Isaiah 25 (BOYCB)

1 OLÚWA, ìwọ ni Ọlọ́run mi;èmi yóò gbé ọ ga èmi ó sìfi ìyìn fún orúkọ rẹnítorí nínú òtítọ́ aláìlẹ́gbẹ́o ti ṣe ohun ńlá,àwọn ohun tí o ti gbèrò o rẹ̀ lọ́jọ́ pípẹ́. 2 Ìwọ ti sọ ìlú di àkójọ àlàpà,ìlú olódi ti di ààtàn,ìlú olódi fún àwọn àjèjì ni kò sí mọ́;a kì yóò tún un kọ́ mọ́. 3 Nítorí náà àwọn ènìyàn alágbára yóòbọ̀wọ̀ fún ọ;àwọn ìlú orílẹ̀-èdè aláìláàánúyóò bu ọlá fún ọ. 4 Ìwọ ti jẹ́ ààbò fún àwọn òtòṣìààbò fún aláìní nínú ìpọ́njú rẹ̀ààbò kúrò lọ́wọ́ ìjìbòòji kúrò lọ́wọ́ ooru.Nítorí pé èémí àwọn ìkàdàbí ìjì tí ó bì lu ògiri 5 àti gẹ́gẹ́ bí ooru ní aginjù.O mú ìdákẹ́ jẹ́ẹ́ bá rògbòdìyàn àwọn àjèjì,gẹ́gẹ́ bí òjìji kurukuru ṣe ń dín ooru kù,bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni orin àwọn ìkà yóò dákẹ́. 6 Ní orí òkè yìí ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogunyóò ti pèsèàsè oúnjẹ àdídùn kan fún gbogbo ènìyànàpèjẹ ti ọtí wáìnì àtijọ́ti ẹran tí ó dára jù àti ti ọtí wáìnìtí ó gbámúṣé. 7 Ní orí òkè yìí ni yóò paaṣọ òkú tí ó ti ń di gbogbo ènìyàn,abala tí ó bo gbogbo orílẹ̀-èdè mọ́lẹ̀, 8 Òun yóò sì gbé ikú mì títí láé. OLÚWA Olódùmarè yóò sì nu gbogbo omijé nù,kúrò ní ojú gbogbo wọn,Òun yóò sì mú ẹ̀gàn àwọn ènìyàn rẹ̀ kúròní gbogbo ilẹ̀ ayé. OLÚWA ni ó ti sọ ọ́. 9 Ní ọjọ́ náà wọn yóò sọ pé,“Nítòótọ́ eléyìí ni Ọlọ́run wa;àwa ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú rẹ̀, òun sì gbà wá là.Èyí ni OLÚWA, àwa gbẹ́kẹ̀lé e,ẹ jẹ́ kí a yọ̀ kí inú wa sì dùn nínú ìgbàlà rẹ̀.” 10 Ọwọ́ OLÚWA yóò sinmi lé orí òkè yìíṣùgbọ́n a ó tẹ Moabu mọ́lẹ̀ lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀;gẹ́gẹ́ bí a ti gún koríko mọ́lẹ̀ di ajílẹ̀. 11 Wọn yóò na ọwọ́ wọn jáde nínú rẹ̀,gẹ́gẹ́ bí òmùwẹ̀ tí ń na ọwọ́ rẹ̀jáde láti lúwẹ̀ẹ́.Ọlọ́run yóò mú ìgbéraga wọn wálẹ̀bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìṣeféfé wà ní ọwọ́ wọn. 12 Òun yóò sì bi gbogbo ògiri gíga alágbára yín lulẹ̀wọn yóò sì wà nílẹ̀,Òun yóò sì mú wọn wá si ilẹ̀,àní sí erùpẹ̀ lásán.

