2 Chronicles 17 (BOYCB)

1 Jehoṣafati ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀ ó sì mú ara rẹ̀ lágbára sí lórí Israẹli. 2 Ó sì fi ogun sínú gbogbo ìlú olódi Juda ó sì kó ẹgbẹ́ ológun ní Juda àti nínú ìlú Efraimu tí Asa baba rẹ̀ ti gbà. 3 OLÚWA sì wà pẹ̀lú Jehoṣafati nítorí, ní ọdún àkọ́kọ́ rẹ̀, ó rìn ní ọ̀nà ti baba rẹ̀ Dafidi ti rìn, kò sì fi ọ̀ràn lọ Baali. 4 Ṣùgbọ́n ó wá Ọlọ́run baba rẹ̀ kiri ó sì tẹ̀lé àṣẹ rẹ̀ ju iṣẹ́ Israẹli. 5 OLÚWA sì fi ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ lábẹ́ àkóso rẹ̀, gbogbo Juda sì mú ẹ̀bùn wá fún Jehoṣafati, bẹ́ẹ̀ ni ó sì ní ọrọ̀ àti ọlá lọ́pọ̀lọ́pọ̀. 6 Ọkàn rẹ̀ sì gbé sókè si ọ̀nà OLÚWA, pẹ̀lúpẹ̀lú, ó sì mú ibi gíga wọn àti ère òrìṣà Aṣerah kúrò ní Juda. 7 Ní ọdún kẹta ìjọba rẹ̀, ó rán àwọn ìjòyè rẹ̀ Bene-Haili, Obadiah, Sekariah, Netaneli, Mikaiah láti máa kọ́ ni nínú ìlú Juda. 8 Wọ́n sì ní díẹ̀ lára àwọn ọmọ Lefi, àní Ṣemaiah, Netaniah, Sebadiah, Asaheli, Ṣemiramotu, Jehonatani, Adonijah, Tobijah àti Tobu-Adonijah àti àwọn àlùfáà Eliṣama àti Jehoramu. 9 Wọ́n ń kọ́ ni ní agbègbè Juda, wọ́n mú ìwé òfin OLÚWA wọ́n sì rìn yíká gbogbo àwọn ìlú Juda wọ́n sì ń kọ́ àwọn ènìyàn. 10 Ìbẹ̀rù OLÚWA bà lórí gbogbo ìjọba ilẹ̀ tí ó yí Juda ká, dé bi pé wọn kò bá Jehoṣafati jagun. 11 Lára àwọn ará Filistini, mú ẹ̀bùn fàdákà gẹ́gẹ́ bí owó ọba wá fún Jehoṣafati, àwọn ará Arabia sì mú ọ̀wọ́ ẹran wá fún un, ẹgbàarindín ní ọ̀ọ́dúnrún (7,700) àgbò àti ẹgbàarindín ní ọ̀ọ́dúnrún (7,700) òbúkọ. 12 Jehoṣafati sì ń di alágbára nínú agbára sí i, ó sì kọ́ ilé olódi àti ilé ìṣúra púpọ̀ ní Juda 13 Ó sì ní ìṣúra ní ìlú Juda. Ó sì tún ní àwọn alágbára jagunjagun akọni ọkùnrin ní Jerusalẹmu. 14 Iye wọn gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn nìwọ̀nyí. Láti Juda, àwọn olórí ìpín kan ti ẹgbẹ̀rún (1,000):Adina olórí, pẹ̀lú ọ̀kẹ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún (300,000) alágbára akọni ọkùnrin. 15 Èkejì, Jehohanani olórí, pẹ̀lú ọ̀kẹ́ mẹ́rìnlá (280,000) ọkùnrin; 16 àtẹ̀lé Amasiah ọmọ Sikri, ẹni tí ó fi ara rẹ̀ fún iṣẹ́ OLÚWA pẹ̀lú ọ̀kẹ́ mẹ́wàá (200,000). 17 Láti ọ̀dọ̀ Benjamini:Eliada, alágbára akọni ọkùnrin pẹ̀lú ọ̀kẹ́ mẹ́wàá (200,000) àwọn jagunjagun ọkùnrin pẹ̀lú ọrun àti àpáta ìhámọ́ra; 18 àtẹ̀lé Jehosabadi, pẹ̀lú ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án (180,000) jagunjagun ọkùnrin múra sílẹ̀ fún ogun. 19 Wọ̀nyí ni àwọn ọkùnrin tí ń dúró níwájú ọba, ní àyíká àwọn ẹni tí ó fi sínú ìlú olódi ní àyíká gbogbo Juda.

