Deuteronomy 34 (BOYCB)
1 Nígbà náà ni Mose gun òkè Nebo láti pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu sí orí Pisga tí ó dojúkọ Jeriko. Níbẹ̀ ni OLÚWA ti fi gbogbo ilẹ̀ hàn án láti Gileadi dé Dani, 2 gbogbo Naftali, ilẹ̀ Efraimu àti Manase, gbogbo ilẹ̀ Juda títí dé Òkun Ńlá, 3 gúúsù àti gbogbo àfonífojì Jeriko, ìlú ọlọ́pẹ dé Soari. 4 Nígbà náà ní OLÚWA sọ fún un pé, “Èyí ni ilẹ̀ tí mo ṣèlérí lórí ìbúra fún Abrahamu, Isaaki, àti Jakọbu nígbà tí mo wí pé, ‘Èmi yóò fi fún irú-ọmọ rẹ.’ Mo ti jẹ́ kí o rí i pẹ̀lú ojú rẹ, ṣùgbọ́n ìwọ kì yóò dé bẹ̀.” 5 Bẹ́ẹ̀ ni Mose ìránṣẹ́ OLÚWA kú ní ilẹ̀ Moabu, bí OLÚWA ti wí. 6 Ó sì sin ín nínú àfonífojì ní ilẹ̀ Moabu, ní òdìkejì Beti-Peori, ṣùgbọ́n títí di òní yìí, kò sí ẹnìkan tí ó mọ ibi tí ibojì i rẹ̀ wà. 7 Mose jẹ́ ẹni ọgọ́fà ọdún nígbà tí ó kú, síbẹ̀ ojú rẹ̀ kò ṣe bàìbàì bẹ́ẹ̀ ni agbára rẹ̀ kò dínkù. 8 Àwọn ọmọ Israẹli sọkún un Mose ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu ní ọgbọ̀n ọjọ́ títí di ìgbà tí ọjọ́ ẹkún àti ọ̀fọ̀ Mose parí. 9 Joṣua ọmọ Nuni kún fún ẹ̀mí ọgbọ́n nítorí Mose ti gbọ́wọ́ ọ rẹ̀ lé e lórí. Àwọn ọmọ Israẹli sì fetí sí i wọ́n sì ṣe ohun tí OLÚWA ti pàṣẹ fún Mose. 10 Láti ìgbà náà kò sì sí wòlíì tí ó dìde ní Israẹli bí i Mose, ẹni tí OLÚWA mọ̀ lójúkojú, 11 tí ó ṣe gbogbo iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu tí OLÚWA rán an láti lọ ṣe ní Ejibiti sí Farao àti sí gbogbo àwọn ìránṣẹ́ ẹ rẹ̀ àti sí gbogbo ilẹ̀ náà. 12 Nítorí kò sí ẹni tí ó tí ì fi gbogbo ọ̀rọ̀ agbára hàn, tàbí ṣe gbogbo ẹ̀rù ńlá tí Mose fihàn ní ojú gbogbo Israẹli.
In Other Versions
Deuteronomy 34 in the ANGEFD
Deuteronomy 34 in the ANTPNG2D
Deuteronomy 34 in the AS21
Deuteronomy 34 in the BAGH
Deuteronomy 34 in the BBPNG
Deuteronomy 34 in the BBT1E
Deuteronomy 34 in the BDS
Deuteronomy 34 in the BEV
Deuteronomy 34 in the BHAD
Deuteronomy 34 in the BIB
Deuteronomy 34 in the BLPT
Deuteronomy 34 in the BNT
Deuteronomy 34 in the BNTABOOT
Deuteronomy 34 in the BNTLV
Deuteronomy 34 in the BOATCB
Deuteronomy 34 in the BOATCB2
Deuteronomy 34 in the BOBCV
Deuteronomy 34 in the BOCNT
Deuteronomy 34 in the BOECS
Deuteronomy 34 in the BOGWICC
Deuteronomy 34 in the BOHCB
Deuteronomy 34 in the BOHCV
Deuteronomy 34 in the BOHLNT
Deuteronomy 34 in the BOHNTLTAL
Deuteronomy 34 in the BOICB
Deuteronomy 34 in the BOILNTAP
Deuteronomy 34 in the BOITCV
Deuteronomy 34 in the BOKCV
Deuteronomy 34 in the BOKCV2
Deuteronomy 34 in the BOKHWOG
Deuteronomy 34 in the BOKSSV
Deuteronomy 34 in the BOLCB
Deuteronomy 34 in the BOLCB2
Deuteronomy 34 in the BOMCV
Deuteronomy 34 in the BONAV
Deuteronomy 34 in the BONCB
Deuteronomy 34 in the BONLT
Deuteronomy 34 in the BONUT2
Deuteronomy 34 in the BOPLNT
Deuteronomy 34 in the BOSCB
Deuteronomy 34 in the BOSNC
Deuteronomy 34 in the BOTLNT
Deuteronomy 34 in the BOVCB
Deuteronomy 34 in the BPBB
Deuteronomy 34 in the BPH
Deuteronomy 34 in the BSB
Deuteronomy 34 in the CCB
Deuteronomy 34 in the CUV
Deuteronomy 34 in the CUVS
Deuteronomy 34 in the DBT
Deuteronomy 34 in the DGDNT
Deuteronomy 34 in the DHNT
