Colossians 4 (BOYCB)

1 Ẹyin ọ̀gá, ẹ máa fi èyí tí ó tọ́ tí ó sì dọ́gba fún àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ yín; kí ẹ sì mọ̀ pé ẹ̀yin pẹ̀lú ní Olúwa kan ní ọ̀run. 2 Ẹ fi ara yín jì fún àdúrà gbígbà, kí ẹ ṣọ́ra kí ẹ sì máa dúpẹ́; 3 ẹ máa gbàdúrà fún wa pẹ̀lú, kí Ọlọ́run lè ṣí ìlẹ̀kùn fún wa fún ọ̀rọ̀ náà, láti máa sọ ohun ìjìnlẹ̀ Kristi, nítorí èyí tí mo ṣe wà nínú ìdè pẹ̀lú. 4 Ẹ gbàdúrà pé kí èmi le è máa kéde rẹ̀ kedere gẹ́gẹ́ bí ó ti tọ́ fún mi. 5 Ẹ jẹ́ ọlọ́gbọ́n ní ti bí ẹ ti ń ṣe pẹ̀lú àwọn tí ń bẹ lóde, kí ẹ sì máa ṣe ṣí àǹfààní tí ẹ bá nílò. 6 Ẹ jẹ́ kí ọ̀rọ̀ yín kí ó dàpọ̀ mọ́ oore-ọ̀fẹ́ nígbà gbogbo, èyí tí a fi iyọ̀ dùn, kí ẹ̀yin kí ó le mọ́ bí ẹ̀yin ó tí máa dá olúkúlùkù ènìyàn lóhùn. 7 Gbogbo bí nǹkan ti rí fún mi ní Tikiku yóò jẹ́ kí ẹ mọ̀. Òun jẹ́ arákùnrin olùfẹ́ àti olóòtítọ́ ìránṣẹ́ àti ẹlẹgbẹ́ nínú Olúwa, 8 ẹni tí èmí ń rán sí yín nítorí èyí kan náà, kí ẹ̀yin lè mọ́ bí a ti wà, kí òun kí ó lè tu ọkàn yín nínú. 9 Òun sì ń bọ̀ pẹ̀lú Onesimu, arákùnrin olóòtítọ́ àti olùfẹ́, ẹni tí í ṣe ọ̀kan nínú yín. Àwọn ní yóò sọ ohun gbogbo tí à ń ṣe níhìn-ín yìí fún un yín. 10 Aristarku, ẹlẹgbẹ́ mí nínú túbú kí i yín, àti Marku, ọmọ arábìnrin Barnaba. (Nípasẹ̀ ẹni tí ẹ̀yin ti gba àṣẹ; bí ó bá sì wá sí ọ̀dọ̀ yín, ẹ gbà á.) 11 Àti Jesu, ẹni tí à ń pè ní Justu, ẹni tí ń ṣe ti àwọn onílà. Àwọn wọ̀nyí nìkan ni olùbáṣiṣẹ́ mí fún ìjọba Ọlọ́run, àwọn ẹni tí ó tí jásí ìtùnú fún mi. 12 Epafira, ẹni tí ń ṣe ọ̀kan nínú yín àti ìránṣẹ́ Kristi Jesu kí i yín. Òun fi ìwàyáàjà gbàdúrà nígbà gbogbo fún un yín, kí ẹ̀yin kí ó lè dúró ní pípé nínú ohun gbogbo nínú ìfẹ́ Ọlọ́run. 13 Nítorí mo jẹ́rìí rẹ̀ pé ó ń ṣiṣẹ́ kárakára fún yín, àti fún àwọn tí ó wà ní Laodikea, àti àwọn tí ó wà ní Hirapoli. 14 Luku, arákùnrin wa ọ̀wọ́n, oníṣègùn, àti Dema ki í yín. 15 Ẹ kí àwọn ará tí ó wà ní Laodikea, àti Nimpa, àti ìjọ tí ó wà ní ilé rẹ̀. 16 Nígbà tí a bá sì ka ìwé yìí ní àárín yín tan, kí ẹ mú kí a kà á pẹ̀lú nínú ìjọ Laodikea; ẹ̀yin pẹ̀lú sì ka èyí tí ó ti Laodikea wá. 17 Kí ẹ sì wí fún Arkippu pe, “Kíyèsi iṣẹ́ ìránṣẹ́ tí ìwọ ti gbà nínú Olúwa kí o sì ṣe é ní kíkún.” 18 Ìkíni láti ọwọ́ èmi Paulu. Ẹ máa rántí ìdè mi. Kí oore-ọ̀fẹ́ kí ó wà pẹ̀lú yín.

