Job 42 (BOYCB)
1 Nígbà náà ní Jobu dá OLÚWA lóhùn, ó sì wí pé, 2 “Èmi mọ̀ pé, ìwọ lè e ṣe ohun gbogbo,àti pé, kò si ìrò inú tí a lè fa sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ rẹ. 3 Ìwọ béèrè, ta ni ẹni tí ń fi ìgbìmọ̀ pamọ́ láìní ìmọ̀?Nítorí náà ní èmi ṣe ń sọ èyí tí èmi kò mọ̀,ohun tí ó ṣe ìyanu jọjọ níwájú mi, ti èmi kò mòye. 4 “Ìwọ wí pé, ‘Gbọ́ tèmi báyìí,èmi ó sì sọ; èmi ó béèrè lọ́wọ́ rẹ,ìwọ yóò sì dá mi lóhùn.’ 5 Etí mi sì ti gbọ́ nípa rẹ,ṣùgbọ́n nísinsin yìí ojú mi ti rí ọ. 6 Ǹjẹ́ nítorí náà èmi kórìíra ara mi,mo sì ronúpìwàdà nínú ekuru àti eérú.” 7 Bẹ́ẹ̀ ó sì rí, lẹ́yìn ìgbà tí OLÚWA ti sọ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí fún Jobu, OLÚWA sì wí fún Elifasi, ará Temani pé, mo bínú sí ọ, àti sí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ méjèèjì, nítorí pé ẹ̀yin kò sọ̀rọ̀, ní ti èmi, ohun tí ó tọ́, bí Jobu ìránṣẹ́ mi ti sọ. 8 Nítorí náà, ẹ mú akọ ẹgbọrọ màlúù méje, àti àgbò méje, kí ẹ sì tọ̀ Jobu ìránṣẹ́ mi lọ, kí ẹ sì fi rú ẹbọ sísun fún ara yín; Jobu ìránṣẹ́ mi yóò sì gbàdúrà fún yin; nítorí pé àdúrà rẹ̀ ní èmi yóò gbà; kí èmi kí ó má ba ṣe si yín bí ìṣìnà yín, ní ti pé ẹ̀yin kò sọ̀rọ̀ ohun tí ó tọ́ sí mi bi Jobu ìránṣẹ́ mi ti ṣe. 9 Bẹ́ẹ̀ ní Elifasi, ara Temani, àti Bilidadi, ará Ṣuhi, àti Sofari, ará Naama lọ, wọ́n sì ṣe gẹ́gẹ́ bí OLÚWA ti pàṣẹ fún wọn. OLÚWA sì gbọ́ àdúrà Jobu. 10 OLÚWA sì yí ìgbèkùn Jobu padà, nígbà tí ó gbàdúrà fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀; OLÚWA sì bùsi ohun gbogbo ti Jobu ní rí ní ìṣẹ́po méjì ohun tí ó ní tẹ́lẹ̀ rí. 11 Nígbà náà ní gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀, àti gbogbo àwọn arábìnrin rẹ̀, àti gbogbo àwọn tí ó ti ṣe ojúlùmọ̀ rẹ̀ rí; wọ́n bá a jẹun nínú ilé rẹ̀. Wọ́n sì ṣe ìdárò rẹ̀, wọ́n sì ṣìpẹ̀ fún un nítorí ibi gbogbo tí OLÚWA ti mú bá a. Olúkúlùkù ènìyàn pẹ̀lú sì fún un ní ẹyọ owó kọ̀ọ̀kan àti olúkúlùkù ni òrùka wúrà etí kọ̀ọ̀kan. 12 Bẹ́ẹ̀ ni OLÚWA bùkún ìgbẹ̀yìn Jobu ju ìṣáájú rẹ̀ lọ; ẹgbàá méje (14,000) àgùntàn, ẹgbẹ̀rún mẹ́fà (6,000) ìbákasẹ, àti ẹgbẹ̀rún (1,000) àjàgà ọ̀dá màlúù, àti ẹgbẹ̀rún (1,000) abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́. 13 Ó sì ní ọmọkùnrin méje àti ọmọbìnrin mẹ́ta. 14 Ó sì sọ orúkọ àkọ́bí ní Jemima, àti orúkọ èkejì ni Kesia àti orúkọ ẹ̀kẹta ní Kereni-Happuki. 15 Àti ní gbogbo ilẹ̀ náà, a kò rí obìnrin tí ó ní ẹwà bí ọmọ Jobu; baba wọ́n sì pínlẹ̀ fún wọn nínú àwọn arákùnrin wọn. 16 Lẹ́yìn èyí Jobu wà ní ayé ní ogóje ọdún, ó sì rí àwọn ọmọ rẹ̀ ọkùnrin àti ọmọ ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, àní ìran mẹ́rin. 17 Bẹ́ẹ̀ ni Jobu kú, ó gbó, ó sì kún fún ọjọ́ púpọ̀.
