Zechariah 11 (BOYCB)
1 Ṣí àwọn ìlẹ̀kùn rẹ sílẹ̀, ìwọ Lebanoni,kí iná bá lè jẹ igi kedari rẹ run. 2 Hu, igi junifa; nítorí igi kedari ṣubú,nítorí tí a ba àwọn igi tí o lógo jẹ́:hu, ẹ̀yin igi óákù tí Baṣani,nítorí gé igbó àjàrà lulẹ̀. 3 Gbọ́ ohun igbe àwọn olùṣọ́-àgùntàn;ògo wọn bàjẹ́;gbọ́ ohùn bíbú àwọn ọmọ kìnnìúnnítorí ògo Jordani bàjẹ́. 4 Báyìí ni OLÚWA Ọlọ́run mi wí: “Bọ́ ọ̀wọ́ ẹran àbọ́pa. 5 Tí àwọn olúwa wọn ń pa wọ́n, tí wọn kò sì ka ara wọn sí pé wọn jẹ̀bi: àti àwọn tí ń tà wọ́n wí pé, ‘Ìbùkún ni fún OLÚWA, nítorí tí mo dí ọlọ́rọ̀!’ Àwọn olùṣọ́-àgùntàn wọn kò sì ṣàánú wọn. 6 Nítorí èmi kì yóò ṣàánú fún àwọn ara ilẹ̀ náà mọ́,” ni OLÚWA wí, “Ṣí kíyèsi í, èmi yóò fi olúkúlùkù ènìyàn lé aládùúgbò rẹ̀ lọ́wọ́, àti lé ọwọ́ ọba rẹ̀, wọn yóò sì fọ́ ilẹ̀ náà, èmi kì yóò sì gbà wọ́n lọ́wọ́ wọn.” 7 Èmi yóò sì bọ́ ẹran àbọ́pa, àní ẹ̀yin òtòṣì nínú ọ̀wọ́ ẹran. Mo sì mu ọ̀pá méjì sọ́dọ̀; mo pè ọ̀kan ni Oore-ọ̀fẹ́, mo pè èkejì ni Àmùrè; mo sì bọ́ ọ̀wọ́ ẹran náà. 8 Olùṣọ́-àgùntàn mẹ́ta ni mo sì gé kúrò ní oṣù kan.Ọkàn mi sì kórìíra wọn, ọkàn wọn pẹ̀lú sì kórìíra mi. 9 Mo sì wí pé, “Èmi kì yóò bọ́ yin: èyí ti ń ku lọ, jẹ́ kí òkú o kú; èyí tí a o ba sì gé kúrò, jẹ́ kí a gé e kúrò; ki olúkúlùkù nínú àwọn ìyókù jẹ́ ẹran-ara ẹnìkejì rẹ̀.” 10 Mo sì mu ọ̀pá mi, ti a ń pè ní Oore-ọ̀fẹ́, mo ṣẹ́ si méjì, ki èmi bá lè da májẹ̀mú mi tí mo tí bá gbogbo àwọn ènìyàn náà dá. 11 Ó sì dá ni ọjọ́ náà, bẹ́ẹ̀ ni àwọn òtòṣì nínú ọ̀wọ́ ẹran náà tí ó dúró tì mí mọ̀ pé, ọ̀rọ̀ OLÚWA ni. 12 Mo sì wí fún wọn pé, “Bí ó bá dára ní ojú yin, ẹ fún mi ni owó ọ̀yà mi; bí bẹ́ẹ̀ kọ́, ẹ mú un lọ́wọ́.” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n wọn ọgbọ̀n owó fàdákà fún iye owó ọ̀yà mi. 13 OLÚWA sì wí fún mi pé, “Sọ ọ sí amọ̀kòkò.” Iye dáradára náà, tí wọn yọ owó mi sí. Mo sì mu ọgbọ̀n owó fàdákà náà, mo sì sọ wọ́n sí àpótí ìṣúra ní ilé OLÚWA. 14 Mo sì ṣẹ́ ọ̀pá mi kejì, àní Àmùrè, sí méjì, kí èmi lè ya ìbátan tí ó wà láàrín Juda àti láàrín Israẹli. 15 OLÚWA sì wí fún mi pé, “Tún mú ohun èlò aṣiwèrè olùṣọ́-àgùntàn kan sọ́dọ̀ rẹ̀. 16 Nítorí Èmi o gbé Olùṣọ́-àgùntàn kan dìde ni ilẹ̀ náà, tí kí yóò bẹ àwọn tí ó ṣègbé wò, ti kì yóò sì wá èyí tí ó yapa; tí kì yóò ṣe ìtọ́jú èyí tí a pa lára tàbí kí ó bọ́ àwọn tí ara wọn dá pépé: Ṣùgbọ́n òun yóò jẹ ẹran èyí tí ó ni ọ̀rá, àwọn èyí tiwọn fi èékánná wọn ya ara wọn pẹ́rẹpẹ̀rẹ. 17 “Ègbé ni fún olùṣọ́-àgùntàn asán náà,tí ó fi ọ̀wọ́ ẹran sílẹ̀!Idà yóò gé apá rẹ̀ àti ojú ọ̀tún rẹ̀:apá rẹ̀ yóò gbẹ pátápátá,ojú ọ̀tún rẹ̀ yóò sì fọ́ pátápátá!”