In Other Versions

2 Chronicles 17 in the ANGEFD

2 Chronicles 17 in the ANTPNG2D

2 Chronicles 17 in the AS21

2 Chronicles 17 in the BAGH

2 Chronicles 17 in the BBPNG

2 Chronicles 17 in the BBT1E

2 Chronicles 17 in the BDS

2 Chronicles 17 in the BEV

2 Chronicles 17 in the BHAD

2 Chronicles 17 in the BIB

2 Chronicles 17 in the BLPT

2 Chronicles 17 in the BNT

2 Chronicles 17 in the BNTABOOT

2 Chronicles 17 in the BNTLV

2 Chronicles 17 in the BOATCB

2 Chronicles 17 in the BOATCB2

2 Chronicles 17 in the BOBCV

2 Chronicles 17 in the BOCNT

2 Chronicles 17 in the BOECS

2 Chronicles 17 in the BOGWICC

2 Chronicles 17 in the BOHCB

2 Chronicles 17 in the BOHCV

2 Chronicles 17 in the BOHLNT

2 Chronicles 17 in the BOHNTLTAL

2 Chronicles 17 in the BOICB

2 Chronicles 17 in the BOILNTAP

2 Chronicles 17 in the BOITCV

2 Chronicles 17 in the BOKCV

2 Chronicles 17 in the BOKCV2

2 Chronicles 17 in the BOKHWOG

2 Chronicles 17 in the BOKSSV

2 Chronicles 17 in the BOLCB

2 Chronicles 17 in the BOLCB2

2 Chronicles 17 in the BOMCV

2 Chronicles 17 in the BONAV

2 Chronicles 17 in the BONCB

2 Chronicles 17 in the BONLT

2 Chronicles 17 in the BONUT2

2 Chronicles 17 in the BOPLNT

2 Chronicles 17 in the BOSCB

2 Chronicles 17 in the BOSNC

2 Chronicles 17 in the BOTLNT

2 Chronicles 17 in the BOVCB

2 Chronicles 17 in the BPBB

2 Chronicles 17 in the BPH

2 Chronicles 17 in the BSB

2 Chronicles 17 in the CCB

2 Chronicles 17 in the CUV

2 Chronicles 17 in the CUVS

2 Chronicles 17 in the DBT

2 Chronicles 17 in the DGDNT

2 Chronicles 17 in the DHNT

2 Chronicles 17 in the DNT

2 Chronicles 17 in the ELBE

2 Chronicles 17 in the EMTV

2 Chronicles 17 in the ESV

2 Chronicles 17 in the FBV

2 Chronicles 17 in the FEB

2 Chronicles 17 in the GGMNT

2 Chronicles 17 in the GNT

2 Chronicles 17 in the HARY

2 Chronicles 17 in the HNT

2 Chronicles 17 in the IRVA

2 Chronicles 17 in the IRVB

2 Chronicles 17 in the IRVG

2 Chronicles 17 in the IRVH

2 Chronicles 17 in the IRVK

2 Chronicles 17 in the IRVM

2 Chronicles 17 in the IRVM2

2 Chronicles 17 in the IRVO

2 Chronicles 17 in the IRVP

2 Chronicles 17 in the IRVT

2 Chronicles 17 in the IRVT2

2 Chronicles 17 in the IRVU

2 Chronicles 17 in the ISVN

2 Chronicles 17 in the JSNT

2 Chronicles 17 in the KAPI

2 Chronicles 17 in the KBT1ETNIK

2 Chronicles 17 in the KBV

2 Chronicles 17 in the KJV

