Ecclesiastes 10 (BOYCB)

1 Gẹ́gẹ́ bí òkú eṣinṣin tí ń fún òróró ìkunra ní òórùn búburú,bẹ́ẹ̀ náà ni òmùgọ̀ díẹ̀ ṣe ń bo ọgbọ́n àti ọlá mọ́lẹ̀. 2 Ọkàn ọlọ́gbọ́n a máa ṣí sí ohun tí ó tọ̀nà,ṣùgbọ́n ọkàn òmùgọ̀ sí ohun tí kò dára. 3 Kódà bí ó ti ṣe ń rìn láàrín ọ̀nà,òmùgọ̀ kò ní ọgbọ́na sì máa fihan gbogbo ènìyàn bí ó ti gọ̀ tó. 4 Bí ìbínú alákòóso bá dìde lòdì sí ọ,ma ṣe fi ààyè rẹ sílẹ̀;ìdákẹ́ jẹ́ẹ́jẹ́ le è tú àṣìṣe ńlá. 5 Ohun ibi kan wà tí mo ti rí lábẹ́ oòrùn,irú àṣìṣe tí ó dìde láti ọ̀dọ̀ alákòóso. 6 A gbé aṣiwèrè sí ọ̀pọ̀ ipò tí ó ga jùlọ,nígbà tí ọlọ́rọ̀ gba àwọn ààyè tí ó kéré jùlọ. 7 Mo ti rí ẹrú lórí ẹṣin,nígbà tí ọmọ-aládé ń fi ẹsẹ̀ rìn bí ẹrú. 8 Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́ kòtò, ó le è ṣubú sínú rẹ̀;ẹnikẹ́ni tí ó bá la inú ògiri, ejò le è ṣán an. 9 Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbe òkúta le è ní ìpalára láti ipasẹ̀ wọn;ẹnikẹ́ni tí ó bá la ìtì igi le è ní ìpalára láti ipasẹ̀ wọn. 10 Bí àáké bá kútí ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ kò sì sí ní pípọ́n;yóò nílò agbára púpọ̀ṣùgbọ́n ọgbọ́n orí ni yóò mú àṣeyọrí wá. 11 Bí ejò bá ṣán ni kí a tó lo oògùn rẹ̀,kò sí èrè kankan fún olóògùn rẹ̀. 12 Ọ̀rọ̀ tí ó wá láti ẹnu ọlọ́gbọ́n a máa ní oore-ọ̀fẹ́ṣùgbọ́n ètè òmùgọ̀ fúnra rẹ̀ ni yóò parun. 13 Ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀ jẹ́ òmùgọ̀;ìparí rẹ̀ sì jẹ́ ìsínwín búburú. 14 Wèrè a sì máa ṣàfikún ọ̀rọ̀. Kò sí ẹni tí ó mọ ohun tí ó ń bọ̀ta ni ó le è sọ fún un ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀? 15 Iṣẹ́ aṣiwèrè a máa dá a lágarakò sì mọ ojú ọ̀nà sí ìlú. 16 Ègbé ni fún ọ, ìwọ ilẹ̀ tí ọba ń ṣe ìránṣẹ́ rẹ̀àti tí àwọn ọmọ-aládé ń ṣe àsè ní òwúrọ̀. 17 Ìbùkún ni fún ọ, ìwọ ilẹ̀ èyí tí ọba rẹ̀ jẹ́ ọmọ ọlọ́lá,àti tí àwọn ọmọ-aládé ń jẹun ní àsìkò tí ó yẹ,fún ìlera, tí kì í ṣe fún ìmutípara. 18 Bí ènìyàn bá ń lọ́ra, àjà ilé a máa jìbí ọwọ́ rẹ̀ bá ń ṣe ọ̀lẹ, ilé a máa jó. 19 Ẹ̀rín rínrín ni a ṣe àsè fún,wáìnì a máa mú ayé dùn,ṣùgbọ́n owó ni ìdáhùn sí ohun gbogbo. 20 Ma ṣe bú ọba, kódà nínú èrò rẹ,tàbí kí o ṣépè fún ọlọ́rọ̀ ní ibi ibùsùn rẹ,nítorí pé ẹyẹ ojú ọ̀run le è gbé ọ̀rọ̀ rẹẹyẹ tí ó sì ní ìyẹ́ apá le è fi ẹjọ́ ohun tí o sọ sùn.

