Zechariah 6 (BOYCB)

1 Mo sì yípadà, mo sì gbé ojú mi sókè, mo sì wò, sì kíyèsi i, kẹ̀kẹ́ mẹ́rin jáde wá láti àárín òkè ńlá méjì, àwọn òkè ńlá náà sì jẹ́ òkè ńlá idẹ. 2 Àwọn ẹṣin pupa wà ní kẹ̀kẹ́ èkínní; àti àwọn ẹṣin dúdú ní kẹ̀kẹ́ èkejì. 3 Àti àwọn ẹṣin funfun ní kẹ̀kẹ́ ẹ̀kẹta; àti àwọn adíkálà àti alágbára ẹṣin ní kẹ̀kẹ́ ẹ̀kẹrin. 4 Mo sì dáhùn, mo sì béèrè lọ́wọ́ angẹli tí ń bá mi sọ̀rọ̀ pé, “Kí ni ìwọ̀nyí, olúwa mi.” 5 Angẹli náà si dáhùn ó sì wí fún mi pé, “Wọ̀nyí ni àwọn ẹ̀mí mẹ́rin ti ọ̀run, tí wọn ń lọ kúrò lẹ́yìn tí wọ́n ti fi ara wọn hàn níwájú Olúwa gbogbo ayé. 6 Àwọn ẹṣin dúdú tí ó wà nínú rẹ̀ jáde lọ sí ilẹ̀ àríwá; àwọn funfun sì jáde lọ si ìwọ̀-oòrùn; àwọn adíkálà sì jáde lọ sí ìhà ilẹ̀ gúúsù.” 7 Àwọn alágbára ẹṣin sì jáde lọ, wọ́n sì ń wá ọ̀nà àti lọ kí wọn bá a lè rìn síyìn-ín sọ́hùn-ún ni ayé; ó sì wí pé, “Ẹ lọ, ẹ lọ rìn síyìn-ín sọ́hùn-ún ní ayé!” Wọ́n sì rín síyìn-ín sọ́hùn-ún ní ayé. 8 Nígbà náà ni ohùn kan sì ké sí mi, ó sì bá mi sọ̀rọ̀ wí pé, “Wò ó, àwọn wọ̀nyí tí ó lọ síhà ilẹ̀ àríwá ti mú ẹ̀mí mi parọ́rọ́ ni ilẹ̀ àríwá.” 9 Ọ̀rọ̀ OLÚWA sì tọ̀ mí wá, wí pé: 10 “Mú nínú ìgbèkùn, nínú àwọn Heldai, tí Tobiah, àti ti Jedaiah, tí ó ti Babeli dé, kí ìwọ sì wá ní ọjọ́ kan náà, kí o sì wọ ilé Josiah ọmọ Sefaniah lọ. 11 Kí o sì mú fàdákà àti wúrà, kí o sì fi ṣe adé púpọ̀, sì gbé wọn ka orí Joṣua ọmọ Josadaki, olórí àlùfáà. 12 Sì sọ fún un pé, ‘Báyìí ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun sọ wí pé, wo ọkùnrin náà ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ẹ̀ka; yóò sì yọ ẹ̀ka láti abẹ́ rẹ̀ wá, yóò si kọ́ tẹmpili OLÚWA wa. 13 Òun ni yóò sì kọ́ tẹmpili OLÚWA òun ni yóò sì wọ̀ ní ògo, yóò sì jókòó, yóò sì jẹ ọba lórí ìtẹ́ rẹ̀; òun ó sì jẹ́ àlùfáà lórí ìtẹ́ rẹ̀; ìmọ̀ àlàáfíà yóò sì wá láàrín àwọn méjèèjì.’ 14 Adé wọ̀nyí yóò sì wà fún Helemu àti fún Tobiah, àti fún Jedaiah, àti fún Heni ọmọ Sefaniah fún ìrántí ni tẹmpili OLÚWA. 15 Àwọn tí ó jìnnà réré yóò wá láti kọ́ tẹmpili OLÚWA, ẹ̀yin yóò sì mọ̀ pé, OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ti rán mi sí yín. Yóò sì rí bẹ́ẹ̀ bí ẹ̀yin yóò bá gbà ohùn OLÚWA, Ọlọ́run yín gbọ́ nítòótọ́.”