In Other Versions
Job 42 in the ANGEFD
Job 42 in the ANTPNG2D
Job 42 in the AS21
Job 42 in the BAGH
Job 42 in the BBPNG
Job 42 in the BBT1E
Job 42 in the BDS
Job 42 in the BEV
Job 42 in the BHAD
Job 42 in the BIB
Job 42 in the BLPT
Job 42 in the BNT
Job 42 in the BNTABOOT
Job 42 in the BNTLV
Job 42 in the BOATCB
Job 42 in the BOATCB2
Job 42 in the BOBCV
Job 42 in the BOCNT
Job 42 in the BOECS
Job 42 in the BOGWICC
Job 42 in the BOHCB
Job 42 in the BOHCV
Job 42 in the BOHLNT
Job 42 in the BOHNTLTAL
Job 42 in the BOICB
Job 42 in the BOILNTAP
Job 42 in the BOITCV
Job 42 in the BOKCV
Job 42 in the BOKCV2
Job 42 in the BOKHWOG
Job 42 in the BOKSSV
Job 42 in the BOLCB
Job 42 in the BOLCB2
Job 42 in the BOMCV
Job 42 in the BONAV
Job 42 in the BONCB
Job 42 in the BONLT
Job 42 in the BONUT2
Job 42 in the BOPLNT
Job 42 in the BOSCB
Job 42 in the BOSNC
Job 42 in the BOTLNT
Job 42 in the BOVCB
Job 42 in the BPBB
Job 42 in the BPH
Job 42 in the BSB
Job 42 in the CCB
Job 42 in the CUV
Job 42 in the CUVS
Job 42 in the DBT
Job 42 in the DGDNT
Job 42 in the DHNT
Job 42 in the DNT
Job 42 in the ELBE
Job 42 in the EMTV
Job 42 in the ESV
Job 42 in the FBV
Job 42 in the FEB
Job 42 in the GGMNT
Job 42 in the GNT
Job 42 in the HARY
Job 42 in the HNT
Job 42 in the IRVA
Job 42 in the IRVB
Job 42 in the IRVG
Job 42 in the IRVH
Job 42 in the IRVK
Job 42 in the IRVM
Job 42 in the IRVM2
Job 42 in the IRVO
Job 42 in the IRVP
Job 42 in the IRVT
Job 42 in the IRVT2
Job 42 in the IRVU
Job 42 in the ISVN
Job 42 in the JSNT
Job 42 in the KAPI
Job 42 in the KBT1ETNIK
Job 42 in the KBV
Job 42 in the KJV
Job 42 in the KNFD
Job 42 in the LBA
Job 42 in the LBLA
Job 42 in the LNT
Job 42 in the LSV
Job 42 in the MAAL
Job 42 in the MBV
Job 42 in the MBV2
Job 42 in the MHNT
Job 42 in the MKNFD
Job 42 in the MNG
Job 42 in the MNT
Job 42 in the MNT2
Job 42 in the MRS1T
Job 42 in the NAA
Job 42 in the NASB
Job 42 in the NBLA
Job 42 in the NBS
Job 42 in the NBVTP
Job 42 in the NET2
Job 42 in the NIV11
Job 42 in the NNT
Job 42 in the NNT2
Job 42 in the NNT3
Job 42 in the PDDPT
Job 42 in the PFNT
Job 42 in the RMNT
Job 42 in the SBIAS
Job 42 in the SBIBS
Job 42 in the SBIBS2
Job 42 in the SBICS
Job 42 in the SBIDS
Job 42 in the SBIGS
Job 42 in the SBIHS
Job 42 in the SBIIS
Job 42 in the SBIIS2
Job 42 in the SBIIS3
Job 42 in the SBIKS
Job 42 in the SBIKS2
Job 42 in the SBIMS
Job 42 in the SBIOS
Job 42 in the SBIPS
Job 42 in the SBISS
Job 42 in the SBITS
Job 42 in the SBITS2
Job 42 in the SBITS3
Job 42 in the SBITS4
Job 42 in the SBIUS
Job 42 in the SBIVS
Job 42 in the SBT
Job 42 in the SBT1E
Job 42 in the SCHL
Job 42 in the SNT
Job 42 in the SUSU
Job 42 in the SUSU2
Job 42 in the SYNO
Job 42 in the TBIAOTANT
Job 42 in the TBT1E
Job 42 in the TBT1E2
Job 42 in the TFTIP
Job 42 in the TFTU
Job 42 in the TGNTATF3T
Job 42 in the THAI
Job 42 in the TNFD
Job 42 in the TNT
Job 42 in the TNTIK
Job 42 in the TNTIL
Job 42 in the TNTIN
Job 42 in the TNTIP
Job 42 in the TNTIZ
Job 42 in the TOMA
Job 42 in the TTENT
Job 42 in the UBG
Job 42 in the UGV
Job 42 in the UGV2
Job 42 in the UGV3
Job 42 in the VBL
Job 42 in the VDCC
Job 42 in the YALU
Job 42 in the YAPE
Job 42 in the YBVTP
Job 42 in the ZBP