2 Chronicles 10 (BOYCB)

1 Rehoboamu sì lọ sí Ṣekemu nítorí gbogbo àwọn ọmọ Israẹli ti lọ síbẹ̀ láti fi jẹ ọba. 2 Nígbà tí Jeroboamu ọmọ Nebati gbọ́ ẹni ti ó wà ní Ejibiti, níbi tí ó ti sá kúrò lọ́dọ̀ ọba Solomoni ó sì padà láti Ejibiti. 3 Bẹ́ẹ̀ ni nígbà náà ó sì ránṣẹ́ sí Jeroboamu àti òun àti gbogbo àwọn Israẹli lọ sí ọ̀dọ̀ Rehoboamu wọ́n sì wí fún pé, 4 “Baba rẹ gbé àjàgà tí ó wúwo lórí wa, ṣùgbọ́n nísinsin yìí ìwọ mú un fúyẹ́, iṣẹ́ líle àti àjàgà wúwo tí ó gbé ka orí wa, àwa yóò sì sìn ọ́.” 5 Rehoboamu sì dáhùn pé, “Ẹ padà wá sọ́dọ̀ mi lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta.” Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ènìyàn náà sì lọ. 6 Nígbà náà ni ọba Rehoboamu fi ọ̀ràn lọ̀ àwọn àgbàgbà tí ó ti ń sin baba rẹ̀ Solomoni nígbà ayé rẹ̀, ó sì bi wọ́n léèrè pe, “Báwo ni ẹ̀yin yóò ṣe gbà mí ní ìmọ̀ràn láti dá àwọn ènìyàn wọ̀nyí lóhùn?” 7 Wọ́n sì dáhùn, “Tí ìwọ yóò bá ṣe rere sí àwọn ènìyàn wọ̀nyí kí o sì ṣe ìre fún wọn, kí o sì fún wọn ní ìdáhùn rere, wọn yóò sì máa jẹ́ ìránṣẹ́ rẹ nígbà gbogbo.” 8 Ṣùgbọ́n Rehoboamu kọ ìmọ̀ràn náà tí àwọn àgbàgbà fi fún un, ó sì fi ọ̀rọ̀ lọ àwọn ọmọ ọkùnrin tí ó ti dàgbàsókè pẹ̀lú rẹ̀ tí wọ́n sì ń dúró níwájú rẹ̀. 9 Ó sì béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “Kí ni ìmọ̀ràn yín? Báwo ni kí a ṣe dá àwọn ènìyàn wọ̀nyí tí wọ́n wí fún mi pé, ‘Mú kí àjàgà tí baba rẹ gbé lé wa kí ó fúyẹ́ díẹ̀.’ ” 10 Àwọn ọ̀dọ́mọdé tí ó ti dàgbà pẹ̀lú rẹ dá a lóhùn pé, “Sọ fún àwọn ènìyàn tí ó wí fún ọ wí pé, ‘Baba rẹ gbé àjàgà wúwo lórí wa, ṣùgbọ́n mú àjàgà wa fúyẹ́,’ wí fún wọn pé, ‘Ìka ọwọ́ mi kékeré, ó nípọn ju ìbàdí baba mi lọ. 11 Baba mi gbé àjàgà wúwo ka orí yín; èmi yóò sì tún mú kí ó wúwo sì í. Baba mi fi pàṣán nà yín; èmi yóò sì nà yín pẹ̀lú àkéekèe.’ ” 12 Ní ọjọ́ kẹta Jeroboamu àti gbogbo ènìyàn sì padà sí ọ̀dọ̀ Rehoboamu, gẹ́gẹ́ bí ọba ti sọ, “Ẹ padà wá sọ́dọ̀ mi ní ọjọ́ kẹta.” 13 Nígbà náà ni ọba dá wọn lóhùn ní ọ̀nà líle. Rehoboamu ọba sì kọ̀ ìmọ̀ràn àwọn àgbàgbà sílẹ̀, 14 Ó sì tẹ̀lé ìmọ̀ràn àwọn ọ̀dọ́mọdé, ó sì wí pé, “Baba mi mú kí àjàgà yín wúwo; èmi yóò sì mú kí ó wúwo jù bẹ́ẹ̀ lọ. Baba mi nà yín pẹ̀lú pàṣán; èmi yóò sì nà yín pẹ̀lú àkéekèe.” 15 Bẹ́ẹ̀ ni ọba kò sì fetísí àwọn ènìyàn, nítorí ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí wá láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni. Láti mú ọ̀rọ̀ OLÚWA ṣẹ tí a ti sọ fún Jeroboamu ọmọ Nebati nípasẹ̀ Ahijah ará Ṣilo. 16 Nígbà tí gbogbo Israẹli rí i wí pé ọba kọ̀ láti gbọ́ tiwọn, wọ́n sì dá ọba lóhùn wí pé,“Ìpín kí ní a ní nínú Dafidi,ìní wo ni a ní nínú ọmọ Jese?Ẹ lọ sí àgọ́ yín, ẹ̀yin Israẹli!Bojútó ilé rẹ, ìwọ Dafidi!”Bẹ́ẹ̀ ní gbogbo àwọn ọmọ Israẹli lọ sí ilé wọn. 17 Ṣùgbọ́n ní ti àwọn ọmọ Israẹli tí ń gbé ní ìlú Juda, Rehoboamu ń jẹ ọba lórí wọn. 18 Ọba Rehoboamu rán Adoniramu jáde, ẹni tí ó wà ní ìkáwọ́ iṣẹ́ onírúurú, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Israẹli sọ ọ́ ní òkúta pa. Ọba Rehoboamu, gbìyànjú láti dé inú kẹ̀kẹ́ rẹ̀ ó sì sálọ sí Jerusalẹmu. 19 Bẹ́ẹ̀ ni Israẹli sì wà ní ìṣọ̀tẹ̀ lórí ilé Dafidi títí fi di òní yìí.

