Psalms 10 (BOYCB)
1 Èéha ti ṣe, OLÚWA, tí ìwọ fi dúró ní òkè réré?Èéha ti ṣe, tí ìwọ fi ara rẹ pamọ́ ní ìgbà ìpọ́njú? 2 Nínú àrékérekè ni ènìyàn búburú tí mu aláìlera,ẹni ti ó mú nínú ìdẹ̀kùn àrékérekè rẹ̀. 3 Nítorí ènìyàn búburú ń ṣògo ìfẹ́ inú ọkàn rẹ̀;Ó bùkún olójúkòkòrò, ó sì ń kẹ́gàn OLÚWA. 4 Ènìyàn búburú kò lè rí nínú ìgbéraga rẹ̀;kò sí ààyè fún Ọlọ́run nínú gbogbo èrò rẹ̀. 5 Ọ̀nà rẹ̀ ń gún régé nígbà gbogbo;òun ń gbéraga, òfin rẹ̀ sì jìnnà sí i;òun kẹ́gàn àwọn ọ̀tá rẹ̀. 6 O wí fún ara rẹ̀, “Kò sí ohun tí ó lè mì mí.Inú mi yóò máa dùn nígbà gbogbo, èmi kò sì ní ní wàhálà.” 7 Ẹnu rẹ̀ kún fún ègún àti irọ́ àti ìtànjẹ;wàhálà àti ohun búburú wà lábẹ́ ahọ́n rẹ̀. 8 Ó lúgọ ní bùba nítòsí ìletò.Ò gọ níbi ìkọ̀kọ̀ láti pa aláìṣẹ̀.Ojú rẹ̀ ń ṣọ́ àwọn tálákà ní ìkọ̀kọ̀. 9 Ó ba ní ní bùba bí i kìnnìún nínú pàǹtí;Ó ba ní bùba láti mú àwọn aláìní ìrànwọ́;ó mú àwọn aláìlólùrànlọ́wọ́, ó sì wọ́ wọn lọ sínú àwọ̀n rẹ̀. 10 Ó ba, ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀;kí tálákà ba à le bọ́ sí ọwọ́ agbára rẹ̀. 11 Ó wí fún ara rẹ̀, “Ọlọ́run ti gbàgbé;Ó pa ojú rẹ̀ mọ́, òun kì yóò rí i láéláé.” 12 Dìde, OLÚWA! Gbé ọwọ́ rẹ sókè, Ọlọ́run.Má ṣe gbàgbé àwọn olùpọ́njú. 13 Èéṣe tí ènìyàn búburú ṣe ń kẹ́gàn Ọlọ́run?Èéṣe tí o fi wí nínú ọkàn ara rẹ̀,“Kò ní pè mí láti ṣe ìṣirò”? 14 Ṣùgbọ́n ìwọ, Ọlọ́run, ni ó rí wàhálà àti ìrora;Ìwọ rò láti fi sí ọwọ́ rẹ.Tálákà fi ara rẹ̀ jì fún ọ;Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ àwọn aláìní baba. 15 Ṣẹ́ apá àwọn ènìyàn búburú àti ènìyàn ibi;pè é láti wá ṣírò fún ìwà ìkà rẹ̀tí a kò le è rí. 16 OLÚWA ń jẹ ọba láé àti láéláé;àwọn orílẹ̀-èdè yóò ṣègbé lórí ilé rẹ. 17 Ìwọ́ gbọ́, OLÚWA, ìfẹ́ àwọn tí a ni lára;Ìwọ gbà wọ́n níyànjú, ó sì gbọ́ igbe wọn, 18 láti ṣe ìdájọ́ àwọn aláìní baba àti àwọn ti a ni lára,kí ọkùnrin, tí ó wà ní ayé,kí ó má ṣe dẹ́rùbà ni mọ́.