In Other Versions

Ecclesiastes 10 in the ANGEFD

Ecclesiastes 10 in the ANTPNG2D

Ecclesiastes 10 in the AS21

Ecclesiastes 10 in the BAGH

Ecclesiastes 10 in the BBPNG

Ecclesiastes 10 in the BBT1E

Ecclesiastes 10 in the BDS

Ecclesiastes 10 in the BEV

Ecclesiastes 10 in the BHAD

Ecclesiastes 10 in the BIB

Ecclesiastes 10 in the BLPT

Ecclesiastes 10 in the BNT

Ecclesiastes 10 in the BNTABOOT

Ecclesiastes 10 in the BNTLV

Ecclesiastes 10 in the BOATCB

Ecclesiastes 10 in the BOATCB2

Ecclesiastes 10 in the BOBCV

Ecclesiastes 10 in the BOCNT

Ecclesiastes 10 in the BOECS

Ecclesiastes 10 in the BOGWICC

Ecclesiastes 10 in the BOHCB

Ecclesiastes 10 in the BOHCV

Ecclesiastes 10 in the BOHLNT

Ecclesiastes 10 in the BOHNTLTAL

Ecclesiastes 10 in the BOICB

Ecclesiastes 10 in the BOILNTAP

Ecclesiastes 10 in the BOITCV

Ecclesiastes 10 in the BOKCV

Ecclesiastes 10 in the BOKCV2

Ecclesiastes 10 in the BOKHWOG

Ecclesiastes 10 in the BOKSSV

Ecclesiastes 10 in the BOLCB

Ecclesiastes 10 in the BOLCB2

Ecclesiastes 10 in the BOMCV

Ecclesiastes 10 in the BONAV

Ecclesiastes 10 in the BONCB

Ecclesiastes 10 in the BONLT

Ecclesiastes 10 in the BONUT2

Ecclesiastes 10 in the BOPLNT

Ecclesiastes 10 in the BOSCB

Ecclesiastes 10 in the BOSNC

Ecclesiastes 10 in the BOTLNT

Ecclesiastes 10 in the BOVCB

Ecclesiastes 10 in the BPBB

Ecclesiastes 10 in the BPH

Ecclesiastes 10 in the BSB

Ecclesiastes 10 in the CCB

Ecclesiastes 10 in the CUV

Ecclesiastes 10 in the CUVS

Ecclesiastes 10 in the DBT

Ecclesiastes 10 in the DGDNT

Ecclesiastes 10 in the DHNT

Ecclesiastes 10 in the DNT

Ecclesiastes 10 in the ELBE

Ecclesiastes 10 in the EMTV

Ecclesiastes 10 in the ESV

Ecclesiastes 10 in the FBV

Ecclesiastes 10 in the FEB

Ecclesiastes 10 in the GGMNT

Ecclesiastes 10 in the GNT

Ecclesiastes 10 in the HARY

Ecclesiastes 10 in the HNT

Ecclesiastes 10 in the IRVA

Ecclesiastes 10 in the IRVB

Ecclesiastes 10 in the IRVG

Ecclesiastes 10 in the IRVH

Ecclesiastes 10 in the IRVK

Ecclesiastes 10 in the IRVM

Ecclesiastes 10 in the IRVM2

Ecclesiastes 10 in the IRVO

Ecclesiastes 10 in the IRVP

Ecclesiastes 10 in the IRVT

Ecclesiastes 10 in the IRVT2

Ecclesiastes 10 in the IRVU

Ecclesiastes 10 in the ISVN

Ecclesiastes 10 in the JSNT

Ecclesiastes 10 in the KAPI

Ecclesiastes 10 in the KBT1ETNIK

Ecclesiastes 10 in the KBV

Ecclesiastes 10 in the KJV

