Proverbs 18 (BOYCB)
1 Ènìyàn tí kò ba ni rẹ́ a máa lépa ìmọ̀ ara rẹ̀;ó kọjú ìjà sí gbogbo ìdájọ́ òdodo. 2 Aláìgbọ́n kò rí inú dídùn sí òyeṣùgbọ́n ó ní inú dídùn sí sísọ èrò tirẹ̀. 3 Nígbà ti ènìyàn búburú dé ni ẹ̀gàn dé,nígbà ti ẹ̀gàn dé ni ìtìjú dé. 4 Ọ̀rọ̀ ẹnu ènìyàn jẹ́ omi jíjìn,ṣùgbọ́n orísun ọgbọ́n jẹ́ odò tí ń sàn. 5 Kò dára kí ènìyàn ṣe ojúsàájú fún ènìyàn búburútàbí kí a fi ìdájọ́ òdodo du aláìṣẹ̀. 6 Ètè aláìgbọ́n dá ìjà sílẹ̀ẹnu rẹ̀ sì ń ṣokùnfà ẹgba. 7 Ẹnu aláìgbọ́n ni ó ba tirẹ̀ jẹ́,ètè rẹ̀ sì jẹ́ ìdẹ̀kùn fún ọkàn rẹ̀. 8 Ọ̀rọ̀ olófòófó dàbí oúnjẹ àdídùn;wọ́n a sì wọ ìsàlẹ̀ inú lọ. 9 Ẹni tí kò ṣe déédé nínú iṣẹ́ rẹ̀arákùnrin ló jẹ́ fún apanirun. 10 Orúkọ OLÚWA, ilé ìṣọ́ agbára ni;olódodo sá wọ inú rẹ̀, ó sì rí ìgbàlà. 11 Ọ̀rọ̀ olówó ni ìlú olódi wọn;wọ́n rò ó bí i wí pé odi tí kò ṣe é gùn ni. 12 Ṣáájú ìṣubú ọkàn ènìyàn a kọ́kọ́ máa gbéraga,ṣùgbọ́n ìrẹ̀lẹ̀ ni ó máa ń ṣáájú ọlá. 13 Ẹni tí ó ń fèsì kí ó tó gbọ́,èyí ni ìwà òmùgọ̀ àti ìtìjú rẹ̀. 14 Ọkàn ènìyàn a máa gbé e ró nígbà àìsàn,ṣùgbọ́n ta ni ó le forí ti ọkàn tí ó rẹ̀wẹ̀sì. 15 Ọkàn olóye ní i gba ìmọ̀;etí ọlọ́gbọ́n ní í ṣe àwárí rẹ̀. 16 Ẹ̀bùn máa ń ṣí ọ̀nà fún ẹni tí ń fún ni lẹ́bùna sì mú un wọlé sí ọ̀dọ̀ àwọn olókìkí. 17 Ẹni tí ó kọ́kọ́ rọjọ́ máa ń dàbí i pé ó jàre,títí ẹlòmíràn yóò fi bọ́ síwájú kí ó sì tú àṣírí gbogbo. 18 Ìbò dídì máa ń parí ìjàa sì mú kí àwọn alátakò méjì jìnnà sí ara wọn. 19 Arákùnrin tí a ṣẹ̀ sí ṣòro yípadà ju ìlú olódi lọ,ìjà wọ sì dàbí ọ̀pá ìdábùú ààfin. 20 Láti inú èso ẹnu rẹ̀ ikùn ènìyàn a yó;láti inú ìkórè ẹnu rẹ̀ ni ó ti jẹ yó. 21 Ikú àti ìyè ń bẹ nípa ahọ́n wọn,àwọn tí ó sì fẹ́ràn rẹ̀ yóò jẹ ẹ́. 22 Ẹni tí ó rí aya fẹ́, rí ohun rere,o sì gba ojúrere lọ́dọ̀ OLÚWA. 23 Tálákà ń bẹ̀bẹ̀ fún àánú,ṣùgbọ́n ọlọ́rọ̀ a dáhùn pẹ̀lú ìkanra. 24 Ènìyàn tí ó ní ọ̀rẹ́ púpọ̀ le è parun,ṣùgbọ́n ọ̀rẹ́ kan wà tí ó súnmọ́ ni tímọ́tímọ́ ju arákùnrin.