2 Chronicles 17 in the KNFD

2 Chronicles 17 in the LBA

2 Chronicles 17 in the LBLA

2 Chronicles 17 in the LNT

2 Chronicles 17 in the LSV

2 Chronicles 17 in the MAAL

2 Chronicles 17 in the MBV

2 Chronicles 17 in the MBV2

2 Chronicles 17 in the MHNT

2 Chronicles 17 in the MKNFD

2 Chronicles 17 in the MNG

2 Chronicles 17 in the MNT

2 Chronicles 17 in the MNT2

2 Chronicles 17 in the MRS1T

2 Chronicles 17 in the NAA

2 Chronicles 17 in the NASB

2 Chronicles 17 in the NBLA

2 Chronicles 17 in the NBS

2 Chronicles 17 in the NBVTP

2 Chronicles 17 in the NET2

2 Chronicles 17 in the NIV11

2 Chronicles 17 in the NNT

2 Chronicles 17 in the NNT2

2 Chronicles 17 in the NNT3

2 Chronicles 17 in the PDDPT

2 Chronicles 17 in the PFNT

2 Chronicles 17 in the RMNT

2 Chronicles 17 in the SBIAS

2 Chronicles 17 in the SBIBS

2 Chronicles 17 in the SBIBS2

2 Chronicles 17 in the SBICS

2 Chronicles 17 in the SBIDS

2 Chronicles 17 in the SBIGS

2 Chronicles 17 in the SBIHS

2 Chronicles 17 in the SBIIS

2 Chronicles 17 in the SBIIS2

2 Chronicles 17 in the SBIIS3

2 Chronicles 17 in the SBIKS

2 Chronicles 17 in the SBIKS2

2 Chronicles 17 in the SBIMS

2 Chronicles 17 in the SBIOS

2 Chronicles 17 in the SBIPS

2 Chronicles 17 in the SBISS

2 Chronicles 17 in the SBITS

2 Chronicles 17 in the SBITS2

2 Chronicles 17 in the SBITS3

2 Chronicles 17 in the SBITS4

2 Chronicles 17 in the SBIUS

2 Chronicles 17 in the SBIVS

2 Chronicles 17 in the SBT

2 Chronicles 17 in the SBT1E

2 Chronicles 17 in the SCHL

2 Chronicles 17 in the SNT

2 Chronicles 17 in the SUSU

2 Chronicles 17 in the SUSU2

2 Chronicles 17 in the SYNO

2 Chronicles 17 in the TBIAOTANT

2 Chronicles 17 in the TBT1E

2 Chronicles 17 in the TBT1E2

2 Chronicles 17 in the TFTIP

2 Chronicles 17 in the TFTU

2 Chronicles 17 in the TGNTATF3T

2 Chronicles 17 in the THAI

2 Chronicles 17 in the TNFD

2 Chronicles 17 in the TNT

2 Chronicles 17 in the TNTIK

2 Chronicles 17 in the TNTIL

2 Chronicles 17 in the TNTIN

2 Chronicles 17 in the TNTIP

2 Chronicles 17 in the TNTIZ

2 Chronicles 17 in the TOMA

2 Chronicles 17 in the TTENT

2 Chronicles 17 in the UBG

2 Chronicles 17 in the UGV

2 Chronicles 17 in the UGV2

2 Chronicles 17 in the UGV3

2 Chronicles 17 in the VBL

2 Chronicles 17 in the VDCC

2 Chronicles 17 in the YALU

2 Chronicles 17 in the YAPE

2 Chronicles 17 in the YBVTP

2 Chronicles 17 in the ZBP