Psalms 51 (BOYCB)

undefined Fún adarí orin. Saamu ti Dafidi. Nígbà ti wòlíì Natani tọ wá, lẹ́yìn tí Dafidi dá ẹ̀ṣẹ̀ àgbèrè rẹ̀ pẹ̀lú Batṣeba. 1 Ṣàánú fún mi, Ọlọ́run,gẹ́gẹ́ bí ìdúró ṣinṣin ìfẹ́ rẹ̀,gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ àánú rẹ̀kí o sì pa gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi rẹ́. 2 Wẹ gbogbo àìṣedéédéé mi nù kúròkí o sì wẹ̀ mi mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ mi! 3 Nítorí mo mọ̀ gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi,nígbà gbogbo ni ẹ̀ṣẹ̀ mi wà níwájú mi. 4 Sí ọ, ìwọ nìkan ṣoṣo, ni mo dẹ́ṣẹ̀ síni mo sì ṣe búburú níwájú rẹ̀,kí a lè dá ọ láre nígbà tí ìwọ bá ń sọ̀rọ̀,kí o sì le wà láìlẹ́bi, nígbà tí ìwọ bá ń ṣe ìdájọ́. 5 Nítòótọ́, nínú ẹ̀ṣẹ̀ ni a ti bí mi,nínú ẹ̀ṣẹ̀ ni ìyá mí sì lóyún mi. 6 Nítòótọ́ ìwọ fẹ́ òtítọ́ ní inú;ìwọ kọ́ mi ní ọgbọ́n ní ìhà ìkọ̀kọ̀. 7 Wẹ̀ mí pẹ̀lú ewé hísópù, èmi yóò sì mọ́;fọ̀ mí, èmi yóò sì funfun ju yìnyín lọ. 8 Jẹ́ kí n gbọ́ ayọ̀ àti inú dídùn;jẹ́ kí gbogbo egungun tí ìwọ ti run kí ó máa yọ̀. 9 Pa ojú rẹ̀ mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ mikí o sì pa gbogbo àwọn àìṣedéédéé mi rẹ́. 10 Dá ọkàn mímọ́ sí inú mi, Ọlọ́run,kí o sì tún ẹ̀mí dídúró ṣinṣin ṣe sínú mi. 11 Má ṣe jù mi nù kúrò níwájú rẹ,kí o má ṣe gba Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ lọ́wọ́ mi. 12 Mú ayọ̀ ìgbàlà rẹ tọ̀ mí wá,kí o sì fún mi ní ẹ̀mí ìfẹ́, tí yóò mú mi dúró. 13 Nígbà náà ni èmi yóò máa kọ́ àwọn olùrékọjá ní ọ̀nà rẹ,àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ yóò sì yí padà sí ọ. 14 Gbà mí kúrò lọ́wọ́ ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀, Ọlọ́run,ìwọ Ọlọ́run ìgbàlà mi,ahọ́n mi yóò sì máa kọrin òdodo rẹ kíkan. 15 OLÚWA, ṣí mi ní ètè mi gbogbo,àti ẹnu mi yóò sì máa kéde ìyìn rẹ. 16 Nítorí ìwọ kò ní inú dídùn sí ẹbọ, tí èmi kò bá mú wá;Ìwọ kò ní inú dídùn sí ọrẹ ẹbọ sísun. 17 Ẹbọ Ọlọ́run ni ìròbìnújẹ́ ọkàn ìròbìnújẹ́ àti ìrora àyà. 18 Ṣe rere ní dídùn inú rẹ sí Sioni,ṣe rere; tún odi Jerusalẹmu mọ. 19 Nígbà náà ni inú rẹ yóò dùn sí ẹbọ òdodo,pẹ̀lú ọrẹ ẹbọ sísun àti ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ọrẹ ẹbọ sísun,nígbà náà ni wọn yóò fi akọ màlúù rú ẹbọ lórí pẹpẹ rẹ.

