2 Corinthians 10 (BOYCB)
1 Ṣùgbọ́n èmi Paulu fúnra mi fi inú tútù àti ìwà pẹ̀lẹ́ Kristi bẹ̀ yín, èmi ẹni ìrẹ̀lẹ̀ lójú yín nígbà tí mo wà láàrín yín, ṣùgbọ́n nígbà tí èmi kò sí, mo di ẹni ìgboyà sí yín. 2 Ṣùgbọ́n èmi bẹ̀ yín pé nígbà tí mo wà láàrín yín, kí èmi ba à lè lo ìgboyà pẹ̀lú ìgbẹ́kẹ̀lé náà, eléyìí tí mo ti fọkàn sí láti fi dojúkọ àwọn kan, ti ń funra sí wa bí ẹni tí ń rìn nípa ìlànà ti ayé yìí. 3 Nítorí pé, bí àwa tilẹ̀ n gbé nínú ayé, ṣùgbọ́n àwa kò jagun nípa ti ara. 4 Nítorí ohun ìjà wa kì í ṣe ti ara, ṣùgbọ́n ó lágbára nínú Ọlọ́run láti wó ibi gíga palẹ̀. 5 Àwa ń sọ gbogbo èrò àti gbogbo ohun gíga ti ń gbe ara rẹ̀ ga sí ìmọ̀ Ọlọ́run kalẹ̀, àwa sì ń di gbogbo èrò ní ìgbèkùn wá sí ìtẹríba fún Kristi. 6 Àwa sì ti murá tan láti jẹ gbogbo àìgbọ́ràn ní yà, nígbà tí ìgbọ́ràn yín bá pé. 7 Ẹ̀yin sì ń wo nǹkan gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti fihàn lóde. Bí ẹnikẹ́ni bá ní ìgboyà nínú ara rẹ̀, ti Kristi ni òun, kí ó tún rò lẹ́ẹ̀kan si pé, bí òun ti jẹ́ ti Kristi, gẹ́gẹ́ bẹ́ẹ̀ ni àwa pẹ̀lú jẹ́ ti Kristi. 8 Nítorí bí mo tilẹ̀ ń ṣògo bí ó ti wù mi nítorí agbára, tí Olúwa ti fi fún wá fún ìdàgbàsókè, dípò fífà yín ṣubú, ojú kí yóò tì mí. 9 Kí ó má ṣe dàbí ẹni pé èmi ń fi ìwé kíkọ dẹ́rùbà yín. 10 Nítorí wọ́n wí pé, “Ìwé rẹ wúwo, wọn sì lágbára; ṣùgbọ́n ní ti ara ìrísí rẹ̀ jẹ aláìlera, ọ̀rọ̀ rẹ kò níláárí.” 11 Kí irú ènìyàn bẹ́ẹ̀ mọ̀ pé, irú ẹni tí àwa jẹ́ nínú ọ̀rọ̀ nípa ìwé kíkọ nígbà tí àwa kò sí, irú ẹni bẹ́ẹ̀ ni àwa sì jẹ́ nínú iṣẹ́ pẹ̀lú nígbà ti àwa bá wà. 12 Nítorí pé àwa kò dáṣà láti ka ara wa mọ́, tàbí láti fi ara wa wé àwọn mìíràn nínú wọn tí ń yin ara wọn; ṣùgbọ́n àwọn fúnra wọn jẹ́ aláìlóye bí wọn ti ń fi ara wọn díwọ̀n ara wọ́n, tí wọ́n sì ń fi ara wọn wé ara wọn. 13 Ṣùgbọ́n àwa kò ṣògo rékọjá ààlà wa, ṣùgbọ́n nípa ààlà ìwọ̀n tí Ọlọ́run ti pín fún wa, èyí tí ó mú kí ó ṣe é ṣe láti dé ọ̀dọ̀ yín. 14 Nítorí àwa kò nawọ́ wa rékọjá rárá, bí ẹni pé àwa kò dé ọ̀dọ̀ yín: nítorí àwa tilẹ̀ dé ọ̀dọ̀ yín pẹ̀lú nínú ìyìnrere Kristi. 15 Àwa kò ṣògo rékọjá ààlà wa, èyí nì, lórí iṣẹ́ ẹlòmíràn, ṣùgbọ́n àwa ní ìrètí pé, bí ìgbàgbọ́ yín ti ń dàgbà sí i, gẹ́gẹ́ bí ààlà wa, àwa ó dí gbígbéga lọ́dọ̀ yín sí i lọ́pọ̀lọ́pọ̀. 16 Kí a bá à lè wàásù ìyìnrere ní àwọn ìlú tí ń bẹ níwájú yín, kí a má sì ṣògo nínú ààlà ẹlòmíràn nípa ohun tí ó wà ní àrọ́wọ́tó. 17 “Ṣùgbọ́n jẹ́ kí ẹni tí ó bá ń ṣògo, kí ó máa ṣògo nínú Olúwa.” 18 Nítorí kì í ṣe ẹni tí ń yin ara rẹ̀ ni ó ní ìtẹ́wọ́gbà, bí kò ṣe ẹni tí Olúwa bá yìn.