In Other Versions

Isaiah 25 in the ANGEFD

Isaiah 25 in the ANTPNG2D

Isaiah 25 in the AS21

Isaiah 25 in the BAGH

Isaiah 25 in the BBPNG

Isaiah 25 in the BBT1E

Isaiah 25 in the BDS

Isaiah 25 in the BEV

Isaiah 25 in the BHAD

Isaiah 25 in the BIB

Isaiah 25 in the BLPT

Isaiah 25 in the BNT

Isaiah 25 in the BNTABOOT

Isaiah 25 in the BNTLV

Isaiah 25 in the BOATCB

Isaiah 25 in the BOATCB2

Isaiah 25 in the BOBCV

Isaiah 25 in the BOCNT

Isaiah 25 in the BOECS

Isaiah 25 in the BOGWICC

Isaiah 25 in the BOHCB

Isaiah 25 in the BOHCV

Isaiah 25 in the BOHLNT

Isaiah 25 in the BOHNTLTAL

Isaiah 25 in the BOICB

Isaiah 25 in the BOILNTAP

Isaiah 25 in the BOITCV

Isaiah 25 in the BOKCV

Isaiah 25 in the BOKCV2

Isaiah 25 in the BOKHWOG

Isaiah 25 in the BOKSSV

Isaiah 25 in the BOLCB

Isaiah 25 in the BOLCB2

Isaiah 25 in the BOMCV

Isaiah 25 in the BONAV

Isaiah 25 in the BONCB

Isaiah 25 in the BONLT

Isaiah 25 in the BONUT2

Isaiah 25 in the BOPLNT

Isaiah 25 in the BOSCB

Isaiah 25 in the BOSNC

Isaiah 25 in the BOTLNT

Isaiah 25 in the BOVCB

Isaiah 25 in the BPBB

Isaiah 25 in the BPH

Isaiah 25 in the BSB

Isaiah 25 in the CCB

Isaiah 25 in the CUV

Isaiah 25 in the CUVS

Isaiah 25 in the DBT

Isaiah 25 in the DGDNT

Isaiah 25 in the DHNT

Isaiah 25 in the DNT

Isaiah 25 in the ELBE

Isaiah 25 in the EMTV

Isaiah 25 in the ESV

Isaiah 25 in the FBV

Isaiah 25 in the FEB

Isaiah 25 in the GGMNT

Isaiah 25 in the GNT

Isaiah 25 in the HARY

Isaiah 25 in the HNT

Isaiah 25 in the IRVA

Isaiah 25 in the IRVB

Isaiah 25 in the IRVG

Isaiah 25 in the IRVH

Isaiah 25 in the IRVK

Isaiah 25 in the IRVM

Isaiah 25 in the IRVM2

Isaiah 25 in the IRVO

Isaiah 25 in the IRVP

Isaiah 25 in the IRVT

Isaiah 25 in the IRVT2

Isaiah 25 in the IRVU

Isaiah 25 in the ISVN

Isaiah 25 in the JSNT

Isaiah 25 in the KAPI

Isaiah 25 in the KBT1ETNIK

Isaiah 25 in the KBV

Isaiah 25 in the KJV

Isaiah 25 in the KNFD

Isaiah 25 in the LBA

Isaiah 25 in the LBLA

Isaiah 25 in the LNT

Isaiah 25 in the LSV

Isaiah 25 in the MAAL

Isaiah 25 in the MBV

Isaiah 25 in the MBV2

Isaiah 25 in the MHNT

Isaiah 25 in the MKNFD

Isaiah 25 in the MNG

Isaiah 25 in the MNT

Isaiah 25 in the MNT2

Isaiah 25 in the MRS1T

Isaiah 25 in the NAA

Isaiah 25 in the NASB

Isaiah 25 in the NBLA

Isaiah 25 in the NBS

Isaiah 25 in the NBVTP

Isaiah 25 in the NET2

Isaiah 25 in the NIV11

Isaiah 25 in the NNT

Isaiah 25 in the NNT2

Isaiah 25 in the NNT3

Isaiah 25 in the PDDPT

Isaiah 25 in the PFNT

Isaiah 25 in the RMNT

Isaiah 25 in the SBIAS

Isaiah 25 in the SBIBS

Isaiah 25 in the SBIBS2

Isaiah 25 in the SBICS

Isaiah 25 in the SBIDS

Isaiah 25 in the SBIGS

Isaiah 25 in the SBIHS

Isaiah 25 in the SBIIS

Isaiah 25 in the SBIIS2

Isaiah 25 in the SBIIS3

Isaiah 25 in the SBIKS

Isaiah 25 in the SBIKS2

Isaiah 25 in the SBIMS

Isaiah 25 in the SBIOS

Isaiah 25 in the SBIPS

Isaiah 25 in the SBISS

Isaiah 25 in the SBITS

Isaiah 25 in the SBITS2

Isaiah 25 in the SBITS3

Isaiah 25 in the SBITS4

Isaiah 25 in the SBIUS

Isaiah 25 in the SBIVS

Isaiah 25 in the SBT

Isaiah 25 in the SBT1E

Isaiah 25 in the SCHL

Isaiah 25 in the SNT

Isaiah 25 in the SUSU

Isaiah 25 in the SUSU2

Isaiah 25 in the SYNO

Isaiah 25 in the TBIAOTANT

Isaiah 25 in the TBT1E

Isaiah 25 in the TBT1E2

Isaiah 25 in the TFTIP

Isaiah 25 in the TFTU

Isaiah 25 in the TGNTATF3T

Isaiah 25 in the THAI

Isaiah 25 in the TNFD

Isaiah 25 in the TNT

Isaiah 25 in the TNTIK

Isaiah 25 in the TNTIL

Isaiah 25 in the TNTIN

Isaiah 25 in the TNTIP

Isaiah 25 in the TNTIZ

Isaiah 25 in the TOMA

Isaiah 25 in the TTENT

Isaiah 25 in the UBG

Isaiah 25 in the UGV

Isaiah 25 in the UGV2

Isaiah 25 in the UGV3

Isaiah 25 in the VBL

Isaiah 25 in the VDCC

Isaiah 25 in the YALU

Isaiah 25 in the YAPE

Isaiah 25 in the YBVTP

Isaiah 25 in the ZBP