2 Samuel 8 (BOYCB)

1 Ó sì ṣe, lẹ́yìn èyí, Dafidi sì kọlu àwọn Filistini, ó sì tẹrí wọn ba, Dafidi sì gba Metegamima lọ́wọ́ àwọn Filistini. 2 Dafidi sì kọlu Moabu, ó sì fi okùn títa kan dì wọ́n, ó sì dá wọn dùbúlẹ̀; ó sì ṣe òsùwọ̀n okùn méjì ni iye àwọn tí yóò dá sí. Àwọn ará Moabu sì ń sin Dafidi, wọn a sì máa mú ẹ̀bùn wá. 3 Dafidi sì kọlu Hadadeseri ọmọ Rehobu, ọba Soba, bí òun sì ti ń lọ láti mú agbára rẹ̀ bọ̀ sípò ni odò Eufurate. 4 Dafidi sì gba ẹgbẹ̀rún (1,000) kẹ̀kẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, àti ẹ̀ẹ́dẹ́gbàárin (7,000) ẹlẹ́ṣin, àti ogún ẹgbẹ̀rún (20,000) àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀. Dafidi sì já gbogbo àwọn ẹṣin kẹ̀kẹ́ wọn ní pàtì, ṣùgbọ́n ó dá ọgọ́rùn-ún kẹ̀kẹ́ sí nínú wọn. 5 Nígbà tí àwọn ará Siria ti Damasku sì wá láti ran Hadadeseri ọba Soba lọ́wọ́, Dafidi sì pa ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000) ènìyàn nínú àwọn ará Siria. 6 Dafidi sì fi àwọn ológun sí Siria ti Damasku, àwọn ará Siria sì wá sin Dafidi, wọn a sì máa mú ẹ̀bùn wá, OLÚWA sì pa Dafidi mọ́ níbikíbi tí o ń lọ. 7 Dafidi sì gba àṣà wúrà tí ó wà lára àwọn ìránṣẹ́ Hadadeseri, ó sì gbé wọn wá sí Jerusalẹmu. 8 Láti Beta, àti láti Berotai, àwọn ìlú Hadadeseri, ọba Dafidi kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ idẹ wá. 9 Nígbà tí Tou ọba Hamati sì gbọ́ pé Dafidi ti pa gbogbo ogun Hadadeseri. 10 Toi sì rán Joramu ọmọ rẹ̀ sí Dafidi ọba, láti kí i, àti láti súre fún un, nítorí pé ó tí bá Hadadeseri jagun, ó sì ti pa á, nítorí tí Hadadeseri sá à ti bá Toi jagun. Joramu sì ni ohun èlò fàdákà, àti ohun èlò wúrà, àti ohun èlò idẹ ní ọwọ́ rẹ̀. 11 Dafidi ọba sì fi wọ́n fún OLÚWA pẹ̀lú fàdákà, àti wúrà tí ó yà sí mímọ́, èyí tí ó ti gbà lọ́wọ́ àwọn orílẹ̀-èdè tí ó ti ṣẹ́gun. 12 Lọ́wọ́ Siria àti lọ́wọ́ Moabu àti lọ́wọ́ àwọn ọmọ Ammoni, àti lọ́wọ́ àwọn Filistini, àti lọ́wọ́ Amaleki, àti nínú ìkógun Hadadeseri ọmọ Rehobu ọba Soba. 13 Dafidi sì ní òkìkí gidigidi nígbà tí ó padà wá ilé láti ibi pípa àwọn ará Siria ní àfonífojì Iyọ̀, àwọn tí o pa jẹ́ ẹgbàá mẹ́sàn (18,000) ènìyàn. 14 Ó sì fi àwọn ológun sí Edomu; àti ní gbogbo Edomu yíká ni òun sì fi ológun sí, gbogbo àwọn tí ó wà ní Edomu sì wá sin Dafidi, OLÚWA sì fún Dafidi ní ìṣẹ́gun níbikíbi tí ó ń lọ. 15 Dafidi sì jẹ ọba lórí gbogbo Israẹli; Dafidi sì ṣe ìdájọ́ àti òtítọ́ fún àwọn ènìyàn rẹ̀. 16 Joabu ọmọ Seruiah ni ó sì ń ṣe olórí ogun; Jehoṣafati ọmọ Ahiludi sì ń ṣe akọ̀wé. 17 Sadoku ọmọ Ahitubu, àti Ahimeleki ọmọ Abiatari, ni àwọn àlùfáà; Seraiah a sì máa ṣe akọ̀wé. 18 Benaiah ọmọ Jehoiada ni ó sì ń ṣe olórí àwọn Kereti, àti àwọn Peleti; àwọn ọmọ Dafidi sì jẹ́ aláṣẹ.

