Judges 10 (BOYCB)
1 Lẹ́yìn ikú Abimeleki, ọkùnrin kan láti ẹ̀yà Isakari tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Tola ọmọ Pua, ọmọ Dodo, dìde láti gba Israẹli sílẹ̀. Ní Ṣamiri tí ó wà ní òkè Efraimu ni ó gbé. 2 Ó ṣe àkóso Israẹli ní ọdún mẹ́tàlélógún. Nígbà tí ó kú wọ́n sìn ín sí Ṣamiri. 3 Jairi ti ẹ̀yà Gileadi ni ó dìde lẹ́yìn rẹ̀, ó ṣàkóso Israẹli ní ọdún méjìlélógún. 4 Àwọn ọgbọ̀n ọmọ tí ó n gun ọgbọ̀n kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́. Wọ́n ṣe àkóso ọgbọ̀n ìlú ní Gileadi, tí a pe orúkọ wọn ní Hafoti-Jairi títí di òní. 5 Nígbà tí Jairi kú wọ́n sin ín sí Kamoni. 6 Àwọn ọmọ Israẹli sì túnṣe ohun tí ó burú lójú OLÚWA. Wọ́n sin Baali àti Aṣtoreti àti àwọn òrìṣà Aramu, òrìṣà Sidoni, òrìṣà Moabu, òrìṣà àwọn ará Ammoni àti òrìṣà àwọn ará Filistini. Nítorí àwọn ará Israẹli kọ OLÚWA sílẹ̀ tí wọn kò sì sìn ín mọ́, 7 ó bínú sí wọn, ó fi wọ́n sílẹ̀ fún àwọn ará Filistini àti Ammoni láti jẹ ẹ́ ní ìyà. 8 Ní ọdún náà, wọ́n tú wọn ká wọ́n sì pọ́n wọn lójú. Fún ọdún méjìdínlógún ni wọ́n fi ni gbogbo àwọn ọmọ Israẹli tí ó wà ní ìlà-oòrùn odò Jordani ní ilẹ̀ àwọn ará Amori lára (èyí nì ní Gileadi). 9 Àwọn ará Ammoni sì la odò Jordani kọjá láti bá Juda, Benjamini àti àwọn ará ilé Efraimu jagun: Israẹli sì dojúkọ ìpọ́njú tó lágbára. 10 Nígbà tí èyí ti ṣẹlẹ̀ àwọn ọmọ Israẹli ké pe OLÚWA wí pé, “Àwa ti ṣẹ̀ sí ọ, nítorí pé àwa ti kọ Ọlọ́run wa sílẹ̀, àwa sì ń sin Baali.” 11 OLÚWA sì dáhùn pé, “Ǹjẹ́ nígbà tí àwọn ará Ejibiti, Amori, Ammoni, Filistini, 12 àwọn ará Sidoni, Amaleki pẹ̀lú Maoni ni yín lára, tí ẹ sì ké pè mí fún ìrànlọ́wọ́, ǹjẹ́ èmi kò gbà yín sílẹ̀ kúrò ní ọwọ́ wọn? 13 Síbẹ̀síbẹ̀ ẹ̀yin kọ̀ mí sílẹ̀ láti sin àwọn ọlọ́run mìíràn, torí ìdí èyí, èmi kì yóò sì tún gbà yín mọ́. 14 Ẹ lọ kí ẹ sì ké pe àwọn òrìṣà tí ẹ̀yin ti yàn fún ara yín. Jẹ́ kí wọn gbà yín sílẹ̀ ní àsìkò ìpọ́njú yín!” 15 Àwọn ọmọ Israẹli sì dá OLÚWA lóhùn pé, “Àwa ti ṣẹ̀, ṣe ohun tí ó bá fẹ́ pẹ̀lú wa, ṣùgbọ́n, jọ̀wọ́ gbà wá sílẹ̀ náání àsìkò yìí.” 16 Nígbà náà ni wọ́n kó gbogbo ọlọ́run àjèjì tí ó wà láàrín wọn kúrò wọ́n sì sin OLÚWA nìkan, ọkàn rẹ̀ kò sì le gbàgbé ìrora Israẹli mọ́. 17 Nígbà tí àwọn ará Ammoni kógun jọ ní Gileadi láti bá Israẹli jà, àwọn ọmọ Israẹli gbárajọpọ̀, wọ́n sì tẹ̀dó ogun ní Mispa. 18 Àwọn ìjòyè: aṣíwájú àwọn ará Gileadi wí fún ará wọn pé, “Ẹnikẹ́ni tí yóò kọ́ ṣígun si àwọn ará Ammoni ni yóò jẹ́ orí fún gbogbo àwọn tí ń gbé ní Gileadi.”
