Leviticus 18 (BOYCB)
1 OLÚWA sọ fún Mose pé: 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé: ‘Èmi ni OLÚWA Ọlọ́run yín. 3 Ẹ kò gbọdọ̀ ṣe bí wọ́n ti ń ṣe ní Ejibiti níbi tí ẹ ti gbé rí, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò sì gbọdọ̀ ṣe bí wọ́n ti ń ṣe ní ilẹ̀ Kenaani níbi tí èmi ń mú yín lọ. Ẹ kò gbọdọ̀ tẹ̀lé ìṣe wọn. 4 Kí ẹ̀yin kí ó sì máa ṣe òfin mi, kí ẹ̀yin sì máa pa ìlànà mi mọ́, láti máa rìn nínú wọn, Èmi ni OLÚWA Ọlọ́run yín. 5 Ẹ̀yin ó sì máa pa ìlànà mi mọ́ àti òfin mi; Ẹni tí ó ba ṣe, yóò yè nípa wọn. Èmi ni OLÚWA. 6 “ ‘Ẹnikẹ́ni nínú yín kò gbọdọ̀ súnmọ́ ìbátan rẹ̀ láti bá a lòpọ̀. Èmí ni OLÚWA. 7 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ tàbùkù baba rẹ nípa bíbá ìyá rẹ lòpọ̀, ìyá rẹ̀ ni, ìwọ kò gbọdọ̀ bá a lòpọ̀. 8 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ tàbùkù baba rẹ nípa bíbá ìyàwó baba rẹ lòpọ̀, nítorí ìhòhò baba rẹ ni. 9 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ bá arábìnrin rẹ tí ó jẹ́ ọmọ ìyá rẹ lòpọ̀, yálà a bí i nílé yín tàbí lóde. 10 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ bá ọmọbìnrin, ọmọ rẹ ọkùnrin lòpọ̀ tàbí ọmọbìnrin ọmọ rẹ obìnrin lòpọ̀ nítorí pé ìhòhò wọn, ìhòhò ìwọ fúnra rẹ̀ ni. 11 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ bá ọmọbìnrin aya baba rẹ lòpọ̀; èyí tí a bí fún baba rẹ nítorí pé arábìnrin rẹ ni. 12 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ bá arábìnrin baba rẹ lòpọ̀ nítorí pé ìbátan baba rẹ ni. 13 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ bá arábìnrin màmá rẹ lòpọ̀ nítorí pé ìbátan ìyá rẹ ni. 14 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ tàbùkù arákùnrin baba rẹ nípa sísún mọ́ aya rẹ̀ láti bá a lòpọ̀ nítorí pé ìyàwó ẹ̀gbọ́n baba rẹ ni. 15 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ bá ọmọ àna obìnrin rẹ lòpọ̀ nítorí pé aya ọmọ rẹ ni. Má ṣe bá a lòpọ̀. 16 “ ‘Má ṣe bá aya ẹ̀gbọ́n rẹ ọkùnrin lòpọ̀ nítorí pé yóò tàbùkù ẹ̀gbọ́n rẹ. 17 “ ‘Má ṣe bá ìyá àti ọmọ rẹ obìnrin lòpọ̀, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò gbọdọ̀ bá ọmọbìnrin ọmọkùnrin rẹ tàbí ọmọbìnrin ọmọbìnrin rẹ lòpọ̀ nítorí pé ìbátan rẹ tímọ́tímọ́ ni: nítorí àbùkù ni. 18 “ ‘Má ṣe fẹ́ àbúrò ìyàwó rẹ obìnrin ní aya gẹ́gẹ́ bí orogún tàbí bá a lòpọ̀, nígbà tí ìyàwó rẹ sì wà láààyè. 19 “ ‘Má ṣe súnmọ́ obìnrin láti bá a lòpọ̀ nígbà tí ó bá ń ṣe nǹkan oṣù, nítorí àkókò àìmọ́ ni. 20 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ bá aya aládùúgbò rẹ lòpọ̀, kí ìwọ má ba à ba ara rẹ jẹ́ pẹ̀lú rẹ̀. 21 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ fi èyíkéyìí nínú àwọn ọmọ rẹ rú ẹbọ lórí pẹpẹ sí òrìṣà Moleki, kí o sì tipa bẹ́ẹ̀ ba orúkọ Ọlọ́run rẹ jẹ́. Èmi ni OLÚWA. 