In Other Versions

2 Chronicles 10 in the ANGEFD

2 Chronicles 10 in the ANTPNG2D

2 Chronicles 10 in the AS21

2 Chronicles 10 in the BAGH

2 Chronicles 10 in the BBPNG

2 Chronicles 10 in the BBT1E

2 Chronicles 10 in the BDS

2 Chronicles 10 in the BEV

2 Chronicles 10 in the BHAD

2 Chronicles 10 in the BIB

2 Chronicles 10 in the BLPT

2 Chronicles 10 in the BNT

2 Chronicles 10 in the BNTABOOT

2 Chronicles 10 in the BNTLV

2 Chronicles 10 in the BOATCB

2 Chronicles 10 in the BOATCB2

2 Chronicles 10 in the BOBCV

2 Chronicles 10 in the BOCNT

2 Chronicles 10 in the BOECS

2 Chronicles 10 in the BOGWICC

2 Chronicles 10 in the BOHCB

2 Chronicles 10 in the BOHCV

2 Chronicles 10 in the BOHLNT

2 Chronicles 10 in the BOHNTLTAL

2 Chronicles 10 in the BOICB

2 Chronicles 10 in the BOILNTAP

2 Chronicles 10 in the BOITCV

2 Chronicles 10 in the BOKCV

2 Chronicles 10 in the BOKCV2

2 Chronicles 10 in the BOKHWOG

2 Chronicles 10 in the BOKSSV

2 Chronicles 10 in the BOLCB

2 Chronicles 10 in the BOLCB2

2 Chronicles 10 in the BOMCV

2 Chronicles 10 in the BONAV

2 Chronicles 10 in the BONCB

2 Chronicles 10 in the BONLT

2 Chronicles 10 in the BONUT2

2 Chronicles 10 in the BOPLNT

2 Chronicles 10 in the BOSCB

2 Chronicles 10 in the BOSNC

2 Chronicles 10 in the BOTLNT

2 Chronicles 10 in the BOVCB

2 Chronicles 10 in the BPBB

2 Chronicles 10 in the BPH

2 Chronicles 10 in the BSB

2 Chronicles 10 in the CCB

2 Chronicles 10 in the CUV

2 Chronicles 10 in the CUVS

2 Chronicles 10 in the DBT

2 Chronicles 10 in the DGDNT

2 Chronicles 10 in the DHNT

2 Chronicles 10 in the DNT

2 Chronicles 10 in the ELBE

2 Chronicles 10 in the EMTV

2 Chronicles 10 in the ESV

2 Chronicles 10 in the FBV

2 Chronicles 10 in the FEB

2 Chronicles 10 in the GGMNT

2 Chronicles 10 in the GNT

2 Chronicles 10 in the HARY

2 Chronicles 10 in the HNT

2 Chronicles 10 in the IRVA

2 Chronicles 10 in the IRVB

2 Chronicles 10 in the IRVG

2 Chronicles 10 in the IRVH

2 Chronicles 10 in the IRVK

2 Chronicles 10 in the IRVM

2 Chronicles 10 in the IRVM2

2 Chronicles 10 in the IRVO

2 Chronicles 10 in the IRVP

2 Chronicles 10 in the IRVT

2 Chronicles 10 in the IRVT2

2 Chronicles 10 in the IRVU

2 Chronicles 10 in the ISVN

2 Chronicles 10 in the JSNT

2 Chronicles 10 in the KAPI

2 Chronicles 10 in the KBT1ETNIK

2 Chronicles 10 in the KBV

2 Chronicles 10 in the KJV