In Other Versions
Proverbs 18 in the ANGEFD
Proverbs 18 in the ANTPNG2D
Proverbs 18 in the AS21
Proverbs 18 in the BAGH
Proverbs 18 in the BBPNG
Proverbs 18 in the BBT1E
Proverbs 18 in the BDS
Proverbs 18 in the BEV
Proverbs 18 in the BHAD
Proverbs 18 in the BIB
Proverbs 18 in the BLPT
Proverbs 18 in the BNT
Proverbs 18 in the BNTABOOT
Proverbs 18 in the BNTLV
Proverbs 18 in the BOATCB
Proverbs 18 in the BOATCB2
Proverbs 18 in the BOBCV
Proverbs 18 in the BOCNT
Proverbs 18 in the BOECS
Proverbs 18 in the BOGWICC
Proverbs 18 in the BOHCB
Proverbs 18 in the BOHCV
Proverbs 18 in the BOHLNT
Proverbs 18 in the BOHNTLTAL
Proverbs 18 in the BOICB
Proverbs 18 in the BOILNTAP
Proverbs 18 in the BOITCV
Proverbs 18 in the BOKCV
Proverbs 18 in the BOKCV2
Proverbs 18 in the BOKHWOG
Proverbs 18 in the BOKSSV
Proverbs 18 in the BOLCB
Proverbs 18 in the BOLCB2
Proverbs 18 in the BOMCV
Proverbs 18 in the BONAV
Proverbs 18 in the BONCB
Proverbs 18 in the BONLT
Proverbs 18 in the BONUT2
Proverbs 18 in the BOPLNT
Proverbs 18 in the BOSCB
Proverbs 18 in the BOSNC
Proverbs 18 in the BOTLNT
Proverbs 18 in the BOVCB
Proverbs 18 in the BPBB
Proverbs 18 in the BPH
Proverbs 18 in the BSB
Proverbs 18 in the CCB
Proverbs 18 in the CUV
Proverbs 18 in the CUVS
Proverbs 18 in the DBT
Proverbs 18 in the DGDNT
Proverbs 18 in the DHNT
Proverbs 18 in the DNT
Proverbs 18 in the ELBE
Proverbs 18 in the EMTV
Proverbs 18 in the ESV
Proverbs 18 in the FBV
Proverbs 18 in the FEB
Proverbs 18 in the GGMNT
Proverbs 18 in the GNT
Proverbs 18 in the HARY
Proverbs 18 in the HNT
Proverbs 18 in the IRVA
Proverbs 18 in the IRVB
Proverbs 18 in the IRVG
Proverbs 18 in the IRVH
Proverbs 18 in the IRVK
Proverbs 18 in the IRVM
Proverbs 18 in the IRVM2
Proverbs 18 in the IRVO
Proverbs 18 in the IRVP
Proverbs 18 in the IRVT
Proverbs 18 in the IRVT2
Proverbs 18 in the IRVU
Proverbs 18 in the ISVN
Proverbs 18 in the JSNT
Proverbs 18 in the KAPI
Proverbs 18 in the KBT1ETNIK
Proverbs 18 in the KBV
Proverbs 18 in the KJV
Proverbs 18 in the KNFD
Proverbs 18 in the LBA
Proverbs 18 in the LBLA
Proverbs 18 in the LNT
Proverbs 18 in the LSV
Proverbs 18 in the MAAL
Proverbs 18 in the MBV
Proverbs 18 in the MBV2
Proverbs 18 in the MHNT
Proverbs 18 in the MKNFD
Proverbs 18 in the MNG
Proverbs 18 in the MNT
Proverbs 18 in the MNT2
Proverbs 18 in the MRS1T
Proverbs 18 in the NAA
Proverbs 18 in the NASB
Proverbs 18 in the NBLA
Proverbs 18 in the NBS
Proverbs 18 in the NBVTP
Proverbs 18 in the NET2
Proverbs 18 in the NIV11
Proverbs 18 in the NNT
Proverbs 18 in the NNT2
Proverbs 18 in the NNT3
Proverbs 18 in the PDDPT
Proverbs 18 in the PFNT
Proverbs 18 in the RMNT
Proverbs 18 in the SBIAS
Proverbs 18 in the SBIBS
Proverbs 18 in the SBIBS2
Proverbs 18 in the SBICS
Proverbs 18 in the SBIDS
Proverbs 18 in the SBIGS
Proverbs 18 in the SBIHS
Proverbs 18 in the SBIIS
Proverbs 18 in the SBIIS2
Proverbs 18 in the SBIIS3
Proverbs 18 in the SBIKS
Proverbs 18 in the SBIKS2
Proverbs 18 in the SBIMS
Proverbs 18 in the SBIOS
Proverbs 18 in the SBIPS
Proverbs 18 in the SBISS
Proverbs 18 in the SBITS
Proverbs 18 in the SBITS2
Proverbs 18 in the SBITS3
Proverbs 18 in the SBITS4
Proverbs 18 in the SBIUS
Proverbs 18 in the SBIVS
Proverbs 18 in the SBT
Proverbs 18 in the SBT1E
Proverbs 18 in the SCHL
Proverbs 18 in the SNT
Proverbs 18 in the SUSU
Proverbs 18 in the SUSU2
Proverbs 18 in the SYNO
Proverbs 18 in the TBIAOTANT
Proverbs 18 in the TBT1E
Proverbs 18 in the TBT1E2
Proverbs 18 in the TFTIP
Proverbs 18 in the TFTU
Proverbs 18 in the TGNTATF3T
Proverbs 18 in the THAI
Proverbs 18 in the TNFD
Proverbs 18 in the TNT
Proverbs 18 in the TNTIK
Proverbs 18 in the TNTIL
Proverbs 18 in the TNTIN
Proverbs 18 in the TNTIP
Proverbs 18 in the TNTIZ
Proverbs 18 in the TOMA
Proverbs 18 in the TTENT
Proverbs 18 in the UBG
Proverbs 18 in the UGV
Proverbs 18 in the UGV2
Proverbs 18 in the UGV3
Proverbs 18 in the VBL
Proverbs 18 in the VDCC
Proverbs 18 in the YALU
Proverbs 18 in the YAPE
Proverbs 18 in the YBVTP
Proverbs 18 in the ZBP