In Other Versions
2 Corinthians 10 in the ANGEFD
2 Corinthians 10 in the ANTPNG2D
2 Corinthians 10 in the AS21
2 Corinthians 10 in the BAGH
2 Corinthians 10 in the BBPNG
2 Corinthians 10 in the BBT1E
2 Corinthians 10 in the BDS
2 Corinthians 10 in the BEV
2 Corinthians 10 in the BHAD
2 Corinthians 10 in the BIB
2 Corinthians 10 in the BLPT
2 Corinthians 10 in the BNT
2 Corinthians 10 in the BNTABOOT
2 Corinthians 10 in the BNTLV
2 Corinthians 10 in the BOATCB
2 Corinthians 10 in the BOATCB2
2 Corinthians 10 in the BOBCV
2 Corinthians 10 in the BOCNT
2 Corinthians 10 in the BOECS
2 Corinthians 10 in the BOGWICC
2 Corinthians 10 in the BOHCB
2 Corinthians 10 in the BOHCV
2 Corinthians 10 in the BOHLNT
2 Corinthians 10 in the BOHNTLTAL
2 Corinthians 10 in the BOICB
2 Corinthians 10 in the BOILNTAP
2 Corinthians 10 in the BOITCV
2 Corinthians 10 in the BOKCV
2 Corinthians 10 in the BOKCV2
2 Corinthians 10 in the BOKHWOG
2 Corinthians 10 in the BOKSSV
2 Corinthians 10 in the BOLCB
2 Corinthians 10 in the BOLCB2
2 Corinthians 10 in the BOMCV
2 Corinthians 10 in the BONAV
2 Corinthians 10 in the BONCB
2 Corinthians 10 in the BONLT
2 Corinthians 10 in the BONUT2
2 Corinthians 10 in the BOPLNT
2 Corinthians 10 in the BOSCB
2 Corinthians 10 in the BOSNC
2 Corinthians 10 in the BOTLNT
2 Corinthians 10 in the BOVCB
2 Corinthians 10 in the BPBB
2 Corinthians 10 in the BPH
2 Corinthians 10 in the BSB
2 Corinthians 10 in the CCB
2 Corinthians 10 in the CUV
2 Corinthians 10 in the CUVS
2 Corinthians 10 in the DBT
2 Corinthians 10 in the DGDNT
2 Corinthians 10 in the DHNT
2 Corinthians 10 in the DNT
2 Corinthians 10 in the ELBE
2 Corinthians 10 in the EMTV
2 Corinthians 10 in the ESV
2 Corinthians 10 in the FBV
2 Corinthians 10 in the FEB
2 Corinthians 10 in the GGMNT
2 Corinthians 10 in the GNT
2 Corinthians 10 in the HARY
2 Corinthians 10 in the HNT
2 Corinthians 10 in the IRVA
2 Corinthians 10 in the IRVB
2 Corinthians 10 in the IRVG
2 Corinthians 10 in the IRVH
2 Corinthians 10 in the IRVK
2 Corinthians 10 in the IRVM
2 Corinthians 10 in the IRVM2
2 Corinthians 10 in the IRVO
2 Corinthians 10 in the IRVP
2 Corinthians 10 in the IRVT
2 Corinthians 10 in the IRVT2
2 Corinthians 10 in the IRVU
2 Corinthians 10 in the ISVN
2 Corinthians 10 in the JSNT
2 Corinthians 10 in the KAPI
2 Corinthians 10 in the KBT1ETNIK
2 Corinthians 10 in the KBV
2 Corinthians 10 in the KJV