In Other Versions

2 Samuel 8 in the ANGEFD

2 Samuel 8 in the ANTPNG2D

2 Samuel 8 in the AS21

2 Samuel 8 in the BAGH

2 Samuel 8 in the BBPNG

2 Samuel 8 in the BBT1E

2 Samuel 8 in the BDS

2 Samuel 8 in the BEV

2 Samuel 8 in the BHAD

2 Samuel 8 in the BIB

2 Samuel 8 in the BLPT

2 Samuel 8 in the BNT

2 Samuel 8 in the BNTABOOT

2 Samuel 8 in the BNTLV

2 Samuel 8 in the BOATCB

2 Samuel 8 in the BOATCB2

2 Samuel 8 in the BOBCV

2 Samuel 8 in the BOCNT

2 Samuel 8 in the BOECS

2 Samuel 8 in the BOGWICC

2 Samuel 8 in the BOHCB

2 Samuel 8 in the BOHCV

2 Samuel 8 in the BOHLNT

2 Samuel 8 in the BOHNTLTAL

2 Samuel 8 in the BOICB

2 Samuel 8 in the BOILNTAP

2 Samuel 8 in the BOITCV

2 Samuel 8 in the BOKCV

2 Samuel 8 in the BOKCV2

2 Samuel 8 in the BOKHWOG

2 Samuel 8 in the BOKSSV

2 Samuel 8 in the BOLCB

2 Samuel 8 in the BOLCB2

2 Samuel 8 in the BOMCV

2 Samuel 8 in the BONAV

2 Samuel 8 in the BONCB

2 Samuel 8 in the BONLT

2 Samuel 8 in the BONUT2

2 Samuel 8 in the BOPLNT

2 Samuel 8 in the BOSCB

2 Samuel 8 in the BOSNC

2 Samuel 8 in the BOTLNT

2 Samuel 8 in the BOVCB

2 Samuel 8 in the BPBB

2 Samuel 8 in the BPH

2 Samuel 8 in the BSB

2 Samuel 8 in the CCB

2 Samuel 8 in the CUV

2 Samuel 8 in the CUVS

2 Samuel 8 in the DBT

2 Samuel 8 in the DGDNT

2 Samuel 8 in the DHNT

2 Samuel 8 in the DNT

2 Samuel 8 in the ELBE

2 Samuel 8 in the EMTV

2 Samuel 8 in the ESV

2 Samuel 8 in the FBV

2 Samuel 8 in the FEB

2 Samuel 8 in the GGMNT

2 Samuel 8 in the GNT

2 Samuel 8 in the HARY

2 Samuel 8 in the HNT

2 Samuel 8 in the IRVA

2 Samuel 8 in the IRVB

2 Samuel 8 in the IRVG

2 Samuel 8 in the IRVH

2 Samuel 8 in the IRVK

2 Samuel 8 in the IRVM

2 Samuel 8 in the IRVM2

2 Samuel 8 in the IRVO

2 Samuel 8 in the IRVP

2 Samuel 8 in the IRVT

2 Samuel 8 in the IRVT2

2 Samuel 8 in the IRVU

2 Samuel 8 in the ISVN

2 Samuel 8 in the JSNT

2 Samuel 8 in the KAPI

2 Samuel 8 in the KBT1ETNIK

2 Samuel 8 in the KBV

2 Samuel 8 in the KJV

2 Samuel 8 in the KNFD

2 Samuel 8 in the LBA

2 Samuel 8 in the LBLA

2 Samuel 8 in the LNT

2 Samuel 8 in the LSV

2 Samuel 8 in the MAAL

2 Samuel 8 in the MBV

2 Samuel 8 in the MBV2

2 Samuel 8 in the MHNT

2 Samuel 8 in the MKNFD

2 Samuel 8 in the MNG

2 Samuel 8 in the MNT

2 Samuel 8 in the MNT2

2 Samuel 8 in the MRS1T

2 Samuel 8 in the NAA

2 Samuel 8 in the NASB

2 Samuel 8 in the NBLA

2 Samuel 8 in the NBS

2 Samuel 8 in the NBVTP

2 Samuel 8 in the NET2

2 Samuel 8 in the NIV11

2 Samuel 8 in the NNT

2 Samuel 8 in the NNT2

2 Samuel 8 in the NNT3

2 Samuel 8 in the PDDPT

2 Samuel 8 in the PFNT

2 Samuel 8 in the RMNT

2 Samuel 8 in the SBIAS

2 Samuel 8 in the SBIBS

2 Samuel 8 in the SBIBS2

2 Samuel 8 in the SBICS

2 Samuel 8 in the SBIDS

2 Samuel 8 in the SBIGS

2 Samuel 8 in the SBIHS

2 Samuel 8 in the SBIIS

2 Samuel 8 in the SBIIS2

2 Samuel 8 in the SBIIS3

2 Samuel 8 in the SBIKS

2 Samuel 8 in the SBIKS2

2 Samuel 8 in the SBIMS

2 Samuel 8 in the SBIOS

2 Samuel 8 in the SBIPS

2 Samuel 8 in the SBISS

2 Samuel 8 in the SBITS

2 Samuel 8 in the SBITS2

2 Samuel 8 in the SBITS3

2 Samuel 8 in the SBITS4

2 Samuel 8 in the SBIUS

2 Samuel 8 in the SBIVS

2 Samuel 8 in the SBT

2 Samuel 8 in the SBT1E

2 Samuel 8 in the SCHL

2 Samuel 8 in the SNT

2 Samuel 8 in the SUSU

2 Samuel 8 in the SUSU2

2 Samuel 8 in the SYNO

2 Samuel 8 in the TBIAOTANT

2 Samuel 8 in the TBT1E

2 Samuel 8 in the TBT1E2

2 Samuel 8 in the TFTIP

2 Samuel 8 in the TFTU

2 Samuel 8 in the TGNTATF3T

2 Samuel 8 in the THAI

2 Samuel 8 in the TNFD

2 Samuel 8 in the TNT

2 Samuel 8 in the TNTIK

2 Samuel 8 in the TNTIL

2 Samuel 8 in the TNTIN

2 Samuel 8 in the TNTIP

2 Samuel 8 in the TNTIZ

2 Samuel 8 in the TOMA

2 Samuel 8 in the TTENT

2 Samuel 8 in the UBG

2 Samuel 8 in the UGV

2 Samuel 8 in the UGV2

2 Samuel 8 in the UGV3

2 Samuel 8 in the VBL

2 Samuel 8 in the VDCC

2 Samuel 8 in the YALU

2 Samuel 8 in the YAPE

2 Samuel 8 in the YBVTP

2 Samuel 8 in the ZBP