Micah 6 (BOYCB)

1 Ẹ fi etí sí ohun tí OLÚWA wí:“Dìde dúró, bẹ ẹ̀bẹ̀ fún ẹjọ́ rẹ níwájú òkè ńlá;sì jẹ́ kí àwọn òkè kéékèèké gbọ́ ohun tí ó fẹ́ wí. 2 “Gbọ́, ìwọ òkè ńlá, ẹ̀sùn OLÚWA;gbọ́, ìwọ ìpìlẹ̀ ilé ayérayé.Nítorí OLÚWA ń bá àwọn ènìyàn rẹ̀ wíjọ́;òun yóò sì bá Israẹli rojọ́. 3 “Ẹ̀yin ènìyàn mi, kí ni mo ṣe fún yín?Àti nínú kí ni mo ti dá yin lágara? Dá mi lóhùn. 4 Nítorí èmi mú un yín gòkè láti ilẹ̀ Ejibiti wá,mo sì rà yín padà láti ilẹ̀ ẹrú wá.Mo rán Mose láti darí yín,bákan náà mo rán Aaroni àti Miriamu síwájú rẹ̀. 5 Ìwọ ènìyàn mi,rántí ohun tí Balaki ọba Moabu gbèròàti ohun tí Balaamu ọmọ Beori dáhùn.Rántí ìrìnàjò rẹ̀ láti Ṣittimu dé Gilgali,kí ìwọ ba le mọ òdodo OLÚWA.” 6 Kí ni èmi yóò ha mú wá síwájú OLÚWAtí èmi ó fi tẹ ara mi ba níwájú Ọlọ́run gíga?Kí èmi ha wá sí iwájú rẹ̀ pẹ̀lú ọrẹ ẹbọ sísun,pẹ̀lú ọmọ màlúù ọlọ́dún kan? 7 Ǹjẹ́ OLÚWA yóò ní inú dídùn sí ẹgbẹgbàarùn-ún àgbò,tàbí sí ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ìṣàn òróró?Èmi yóò ha fi àkọ́bí mi sílẹ̀ fún ìré-òfin-kọjá mi,èso inú ara mi fún ẹ̀ṣẹ̀ ọkàn mi? 8 Ó ti fihàn ọ́, ìwọ ènìyàn, ohun tí ó dára,àti ohun tí OLÚWA ń béèrè lọ́wọ́ rẹ?Bí kò ṣe láti ṣe òtítọ́, kí o sì fẹ́ràn àánú,àti kí o rìn ní ìrẹ̀lẹ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run rẹ̀. 9 Gbọ́! Ohùn OLÚWA kígbe sí ìlú ńlá náà,láti jẹ ọlọ́gbọ́n ni láti bẹ̀rù orúkọ rẹ.“Ẹ kíyèsi ọ̀pá rẹ̀ gbọ́ ọ̀pá àti Ẹni náà tí ó yàn án. 10 Ǹjẹ́ ìṣúra ìwà búburú ha wàní ilé ènìyàn búburú síbẹ̀,àti òsùwọ̀n àìkún tí ó jẹ́ ohun ìbínú? 11 Ǹjẹ́ èmi ha lè kà wọ́n sí mímọ́pẹ̀lú òsùwọ̀n búburú,pẹ̀lú àpò òsùwọ̀n ẹ̀tàn? 12 Àwọn ọlọ́rọ̀ inú rẹ̀ kún fún ìwà ipá;àwọn tí ń gbé inú rẹ̀ ti ọ̀rọ̀ èkéàti ahọ́n wọn ń sọ ẹ̀tàn? 13 Nítorí náà ni èmi yóò ṣe mú ọ ṣàìsàn ní lílù ọ́,láti sọ ọ́ dahoro nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ. 14 Ìwọ yóò jẹun ṣùgbọ́n kì yóò yó;ìyàn yóò wà láàrín rẹ.Ìwọ yóò kó pamọ́, ṣùgbọ́n ìwọ kì yóò lò láìléwu,nítorí ohun tí ìwọ kò pamọ́ ni èmi yóò fi fún idà. 15 Ìwọ yóò gbìn ṣùgbọ́n ìwọ kì yóò kórèìwọ yóò tẹ olifi,ṣùgbọ́n ìwọ kì yóò fi òróró rẹ̀ kún ara rẹ;ìwọ yóò tẹ èso àjàrà, ṣùgbọ́n ìwọ kì yóò mu wáìnì. 16 Nítorí tí ìwọ ti pa òfin Omri mọ́,àti gbogbo iṣẹ́ ilé Ahabu,tí ó sì ti tẹ̀lé ìmọ̀ràn wọn,nítorí náà ni èmi yóò ṣe mú ọ fún ìparunàti àwọn ènìyàn rẹ fún ìfiṣe ẹlẹ́yà;ìwọ yóò sì ru ẹ̀gàn àwọn ènìyàn mi.”