In Other Versions
Zechariah 11 in the ANGEFD
Zechariah 11 in the ANTPNG2D
Zechariah 11 in the AS21
Zechariah 11 in the BAGH
Zechariah 11 in the BBPNG
Zechariah 11 in the BBT1E
Zechariah 11 in the BDS
Zechariah 11 in the BEV
Zechariah 11 in the BHAD
Zechariah 11 in the BIB
Zechariah 11 in the BLPT
Zechariah 11 in the BNT
Zechariah 11 in the BNTABOOT
Zechariah 11 in the BNTLV
Zechariah 11 in the BOATCB
Zechariah 11 in the BOATCB2
Zechariah 11 in the BOBCV
Zechariah 11 in the BOCNT
Zechariah 11 in the BOECS
Zechariah 11 in the BOGWICC
Zechariah 11 in the BOHCB
Zechariah 11 in the BOHCV
Zechariah 11 in the BOHLNT
Zechariah 11 in the BOHNTLTAL
Zechariah 11 in the BOICB
Zechariah 11 in the BOILNTAP
Zechariah 11 in the BOITCV
Zechariah 11 in the BOKCV
Zechariah 11 in the BOKCV2
Zechariah 11 in the BOKHWOG
Zechariah 11 in the BOKSSV
Zechariah 11 in the BOLCB
Zechariah 11 in the BOLCB2
Zechariah 11 in the BOMCV
Zechariah 11 in the BONAV
Zechariah 11 in the BONCB
Zechariah 11 in the BONLT
Zechariah 11 in the BONUT2
Zechariah 11 in the BOPLNT
Zechariah 11 in the BOSCB
Zechariah 11 in the BOSNC
Zechariah 11 in the BOTLNT
Zechariah 11 in the BOVCB
Zechariah 11 in the BPBB
Zechariah 11 in the BPH
Zechariah 11 in the BSB
Zechariah 11 in the CCB
Zechariah 11 in the CUV
Zechariah 11 in the CUVS
Zechariah 11 in the DBT
Zechariah 11 in the DGDNT
Zechariah 11 in the DHNT
Zechariah 11 in the DNT
Zechariah 11 in the ELBE
Zechariah 11 in the EMTV
Zechariah 11 in the ESV
Zechariah 11 in the FBV
Zechariah 11 in the FEB
Zechariah 11 in the GGMNT
Zechariah 11 in the GNT
Zechariah 11 in the HARY
Zechariah 11 in the HNT
Zechariah 11 in the IRVA
Zechariah 11 in the IRVB
Zechariah 11 in the IRVG
Zechariah 11 in the IRVH
Zechariah 11 in the IRVK
Zechariah 11 in the IRVM
Zechariah 11 in the IRVM2
Zechariah 11 in the IRVO
Zechariah 11 in the IRVP
Zechariah 11 in the IRVT
Zechariah 11 in the IRVT2
Zechariah 11 in the IRVU
Zechariah 11 in the ISVN
