Isaiah 62 (BOYCB)
1 Nítorí Sioni èmi kì yóò dákẹ́,nítorí i Jerusalẹmu èmi kì yóò sinmi ẹnu,títí tí òdodo rẹ̀ yóò fi tàn bí òwúrọ̀,àti ìgbàlà rẹ̀ bí i fìtílà tí ń jó geere. 2 Àwọn orílẹ̀-èdè yóò rí òdodo rẹ,àti gbogbo ọba ògo rẹa ó sì máa pè ọ́ ní orúkọ mìírànèyí tí ẹnu OLÚWA yóò fi fún un. 3 Ìwọ yóò sì jẹ́ adé dídán ní ọwọ́ OLÚWA,adé ọba ní ọwọ́ Ọlọ́run rẹ. 4 Wọn kì yóò pè ọ́ ní ìkọ̀sílẹ̀ mọ́tàbí kí wọ́n pe ilẹ̀ rẹ ní ahoro.Ṣùgbọ́n a ó máa pè ọ́ ní Hẹfsiba,àti ilẹ̀ rẹ ní Beula;nítorí OLÚWA yóò yọ́nú sí ọàti ilẹ̀ rẹ ni a ó gbé níyàwó. 5 Gẹ́gẹ́ bí ọ̀dọ́mọkùnrin tí í gbé ọ̀dọ́mọbìnrin níyàwó,bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọkùnrin rẹ yóò gbé ọ níyàwóGẹ́gẹ́ bí ọkọ ìyàwó ṣe é yọ̀ lórí ìyàwó rẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni Ọlọ́run rẹ yóò yọ̀ lórí rẹ. 6 Èmi ti fi olùṣọ́ ránṣẹ́ sórí odi rẹ ìwọ Jerusalẹmu;wọn kì yóò lè dákẹ́ tọ̀sán tòru.Ẹ̀yin tí ń ké pe OLÚWA,ẹ má ṣe fúnra yín ní ìsinmi, 7 àti kí ẹ má ṣe fún òun pẹ̀lú ní ìsinmitítí tí yóò fi fi ìdí Jerusalẹmu múlẹ̀tí yóò sì fi ṣe ìyìn orí ilẹ̀ ayé. 8 OLÚWA ti búra pẹ̀lú ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀àti nípa agbára apá rẹ:“Èmi kì yóò jẹ́ kí ìyẹ̀fun rẹdi oúnjẹ fún ọ̀tá rẹbẹ́ẹ̀ ni àwọn àjèjì kì yóò mu wáìnìtuntun rẹ mọ́èyí tí ìwọ ti ṣe làálàá fún; 9 ṣùgbọ́n àwọn tí ó bá kóórè rẹ̀ ni yóò jẹ ẹ́,tí wọn ó sì yin OLÚWA,àti àwọn tí wọ́n bá kó àjàrà jọ ni wọn ó mú un,nínú àgbàlá ilé mímọ́ mi.” 10 Ẹ kọjá, ẹ kọjá ní ẹnu ibodè náà!Ẹ tún ọ̀nà ṣe fún àwọn ènìyàn.Ẹ mọ ọ́n sókè, ṣe ojú ọ̀nà òpópó!Ẹ ṣa òkúta kúrò.Ẹ gbé àsíá sókè fún àwọn orílẹ̀-èdè. 11 OLÚWA ti ṣe ìkédetítí dé òpin ilẹ̀ ayé:“Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Sioni pé,‘Kíyèsi i, Olùgbàlà rẹ ń bọ̀!Kíyèsi i, èrè ń bẹ pẹ̀lú rẹ̀,àti ẹ̀san rẹ̀ pẹ̀lú n tẹ̀lé e lẹ́yìn.’ ” 12 A ó sì pè wọ́n ní Ènìyàn Mímọ́,ẹni ìràpadà OLÚWA;a ó sì máa pè ọ́ ní ìwákiri,ìlú tí a kì yóò kọ̀sílẹ̀.
