2 Chronicles 2 (BOYCB)
1 Solomoni pinnu láti kọ́ ilé fún orúkọ OLÚWA àti ilé kan fún ìjọba rẹ̀ 2 Solomoni sì yan ẹgbẹ̀rún ní ọ̀nà àádọ́rin (70,000) àwọn ọkùnrin láti ru ẹrù àti ọ̀kẹ́ mẹ́rin (80,000) àwọn ọkùnrin gẹ́gẹ́ bi olùgé-òkúta ní àwọn òkè àti ẹgbẹ̀rún mẹ́rìndínlógójì (36,000) gẹ́gẹ́ bí àwọn alábojútó lórí wọn. 3 Solomoni rán iṣẹ́ yìí sí Hiramu ọba Tire:“Rán àwọn igi kedari sí mi gẹ́gẹ́ bí o ti ṣe fún baba à mi Dafidi. Nígbà tí ó fi igi kedari ránṣẹ́ sí i láti kọ́ ààfin tí ó ń gbé. 4 Nísinsin yìí, èmi n kọ́ ilé kan fún orúkọ OLÚWA Ọlọ́run mi àti láti yà á sí mímọ́ fún un àti láti sun tùràrí olóòórùn dídùn níwájú rẹ̀, fún gbígbé àkàrà ìfihàn ìgbàkúgbà, àti fún ṣíṣe ẹbọ sísun ní gbogbo àárọ̀ àti ìrọ̀lẹ́ àti ní ọjọọjọ́ ìsinmi àti oṣù tuntun àti ní àjọ̀dún tí a yàn ti OLÚWA Ọlọ́run wa. Èyí ni àṣẹ fún Israẹli láéláé. 5 “Ilé OLÚWA tí èmi yóò kọ́ yóò tóbi, nítorí pé Ọlọ́run wa tóbi ju gbogbo àwọn ọlọ́run mìíràn lọ. 6 Ṣùgbọ́n ta ni ó le è kọ́ ilé fún OLÚWA, níwọ̀n ìgbà tí àwọn ọ̀run, àní ọ̀run àwọn ọ̀run tó ga jùlọ, kò le è gbà á? Ta ni èmi nígbà náà láti kọ́ ilé fún OLÚWA, bí kò ṣe kìkì àti sun ẹbọ sun ẹbọ níwájú rẹ̀? 7 “Nítorí náà, rán ọkùnrin kan sí mi, tí a kọ́ láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú wúrà àti fàdákà àti idẹ àti irin, àti ní àwọ̀ àlùkò àti àwọ̀ pupa fòò àti ní àwọ̀ ojú ọ̀run, tí ó jẹ́ onímọ̀ nínú iṣẹ́ igi gbígbẹ́ láti ṣiṣẹ́ ní Juda àti Jerusalẹmu pẹ̀lú àwọn onímọ̀ oníṣọ̀nà tí baba à mi Dafidi pèsè. 8 “Fi ìtì igi kedari, junifa àti algumu ránṣẹ́ sí mi, láti Lebanoni, nítorí tí mo mọ̀ pé àwọn ọkùnrin rẹ ní ìmọ̀ nínú gígé igi rírẹ́. Àwọn ọkùnrin mi yóò ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ọkùnrin rẹ. 9 Láti pèsè ọ̀pọ̀ igi rírẹ́ fún mi, nítorí ilé OLÚWA tí mo kọ́ gbọdọ̀ tóbi kí o sì lógo púpọ̀. 10 Èmi yóò fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ, àwọn ọkùnrin agégi tí ó ń gé ìtì igi náà ni ogún ẹgbẹ̀rún (20,000), alikama ilẹ̀ àti ogún ẹgbẹ̀rún (20,000), ọ̀pọ̀lọpọ̀ ti barle; ogún ẹgbẹ̀rún (20,000), bati ọtí wáìnì àti ogún ẹgbẹ̀rún (20,000) bati òróró olifi.” 11 Hiramu ọba Tire fèsì padà nípasẹ̀ ìwé sí Solomoni:“Nítorí tí OLÚWA fẹ́ràn àwọn ènìyàn rẹ̀, ó ti ṣe ọ́ ní ọba wọn.” 12 Hiramu fi kún un pe,“Ìyìn ni fún OLÚWA, Ọlọ́run Israẹli, tí ó dá ọ̀run òun ayé! O ti fún ọba Dafidi ní ọmọ tí ó gbọ́n, tí ó kún fún ìmọ̀ àti òye, tí yóò kọ́ ilé fún OLÚWA àti ààfin fún ara rẹ̀. 