Zechariah 12 (BOYCB)
1 Ọ̀rọ̀-ìmọ̀. Ọ̀rọ̀ OLÚWA fún Israẹli ni. OLÚWA wí, ẹni tí ó na àwọn ọ̀run, tí ó sì fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀, tí ó sì da ẹ̀mí ènìyàn tí ń bẹ ni inú rẹ̀, 2 “Kíyèsi í, èmi yóò sọ Jerusalẹmu dí àgọ́ ìwárìrì sí gbogbo ènìyàn yíká, nígbà tí wọn yóò dó ti Juda àti Jerusalẹmu. 3 Ní ọjọ́ náà, nígbà tí gbogbo orílẹ̀-èdè ayé bá parapọ̀ sí i, ni èmi yóò sọ Jerusalẹmu di òkúta ti ko ṣe yí kúrò fún gbogbo ènìyàn, gbogbo àwọn tí ó bá sì fẹ́ yí i ni a ó gé sí wẹ́wẹ́, 4 ní ọjọ́ náà,” ni OLÚWA wí, “Ni èmi yóò fi ìdágìrì lu gbogbo ẹṣin, àti fi òmùgọ̀ kọlu ẹni tí ń gun un; èmi yóò sì ṣí ojú mi sí ilé Juda, èmi yóò sì bu ìfọ́jú lu gbogbo ẹṣin tí orílẹ̀-èdè. 5 Àti àwọn baálẹ̀ Juda yóò sì wí ni ọkàn wọn pé, ‘Àwọn ara Jerusalẹmu ni agbára mi nípa OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ni Ọlọ́run wọn.’ 6 “Ní ọjọ́ náà, ni èmi yóò ṣe àwọn baálẹ̀ Juda bí ààrò iná kan láàrín igi, àti bi ẹ̀fúùfù iná láàrín ìtí; wọn yóò sì jẹ gbogbo àwọn ènìyàn run yíká lápá ọ̀tún àti lápá òsì, a ó sì tún máa gbé inú Jerusalẹmu ní ipò rẹ̀. 7 “OLÚWA pẹ̀lú yóò kọ́ tètè gba àgọ́ Juda là ná, kí ògo ilé Dafidi àti ògo àwọn ara Jerusalẹmu má ba gbé ara wọn ga sí Juda. 8 Ní ọjọ́ náà ni OLÚWA yóò dáàbò bò àwọn tí ń gbé Jerusalẹmu; ẹni tí ó bá sì ṣe àìlera nínú wọn ní ọjọ́ náà, yóò dàbí Dafidi; ilé Dafidi yóò sì dàbí Ọlọ́run, bí angẹli OLÚWA níwájú wọn. 9 Yóò sì ṣe ni ọjọ́ náà, èmi yóò wá láti pa gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè run tí ó wá kọjú ìjà sí Jerusalẹmu.” 10 “Èmi ó sì tu ẹ̀mí oore-ọ̀fẹ́ àti ẹ̀bẹ̀ sórí ilé Dafidi àti sórí Jerusalẹmu, wọn ó sì máa wo ẹni tí wọn tí gún ni ọ̀kọ̀, wọn ó sì máa ṣọ̀fọ̀ rẹ̀, bí ẹnìkan ti ń ṣọ̀fọ̀ fún ọmọ rẹ̀ kan ṣoṣo àti gẹ́gẹ́ bí ènìyàn tí wọn yóò sì wà ni ìbànújẹ́, bí ẹni tí ń banújẹ́ fún àkọ́bí rẹ̀. 11 Ní ọjọ́ náà ni ẹkún, ńlá ńlá yóò wà ni Jerusalẹmu, gẹ́gẹ́ bí ọ̀fọ̀ Hadadi Rimoni ni àfonífojì Megido. 12 Ilẹ̀ náà yóò ṣọ̀fọ̀, ìdílé, kọ̀ọ̀kan fun ara rẹ, lọ́tọ̀ọ̀tọ̀; ìdílé Dafidi lọ́tọ̀; àti àwọn aya wọn lọ́tọ̀; ìdílé Natani lọ́tọ̀, àti àwọn aya wọn lọ́tọ́. 13 Ìdílé Lefi lọ́tọ̀, àti àwọn aya wọn lọ́tọ̀; ìdílé Ṣimei lọ́tọ̀, àti àwọn aya wọn lọ́tọ̀. 14 Gbogbo àwọn ìdílé tí o kù, ìdílé, ìdílé, lọ́tọ̀ọ̀tọ̀, àti àwọn aya wọn lọ́tọ̀ọ̀tọ̀.