22 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ bá ọkùnrin lòpọ̀ bí ìgbà tí ènìyàn ń bá obìnrin lòpọ̀: ìríra ni èyí jẹ́. 23 “ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ bá ẹranko lòpọ̀ kí ìwọ má ba à ba ara rẹ jẹ́. Obìnrin kò sì gbọdọ̀ jọ̀wọ́ ara rẹ̀ sílẹ̀ fún ẹranko láti bá a lòpọ̀, ohun tó lòdì ni. 24 “ ‘Má ṣe fi àwọn nǹkan wọ̀nyí ba ara rẹ jẹ́, torí pé nínú àwọn nǹkan wọ̀nyí ni àwọn orílẹ̀-èdè tí mo lé kúrò níwájú yín ti ba ara wọn jẹ́. 25 Nítorí pé ilẹ̀ náà di àìmọ́ nítorí náà mo fi ìyà jẹ ẹ́ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀. Ilẹ̀ náà sì pọ àwọn olùgbé ibẹ̀ jáde. 26 Ṣùgbọ́n kí ẹ máa pa àṣẹ àti òfin mi mọ́. Onílé tàbí àjèjì tó ń gbé láàrín yín kò gbọdọ̀ ṣe ọ̀kan nínú àwọn ohun ìríra wọ̀nyí. 27 Nítorí pé gbogbo ohun ìríra wọ̀nyí ni àwọn ènìyàn tí wọ́n ti gbé ilẹ̀ náà ṣáájú yín ti ṣe tí ó sì mú kí ilẹ̀ náà di aláìmọ́. 28 Bí ẹ bá sọ ilẹ̀ náà di àìmọ́ yóò pọ̀ yín jáde bí ó ti pọ àwọn orílẹ̀-èdè tí ó ti wá ṣáájú yín jáde. 29 “ ‘Ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣe ohun ìríra wọ̀nyí, kí ẹ gé irú ẹni náà kúrò láàrín àwọn ènìyàn. 30 Nítorí náà ẹ gbọdọ̀ ṣe ohun tí mo fẹ́, kí ẹ má sì lọ́wọ́ nínú àṣà ìríra wọ̀nyí, tí wọn ń ṣe kí ẹ tó dé. Ẹ má ṣe fi wọ́n ba ara yín jẹ́. Èmi ni OLÚWA Ọlọ́run yín.’ ”
In Other Versions
Leviticus 18 in the ANGEFD
Leviticus 18 in the ANTPNG2D
Leviticus 18 in the AS21
Leviticus 18 in the BAGH
Leviticus 18 in the BBPNG
Leviticus 18 in the BBT1E
Leviticus 18 in the BDS
Leviticus 18 in the BEV
Leviticus 18 in the BHAD
Leviticus 18 in the BIB
Leviticus 18 in the BLPT
Leviticus 18 in the BNT
Leviticus 18 in the BNTABOOT
Leviticus 18 in the BNTLV
Leviticus 18 in the BOATCB
Leviticus 18 in the BOATCB2
Leviticus 18 in the BOBCV
Leviticus 18 in the BOCNT
Leviticus 18 in the BOECS
Leviticus 18 in the BOGWICC
Leviticus 18 in the BOHCB
Leviticus 18 in the BOHCV
Leviticus 18 in the BOHLNT
Leviticus 18 in the BOHNTLTAL
Leviticus 18 in the BOICB
Leviticus 18 in the BOILNTAP
Leviticus 18 in the BOITCV
Leviticus 18 in the BOKCV
Leviticus 18 in the BOKCV2
Leviticus 18 in the BOKHWOG
Leviticus 18 in the BOKSSV
Leviticus 18 in the BOLCB
Leviticus 18 in the BOLCB2
Leviticus 18 in the BOMCV
Leviticus 18 in the BONAV
Leviticus 18 in the BONCB
Leviticus 18 in the BONLT
Leviticus 18 in the BONUT2
Leviticus 18 in the BOPLNT
Leviticus 18 in the BOSCB
Leviticus 18 in the BOSNC
Leviticus 18 in the BOTLNT
Leviticus 18 in the BOVCB
Leviticus 18 in the BPBB
Leviticus 18 in the BPH
Leviticus 18 in the BSB
Leviticus 18 in the CCB
Leviticus 18 in the CUV
Leviticus 18 in the CUVS
Leviticus 18 in the DBT
Leviticus 18 in the DGDNT
Leviticus 18 in the DHNT
Leviticus 18 in the DNT
Leviticus 18 in the ELBE
Leviticus 18 in the EMTV
Leviticus 18 in the ESV