In Other Versions
Psalms 10 in the ANGEFD
Psalms 10 in the ANTPNG2D
Psalms 10 in the AS21
Psalms 10 in the BAGH
Psalms 10 in the BBPNG
Psalms 10 in the BBT1E
Psalms 10 in the BDS
Psalms 10 in the BEV
Psalms 10 in the BHAD
Psalms 10 in the BIB
Psalms 10 in the BLPT
Psalms 10 in the BNT
Psalms 10 in the BNTABOOT
Psalms 10 in the BNTLV
Psalms 10 in the BOATCB
Psalms 10 in the BOATCB2
Psalms 10 in the BOBCV
Psalms 10 in the BOCNT
Psalms 10 in the BOECS
Psalms 10 in the BOGWICC
Psalms 10 in the BOHCB
Psalms 10 in the BOHCV
Psalms 10 in the BOHLNT
Psalms 10 in the BOHNTLTAL
Psalms 10 in the BOICB
Psalms 10 in the BOILNTAP
Psalms 10 in the BOITCV
Psalms 10 in the BOKCV
Psalms 10 in the BOKCV2
Psalms 10 in the BOKHWOG
Psalms 10 in the BOKSSV
Psalms 10 in the BOLCB
Psalms 10 in the BOLCB2
Psalms 10 in the BOMCV
Psalms 10 in the BONAV
Psalms 10 in the BONCB
Psalms 10 in the BONLT
Psalms 10 in the BONUT2
Psalms 10 in the BOPLNT
Psalms 10 in the BOSCB
Psalms 10 in the BOSNC
Psalms 10 in the BOTLNT
Psalms 10 in the BOVCB
Psalms 10 in the BPBB
Psalms 10 in the BPH
Psalms 10 in the BSB
Psalms 10 in the CCB
Psalms 10 in the CUV
Psalms 10 in the CUVS
Psalms 10 in the DBT
Psalms 10 in the DGDNT
Psalms 10 in the DHNT
Psalms 10 in the DNT
Psalms 10 in the ELBE
Psalms 10 in the EMTV
Psalms 10 in the ESV
Psalms 10 in the FBV
Psalms 10 in the FEB
Psalms 10 in the GGMNT
Psalms 10 in the GNT
Psalms 10 in the HARY
Psalms 10 in the HNT
Psalms 10 in the IRVA
Psalms 10 in the IRVB
Psalms 10 in the IRVG
Psalms 10 in the IRVH
Psalms 10 in the IRVK
Psalms 10 in the IRVM
Psalms 10 in the IRVM2
Psalms 10 in the IRVO
Psalms 10 in the IRVP
Psalms 10 in the IRVT
Psalms 10 in the IRVT2
Psalms 10 in the IRVU
Psalms 10 in the ISVN
Psalms 10 in the JSNT
Psalms 10 in the KAPI
Psalms 10 in the KBT1ETNIK
Psalms 10 in the KBV
Psalms 10 in the KJV
Psalms 10 in the KNFD
Psalms 10 in the LBA
Psalms 10 in the LBLA
Psalms 10 in the LNT
Psalms 10 in the LSV
Psalms 10 in the MAAL
Psalms 10 in the MBV
Psalms 10 in the MBV2
Psalms 10 in the MHNT
Psalms 10 in the MKNFD
Psalms 10 in the MNG
Psalms 10 in the MNT
Psalms 10 in the MNT2
Psalms 10 in the MRS1T
Psalms 10 in the NAA
Psalms 10 in the NASB
Psalms 10 in the NBLA
Psalms 10 in the NBS
Psalms 10 in the NBVTP
Psalms 10 in the NET2
Psalms 10 in the NIV11
Psalms 10 in the NNT
Psalms 10 in the NNT2
Psalms 10 in the NNT3
Psalms 10 in the PDDPT
Psalms 10 in the PFNT
Psalms 10 in the RMNT
Psalms 10 in the SBIAS
Psalms 10 in the SBIBS
Psalms 10 in the SBIBS2
Psalms 10 in the SBICS
Psalms 10 in the SBIDS
Psalms 10 in the SBIGS
Psalms 10 in the SBIHS
Psalms 10 in the SBIIS
Psalms 10 in the SBIIS2
Psalms 10 in the SBIIS3
Psalms 10 in the SBIKS
Psalms 10 in the SBIKS2
Psalms 10 in the SBIMS
Psalms 10 in the SBIOS
Psalms 10 in the SBIPS
Psalms 10 in the SBISS
Psalms 10 in the SBITS
Psalms 10 in the SBITS2
Psalms 10 in the SBITS3
Psalms 10 in the SBITS4
Psalms 10 in the SBIUS
Psalms 10 in the SBIVS
Psalms 10 in the SBT
Psalms 10 in the SBT1E
Psalms 10 in the SCHL
Psalms 10 in the SNT
Psalms 10 in the SUSU
Psalms 10 in the SUSU2
Psalms 10 in the SYNO
Psalms 10 in the TBIAOTANT
Psalms 10 in the TBT1E
Psalms 10 in the TBT1E2
Psalms 10 in the TFTIP
Psalms 10 in the TFTU
Psalms 10 in the TGNTATF3T
Psalms 10 in the THAI
Psalms 10 in the TNFD
Psalms 10 in the TNT
Psalms 10 in the TNTIK
Psalms 10 in the TNTIL
Psalms 10 in the TNTIN
Psalms 10 in the TNTIP
Psalms 10 in the TNTIZ
Psalms 10 in the TOMA
Psalms 10 in the TTENT
Psalms 10 in the UBG
Psalms 10 in the UGV
Psalms 10 in the UGV2
Psalms 10 in the UGV3
Psalms 10 in the VBL
Psalms 10 in the VDCC
Psalms 10 in the YALU
Psalms 10 in the YAPE
Psalms 10 in the YBVTP
Psalms 10 in the ZBP