Isaiah 50 (BOYCB)
1 Ohun tí OLÚWA wí nìyìí:“Níbo ni ìwé-ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀ ìyá rẹ wàèyí tí mo fi lé e lọ?Tàbí èwo nínú àwọn olùyánilówó mini mo tà ọ́ fún?Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ ni a fi tà ọ́;nítorí àìṣedéédéé rẹ ni a fi lé ìyá rẹ lọ. 2 Nígbà tí mo wá, èéṣe tí a kò fi rí ẹnìkan?Nígbà tí mo pè, èéṣe tí kò fi sí ẹnìkan láti dáhùn?Ọwọ́ mi a kúrú láti gbà ọ́?Èmi kò ha ní agbára láti gbà ọ́ bí?Nípa ìbáwí lásán, Èmi gbẹ omi òkun,Èmi yí àwọn odò sí aṣálẹ̀;àwọn ẹja wọn rà fún àìsí omiwọ́n sì kú fún òǹgbẹ. 3 Èmi fi òkùnkùn bo sánmọ̀mo sì fi aṣọ ọ̀fọ̀ ṣe ìbòrí rẹ̀.” 4 OLÚWA Olódùmarè ti fún mi ni ahọ́n tí a fi iṣẹ́ rán,láti mọ àwọn ọ̀rọ̀ tí ó lè gbé àwọn aláàárẹ̀ ró.O jí mi láràárọ̀,o jí etí mi láti gbọ́ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí à ń kọ́. 5 OLÚWA Olódùmarè ti ṣí mi ní etí,bẹ́ẹ̀ ni èmi kò ṣọ̀tẹ̀ rí;Èmi kò sì padà sẹ́yìn. 6 Mo ṣí ẹ̀yìn mi sílẹ̀ fún àwọn tí ó ń nà mí,àti ẹ̀rẹ̀kẹ́ mi fún àwọn tí ń fa irùngbọ̀n mi;Èmi kò fi ojú mi pamọ́kúrò lọ́wọ́ ẹlẹ́yà àti ìyọṣùtì sí. 7 Nítorí OLÚWA Olódùmarè ràn mí lọ́wọ́,a kì yóò dójútì mí.Nítorí náà ni mo ṣe gbé ojú mi ró bí òkúta akọèmi sì mọ pé, ojú kò ní tì mí. 8 Ẹni tí ó dá mi láre wà nítòsí.Ta ni ẹni náà tí yóò fẹ̀sùn kàn mí?Jẹ́ kí a kojú ara wa!Ta ni olùfisùn mi?Jẹ́ kí ó kò mí lójú! 9 OLÚWA Olódùmarè ni ó ń ràn mí lọ́wọ́.Ta ni ẹni náà tí yóò dá mi lẹ́bi?Gbogbo wọn yóò gbó bí aṣọ;kòkòrò ni yóò sì jẹ wọn run. 10 Ta ni nínú yín tí ó bẹ̀rù OLÚWAtí ó sì ń gbọ́rọ̀ sí ìránṣẹ́ rẹ̀ lẹ́nu?Jẹ́ kí ẹni tí ń rìn ní òkùnkùntí kò ní ìmọ́lẹ̀,kí ó gbẹ́kẹ̀lé orúkọ OLÚWAkí o sì gbẹ́kẹ̀lé Ọlọ́run rẹ̀. 11 Ṣùgbọ́n ní àkókò yìí, gbogbo ẹ̀yin ti ń tannátí ẹ sì ń fi pèsè iná ìléwọ́ fún ara yín,ẹ lọ, kí ẹ sì máa rìn nínú ìmọ́lẹ̀ iná yín,àti nínú ẹta iná tí ẹ ti dá.Èyí ni yóò jẹ́ tiyín láti ọwọ́ mi wá.Ẹ̀yin ó dùbúlẹ̀ nínú ìrora.