13 “Èmi ń rán Huramu-Abi, ọkùnrin tí ó kún fún ìmọ̀ àti òye sí ọ. 14 Ọmọbìnrin kan nínú àwọn ọmọbìnrin Dani àti tí baba a rẹ̀ wá láti Tire tí ó gbọ́ngbọ́n àti ṣiṣẹ́ ní wúrà àti ní fàdákà, ní idẹ, ní irin, ní òkúta àti ní ìtì igi, ní èse-àlùkò, ní aláró, àti ní ọ̀gbọ̀ tí ó dára, àti òdòdó, láti gbẹ́ onírúurú ohun gbígbẹ́ pẹ̀lú, àti láti ṣe àwárí ìmọ̀ ẹ̀rọ irú ẹ̀yàkẹ́yà tí a ó fún un ṣe. Òun yóò ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ọlọ́gbọ́n rẹ̀, àti pẹ̀lú àwọn ọlọ́gbọ́n olúwa mi, Dafidi baba a rẹ. 15 “Nísinsin yìí, jẹ́ kí olúwa mi rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ ní alikama àti barle àti òróró Olifi náà àti ọtí tí ó ti ṣe ìlérí. 16 Àwa yóò sì gé gbogbo àwọn ìtí igi láti Lebanoni tí ìwọ yóò lò pẹ̀lú a ó gbé wọn fò lójú omi òkun lọ sí Joppa. Lẹ́yìn náà ìwọ lè kó wọn gòkè lọ sí Jerusalẹmu.” 17 Solomoni ka iye àwọn àjèjì tí ó wà ní Israẹli lẹ́yìn kíka iye wọn tí baba a rẹ̀ Dafidi ti ṣe; a sì ka iye wọn sí ọ̀kẹ́ mẹ́jọ ó dín egbèjìlélọ́gbọ̀n (153,600). 18 Ó sì yan ẹgbẹ̀rún ní ọ̀nà àádọ́rin (70,000) nínú wọn láti ru ẹrù, àti ọ̀kẹ́ mẹ́rin (80,000) láti ṣe àgọ́ òkúta lórí òkè, àti egbèjìdínlógún (3,600) alábojútó láti kó àwọn ènìyàn ṣiṣẹ́.
In Other Versions
2 Chronicles 2 in the ANGEFD
2 Chronicles 2 in the ANTPNG2D
2 Chronicles 2 in the AS21
2 Chronicles 2 in the BAGH
2 Chronicles 2 in the BBPNG
2 Chronicles 2 in the BBT1E
2 Chronicles 2 in the BDS
2 Chronicles 2 in the BEV
2 Chronicles 2 in the BHAD
2 Chronicles 2 in the BIB
2 Chronicles 2 in the BLPT
2 Chronicles 2 in the BNT
2 Chronicles 2 in the BNTABOOT
2 Chronicles 2 in the BNTLV
2 Chronicles 2 in the BOATCB
2 Chronicles 2 in the BOATCB2
2 Chronicles 2 in the BOBCV
2 Chronicles 2 in the BOCNT
2 Chronicles 2 in the BOECS
2 Chronicles 2 in the BOGWICC
2 Chronicles 2 in the BOHCB
2 Chronicles 2 in the BOHCV
2 Chronicles 2 in the BOHLNT
2 Chronicles 2 in the BOHNTLTAL
2 Chronicles 2 in the BOICB
2 Chronicles 2 in the BOILNTAP
2 Chronicles 2 in the BOITCV
2 Chronicles 2 in the BOKCV
2 Chronicles 2 in the BOKCV2
2 Chronicles 2 in the BOKHWOG
2 Chronicles 2 in the BOKSSV
2 Chronicles 2 in the BOLCB
2 Chronicles 2 in the BOLCB2
2 Chronicles 2 in the BOMCV
2 Chronicles 2 in the BONAV
2 Chronicles 2 in the BONCB
2 Chronicles 2 in the BONLT
2 Chronicles 2 in the BONUT2
2 Chronicles 2 in the BOPLNT
2 Chronicles 2 in the BOSCB
2 Chronicles 2 in the BOSNC
2 Chronicles 2 in the BOTLNT
2 Chronicles 2 in the BOVCB
2 Chronicles 2 in the BPBB
2 Chronicles 2 in the BPH
2 Chronicles 2 in the BSB
2 Chronicles 2 in the CCB
2 Chronicles 2 in the CUV
2 Chronicles 2 in the CUVS
2 Chronicles 2 in the DBT
2 Chronicles 2 in the DGDNT
2 Chronicles 2 in the DHNT
2 Chronicles 2 in the DNT
2 Chronicles 2 in the ELBE
2 Chronicles 2 in the EMTV
2 Chronicles 2 in the ESV
2 Chronicles 2 in the FBV
2 Chronicles 2 in the FEB
2 Chronicles 2 in the GGMNT
2 Chronicles 2 in the GNT
2 Chronicles 2 in the HARY
2 Chronicles 2 in the HNT
2 Chronicles 2 in the IRVA
2 Chronicles 2 in the IRVB
