí ẹ ti gba ìtẹ́lọ́rùn gidiẹ dìde kí ẹ tẹ́tí sí mi,ẹ̀yin ọ̀dọ́mọbìnrin tí ọkàn yín ti balẹ̀,ẹ gbọ́ ohun tí mo fẹ́ sọ! 10 Ní ó lé díẹ̀ ní ọdún kanẹ̀yin tí ọkàn an yín balẹ̀ yóò wárìrì;ìkórè àjàrà kò ní múnádóko,bẹ́ẹ̀ ni ìkórè èso kò ní sí. 11 Wárìrì, ẹ̀yin obìnrin onítẹ̀lọ́rùn;bẹ̀rù, ẹ̀yin ọ̀dọ́mọbìnrin tí ẹ rò pé ọkàn yín balẹ̀!Ẹ bọ́ aṣọ yín kúrò,ẹ ró aṣọ ọ̀fọ̀ mọ́ ẹ̀gbẹ́ yín. 12 Ẹ lu ọmú yín fún pápá ìgbádùn náà,fún àwọn àjàrà eléso 13 àti fún ilẹ̀ àwọn ènìyàn mi,ilẹ̀ tí ó ti kún fún ẹ̀gún àti ẹ̀wọ̀n,bẹ́ẹ̀ ni, kẹ́dùn fún gbogbo ilé ìturaàti fún ìlú àríyá yìí. 14 Ilé olódi ni a ó kọ̀sílẹ̀,ìlù aláriwo ni a ó kọ̀ tì;ilé olódi àti ilé ìṣọ́ ni yóò di ihò títí láéláé,ìdùnnú àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ àti pápáoko fún àwọn ẹran ọ̀sìn, 15 títí a ó fi tú Ẹ̀mí sí wa lórí láti òkè wá,àti ti aṣálẹ̀ tí yóò dí pápá oko ọlọ́ràáàti tí pápá ọlọ́ràá yóò dàbí ẹgàn. 16 Ẹ̀tọ́ yóò máa gbé ní inú aṣálẹ̀àti òdodo yóò sì máa gbé ní pápá oko ọlọ́ràá. 17 Èso òdodo náà yóò sì jẹ́ àlàáfíà;àbájáde òdodo yóò sì jẹ́ ìdákẹ́ jẹ́ẹ́ àti ìgbẹ́kẹ̀lé títí láé. 18 Àwọn ènìyàn mi yóò máa gbé ní ibùgbé àlàáfíà,ní ibùgbé ìdánilójú,ní àwọn ibi ìsinmi tí ó parọ́rọ́. 19 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé yìnyín ti tẹ́jú igbó pẹrẹsẹàti tí ojú ìlú ti tẹ́ pẹrẹsẹ pátápátá, 20 báwo ni ẹ ó ti jẹ́ alábùkún tó,nípa gbígbin irúgbìn sí ipa odò gbogbo,àti nípa jíjẹ́ kí àwọn màlúù yín àtiàwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ jẹ láìsí ìdíwọ́.
In Other Versions
Isaiah 32 in the ANGEFD
Isaiah 32 in the ANTPNG2D
Isaiah 32 in the AS21
Isaiah 32 in the BAGH
Isaiah 32 in the BBPNG
Isaiah 32 in the BBT1E
Isaiah 32 in the BDS
Isaiah 32 in the BEV
Isaiah 32 in the BHAD
Isaiah 32 in the BIB
Isaiah 32 in the BLPT
Isaiah 32 in the BNT
Isaiah 32 in the BNTABOOT
Isaiah 32 in the BNTLV
Isaiah 32 in the BOATCB
Isaiah 32 in the BOATCB2
Isaiah 32 in the BOBCV
Isaiah 32 in the BOCNT
Isaiah 32 in the BOECS
Isaiah 32 in the BOGWICC
Isaiah 32 in the BOHCB
Isaiah 32 in the BOHCV
Isaiah 32 in the BOHLNT
Isaiah 32 in the BOHNTLTAL
Isaiah 32 in the BOICB
Isaiah 32 in the BOILNTAP
Isaiah 32 in the BOITCV
Isaiah 32 in the BOKCV
Isaiah 32 in the BOKCV2
Isaiah 32 in the BOKHWOG
Isaiah 32 in the BOKSSV
Isaiah 32 in the BOLCB
Isaiah 32 in the BOLCB2
Isaiah 32 in the BOMCV
Isaiah 32 in the BONAV
Isaiah 32 in the BONCB
Isaiah 32 in the BONLT
Isaiah 32 in the BONUT2
Isaiah 32 in the BOPLNT
Isaiah 32 in the BOSCB
Isaiah 32 in the BOSNC
Isaiah 32 in the BOTLNT
Isaiah 32 in the BOVCB
Isaiah 32 in the BPBB
Isaiah 32 in the BPH
Isaiah 32 in the BSB
Isaiah 32 in the CCB