Leviticus 18 in the FBV
Leviticus 18 in the FEB
Leviticus 18 in the GGMNT
Leviticus 18 in the GNT
Leviticus 18 in the HARY
Leviticus 18 in the HNT
Leviticus 18 in the IRVA
Leviticus 18 in the IRVB
Leviticus 18 in the IRVG
Leviticus 18 in the IRVH
Leviticus 18 in the IRVK
Leviticus 18 in the IRVM
Leviticus 18 in the IRVM2
Leviticus 18 in the IRVO
Leviticus 18 in the IRVP
Leviticus 18 in the IRVT
Leviticus 18 in the IRVT2
Leviticus 18 in the IRVU
Leviticus 18 in the ISVN
Leviticus 18 in the JSNT
Leviticus 18 in the KAPI
Leviticus 18 in the KBT1ETNIK
Leviticus 18 in the KBV
Leviticus 18 in the KJV
Leviticus 18 in the KNFD
Leviticus 18 in the LBA
Leviticus 18 in the LBLA
Leviticus 18 in the LNT
Leviticus 18 in the LSV
Leviticus 18 in the MAAL
Leviticus 18 in the MBV
Leviticus 18 in the MBV2
Leviticus 18 in the MHNT
Leviticus 18 in the MKNFD
Leviticus 18 in the MNG
Leviticus 18 in the MNT
Leviticus 18 in the MNT2
Leviticus 18 in the MRS1T
Leviticus 18 in the NAA
Leviticus 18 in the NASB
Leviticus 18 in the NBLA
Leviticus 18 in the NBS
Leviticus 18 in the NBVTP
Leviticus 18 in the NET2
Leviticus 18 in the NIV11
Leviticus 18 in the NNT
Leviticus 18 in the NNT2
Leviticus 18 in the NNT3
Leviticus 18 in the PDDPT
Leviticus 18 in the PFNT
Leviticus 18 in the RMNT
Leviticus 18 in the SBIAS
Leviticus 18 in the SBIBS
Leviticus 18 in the SBIBS2
Leviticus 18 in the SBICS
Leviticus 18 in the SBIDS
Leviticus 18 in the SBIGS
Leviticus 18 in the SBIHS
Leviticus 18 in the SBIIS
Leviticus 18 in the SBIIS2
Leviticus 18 in the SBIIS3
Leviticus 18 in the SBIKS
Leviticus 18 in the SBIKS2
Leviticus 18 in the SBIMS
Leviticus 18 in the SBIOS
Leviticus 18 in the SBIPS
Leviticus 18 in the SBISS
Leviticus 18 in the SBITS
Leviticus 18 in the SBITS2
Leviticus 18 in the SBITS3
Leviticus 18 in the SBITS4
Leviticus 18 in the SBIUS
Leviticus 18 in the SBIVS
Leviticus 18 in the SBT
Leviticus 18 in the SBT1E
Leviticus 18 in the SCHL
Leviticus 18 in the SNT
Leviticus 18 in the SUSU
Leviticus 18 in the SUSU2
Leviticus 18 in the SYNO
Leviticus 18 in the TBIAOTANT
Leviticus 18 in the TBT1E
Leviticus 18 in the TBT1E2
Leviticus 18 in the TFTIP
Leviticus 18 in the TFTU
Leviticus 18 in the TGNTATF3T
Leviticus 18 in the THAI
Leviticus 18 in the TNFD
Leviticus 18 in the TNT
Leviticus 18 in the TNTIK
Leviticus 18 in the TNTIL
Leviticus 18 in the TNTIN
Leviticus 18 in the TNTIP
Leviticus 18 in the TNTIZ
Leviticus 18 in the TOMA
Leviticus 18 in the TTENT
Leviticus 18 in the UBG
Leviticus 18 in the UGV
Leviticus 18 in the UGV2
Leviticus 18 in the UGV3
Leviticus 18 in the VBL
Leviticus 18 in the VDCC
Leviticus 18 in the YALU
Leviticus 18 in the YAPE
Leviticus 18 in the YBVTP
Leviticus 18 in the ZBP