In Other Versions

Psalms 51 in the ANGEFD

Psalms 51 in the ANTPNG2D

Psalms 51 in the AS21

Psalms 51 in the BAGH

Psalms 51 in the BBPNG

Psalms 51 in the BBT1E

Psalms 51 in the BDS

Psalms 51 in the BEV

Psalms 51 in the BHAD

Psalms 51 in the BIB

Psalms 51 in the BLPT

Psalms 51 in the BNT

Psalms 51 in the BNTABOOT

Psalms 51 in the BNTLV

Psalms 51 in the BOATCB

Psalms 51 in the BOATCB2

Psalms 51 in the BOBCV

Psalms 51 in the BOCNT

Psalms 51 in the BOECS

Psalms 51 in the BOGWICC

Psalms 51 in the BOHCB

Psalms 51 in the BOHCV

Psalms 51 in the BOHLNT

Psalms 51 in the BOHNTLTAL

Psalms 51 in the BOICB

Psalms 51 in the BOILNTAP

Psalms 51 in the BOITCV

Psalms 51 in the BOKCV

Psalms 51 in the BOKCV2

Psalms 51 in the BOKHWOG

Psalms 51 in the BOKSSV

Psalms 51 in the BOLCB

Psalms 51 in the BOLCB2

Psalms 51 in the BOMCV

Psalms 51 in the BONAV

Psalms 51 in the BONCB

Psalms 51 in the BONLT

Psalms 51 in the BONUT2

Psalms 51 in the BOPLNT

Psalms 51 in the BOSCB

Psalms 51 in the BOSNC

Psalms 51 in the BOTLNT

Psalms 51 in the BOVCB

Psalms 51 in the BPBB

Psalms 51 in the BPH

Psalms 51 in the BSB

Psalms 51 in the CCB

Psalms 51 in the CUV

Psalms 51 in the CUVS

Psalms 51 in the DBT

Psalms 51 in the DGDNT

Psalms 51 in the DHNT

Psalms 51 in the DNT

Psalms 51 in the ELBE

Psalms 51 in the EMTV

Psalms 51 in the ESV

Psalms 51 in the FBV

Psalms 51 in the FEB

Psalms 51 in the GGMNT

Psalms 51 in the GNT

Psalms 51 in the HARY

Psalms 51 in the HNT

Psalms 51 in the IRVA

Psalms 51 in the IRVB

Psalms 51 in the IRVG

Psalms 51 in the IRVH

Psalms 51 in the IRVK

Psalms 51 in the IRVM

Psalms 51 in the IRVM2

Psalms 51 in the IRVO

Psalms 51 in the IRVP

Psalms 51 in the IRVT

Psalms 51 in the IRVT2

Psalms 51 in the IRVU

Psalms 51 in the ISVN

Psalms 51 in the JSNT

Psalms 51 in the KAPI

Psalms 51 in the KBT1ETNIK

Psalms 51 in the KBV

Psalms 51 in the KJV

Psalms 51 in the KNFD

Psalms 51 in the LBA

Psalms 51 in the LBLA

Psalms 51 in the LNT

Psalms 51 in the LSV

Psalms 51 in the MAAL

Psalms 51 in the MBV

Psalms 51 in the MBV2

Psalms 51 in the MHNT

Psalms 51 in the MKNFD

Psalms 51 in the MNG

Psalms 51 in the MNT

Psalms 51 in the MNT2

Psalms 51 in the MRS1T

Psalms 51 in the NAA

Psalms 51 in the NASB

Psalms 51 in the NBLA

Psalms 51 in the NBS

Psalms 51 in the NBVTP

Psalms 51 in the NET2

Psalms 51 in the NIV11

Psalms 51 in the NNT

Psalms 51 in the NNT2

Psalms 51 in the NNT3

Psalms 51 in the PDDPT

Psalms 51 in the PFNT

Psalms 51 in the RMNT

Psalms 51 in the SBIAS

Psalms 51 in the SBIBS

Psalms 51 in the SBIBS2

Psalms 51 in the SBICS

Psalms 51 in the SBIDS

Psalms 51 in the SBIGS

Psalms 51 in the SBIHS

Psalms 51 in the SBIIS

Psalms 51 in the SBIIS2

Psalms 51 in the SBIIS3

Psalms 51 in the SBIKS

Psalms 51 in the SBIKS2

Psalms 51 in the SBIMS

Psalms 51 in the SBIOS

Psalms 51 in the SBIPS

Psalms 51 in the SBISS

Psalms 51 in the SBITS

Psalms 51 in the SBITS2

Psalms 51 in the SBITS3

Psalms 51 in the SBITS4

Psalms 51 in the SBIUS

Psalms 51 in the SBIVS

Psalms 51 in the SBT

Psalms 51 in the SBT1E

Psalms 51 in the SCHL

Psalms 51 in the SNT

Psalms 51 in the SUSU

Psalms 51 in the SUSU2

Psalms 51 in the SYNO

Psalms 51 in the TBIAOTANT

Psalms 51 in the TBT1E

Psalms 51 in the TBT1E2

Psalms 51 in the TFTIP

Psalms 51 in the TFTU

Psalms 51 in the TGNTATF3T

Psalms 51 in the THAI

Psalms 51 in the TNFD

Psalms 51 in the TNT

Psalms 51 in the TNTIK

Psalms 51 in the TNTIL

Psalms 51 in the TNTIN

Psalms 51 in the TNTIP

Psalms 51 in the TNTIZ

Psalms 51 in the TOMA

Psalms 51 in the TTENT

Psalms 51 in the UBG

Psalms 51 in the UGV

Psalms 51 in the UGV2

Psalms 51 in the UGV3

Psalms 51 in the VBL

Psalms 51 in the VDCC

Psalms 51 in the YALU

Psalms 51 in the YAPE

Psalms 51 in the YBVTP

Psalms 51 in the ZBP