In Other Versions
Isaiah 50 in the ANGEFD
Isaiah 50 in the ANTPNG2D
Isaiah 50 in the AS21
Isaiah 50 in the BAGH
Isaiah 50 in the BBPNG
Isaiah 50 in the BBT1E
Isaiah 50 in the BDS
Isaiah 50 in the BEV
Isaiah 50 in the BHAD
Isaiah 50 in the BIB
Isaiah 50 in the BLPT
Isaiah 50 in the BNT
Isaiah 50 in the BNTABOOT
Isaiah 50 in the BNTLV
Isaiah 50 in the BOATCB
Isaiah 50 in the BOATCB2
Isaiah 50 in the BOBCV
Isaiah 50 in the BOCNT
Isaiah 50 in the BOECS
Isaiah 50 in the BOGWICC
Isaiah 50 in the BOHCB
Isaiah 50 in the BOHCV
Isaiah 50 in the BOHLNT
Isaiah 50 in the BOHNTLTAL
Isaiah 50 in the BOICB
Isaiah 50 in the BOILNTAP
Isaiah 50 in the BOITCV
Isaiah 50 in the BOKCV
Isaiah 50 in the BOKCV2
Isaiah 50 in the BOKHWOG
Isaiah 50 in the BOKSSV
Isaiah 50 in the BOLCB
Isaiah 50 in the BOLCB2
Isaiah 50 in the BOMCV
Isaiah 50 in the BONAV
Isaiah 50 in the BONCB
Isaiah 50 in the BONLT
Isaiah 50 in the BONUT2
Isaiah 50 in the BOPLNT
Isaiah 50 in the BOSCB
Isaiah 50 in the BOSNC
Isaiah 50 in the BOTLNT
Isaiah 50 in the BOVCB
Isaiah 50 in the BPBB
Isaiah 50 in the BPH
Isaiah 50 in the BSB
Isaiah 50 in the CCB
Isaiah 50 in the CUV
Isaiah 50 in the CUVS
Isaiah 50 in the DBT
Isaiah 50 in the DGDNT
Isaiah 50 in the DHNT
Isaiah 50 in the DNT
Isaiah 50 in the ELBE
Isaiah 50 in the EMTV
Isaiah 50 in the ESV
Isaiah 50 in the FBV
Isaiah 50 in the FEB
Isaiah 50 in the GGMNT
Isaiah 50 in the GNT
Isaiah 50 in the HARY
Isaiah 50 in the HNT
Isaiah 50 in the IRVA
Isaiah 50 in the IRVB
Isaiah 50 in the IRVG
Isaiah 50 in the IRVH
Isaiah 50 in the IRVK
Isaiah 50 in the IRVM
Isaiah 50 in the IRVM2
Isaiah 50 in the IRVO
Isaiah 50 in the IRVP
Isaiah 50 in the IRVT
Isaiah 50 in the IRVT2
Isaiah 50 in the IRVU
Isaiah 50 in the ISVN
Isaiah 50 in the JSNT
Isaiah 50 in the KAPI
Isaiah 50 in the KBT1ETNIK
Isaiah 50 in the KBV
Isaiah 50 in the KJV
Isaiah 50 in the KNFD
Isaiah 50 in the LBA
Isaiah 50 in the LBLA
Isaiah 50 in the LNT
Isaiah 50 in the LSV
Isaiah 50 in the MAAL
Isaiah 50 in the MBV
Isaiah 50 in the MBV2
Isaiah 50 in the MHNT
Isaiah 50 in the MKNFD
Isaiah 50 in the MNG
Isaiah 50 in the MNT
Isaiah 50 in the MNT2
Isaiah 50 in the MRS1T
Isaiah 50 in the NAA
Isaiah 50 in the NASB
Isaiah 50 in the NBLA
Isaiah 50 in the NBS
Isaiah 50 in the NBVTP
Isaiah 50 in the NET2
Isaiah 50 in the NIV11
Isaiah 50 in the NNT
Isaiah 50 in the NNT2
Isaiah 50 in the NNT3
Isaiah 50 in the PDDPT
Isaiah 50 in the PFNT
Isaiah 50 in the RMNT
Isaiah 50 in the SBIAS
Isaiah 50 in the SBIBS
Isaiah 50 in the SBIBS2
Isaiah 50 in the SBICS
Isaiah 50 in the SBIDS
Isaiah 50 in the SBIGS
Isaiah 50 in the SBIHS
Isaiah 50 in the SBIIS
Isaiah 50 in the SBIIS2
Isaiah 50 in the SBIIS3
Isaiah 50 in the SBIKS
Isaiah 50 in the SBIKS2
Isaiah 50 in the SBIMS
Isaiah 50 in the SBIOS
Isaiah 50 in the SBIPS
Isaiah 50 in the SBISS
Isaiah 50 in the SBITS
Isaiah 50 in the SBITS2
Isaiah 50 in the SBITS3
Isaiah 50 in the SBITS4
Isaiah 50 in the SBIUS
Isaiah 50 in the SBIVS
Isaiah 50 in the SBT
Isaiah 50 in the SBT1E
Isaiah 50 in the SCHL
Isaiah 50 in the SNT
Isaiah 50 in the SUSU
Isaiah 50 in the SUSU2
Isaiah 50 in the SYNO
Isaiah 50 in the TBIAOTANT
Isaiah 50 in the TBT1E
Isaiah 50 in the TBT1E2
Isaiah 50 in the TFTIP
Isaiah 50 in the TFTU
Isaiah 50 in the TGNTATF3T
Isaiah 50 in the THAI
Isaiah 50 in the TNFD
Isaiah 50 in the TNT
Isaiah 50 in the TNTIK
Isaiah 50 in the TNTIL
Isaiah 50 in the TNTIN
Isaiah 50 in the TNTIP
Isaiah 50 in the TNTIZ
Isaiah 50 in the TOMA
Isaiah 50 in the TTENT
Isaiah 50 in the UBG
Isaiah 50 in the UGV
Isaiah 50 in the UGV2
Isaiah 50 in the UGV3
Isaiah 50 in the VBL
Isaiah 50 in the VDCC
Isaiah 50 in the YALU
Isaiah 50 in the YAPE
Isaiah 50 in the YBVTP
Isaiah 50 in the ZBP