2 Corinthians 10 in the KNFD
2 Corinthians 10 in the LBA
2 Corinthians 10 in the LBLA
2 Corinthians 10 in the LNT
2 Corinthians 10 in the LSV
2 Corinthians 10 in the MAAL
2 Corinthians 10 in the MBV
2 Corinthians 10 in the MBV2
2 Corinthians 10 in the MHNT
2 Corinthians 10 in the MKNFD
2 Corinthians 10 in the MNG
2 Corinthians 10 in the MNT
2 Corinthians 10 in the MNT2
2 Corinthians 10 in the MRS1T
2 Corinthians 10 in the NAA
2 Corinthians 10 in the NASB
2 Corinthians 10 in the NBLA
2 Corinthians 10 in the NBS
2 Corinthians 10 in the NBVTP
2 Corinthians 10 in the NET2
2 Corinthians 10 in the NIV11
2 Corinthians 10 in the NNT
2 Corinthians 10 in the NNT2
2 Corinthians 10 in the NNT3
2 Corinthians 10 in the PDDPT
2 Corinthians 10 in the PFNT
2 Corinthians 10 in the RMNT
2 Corinthians 10 in the SBIAS
2 Corinthians 10 in the SBIBS
2 Corinthians 10 in the SBIBS2
2 Corinthians 10 in the SBICS
2 Corinthians 10 in the SBIDS
2 Corinthians 10 in the SBIGS
2 Corinthians 10 in the SBIHS
2 Corinthians 10 in the SBIIS
2 Corinthians 10 in the SBIIS2
2 Corinthians 10 in the SBIIS3
2 Corinthians 10 in the SBIKS
2 Corinthians 10 in the SBIKS2
2 Corinthians 10 in the SBIMS
2 Corinthians 10 in the SBIOS
2 Corinthians 10 in the SBIPS
2 Corinthians 10 in the SBISS
2 Corinthians 10 in the SBITS
2 Corinthians 10 in the SBITS2
2 Corinthians 10 in the SBITS3
2 Corinthians 10 in the SBITS4
2 Corinthians 10 in the SBIUS
2 Corinthians 10 in the SBIVS
2 Corinthians 10 in the SBT
2 Corinthians 10 in the SBT1E
2 Corinthians 10 in the SCHL
2 Corinthians 10 in the SNT
2 Corinthians 10 in the SUSU
2 Corinthians 10 in the SUSU2
2 Corinthians 10 in the SYNO
2 Corinthians 10 in the TBIAOTANT
2 Corinthians 10 in the TBT1E
2 Corinthians 10 in the TBT1E2
2 Corinthians 10 in the TFTIP
2 Corinthians 10 in the TFTU
2 Corinthians 10 in the TGNTATF3T
2 Corinthians 10 in the THAI
2 Corinthians 10 in the TNFD
2 Corinthians 10 in the TNT
2 Corinthians 10 in the TNTIK
2 Corinthians 10 in the TNTIL
2 Corinthians 10 in the TNTIN
2 Corinthians 10 in the TNTIP
2 Corinthians 10 in the TNTIZ
2 Corinthians 10 in the TOMA
2 Corinthians 10 in the TTENT
2 Corinthians 10 in the UBG
2 Corinthians 10 in the UGV
2 Corinthians 10 in the UGV2
2 Corinthians 10 in the UGV3
2 Corinthians 10 in the VBL
2 Corinthians 10 in the VDCC
2 Corinthians 10 in the YALU
2 Corinthians 10 in the YAPE
2 Corinthians 10 in the YBVTP
2 Corinthians 10 in the ZBP