Isaiah 32 in the CUV
Isaiah 32 in the CUVS
Isaiah 32 in the DBT
Isaiah 32 in the DGDNT
Isaiah 32 in the DHNT
Isaiah 32 in the DNT
Isaiah 32 in the ELBE
Isaiah 32 in the EMTV
Isaiah 32 in the ESV
Isaiah 32 in the FBV
Isaiah 32 in the FEB
Isaiah 32 in the GGMNT
Isaiah 32 in the GNT
Isaiah 32 in the HARY
Isaiah 32 in the HNT
Isaiah 32 in the IRVA
Isaiah 32 in the IRVB
Isaiah 32 in the IRVG
Isaiah 32 in the IRVH
Isaiah 32 in the IRVK
Isaiah 32 in the IRVM
Isaiah 32 in the IRVM2
Isaiah 32 in the IRVO
Isaiah 32 in the IRVP
Isaiah 32 in the IRVT
Isaiah 32 in the IRVT2
Isaiah 32 in the IRVU
Isaiah 32 in the ISVN
Isaiah 32 in the JSNT
Isaiah 32 in the KAPI
Isaiah 32 in the KBT1ETNIK
Isaiah 32 in the KBV
Isaiah 32 in the KJV
Isaiah 32 in the KNFD
Isaiah 32 in the LBA
Isaiah 32 in the LBLA
Isaiah 32 in the LNT
Isaiah 32 in the LSV
Isaiah 32 in the MAAL
Isaiah 32 in the MBV
Isaiah 32 in the MBV2
Isaiah 32 in the MHNT
Isaiah 32 in the MKNFD
Isaiah 32 in the MNG
Isaiah 32 in the MNT
Isaiah 32 in the MNT2
Isaiah 32 in the MRS1T
Isaiah 32 in the NAA
Isaiah 32 in the NASB
Isaiah 32 in the NBLA
Isaiah 32 in the NBS
Isaiah 32 in the NBVTP
Isaiah 32 in the NET2
Isaiah 32 in the NIV11
Isaiah 32 in the NNT
Isaiah 32 in the NNT2
Isaiah 32 in the NNT3
Isaiah 32 in the PDDPT
Isaiah 32 in the PFNT
Isaiah 32 in the RMNT
Isaiah 32 in the SBIAS
Isaiah 32 in the SBIBS
Isaiah 32 in the SBIBS2
Isaiah 32 in the SBICS
Isaiah 32 in the SBIDS
Isaiah 32 in the SBIGS
Isaiah 32 in the SBIHS
Isaiah 32 in the SBIIS
Isaiah 32 in the SBIIS2
Isaiah 32 in the SBIIS3
Isaiah 32 in the SBIKS
Isaiah 32 in the SBIKS2
Isaiah 32 in the SBIMS
Isaiah 32 in the SBIOS
Isaiah 32 in the SBIPS
Isaiah 32 in the SBISS
Isaiah 32 in the SBITS
Isaiah 32 in the SBITS2
Isaiah 32 in the SBITS3
Isaiah 32 in the SBITS4
Isaiah 32 in the SBIUS
Isaiah 32 in the SBIVS
Isaiah 32 in the SBT
Isaiah 32 in the SBT1E
Isaiah 32 in the SCHL
Isaiah 32 in the SNT
Isaiah 32 in the SUSU
Isaiah 32 in the SUSU2
Isaiah 32 in the SYNO
Isaiah 32 in the TBIAOTANT
Isaiah 32 in the TBT1E
Isaiah 32 in the TBT1E2
Isaiah 32 in the TFTIP
Isaiah 32 in the TFTU
Isaiah 32 in the TGNTATF3T
Isaiah 32 in the THAI
Isaiah 32 in the TNFD
Isaiah 32 in the TNT
Isaiah 32 in the TNTIK
Isaiah 32 in the TNTIL
Isaiah 32 in the TNTIN
Isaiah 32 in the TNTIP
Isaiah 32 in the TNTIZ
Isaiah 32 in the TOMA
Isaiah 32 in the TTENT
Isaiah 32 in the UBG
Isaiah 32 in the UGV
Isaiah 32 in the UGV2
Isaiah 32 in the UGV3
Isaiah 32 in the VBL
Isaiah 32 in the VDCC
Isaiah 32 in the YALU
Isaiah 32 in the YAPE
Isaiah 32 in the YBVTP
Isaiah 32 in the ZBP