Proverbs 2 (BOYCB)
1 Ọmọ mi, bí ìwọ bá gba ọ̀rọ̀ mi,tí ìwọ sì pa òfin mi mọ́ sí inú rẹ, 2 tí ìwọ dẹtí rẹ sílẹ̀ sí ọgbọ́ntí ìwọ sì fi ọkàn rẹ sí òye, 3 àní, bí ìwọ bá ké tọ ìmọ̀ lẹ́yìn,tí ìwọ sì gbé ohùn rẹ sókè fún òye 4 bí ìwọ bá ṣàfẹ́rí rẹ̀ bí i fàdákàtí ìwọ sì wa kiri bí ìṣúra tí a fi pamọ́. 5 Nígbà náà ni ìwọ yóò bẹ̀rù OLÚWA,ìwọ yóò sì rí ìmọ̀ Ọlọ́run. 6 Nítorí OLÚWA ni ó ń fún ni ní ọgbọ́n,láti ẹnu rẹ̀ sì ni ìmọ̀ àti òye ti ń wá. 7 Ó to ìgbàlà fún àwọn olódodo,Òun ni asà fún àwọn tí ń rìn déédé, 8 Ó pa ipa ọ̀nà ìdájọ́ mọ́Ó sì ń pa ọ̀nà àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ mọ́. 9 Nígbà náà ni ìwọ yóò mọ òdodo àti ìdájọ́,àti àìṣègbè—gbogbo ipa ọ̀nà rere. 10 Nítorí ọgbọ́n yóò wọ inú ọkàn rẹìmọ̀ yóò sì jẹ́ ìtura fún ọkàn rẹ. 11 Ìmòye yóò pa ọ mọ́òye yóò sì máa ṣọ́ ọ. 12 Ọgbọ́n yóò gbà ọ́ là kúrò ní ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú,lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn tí ọrọ̀ ọ wọn jẹ́ àyídáyidà, 13 ẹni tí ó kúrò ní ọ̀nà ìdúró ṣinṣinláti rìn ní ọ̀nà tí ó ṣókùnkùn, 14 ẹni tí ó yọ̀ nínú ṣíṣe búburú,tí ó ṣe inú dídùn sí àyídáyidà àwọn ènìyàn ibi, 15 ọ̀nà ẹni tí ó wọ́tí wọ́n sì jẹ́ alárékérekè ní ọ̀nà wọn. 16 Yóò gba ìwọ pẹ̀lú là kúrò lọ́wọ́ àwọn àjèjì obìnrin,àní, lọ́wọ́ obìnrin àjèjì tí ń fi ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ tannijẹ, 17 ẹni tí ó ti kọ ọkọ àkọ́fẹ́ ìgbà èwe rẹ̀ sílẹ̀tí ó sì gbàgbé májẹ̀mú tí ó ti dá níwájú Ọlọ́run rẹ̀. 18 Nítorí ilé rẹ̀ jẹ́ ọ̀nà sí ikúipa ọ̀nà rẹ̀ sọ́dọ̀ àwọn òkú. 19 Kò sẹ́ni tó lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ tí ó padàbẹ́ẹ̀ ni wọn kì í dé ọ̀nà ìyè. 20 Bẹ́ẹ̀ ni ìwọ yóò rìn ní ọ̀nà àwọn ènìyàn rerekí ìwọ kí ó sì pa ọ̀nà àwọn olódodo mọ́. 21 Nítorí ẹni dídúró ṣinṣin yóò gbé ní ilé náààwọn aláìlẹ́gàn sì ni yóò máa wà nínú rẹ̀. 22 Ṣùgbọ́n a ó ké ènìyàn búburú kúrò lórí ilẹ̀ náàa ó sì fa àwọn aláìṣòótọ́ tu kúrò lórí rẹ̀.
