Esther 7 (BOYCB)
1 Ọba àti Hamani sì lọ sí àpèjẹ pẹ̀lú Esteri ayaba, 2 bí wọ́n sì ṣe ń mu wáìnì ní ọjọ́ kejì yìí, ọba sì tún béèrè pé, “Esteri ayaba, kí ni ẹ̀bẹ̀ rẹ? A ó sì fi fún ọ. Kí ni ìbéèrè rẹ? Bí ó tilẹ̀ jẹ́ ìdajì ìjọba à mi, n ó fi fún ọ.” 3 Nígbà náà ni ayaba Esteri dáhùn, “Bí èmi bá rí ojúrere rẹ, ìwọ ọba, bí ó bá sì tẹ́ ọláńlá à rẹ lọ́rùn, fún mi ní ẹ̀mí mi, èyí ni ẹ̀bẹ̀ mi. Kí o sì pa àwọn ènìyàn mi mọ́—èyí ni ìbéèrè mi. 4 Nítorí a ti ta èmi àti àwọn ènìyàn mi fún àwọn tí yóò pa wá run, à ti ṣe ìdájọ́ wa fún pípa àti píparẹ́. Bí a bá tilẹ̀ tà wá bí ẹrúkùnrin àti ẹrúbìnrin, ǹ bá dákẹ́, nítorí irú ìpọ́njú bẹ́ẹ̀ kò tó èyí tí à ń yọ ọba lẹ́nu sí.” 5 Ọba Ahaswerusi bi Esteri ayaba léèrè pé, “Ta a ni ẹni náà? Níbo ni ẹni náà wà tí kò bẹ̀rù láti ṣe irú nǹkan bẹ́ẹ̀?” 6 Esteri sọ wí pé, “Alátakò àti ọ̀tá náà ni Hamani aláìníláárí yìí.”Nígbà náà ni Hamani wárìrì níwájú ọba àti ayaba. 7 Ọba sì dìde pẹ̀lú ìbínú, ó fi wáìnì sílẹ̀ ó sì jáde lọ sí àgbàlá ààfin. Ṣùgbọ́n nígbà tí Hamani, ti rí i dájú pé ọba ti pinnu láti pa òun, ó dúró lẹ́yìn láti bẹ Esteri ayaba nítorí ẹ̀mí rẹ̀. 8 Bí ọba ṣe padà dé láti àgbàlá ààfin wá sí gbọ̀ngàn àsè náà, Hamani ṣubú sórí àga tí Esteri ayaba fẹ̀yìn tì.Ọba sì pariwo pé, “Yóò ha tún tẹ́ ayaba níbí yìí, nínú ilé, ní ojú mi bí?”Ní kété tí ọba sọ ọ̀rọ̀ yìí jáde, wọ́n da aṣọ bo Hamani lójú. 9 Nígbà náà Harbona ọ̀kan nínú àwọn ìwẹ̀fà tó ń dúró níwájú ọba, sọ wí pé, “Igi tí ó ga tó ìwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà marunlélaadọrin ni Hamani ti rì sí ẹ̀gbẹ́ ilé e rẹ̀. Ó ṣe é fún Mordekai, ẹni tí ó sọ̀rọ̀ jáde láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ọba.”Ọba wí pé, ẹ so ó rọ̀ sórí i rẹ́! 10 Wọ́n sì so Hamani sórí igi tí ó ti pèsè sílẹ̀ fún Mordekai, ìbínú ọba sì rọ̀.