In Other Versions

Colossians 4 in the ANGEFD

Colossians 4 in the ANTPNG2D

Colossians 4 in the AS21

Colossians 4 in the BAGH

Colossians 4 in the BBPNG

Colossians 4 in the BBT1E

Colossians 4 in the BDS

Colossians 4 in the BEV

Colossians 4 in the BHAD

Colossians 4 in the BIB

Colossians 4 in the BLPT

Colossians 4 in the BNT

Colossians 4 in the BNTABOOT

Colossians 4 in the BNTLV

Colossians 4 in the BOATCB

Colossians 4 in the BOATCB2

Colossians 4 in the BOBCV

Colossians 4 in the BOCNT

Colossians 4 in the BOECS

Colossians 4 in the BOGWICC

Colossians 4 in the BOHCB

Colossians 4 in the BOHCV

Colossians 4 in the BOHLNT

Colossians 4 in the BOHNTLTAL

Colossians 4 in the BOICB

Colossians 4 in the BOILNTAP

Colossians 4 in the BOITCV

Colossians 4 in the BOKCV

Colossians 4 in the BOKCV2

Colossians 4 in the BOKHWOG

Colossians 4 in the BOKSSV

Colossians 4 in the BOLCB

Colossians 4 in the BOLCB2

Colossians 4 in the BOMCV

Colossians 4 in the BONAV

Colossians 4 in the BONCB

Colossians 4 in the BONLT

Colossians 4 in the BONUT2

Colossians 4 in the BOPLNT

Colossians 4 in the BOSCB

Colossians 4 in the BOSNC

Colossians 4 in the BOTLNT

Colossians 4 in the BOVCB

Colossians 4 in the BPBB

Colossians 4 in the BPH

Colossians 4 in the BSB

Colossians 4 in the CCB

Colossians 4 in the CUV

Colossians 4 in the CUVS

Colossians 4 in the DBT

Colossians 4 in the DGDNT

Colossians 4 in the DHNT

Colossians 4 in the DNT

Colossians 4 in the ELBE

Colossians 4 in the EMTV

Colossians 4 in the ESV

Colossians 4 in the FBV

Colossians 4 in the FEB

Colossians 4 in the GGMNT

Colossians 4 in the GNT

Colossians 4 in the HARY

Colossians 4 in the HNT

Colossians 4 in the IRVA

Colossians 4 in the IRVB

Colossians 4 in the IRVG

Colossians 4 in the IRVH

Colossians 4 in the IRVK

Colossians 4 in the IRVM

Colossians 4 in the IRVM2

Colossians 4 in the IRVO

Colossians 4 in the IRVP

Colossians 4 in the IRVT

Colossians 4 in the IRVT2

Colossians 4 in the IRVU

Colossians 4 in the ISVN

Colossians 4 in the JSNT

Colossians 4 in the KAPI

Colossians 4 in the KBT1ETNIK

Colossians 4 in the KBV

Colossians 4 in the KJV

Colossians 4 in the KNFD

Colossians 4 in the LBA

Colossians 4 in the LBLA

Colossians 4 in the LNT

Colossians 4 in the LSV

Colossians 4 in the MAAL

Colossians 4 in the MBV

Colossians 4 in the MBV2

Colossians 4 in the MHNT

Colossians 4 in the MKNFD

Colossians 4 in the MNG

Colossians 4 in the MNT

Colossians 4 in the MNT2

Colossians 4 in the MRS1T

Colossians 4 in the NAA

Colossians 4 in the NASB

Colossians 4 in the NBLA

Colossians 4 in the NBS

Colossians 4 in the NBVTP

Colossians 4 in the NET2

Colossians 4 in the NIV11

Colossians 4 in the NNT

Colossians 4 in the NNT2

Colossians 4 in the NNT3

Colossians 4 in the PDDPT

Colossians 4 in the PFNT

Colossians 4 in the RMNT

Colossians 4 in the SBIAS

Colossians 4 in the SBIBS

Colossians 4 in the SBIBS2

Colossians 4 in the SBICS

Colossians 4 in the SBIDS

Colossians 4 in the SBIGS

Colossians 4 in the SBIHS

Colossians 4 in the SBIIS

Colossians 4 in the SBIIS2

Colossians 4 in the SBIIS3

Colossians 4 in the SBIKS

Colossians 4 in the SBIKS2

Colossians 4 in the SBIMS

Colossians 4 in the SBIOS

Colossians 4 in the SBIPS

Colossians 4 in the SBISS

Colossians 4 in the SBITS

Colossians 4 in the SBITS2

Colossians 4 in the SBITS3

Colossians 4 in the SBITS4

Colossians 4 in the SBIUS

Colossians 4 in the SBIVS

Colossians 4 in the SBT

Colossians 4 in the SBT1E

Colossians 4 in the SCHL

Colossians 4 in the SNT

Colossians 4 in the SUSU

Colossians 4 in the SUSU2

Colossians 4 in the SYNO

Colossians 4 in the TBIAOTANT

Colossians 4 in the TBT1E

Colossians 4 in the TBT1E2

Colossians 4 in the TFTIP

Colossians 4 in the TFTU

Colossians 4 in the TGNTATF3T

Colossians 4 in the THAI

Colossians 4 in the TNFD

Colossians 4 in the TNT

Colossians 4 in the TNTIK

Colossians 4 in the TNTIL

Colossians 4 in the TNTIN

Colossians 4 in the TNTIP

Colossians 4 in the TNTIZ

Colossians 4 in the TOMA

Colossians 4 in the TTENT

Colossians 4 in the UBG

Colossians 4 in the UGV

Colossians 4 in the UGV2

Colossians 4 in the UGV3

Colossians 4 in the VBL

Colossians 4 in the VDCC

Colossians 4 in the YALU

Colossians 4 in the YAPE

Colossians 4 in the YBVTP

Colossians 4 in the ZBP