In Other Versions
Judges 10 in the ANGEFD
Judges 10 in the ANTPNG2D
Judges 10 in the AS21
Judges 10 in the BAGH
Judges 10 in the BBPNG
Judges 10 in the BBT1E
Judges 10 in the BDS
Judges 10 in the BEV
Judges 10 in the BHAD
Judges 10 in the BIB
Judges 10 in the BLPT
Judges 10 in the BNT
Judges 10 in the BNTABOOT
Judges 10 in the BNTLV
Judges 10 in the BOATCB
Judges 10 in the BOATCB2
Judges 10 in the BOBCV
Judges 10 in the BOCNT
Judges 10 in the BOECS
Judges 10 in the BOGWICC
Judges 10 in the BOHCB
Judges 10 in the BOHCV
Judges 10 in the BOHLNT
Judges 10 in the BOHNTLTAL
Judges 10 in the BOICB
Judges 10 in the BOILNTAP
Judges 10 in the BOITCV
Judges 10 in the BOKCV
Judges 10 in the BOKCV2
Judges 10 in the BOKHWOG
Judges 10 in the BOKSSV
Judges 10 in the BOLCB
Judges 10 in the BOLCB2
Judges 10 in the BOMCV
Judges 10 in the BONAV
Judges 10 in the BONCB
Judges 10 in the BONLT
Judges 10 in the BONUT2
Judges 10 in the BOPLNT
Judges 10 in the BOSCB
Judges 10 in the BOSNC
Judges 10 in the BOTLNT
Judges 10 in the BOVCB
Judges 10 in the BPBB
Judges 10 in the BPH
Judges 10 in the BSB
Judges 10 in the CCB
Judges 10 in the CUV
Judges 10 in the CUVS
Judges 10 in the DBT
Judges 10 in the DGDNT
Judges 10 in the DHNT
Judges 10 in the DNT
Judges 10 in the ELBE
Judges 10 in the EMTV
Judges 10 in the ESV
Judges 10 in the FBV
Judges 10 in the FEB
Judges 10 in the GGMNT
Judges 10 in the GNT
Judges 10 in the HARY
Judges 10 in the HNT
Judges 10 in the IRVA
Judges 10 in the IRVB
Judges 10 in the IRVG
Judges 10 in the IRVH
Judges 10 in the IRVK
Judges 10 in the IRVM
Judges 10 in the IRVM2
Judges 10 in the IRVO
Judges 10 in the IRVP
Judges 10 in the IRVT
Judges 10 in the IRVT2
Judges 10 in the IRVU
Judges 10 in the ISVN
Judges 10 in the JSNT
Judges 10 in the KAPI
Judges 10 in the KBT1ETNIK
Judges 10 in the KBV
Judges 10 in the KJV
Judges 10 in the KNFD
Judges 10 in the LBA
Judges 10 in the LBLA
Judges 10 in the LNT
Judges 10 in the LSV
Judges 10 in the MAAL
Judges 10 in the MBV
Judges 10 in the MBV2
Judges 10 in the MHNT
Judges 10 in the MKNFD
Judges 10 in the MNG
Judges 10 in the MNT
Judges 10 in the MNT2
Judges 10 in the MRS1T
Judges 10 in the NAA
Judges 10 in the NASB
Judges 10 in the NBLA
Judges 10 in the NBS
Judges 10 in the NBVTP
Judges 10 in the NET2
Judges 10 in the NIV11
Judges 10 in the NNT
Judges 10 in the NNT2
Judges 10 in the NNT3
Judges 10 in the PDDPT
Judges 10 in the PFNT
Judges 10 in the RMNT
Judges 10 in the SBIAS
Judges 10 in the SBIBS
Judges 10 in the SBIBS2
Judges 10 in the SBICS
Judges 10 in the SBIDS
Judges 10 in the SBIGS
Judges 10 in the SBIHS
Judges 10 in the SBIIS
Judges 10 in the SBIIS2
Judges 10 in the SBIIS3
Judges 10 in the SBIKS
Judges 10 in the SBIKS2
Judges 10 in the SBIMS
Judges 10 in the SBIOS
Judges 10 in the SBIPS
Judges 10 in the SBISS
Judges 10 in the SBITS
Judges 10 in the SBITS2
Judges 10 in the SBITS3
Judges 10 in the SBITS4
Judges 10 in the SBIUS
Judges 10 in the SBIVS
Judges 10 in the SBT
Judges 10 in the SBT1E
Judges 10 in the SCHL
Judges 10 in the SNT
Judges 10 in the SUSU
Judges 10 in the SUSU2
Judges 10 in the SYNO
Judges 10 in the TBIAOTANT
Judges 10 in the TBT1E
Judges 10 in the TBT1E2
Judges 10 in the TFTIP
Judges 10 in the TFTU
Judges 10 in the TGNTATF3T
Judges 10 in the THAI
Judges 10 in the TNFD
Judges 10 in the TNT
Judges 10 in the TNTIK
Judges 10 in the TNTIL
Judges 10 in the TNTIN
Judges 10 in the TNTIP
Judges 10 in the TNTIZ
Judges 10 in the TOMA
Judges 10 in the TTENT
Judges 10 in the UBG
Judges 10 in the UGV
Judges 10 in the UGV2
Judges 10 in the UGV3
Judges 10 in the VBL
Judges 10 in the VDCC
Judges 10 in the YALU
Judges 10 in the YAPE
Judges 10 in the YBVTP
Judges 10 in the ZBP