2 Chronicles 10 in the KNFD

2 Chronicles 10 in the LBA

2 Chronicles 10 in the LBLA

2 Chronicles 10 in the LNT

2 Chronicles 10 in the LSV

2 Chronicles 10 in the MAAL

2 Chronicles 10 in the MBV

2 Chronicles 10 in the MBV2

2 Chronicles 10 in the MHNT

2 Chronicles 10 in the MKNFD

2 Chronicles 10 in the MNG

2 Chronicles 10 in the MNT

2 Chronicles 10 in the MNT2

2 Chronicles 10 in the MRS1T

2 Chronicles 10 in the NAA

2 Chronicles 10 in the NASB

2 Chronicles 10 in the NBLA

2 Chronicles 10 in the NBS

2 Chronicles 10 in the NBVTP

2 Chronicles 10 in the NET2

2 Chronicles 10 in the NIV11

2 Chronicles 10 in the NNT

2 Chronicles 10 in the NNT2

2 Chronicles 10 in the NNT3

2 Chronicles 10 in the PDDPT

2 Chronicles 10 in the PFNT

2 Chronicles 10 in the RMNT

2 Chronicles 10 in the SBIAS

2 Chronicles 10 in the SBIBS

2 Chronicles 10 in the SBIBS2

2 Chronicles 10 in the SBICS

2 Chronicles 10 in the SBIDS

2 Chronicles 10 in the SBIGS

2 Chronicles 10 in the SBIHS

2 Chronicles 10 in the SBIIS

2 Chronicles 10 in the SBIIS2

2 Chronicles 10 in the SBIIS3

2 Chronicles 10 in the SBIKS

2 Chronicles 10 in the SBIKS2

2 Chronicles 10 in the SBIMS

2 Chronicles 10 in the SBIOS

2 Chronicles 10 in the SBIPS

2 Chronicles 10 in the SBISS

2 Chronicles 10 in the SBITS

2 Chronicles 10 in the SBITS2

2 Chronicles 10 in the SBITS3

2 Chronicles 10 in the SBITS4

2 Chronicles 10 in the SBIUS

2 Chronicles 10 in the SBIVS

2 Chronicles 10 in the SBT

2 Chronicles 10 in the SBT1E

2 Chronicles 10 in the SCHL

2 Chronicles 10 in the SNT

2 Chronicles 10 in the SUSU

2 Chronicles 10 in the SUSU2

2 Chronicles 10 in the SYNO

2 Chronicles 10 in the TBIAOTANT

2 Chronicles 10 in the TBT1E

2 Chronicles 10 in the TBT1E2

2 Chronicles 10 in the TFTIP

2 Chronicles 10 in the TFTU

2 Chronicles 10 in the TGNTATF3T

2 Chronicles 10 in the THAI

2 Chronicles 10 in the TNFD

2 Chronicles 10 in the TNT

2 Chronicles 10 in the TNTIK

2 Chronicles 10 in the TNTIL

2 Chronicles 10 in the TNTIN

2 Chronicles 10 in the TNTIP

2 Chronicles 10 in the TNTIZ

2 Chronicles 10 in the TOMA

2 Chronicles 10 in the TTENT

2 Chronicles 10 in the UBG

2 Chronicles 10 in the UGV

2 Chronicles 10 in the UGV2

2 Chronicles 10 in the UGV3

2 Chronicles 10 in the VBL

2 Chronicles 10 in the VDCC

2 Chronicles 10 in the YALU

2 Chronicles 10 in the YAPE

2 Chronicles 10 in the YBVTP

2 Chronicles 10 in the ZBP