In Other Versions
Zechariah 12 in the ANGEFD
Zechariah 12 in the ANTPNG2D
Zechariah 12 in the AS21
Zechariah 12 in the BAGH
Zechariah 12 in the BBPNG
Zechariah 12 in the BBT1E
Zechariah 12 in the BDS
Zechariah 12 in the BEV
Zechariah 12 in the BHAD
Zechariah 12 in the BIB
Zechariah 12 in the BLPT
Zechariah 12 in the BNT
Zechariah 12 in the BNTABOOT
Zechariah 12 in the BNTLV
Zechariah 12 in the BOATCB
Zechariah 12 in the BOATCB2
Zechariah 12 in the BOBCV
Zechariah 12 in the BOCNT
Zechariah 12 in the BOECS
Zechariah 12 in the BOGWICC
Zechariah 12 in the BOHCB
Zechariah 12 in the BOHCV
Zechariah 12 in the BOHLNT
Zechariah 12 in the BOHNTLTAL
Zechariah 12 in the BOICB
Zechariah 12 in the BOILNTAP
Zechariah 12 in the BOITCV
Zechariah 12 in the BOKCV
Zechariah 12 in the BOKCV2
Zechariah 12 in the BOKHWOG
Zechariah 12 in the BOKSSV
Zechariah 12 in the BOLCB
Zechariah 12 in the BOLCB2
Zechariah 12 in the BOMCV
Zechariah 12 in the BONAV
Zechariah 12 in the BONCB
Zechariah 12 in the BONLT
Zechariah 12 in the BONUT2
Zechariah 12 in the BOPLNT
Zechariah 12 in the BOSCB
Zechariah 12 in the BOSNC
Zechariah 12 in the BOTLNT
Zechariah 12 in the BOVCB
Zechariah 12 in the BPBB
Zechariah 12 in the BPH
Zechariah 12 in the BSB
Zechariah 12 in the CCB
Zechariah 12 in the CUV
Zechariah 12 in the CUVS
Zechariah 12 in the DBT
Zechariah 12 in the DGDNT
Zechariah 12 in the DHNT
Zechariah 12 in the DNT
Zechariah 12 in the ELBE
Zechariah 12 in the EMTV
Zechariah 12 in the ESV
Zechariah 12 in the FBV
Zechariah 12 in the FEB
Zechariah 12 in the GGMNT
Zechariah 12 in the GNT
Zechariah 12 in the HARY
Zechariah 12 in the HNT
Zechariah 12 in the IRVA
Zechariah 12 in the IRVB
Zechariah 12 in the IRVG
Zechariah 12 in the IRVH
Zechariah 12 in the IRVK
Zechariah 12 in the IRVM
Zechariah 12 in the IRVM2
Zechariah 12 in the IRVO
Zechariah 12 in the IRVP
Zechariah 12 in the IRVT
Zechariah 12 in the IRVT2
Zechariah 12 in the IRVU
Zechariah 12 in the ISVN
Zechariah 12 in the JSNT
Zechariah 12 in the KAPI
Zechariah 12 in the KBT1ETNIK
Zechariah 12 in the KBV
Zechariah 12 in the KJV
Zechariah 12 in the KNFD
Zechariah 12 in the LBA
Zechariah 12 in the LBLA
Zechariah 12 in the LNT
Zechariah 12 in the LSV
Zechariah 12 in the MAAL
Zechariah 12 in the MBV
Zechariah 12 in the MBV2
Zechariah 12 in the MHNT
Zechariah 12 in the MKNFD
Zechariah 12 in the MNG
Zechariah 12 in the MNT
Zechariah 12 in the MNT2
Zechariah 12 in the MRS1T
Zechariah 12 in the NAA
Zechariah 12 in the NASB
Zechariah 12 in the NBLA
Zechariah 12 in the NBS
Zechariah 12 in the NBVTP
Zechariah 12 in the NET2
Zechariah 12 in the NIV11
Zechariah 12 in the NNT
Zechariah 12 in the NNT2
Zechariah 12 in the NNT3
Zechariah 12 in the PDDPT
Zechariah 12 in the PFNT
Zechariah 12 in the RMNT
Zechariah 12 in the SBIAS
Zechariah 12 in the SBIBS
Zechariah 12 in the SBIBS2
Zechariah 12 in the SBICS
Zechariah 12 in the SBIDS
Zechariah 12 in the SBIGS
Zechariah 12 in the SBIHS
Zechariah 12 in the SBIIS
Zechariah 12 in the SBIIS2
Zechariah 12 in the SBIIS3
Zechariah 12 in the SBIKS
Zechariah 12 in the SBIKS2
Zechariah 12 in the SBIMS
Zechariah 12 in the SBIOS
Zechariah 12 in the SBIPS
Zechariah 12 in the SBISS
Zechariah 12 in the SBITS
Zechariah 12 in the SBITS2
Zechariah 12 in the SBITS3
Zechariah 12 in the SBITS4
Zechariah 12 in the SBIUS
Zechariah 12 in the SBIVS
Zechariah 12 in the SBT
Zechariah 12 in the SBT1E
Zechariah 12 in the SCHL
Zechariah 12 in the SNT
Zechariah 12 in the SUSU
Zechariah 12 in the SUSU2
Zechariah 12 in the SYNO
Zechariah 12 in the TBIAOTANT
Zechariah 12 in the TBT1E
Zechariah 12 in the TBT1E2
Zechariah 12 in the TFTIP
Zechariah 12 in the TFTU
Zechariah 12 in the TGNTATF3T
Zechariah 12 in the THAI
Zechariah 12 in the TNFD
Zechariah 12 in the TNT
Zechariah 12 in the TNTIK
Zechariah 12 in the TNTIL
Zechariah 12 in the TNTIN
Zechariah 12 in the TNTIP
Zechariah 12 in the TNTIZ
Zechariah 12 in the TOMA
Zechariah 12 in the TTENT
Zechariah 12 in the UBG
Zechariah 12 in the UGV
Zechariah 12 in the UGV2
Zechariah 12 in the UGV3
Zechariah 12 in the VBL
Zechariah 12 in the VDCC
Zechariah 12 in the YALU
Zechariah 12 in the YAPE
Zechariah 12 in the YBVTP
Zechariah 12 in the ZBP