Deuteronomy 34 in the DNT
Deuteronomy 34 in the ELBE
Deuteronomy 34 in the EMTV
Deuteronomy 34 in the ESV
Deuteronomy 34 in the FBV
Deuteronomy 34 in the FEB
Deuteronomy 34 in the GGMNT
Deuteronomy 34 in the GNT
Deuteronomy 34 in the HARY
Deuteronomy 34 in the HNT
Deuteronomy 34 in the IRVA
Deuteronomy 34 in the IRVB
Deuteronomy 34 in the IRVG
Deuteronomy 34 in the IRVH
Deuteronomy 34 in the IRVK
Deuteronomy 34 in the IRVM
Deuteronomy 34 in the IRVM2
Deuteronomy 34 in the IRVO
Deuteronomy 34 in the IRVP
Deuteronomy 34 in the IRVT
Deuteronomy 34 in the IRVT2
Deuteronomy 34 in the IRVU
Deuteronomy 34 in the ISVN
Deuteronomy 34 in the JSNT
Deuteronomy 34 in the KAPI
Deuteronomy 34 in the KBT1ETNIK
Deuteronomy 34 in the KBV
Deuteronomy 34 in the KJV
Deuteronomy 34 in the KNFD
Deuteronomy 34 in the LBA
Deuteronomy 34 in the LBLA
Deuteronomy 34 in the LNT
Deuteronomy 34 in the LSV
Deuteronomy 34 in the MAAL
Deuteronomy 34 in the MBV
Deuteronomy 34 in the MBV2
Deuteronomy 34 in the MHNT
Deuteronomy 34 in the MKNFD
Deuteronomy 34 in the MNG
Deuteronomy 34 in the MNT
Deuteronomy 34 in the MNT2
Deuteronomy 34 in the MRS1T
Deuteronomy 34 in the NAA
Deuteronomy 34 in the NASB
Deuteronomy 34 in the NBLA
Deuteronomy 34 in the NBS
Deuteronomy 34 in the NBVTP
Deuteronomy 34 in the NET2
Deuteronomy 34 in the NIV11
Deuteronomy 34 in the NNT
Deuteronomy 34 in the NNT2
Deuteronomy 34 in the NNT3
Deuteronomy 34 in the PDDPT
Deuteronomy 34 in the PFNT
Deuteronomy 34 in the RMNT
Deuteronomy 34 in the SBIAS
Deuteronomy 34 in the SBIBS
Deuteronomy 34 in the SBIBS2
Deuteronomy 34 in the SBICS
Deuteronomy 34 in the SBIDS
Deuteronomy 34 in the SBIGS
Deuteronomy 34 in the SBIHS
Deuteronomy 34 in the SBIIS
Deuteronomy 34 in the SBIIS2
Deuteronomy 34 in the SBIIS3
Deuteronomy 34 in the SBIKS
Deuteronomy 34 in the SBIKS2
Deuteronomy 34 in the SBIMS
Deuteronomy 34 in the SBIOS
Deuteronomy 34 in the SBIPS
Deuteronomy 34 in the SBISS
Deuteronomy 34 in the SBITS
Deuteronomy 34 in the SBITS2
Deuteronomy 34 in the SBITS3
Deuteronomy 34 in the SBITS4
Deuteronomy 34 in the SBIUS
Deuteronomy 34 in the SBIVS
Deuteronomy 34 in the SBT
Deuteronomy 34 in the SBT1E
Deuteronomy 34 in the SCHL
Deuteronomy 34 in the SNT
Deuteronomy 34 in the SUSU
Deuteronomy 34 in the SUSU2
Deuteronomy 34 in the SYNO
Deuteronomy 34 in the TBIAOTANT
Deuteronomy 34 in the TBT1E
Deuteronomy 34 in the TBT1E2
Deuteronomy 34 in the TFTIP
Deuteronomy 34 in the TFTU
Deuteronomy 34 in the TGNTATF3T
Deuteronomy 34 in the THAI
Deuteronomy 34 in the TNFD
Deuteronomy 34 in the TNT
Deuteronomy 34 in the TNTIK
Deuteronomy 34 in the TNTIL
Deuteronomy 34 in the TNTIN
Deuteronomy 34 in the TNTIP
Deuteronomy 34 in the TNTIZ
Deuteronomy 34 in the TOMA
Deuteronomy 34 in the TTENT
Deuteronomy 34 in the UBG
Deuteronomy 34 in the UGV
Deuteronomy 34 in the UGV2
Deuteronomy 34 in the UGV3
Deuteronomy 34 in the VBL
Deuteronomy 34 in the VDCC
Deuteronomy 34 in the YALU
Deuteronomy 34 in the YAPE
Deuteronomy 34 in the YBVTP
Deuteronomy 34 in the ZBP