Zechariah 11 in the JSNT
Zechariah 11 in the KAPI
Zechariah 11 in the KBT1ETNIK
Zechariah 11 in the KBV
Zechariah 11 in the KJV
Zechariah 11 in the KNFD
Zechariah 11 in the LBA
Zechariah 11 in the LBLA
Zechariah 11 in the LNT
Zechariah 11 in the LSV
Zechariah 11 in the MAAL
Zechariah 11 in the MBV
Zechariah 11 in the MBV2
Zechariah 11 in the MHNT
Zechariah 11 in the MKNFD
Zechariah 11 in the MNG
Zechariah 11 in the MNT
Zechariah 11 in the MNT2
Zechariah 11 in the MRS1T
Zechariah 11 in the NAA
Zechariah 11 in the NASB
Zechariah 11 in the NBLA
Zechariah 11 in the NBS
Zechariah 11 in the NBVTP
Zechariah 11 in the NET2
Zechariah 11 in the NIV11
Zechariah 11 in the NNT
Zechariah 11 in the NNT2
Zechariah 11 in the NNT3
Zechariah 11 in the PDDPT
Zechariah 11 in the PFNT
Zechariah 11 in the RMNT
Zechariah 11 in the SBIAS
Zechariah 11 in the SBIBS
Zechariah 11 in the SBIBS2
Zechariah 11 in the SBICS
Zechariah 11 in the SBIDS
Zechariah 11 in the SBIGS
Zechariah 11 in the SBIHS
Zechariah 11 in the SBIIS
Zechariah 11 in the SBIIS2
Zechariah 11 in the SBIIS3
Zechariah 11 in the SBIKS
Zechariah 11 in the SBIKS2
Zechariah 11 in the SBIMS
Zechariah 11 in the SBIOS
Zechariah 11 in the SBIPS
Zechariah 11 in the SBISS
Zechariah 11 in the SBITS
Zechariah 11 in the SBITS2
Zechariah 11 in the SBITS3
Zechariah 11 in the SBITS4
Zechariah 11 in the SBIUS
Zechariah 11 in the SBIVS
Zechariah 11 in the SBT
Zechariah 11 in the SBT1E
Zechariah 11 in the SCHL
Zechariah 11 in the SNT
Zechariah 11 in the SUSU
Zechariah 11 in the SUSU2
Zechariah 11 in the SYNO
Zechariah 11 in the TBIAOTANT
Zechariah 11 in the TBT1E
Zechariah 11 in the TBT1E2
Zechariah 11 in the TFTIP
Zechariah 11 in the TFTU
Zechariah 11 in the TGNTATF3T
Zechariah 11 in the THAI
Zechariah 11 in the TNFD
Zechariah 11 in the TNT
Zechariah 11 in the TNTIK
Zechariah 11 in the TNTIL
Zechariah 11 in the TNTIN
Zechariah 11 in the TNTIP
Zechariah 11 in the TNTIZ
Zechariah 11 in the TOMA
Zechariah 11 in the TTENT
Zechariah 11 in the UBG
Zechariah 11 in the UGV
Zechariah 11 in the UGV2
Zechariah 11 in the UGV3
Zechariah 11 in the VBL
Zechariah 11 in the VDCC
Zechariah 11 in the YALU
Zechariah 11 in the YAPE
Zechariah 11 in the YBVTP
Zechariah 11 in the ZBP