Ecclesiastes 10 in the KNFD

Ecclesiastes 10 in the LBA

Ecclesiastes 10 in the LBLA

Ecclesiastes 10 in the LNT

Ecclesiastes 10 in the LSV

Ecclesiastes 10 in the MAAL

Ecclesiastes 10 in the MBV

Ecclesiastes 10 in the MBV2

Ecclesiastes 10 in the MHNT

Ecclesiastes 10 in the MKNFD

Ecclesiastes 10 in the MNG

Ecclesiastes 10 in the MNT

Ecclesiastes 10 in the MNT2

Ecclesiastes 10 in the MRS1T

Ecclesiastes 10 in the NAA

Ecclesiastes 10 in the NASB

Ecclesiastes 10 in the NBLA

Ecclesiastes 10 in the NBS

Ecclesiastes 10 in the NBVTP

Ecclesiastes 10 in the NET2

Ecclesiastes 10 in the NIV11

Ecclesiastes 10 in the NNT

Ecclesiastes 10 in the NNT2

Ecclesiastes 10 in the NNT3

Ecclesiastes 10 in the PDDPT

Ecclesiastes 10 in the PFNT

Ecclesiastes 10 in the RMNT

Ecclesiastes 10 in the SBIAS

Ecclesiastes 10 in the SBIBS

Ecclesiastes 10 in the SBIBS2

Ecclesiastes 10 in the SBICS

Ecclesiastes 10 in the SBIDS

Ecclesiastes 10 in the SBIGS

Ecclesiastes 10 in the SBIHS

Ecclesiastes 10 in the SBIIS

Ecclesiastes 10 in the SBIIS2

Ecclesiastes 10 in the SBIIS3

Ecclesiastes 10 in the SBIKS

Ecclesiastes 10 in the SBIKS2

Ecclesiastes 10 in the SBIMS

Ecclesiastes 10 in the SBIOS

Ecclesiastes 10 in the SBIPS

Ecclesiastes 10 in the SBISS

Ecclesiastes 10 in the SBITS

Ecclesiastes 10 in the SBITS2

Ecclesiastes 10 in the SBITS3

Ecclesiastes 10 in the SBITS4

Ecclesiastes 10 in the SBIUS

Ecclesiastes 10 in the SBIVS

Ecclesiastes 10 in the SBT

Ecclesiastes 10 in the SBT1E

Ecclesiastes 10 in the SCHL

Ecclesiastes 10 in the SNT

Ecclesiastes 10 in the SUSU

Ecclesiastes 10 in the SUSU2

Ecclesiastes 10 in the SYNO

Ecclesiastes 10 in the TBIAOTANT

Ecclesiastes 10 in the TBT1E

Ecclesiastes 10 in the TBT1E2

Ecclesiastes 10 in the TFTIP

Ecclesiastes 10 in the TFTU

Ecclesiastes 10 in the TGNTATF3T

Ecclesiastes 10 in the THAI

Ecclesiastes 10 in the TNFD

Ecclesiastes 10 in the TNT

Ecclesiastes 10 in the TNTIK

Ecclesiastes 10 in the TNTIL

Ecclesiastes 10 in the TNTIN

Ecclesiastes 10 in the TNTIP

Ecclesiastes 10 in the TNTIZ

Ecclesiastes 10 in the TOMA

Ecclesiastes 10 in the TTENT

Ecclesiastes 10 in the UBG

Ecclesiastes 10 in the UGV

Ecclesiastes 10 in the UGV2

Ecclesiastes 10 in the UGV3

Ecclesiastes 10 in the VBL

Ecclesiastes 10 in the VDCC

Ecclesiastes 10 in the YALU

Ecclesiastes 10 in the YAPE

Ecclesiastes 10 in the YBVTP

Ecclesiastes 10 in the ZBP