2 Chronicles 2 in the IRVG
2 Chronicles 2 in the IRVH
2 Chronicles 2 in the IRVK
2 Chronicles 2 in the IRVM
2 Chronicles 2 in the IRVM2
2 Chronicles 2 in the IRVO
2 Chronicles 2 in the IRVP
2 Chronicles 2 in the IRVT
2 Chronicles 2 in the IRVT2
2 Chronicles 2 in the IRVU
2 Chronicles 2 in the ISVN
2 Chronicles 2 in the JSNT
2 Chronicles 2 in the KAPI
2 Chronicles 2 in the KBT1ETNIK
2 Chronicles 2 in the KBV
2 Chronicles 2 in the KJV
2 Chronicles 2 in the KNFD
2 Chronicles 2 in the LBA
2 Chronicles 2 in the LBLA
2 Chronicles 2 in the LNT
2 Chronicles 2 in the LSV
2 Chronicles 2 in the MAAL
2 Chronicles 2 in the MBV
2 Chronicles 2 in the MBV2
2 Chronicles 2 in the MHNT
2 Chronicles 2 in the MKNFD
2 Chronicles 2 in the MNG
2 Chronicles 2 in the MNT
2 Chronicles 2 in the MNT2
2 Chronicles 2 in the MRS1T
2 Chronicles 2 in the NAA
2 Chronicles 2 in the NASB
2 Chronicles 2 in the NBLA
2 Chronicles 2 in the NBS
2 Chronicles 2 in the NBVTP
2 Chronicles 2 in the NET2
2 Chronicles 2 in the NIV11
2 Chronicles 2 in the NNT
2 Chronicles 2 in the NNT2
2 Chronicles 2 in the NNT3
2 Chronicles 2 in the PDDPT
2 Chronicles 2 in the PFNT
2 Chronicles 2 in the RMNT
2 Chronicles 2 in the SBIAS
2 Chronicles 2 in the SBIBS
2 Chronicles 2 in the SBIBS2
2 Chronicles 2 in the SBICS
2 Chronicles 2 in the SBIDS
2 Chronicles 2 in the SBIGS
2 Chronicles 2 in the SBIHS
2 Chronicles 2 in the SBIIS
2 Chronicles 2 in the SBIIS2
2 Chronicles 2 in the SBIIS3
2 Chronicles 2 in the SBIKS
2 Chronicles 2 in the SBIKS2
2 Chronicles 2 in the SBIMS
2 Chronicles 2 in the SBIOS
2 Chronicles 2 in the SBIPS
2 Chronicles 2 in the SBISS
2 Chronicles 2 in the SBITS
2 Chronicles 2 in the SBITS2
2 Chronicles 2 in the SBITS3
2 Chronicles 2 in the SBITS4
2 Chronicles 2 in the SBIUS
2 Chronicles 2 in the SBIVS
2 Chronicles 2 in the SBT
2 Chronicles 2 in the SBT1E
2 Chronicles 2 in the SCHL
2 Chronicles 2 in the SNT
2 Chronicles 2 in the SUSU
2 Chronicles 2 in the SUSU2
2 Chronicles 2 in the SYNO
2 Chronicles 2 in the TBIAOTANT
2 Chronicles 2 in the TBT1E
2 Chronicles 2 in the TBT1E2
2 Chronicles 2 in the TFTIP
2 Chronicles 2 in the TFTU
2 Chronicles 2 in the TGNTATF3T
2 Chronicles 2 in the THAI
2 Chronicles 2 in the TNFD
2 Chronicles 2 in the TNT
2 Chronicles 2 in the TNTIK
2 Chronicles 2 in the TNTIL
2 Chronicles 2 in the TNTIN
2 Chronicles 2 in the TNTIP
2 Chronicles 2 in the TNTIZ
2 Chronicles 2 in the TOMA
2 Chronicles 2 in the TTENT
2 Chronicles 2 in the UBG
2 Chronicles 2 in the UGV
2 Chronicles 2 in the UGV2
2 Chronicles 2 in the UGV3
2 Chronicles 2 in the VBL
2 Chronicles 2 in the VDCC
2 Chronicles 2 in the YALU
2 Chronicles 2 in the YAPE
2 Chronicles 2 in the YBVTP
2 Chronicles 2 in the ZBP