In Other Versions
Esther 7 in the ANGEFD
Esther 7 in the ANTPNG2D
Esther 7 in the AS21
Esther 7 in the BAGH
Esther 7 in the BBPNG
Esther 7 in the BBT1E
Esther 7 in the BDS
Esther 7 in the BEV
Esther 7 in the BHAD
Esther 7 in the BIB
Esther 7 in the BLPT
Esther 7 in the BNT
Esther 7 in the BNTABOOT
Esther 7 in the BNTLV
Esther 7 in the BOATCB
Esther 7 in the BOATCB2
Esther 7 in the BOBCV
Esther 7 in the BOCNT
Esther 7 in the BOECS
Esther 7 in the BOGWICC
Esther 7 in the BOHCB
Esther 7 in the BOHCV
Esther 7 in the BOHLNT
Esther 7 in the BOHNTLTAL
Esther 7 in the BOICB
Esther 7 in the BOILNTAP
Esther 7 in the BOITCV
Esther 7 in the BOKCV
Esther 7 in the BOKCV2
Esther 7 in the BOKHWOG
Esther 7 in the BOKSSV
Esther 7 in the BOLCB
Esther 7 in the BOLCB2
Esther 7 in the BOMCV
Esther 7 in the BONAV
Esther 7 in the BONCB
Esther 7 in the BONLT
Esther 7 in the BONUT2
Esther 7 in the BOPLNT
Esther 7 in the BOSCB
Esther 7 in the BOSNC
Esther 7 in the BOTLNT
Esther 7 in the BOVCB
Esther 7 in the BPBB
Esther 7 in the BPH
Esther 7 in the BSB
Esther 7 in the CCB
Esther 7 in the CUV
Esther 7 in the CUVS
Esther 7 in the DBT
Esther 7 in the DGDNT
Esther 7 in the DHNT
Esther 7 in the DNT
Esther 7 in the ELBE
Esther 7 in the EMTV
Esther 7 in the ESV
Esther 7 in the FBV
Esther 7 in the FEB
Esther 7 in the GGMNT
Esther 7 in the GNT
Esther 7 in the HARY
Esther 7 in the HNT
Esther 7 in the IRVA
Esther 7 in the IRVB
Esther 7 in the IRVG
Esther 7 in the IRVH
Esther 7 in the IRVK
Esther 7 in the IRVM
Esther 7 in the IRVM2
Esther 7 in the IRVO
Esther 7 in the IRVP
Esther 7 in the IRVT
Esther 7 in the IRVT2
Esther 7 in the IRVU
Esther 7 in the ISVN
Esther 7 in the JSNT
Esther 7 in the KAPI
Esther 7 in the KBT1ETNIK
Esther 7 in the KBV
Esther 7 in the KJV
Esther 7 in the KNFD
Esther 7 in the LBA
Esther 7 in the LBLA
Esther 7 in the LNT
Esther 7 in the LSV
Esther 7 in the MAAL
Esther 7 in the MBV
Esther 7 in the MBV2
Esther 7 in the MHNT
Esther 7 in the MKNFD
Esther 7 in the MNG
Esther 7 in the MNT
Esther 7 in the MNT2
Esther 7 in the MRS1T
Esther 7 in the NAA
Esther 7 in the NASB
Esther 7 in the NBLA
Esther 7 in the NBS
Esther 7 in the NBVTP
Esther 7 in the NET2
Esther 7 in the NIV11
Esther 7 in the NNT
Esther 7 in the NNT2
Esther 7 in the NNT3
Esther 7 in the PDDPT
Esther 7 in the PFNT
Esther 7 in the RMNT
Esther 7 in the SBIAS
Esther 7 in the SBIBS
Esther 7 in the SBIBS2
Esther 7 in the SBICS
Esther 7 in the SBIDS
Esther 7 in the SBIGS
Esther 7 in the SBIHS
Esther 7 in the SBIIS
Esther 7 in the SBIIS2
Esther 7 in the SBIIS3
Esther 7 in the SBIKS
Esther 7 in the SBIKS2
Esther 7 in the SBIMS
Esther 7 in the SBIOS
Esther 7 in the SBIPS
Esther 7 in the SBISS
Esther 7 in the SBITS
Esther 7 in the SBITS2
Esther 7 in the SBITS3
Esther 7 in the SBITS4
Esther 7 in the SBIUS
Esther 7 in the SBIVS
Esther 7 in the SBT
Esther 7 in the SBT1E
Esther 7 in the SCHL
Esther 7 in the SNT
Esther 7 in the SUSU
Esther 7 in the SUSU2
Esther 7 in the SYNO
Esther 7 in the TBIAOTANT
Esther 7 in the TBT1E
Esther 7 in the TBT1E2
Esther 7 in the TFTIP
Esther 7 in the TFTU
Esther 7 in the TGNTATF3T
Esther 7 in the THAI
Esther 7 in the TNFD
Esther 7 in the TNT
Esther 7 in the TNTIK
Esther 7 in the TNTIL
Esther 7 in the TNTIN
Esther 7 in the TNTIP
Esther 7 in the TNTIZ
Esther 7 in the TOMA
Esther 7 in the TTENT
Esther 7 in the UBG
Esther 7 in the UGV
Esther 7 in the UGV2
Esther 7 in the UGV3
Esther 7 in the VBL
Esther 7 in the VDCC
Esther 7 in the YALU
Esther 7 in the YAPE
Esther 7 in the YBVTP
Esther 7 in the ZBP