Psalms 117 (BOYCB)
1 Ẹ yin OLÚWA, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè;ẹ pòkìkí rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn. 2 Nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí ó ní sí wa,àti òtítọ́ OLÚWA dúró láéláé. Ẹ yin OLÚWA!