In Other Versions

Micah 6 in the ANGEFD

Micah 6 in the ANTPNG2D

Micah 6 in the AS21

Micah 6 in the BAGH

Micah 6 in the BBPNG

Micah 6 in the BBT1E

Micah 6 in the BDS

Micah 6 in the BEV

Micah 6 in the BHAD

Micah 6 in the BIB

Micah 6 in the BLPT

Micah 6 in the BNT

Micah 6 in the BNTABOOT

Micah 6 in the BNTLV

Micah 6 in the BOATCB

Micah 6 in the BOATCB2

Micah 6 in the BOBCV

Micah 6 in the BOCNT

Micah 6 in the BOECS

Micah 6 in the BOGWICC

Micah 6 in the BOHCB

Micah 6 in the BOHCV

Micah 6 in the BOHLNT

Micah 6 in the BOHNTLTAL

Micah 6 in the BOICB

Micah 6 in the BOILNTAP

Micah 6 in the BOITCV

Micah 6 in the BOKCV

Micah 6 in the BOKCV2

Micah 6 in the BOKHWOG

Micah 6 in the BOKSSV

Micah 6 in the BOLCB

Micah 6 in the BOLCB2

Micah 6 in the BOMCV

Micah 6 in the BONAV

Micah 6 in the BONCB

Micah 6 in the BONLT

Micah 6 in the BONUT2

Micah 6 in the BOPLNT

Micah 6 in the BOSCB

Micah 6 in the BOSNC

Micah 6 in the BOTLNT

Micah 6 in the BOVCB

Micah 6 in the BPBB

Micah 6 in the BPH

Micah 6 in the BSB

Micah 6 in the CCB

Micah 6 in the CUV

Micah 6 in the CUVS

Micah 6 in the DBT

Micah 6 in the DGDNT

Micah 6 in the DHNT

Micah 6 in the DNT

Micah 6 in the ELBE

Micah 6 in the EMTV

Micah 6 in the ESV

Micah 6 in the FBV

Micah 6 in the FEB

Micah 6 in the GGMNT

Micah 6 in the GNT

Micah 6 in the HARY

Micah 6 in the HNT

Micah 6 in the IRVA

Micah 6 in the IRVB

Micah 6 in the IRVG

Micah 6 in the IRVH

Micah 6 in the IRVK

Micah 6 in the IRVM

Micah 6 in the IRVM2

Micah 6 in the IRVO

Micah 6 in the IRVP

Micah 6 in the IRVT

Micah 6 in the IRVT2

Micah 6 in the IRVU

Micah 6 in the ISVN

Micah 6 in the JSNT

Micah 6 in the KAPI

Micah 6 in the KBT1ETNIK

Micah 6 in the KBV

Micah 6 in the KJV

Micah 6 in the KNFD

Micah 6 in the LBA

Micah 6 in the LBLA

Micah 6 in the LNT

Micah 6 in the LSV

Micah 6 in the MAAL

Micah 6 in the MBV

Micah 6 in the MBV2

Micah 6 in the MHNT

Micah 6 in the MKNFD

Micah 6 in the MNG

Micah 6 in the MNT

Micah 6 in the MNT2

Micah 6 in the MRS1T

Micah 6 in the NAA

Micah 6 in the NASB

Micah 6 in the NBLA

Micah 6 in the NBS

Micah 6 in the NBVTP

Micah 6 in the NET2

Micah 6 in the NIV11

Micah 6 in the NNT

Micah 6 in the NNT2

Micah 6 in the NNT3

Micah 6 in the PDDPT

Micah 6 in the PFNT

Micah 6 in the RMNT

Micah 6 in the SBIAS

Micah 6 in the SBIBS

Micah 6 in the SBIBS2

Micah 6 in the SBICS

Micah 6 in the SBIDS

Micah 6 in the SBIGS

Micah 6 in the SBIHS

Micah 6 in the SBIIS

Micah 6 in the SBIIS2

Micah 6 in the SBIIS3

Micah 6 in the SBIKS

Micah 6 in the SBIKS2

Micah 6 in the SBIMS

Micah 6 in the SBIOS

Micah 6 in the SBIPS

Micah 6 in the SBISS

Micah 6 in the SBITS

Micah 6 in the SBITS2

Micah 6 in the SBITS3

Micah 6 in the SBITS4

Micah 6 in the SBIUS

Micah 6 in the SBIVS

Micah 6 in the SBT

Micah 6 in the SBT1E

Micah 6 in the SCHL

Micah 6 in the SNT

Micah 6 in the SUSU

Micah 6 in the SUSU2

Micah 6 in the SYNO

Micah 6 in the TBIAOTANT

Micah 6 in the TBT1E

Micah 6 in the TBT1E2

Micah 6 in the TFTIP

Micah 6 in the TFTU

Micah 6 in the TGNTATF3T

Micah 6 in the THAI

Micah 6 in the TNFD

Micah 6 in the TNT

Micah 6 in the TNTIK

Micah 6 in the TNTIL

Micah 6 in the TNTIN

Micah 6 in the TNTIP

Micah 6 in the TNTIZ

Micah 6 in the TOMA

Micah 6 in the TTENT

Micah 6 in the UBG

Micah 6 in the UGV

Micah 6 in the UGV2

Micah 6 in the UGV3

Micah 6 in the VBL

Micah 6 in the VDCC

Micah 6 in the YALU

Micah 6 in the YAPE

Micah 6 in the YBVTP

Micah 6 in the ZBP