In Other Versions
Proverbs 2 in the ANGEFD
Proverbs 2 in the ANTPNG2D
Proverbs 2 in the AS21
Proverbs 2 in the BAGH
Proverbs 2 in the BBPNG
Proverbs 2 in the BBT1E
Proverbs 2 in the BDS
Proverbs 2 in the BEV
Proverbs 2 in the BHAD
Proverbs 2 in the BIB
Proverbs 2 in the BLPT
Proverbs 2 in the BNT
Proverbs 2 in the BNTABOOT
Proverbs 2 in the BNTLV
Proverbs 2 in the BOATCB
Proverbs 2 in the BOATCB2
Proverbs 2 in the BOBCV
Proverbs 2 in the BOCNT
Proverbs 2 in the BOECS
Proverbs 2 in the BOGWICC
Proverbs 2 in the BOHCB
Proverbs 2 in the BOHCV
Proverbs 2 in the BOHLNT
Proverbs 2 in the BOHNTLTAL
Proverbs 2 in the BOICB
Proverbs 2 in the BOILNTAP
Proverbs 2 in the BOITCV
Proverbs 2 in the BOKCV
Proverbs 2 in the BOKCV2
Proverbs 2 in the BOKHWOG
Proverbs 2 in the BOKSSV
Proverbs 2 in the BOLCB
Proverbs 2 in the BOLCB2
Proverbs 2 in the BOMCV
Proverbs 2 in the BONAV
Proverbs 2 in the BONCB
Proverbs 2 in the BONLT
Proverbs 2 in the BONUT2
Proverbs 2 in the BOPLNT
Proverbs 2 in the BOSCB
Proverbs 2 in the BOSNC
Proverbs 2 in the BOTLNT
Proverbs 2 in the BOVCB
Proverbs 2 in the BPBB
Proverbs 2 in the BPH
Proverbs 2 in the BSB
Proverbs 2 in the CCB
Proverbs 2 in the CUV
Proverbs 2 in the CUVS
Proverbs 2 in the DBT
Proverbs 2 in the DGDNT
Proverbs 2 in the DHNT
Proverbs 2 in the DNT
Proverbs 2 in the ELBE
Proverbs 2 in the EMTV
Proverbs 2 in the ESV
Proverbs 2 in the FBV
Proverbs 2 in the FEB
Proverbs 2 in the GGMNT
Proverbs 2 in the GNT
Proverbs 2 in the HARY
Proverbs 2 in the HNT
Proverbs 2 in the IRVA
Proverbs 2 in the IRVB
Proverbs 2 in the IRVG
Proverbs 2 in the IRVH
Proverbs 2 in the IRVK
Proverbs 2 in the IRVM
Proverbs 2 in the IRVM2
Proverbs 2 in the IRVO
Proverbs 2 in the IRVP
Proverbs 2 in the IRVT
Proverbs 2 in the IRVT2
Proverbs 2 in the IRVU
Proverbs 2 in the ISVN
Proverbs 2 in the JSNT
Proverbs 2 in the KAPI
Proverbs 2 in the KBT1ETNIK
Proverbs 2 in the KBV
Proverbs 2 in the KJV
Proverbs 2 in the KNFD
Proverbs 2 in the LBA
Proverbs 2 in the LBLA
Proverbs 2 in the LNT
Proverbs 2 in the LSV
Proverbs 2 in the MAAL
Proverbs 2 in the MBV
Proverbs 2 in the MBV2
Proverbs 2 in the MHNT
Proverbs 2 in the MKNFD
Proverbs 2 in the MNG
Proverbs 2 in the MNT
Proverbs 2 in the MNT2
Proverbs 2 in the MRS1T
Proverbs 2 in the NAA
Proverbs 2 in the NASB
Proverbs 2 in the NBLA
Proverbs 2 in the NBS
Proverbs 2 in the NBVTP
Proverbs 2 in the NET2
Proverbs 2 in the NIV11
Proverbs 2 in the NNT
Proverbs 2 in the NNT2
Proverbs 2 in the NNT3
Proverbs 2 in the PDDPT
Proverbs 2 in the PFNT
Proverbs 2 in the RMNT
Proverbs 2 in the SBIAS
Proverbs 2 in the SBIBS
Proverbs 2 in the SBIBS2
Proverbs 2 in the SBICS
Proverbs 2 in the SBIDS
Proverbs 2 in the SBIGS
Proverbs 2 in the SBIHS
Proverbs 2 in the SBIIS
Proverbs 2 in the SBIIS2
Proverbs 2 in the SBIIS3
Proverbs 2 in the SBIKS
Proverbs 2 in the SBIKS2
Proverbs 2 in the SBIMS
Proverbs 2 in the SBIOS
Proverbs 2 in the SBIPS
Proverbs 2 in the SBISS
Proverbs 2 in the SBITS
Proverbs 2 in the SBITS2
Proverbs 2 in the SBITS3
Proverbs 2 in the SBITS4
Proverbs 2 in the SBIUS
Proverbs 2 in the SBIVS
Proverbs 2 in the SBT
Proverbs 2 in the SBT1E
Proverbs 2 in the SCHL
Proverbs 2 in the SNT
Proverbs 2 in the SUSU
Proverbs 2 in the SUSU2
Proverbs 2 in the SYNO
Proverbs 2 in the TBIAOTANT
Proverbs 2 in the TBT1E
Proverbs 2 in the TBT1E2
Proverbs 2 in the TFTIP
Proverbs 2 in the TFTU
Proverbs 2 in the TGNTATF3T
Proverbs 2 in the THAI
Proverbs 2 in the TNFD
Proverbs 2 in the TNT
Proverbs 2 in the TNTIK
Proverbs 2 in the TNTIL
Proverbs 2 in the TNTIN
Proverbs 2 in the TNTIP
Proverbs 2 in the TNTIZ
Proverbs 2 in the TOMA
Proverbs 2 in the TTENT
Proverbs 2 in the UBG
Proverbs 2 in the UGV
Proverbs 2 in the UGV2
Proverbs 2 in the UGV3
Proverbs 2 in the VBL
Proverbs 2 in the VDCC
Proverbs 2 in the YALU
Proverbs 2 in the YAPE
Proverbs 2 in the YBVTP
Proverbs 2 in the ZBP