In Other Versions

Zechariah 6 in the ANGEFD

Zechariah 6 in the ANTPNG2D

Zechariah 6 in the AS21

Zechariah 6 in the BAGH

Zechariah 6 in the BBPNG

Zechariah 6 in the BBT1E

Zechariah 6 in the BDS

Zechariah 6 in the BEV

Zechariah 6 in the BHAD

Zechariah 6 in the BIB

Zechariah 6 in the BLPT

Zechariah 6 in the BNT

Zechariah 6 in the BNTABOOT

Zechariah 6 in the BNTLV

Zechariah 6 in the BOATCB

Zechariah 6 in the BOATCB2

Zechariah 6 in the BOBCV

Zechariah 6 in the BOCNT

Zechariah 6 in the BOECS

Zechariah 6 in the BOGWICC

Zechariah 6 in the BOHCB

Zechariah 6 in the BOHCV

Zechariah 6 in the BOHLNT

Zechariah 6 in the BOHNTLTAL

Zechariah 6 in the BOICB

Zechariah 6 in the BOILNTAP

Zechariah 6 in the BOITCV

Zechariah 6 in the BOKCV

Zechariah 6 in the BOKCV2

Zechariah 6 in the BOKHWOG

Zechariah 6 in the BOKSSV

Zechariah 6 in the BOLCB

Zechariah 6 in the BOLCB2

Zechariah 6 in the BOMCV

Zechariah 6 in the BONAV

Zechariah 6 in the BONCB

Zechariah 6 in the BONLT

Zechariah 6 in the BONUT2

Zechariah 6 in the BOPLNT

Zechariah 6 in the BOSCB

Zechariah 6 in the BOSNC

Zechariah 6 in the BOTLNT

Zechariah 6 in the BOVCB

Zechariah 6 in the BPBB

Zechariah 6 in the BPH

Zechariah 6 in the BSB

Zechariah 6 in the CCB

Zechariah 6 in the CUV

Zechariah 6 in the CUVS

Zechariah 6 in the DBT

Zechariah 6 in the DGDNT

Zechariah 6 in the DHNT

Zechariah 6 in the DNT

Zechariah 6 in the ELBE

Zechariah 6 in the EMTV

Zechariah 6 in the ESV

Zechariah 6 in the FBV

Zechariah 6 in the FEB

Zechariah 6 in the GGMNT

Zechariah 6 in the GNT

Zechariah 6 in the HARY

Zechariah 6 in the HNT

Zechariah 6 in the IRVA

Zechariah 6 in the IRVB

Zechariah 6 in the IRVG

Zechariah 6 in the IRVH

Zechariah 6 in the IRVK

Zechariah 6 in the IRVM

Zechariah 6 in the IRVM2

Zechariah 6 in the IRVO

Zechariah 6 in the IRVP

Zechariah 6 in the IRVT

Zechariah 6 in the IRVT2

Zechariah 6 in the IRVU

Zechariah 6 in the ISVN

Zechariah 6 in the JSNT

Zechariah 6 in the KAPI

Zechariah 6 in the KBT1ETNIK

Zechariah 6 in the KBV

Zechariah 6 in the KJV

Zechariah 6 in the KNFD

Zechariah 6 in the LBA

Zechariah 6 in the LBLA

Zechariah 6 in the LNT

Zechariah 6 in the LSV

Zechariah 6 in the MAAL

Zechariah 6 in the MBV

Zechariah 6 in the MBV2

Zechariah 6 in the MHNT

Zechariah 6 in the MKNFD

Zechariah 6 in the MNG

Zechariah 6 in the MNT

Zechariah 6 in the MNT2

Zechariah 6 in the MRS1T

Zechariah 6 in the NAA

Zechariah 6 in the NASB

Zechariah 6 in the NBLA

Zechariah 6 in the NBS

Zechariah 6 in the NBVTP

Zechariah 6 in the NET2

Zechariah 6 in the NIV11

Zechariah 6 in the NNT

Zechariah 6 in the NNT2

Zechariah 6 in the NNT3

Zechariah 6 in the PDDPT

Zechariah 6 in the PFNT

Zechariah 6 in the RMNT

Zechariah 6 in the SBIAS

Zechariah 6 in the SBIBS

Zechariah 6 in the SBIBS2

Zechariah 6 in the SBICS

Zechariah 6 in the SBIDS

Zechariah 6 in the SBIGS

Zechariah 6 in the SBIHS

Zechariah 6 in the SBIIS

Zechariah 6 in the SBIIS2

Zechariah 6 in the SBIIS3

Zechariah 6 in the SBIKS

Zechariah 6 in the SBIKS2

Zechariah 6 in the SBIMS

Zechariah 6 in the SBIOS

Zechariah 6 in the SBIPS

Zechariah 6 in the SBISS

Zechariah 6 in the SBITS

Zechariah 6 in the SBITS2

Zechariah 6 in the SBITS3

Zechariah 6 in the SBITS4

Zechariah 6 in the SBIUS

Zechariah 6 in the SBIVS

Zechariah 6 in the SBT

Zechariah 6 in the SBT1E

Zechariah 6 in the SCHL

Zechariah 6 in the SNT

Zechariah 6 in the SUSU

Zechariah 6 in the SUSU2

Zechariah 6 in the SYNO

Zechariah 6 in the TBIAOTANT

Zechariah 6 in the TBT1E

Zechariah 6 in the TBT1E2

Zechariah 6 in the TFTIP

Zechariah 6 in the TFTU

Zechariah 6 in the TGNTATF3T

Zechariah 6 in the THAI

Zechariah 6 in the TNFD

Zechariah 6 in the TNT

Zechariah 6 in the TNTIK

Zechariah 6 in the TNTIL

Zechariah 6 in the TNTIN

Zechariah 6 in the TNTIP

Zechariah 6 in the TNTIZ

Zechariah 6 in the TOMA

Zechariah 6 in the TTENT

Zechariah 6 in the UBG

Zechariah 6 in the UGV

Zechariah 6 in the UGV2

Zechariah 6 in the UGV3

Zechariah 6 in the VBL

Zechariah 6 in the VDCC

Zechariah 6 in the YALU

Zechariah 6 in the YAPE

Zechariah 6 in the YBVTP

Zechariah 6 in the ZBP