In Other Versions
Isaiah 62 in the ANGEFD
Isaiah 62 in the ANTPNG2D
Isaiah 62 in the AS21
Isaiah 62 in the BAGH
Isaiah 62 in the BBPNG
Isaiah 62 in the BBT1E
Isaiah 62 in the BDS
Isaiah 62 in the BEV
Isaiah 62 in the BHAD
Isaiah 62 in the BIB
Isaiah 62 in the BLPT
Isaiah 62 in the BNT
Isaiah 62 in the BNTABOOT
Isaiah 62 in the BNTLV
Isaiah 62 in the BOATCB
Isaiah 62 in the BOATCB2
Isaiah 62 in the BOBCV
Isaiah 62 in the BOCNT
Isaiah 62 in the BOECS
Isaiah 62 in the BOGWICC
Isaiah 62 in the BOHCB
Isaiah 62 in the BOHCV
Isaiah 62 in the BOHLNT
Isaiah 62 in the BOHNTLTAL
Isaiah 62 in the BOICB
Isaiah 62 in the BOILNTAP
Isaiah 62 in the BOITCV
Isaiah 62 in the BOKCV
Isaiah 62 in the BOKCV2
Isaiah 62 in the BOKHWOG
Isaiah 62 in the BOKSSV
Isaiah 62 in the BOLCB
Isaiah 62 in the BOLCB2
Isaiah 62 in the BOMCV
Isaiah 62 in the BONAV
Isaiah 62 in the BONCB
Isaiah 62 in the BONLT
Isaiah 62 in the BONUT2
Isaiah 62 in the BOPLNT
Isaiah 62 in the BOSCB
Isaiah 62 in the BOSNC
Isaiah 62 in the BOTLNT
Isaiah 62 in the BOVCB
Isaiah 62 in the BPBB
Isaiah 62 in the BPH
Isaiah 62 in the BSB
Isaiah 62 in the CCB
Isaiah 62 in the CUV
Isaiah 62 in the CUVS
Isaiah 62 in the DBT
Isaiah 62 in the DGDNT
Isaiah 62 in the DHNT
Isaiah 62 in the DNT
Isaiah 62 in the ELBE
Isaiah 62 in the EMTV
Isaiah 62 in the ESV
Isaiah 62 in the FBV
Isaiah 62 in the FEB
Isaiah 62 in the GGMNT
Isaiah 62 in the GNT
Isaiah 62 in the HARY
Isaiah 62 in the HNT
Isaiah 62 in the IRVA
Isaiah 62 in the IRVB
Isaiah 62 in the IRVG
Isaiah 62 in the IRVH
Isaiah 62 in the IRVK
Isaiah 62 in the IRVM
Isaiah 62 in the IRVM2
Isaiah 62 in the IRVO
Isaiah 62 in the IRVP
Isaiah 62 in the IRVT
Isaiah 62 in the IRVT2
Isaiah 62 in the IRVU
Isaiah 62 in the ISVN
Isaiah 62 in the JSNT
Isaiah 62 in the KAPI
Isaiah 62 in the KBT1ETNIK
Isaiah 62 in the KBV
Isaiah 62 in the KJV
Isaiah 62 in the KNFD
Isaiah 62 in the LBA
Isaiah 62 in the LBLA
Isaiah 62 in the LNT
Isaiah 62 in the LSV
Isaiah 62 in the MAAL
Isaiah 62 in the MBV
Isaiah 62 in the MBV2
Isaiah 62 in the MHNT
Isaiah 62 in the MKNFD
Isaiah 62 in the MNG
Isaiah 62 in the MNT
Isaiah 62 in the MNT2
Isaiah 62 in the MRS1T
Isaiah 62 in the NAA
Isaiah 62 in the NASB
Isaiah 62 in the NBLA
Isaiah 62 in the NBS
Isaiah 62 in the NBVTP
Isaiah 62 in the NET2
Isaiah 62 in the NIV11
Isaiah 62 in the NNT
Isaiah 62 in the NNT2
Isaiah 62 in the NNT3
Isaiah 62 in the PDDPT
Isaiah 62 in the PFNT
Isaiah 62 in the RMNT
Isaiah 62 in the SBIAS
Isaiah 62 in the SBIBS
Isaiah 62 in the SBIBS2
Isaiah 62 in the SBICS
Isaiah 62 in the SBIDS
Isaiah 62 in the SBIGS
Isaiah 62 in the SBIHS
Isaiah 62 in the SBIIS
Isaiah 62 in the SBIIS2
Isaiah 62 in the SBIIS3
Isaiah 62 in the SBIKS
Isaiah 62 in the SBIKS2
Isaiah 62 in the SBIMS
Isaiah 62 in the SBIOS
Isaiah 62 in the SBIPS
Isaiah 62 in the SBISS
Isaiah 62 in the SBITS
Isaiah 62 in the SBITS2
Isaiah 62 in the SBITS3
Isaiah 62 in the SBITS4
Isaiah 62 in the SBIUS
Isaiah 62 in the SBIVS
Isaiah 62 in the SBT
Isaiah 62 in the SBT1E
Isaiah 62 in the SCHL
Isaiah 62 in the SNT
Isaiah 62 in the SUSU
Isaiah 62 in the SUSU2
Isaiah 62 in the SYNO
Isaiah 62 in the TBIAOTANT
Isaiah 62 in the TBT1E
Isaiah 62 in the TBT1E2
Isaiah 62 in the TFTIP
Isaiah 62 in the TFTU
Isaiah 62 in the TGNTATF3T
Isaiah 62 in the THAI
Isaiah 62 in the TNFD
Isaiah 62 in the TNT
Isaiah 62 in the TNTIK
Isaiah 62 in the TNTIL
Isaiah 62 in the TNTIN
Isaiah 62 in the TNTIP
Isaiah 62 in the TNTIZ
Isaiah 62 in the TOMA
Isaiah 62 in the TTENT
Isaiah 62 in the UBG
Isaiah 62 in the UGV
Isaiah 62 in the UGV2
Isaiah 62 in the UGV3
Isaiah 62 in the VBL
Isaiah 62 in the VDCC
Isaiah 62 in the YALU
Isaiah 62 in the YAPE
Isaiah 62 in the YBVTP
Isaiah 62 in the ZBP