Ecclesiastes 5 (BOYCB)

1 Ṣọ́ ìrìn rẹ nígbà tí o bá lọ sí ilé Ọlọ́run. Kí ìwọ kí ó sì múra láti gbọ́ ju àti ṣe ìrúbọ aṣiwèrè, tí kò mọ̀ wí pé òun ń ṣe búburú. 2 Má ṣe yára pẹ̀lú ẹnu un rẹ,má sọ ohunkóhun níwájú Ọlọ́run.Ọlọ́run ń bẹ ní ọ̀runìwọ sì wà ní ayé,nítorí náà jẹ́ kí ọ̀rọ̀ rẹ mọ ní ìwọ̀n. 3 Gẹ́gẹ́ bí àlá tí ń wá, nígbà tí ìlépa púpọ̀ wà,bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ òmùgọ̀ nígbà tí ọ̀rọ̀ bá pọ̀jù. 4 Nígbà tí o bá ṣe ìlérí sí Ọlọ́run, má ṣe pẹ́ ní mímúṣẹ, kò ní inú dídùn sí òmùgọ̀, mú ìlérí rẹ sẹ. 5 Ó sàn láti má jẹ́ ẹ̀jẹ́, ju wí pé kí a jẹ́ ẹ̀jẹ́ kí a má mu ṣẹ lọ. 6 Má ṣe jẹ́ kí ẹnu rẹ tì ọ́ sínú ẹ̀ṣẹ̀. Má sì ṣe sọ fún òjíṣẹ́ ilé ìsìn pé, “Àṣìṣe ni ẹ̀jẹ́ mi.” Kí ló dé tí Ọlọ́run fi le è bínú sí ọ, kí ó sì ba iṣẹ́ ọwọ́ rẹ jẹ́? 7 Asán ni ọ̀pọ̀ àlá àti ọ̀rọ̀ púpọ̀. Nítorí náà dúró nínú ìbẹ̀rù Ọlọ́run. 8 Bí o bá rí tálákà tí wọ́n ń ni lára ní ojú púpọ̀, tí a sì ń fi òtítọ́ àti ẹ̀tọ́ rẹ̀ dù ú, má ṣe jẹ́ kí ó yà ọ́ lẹ́nu láti rí irú nǹkan bẹ́ẹ̀, nítorí pé ẹni tí ó wà ní ipò gíga máa ń mọ́ òṣìṣẹ́ tí ó wà lábẹ́ rẹ̀ lójú ni, síbẹ̀ àwọn kan sì wà tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn méjèèjì. 9 Gbogbo wọn ni ó ń pín èrè tí wọ́n bá rí lórí ilẹ̀, àní ọba pàápàá ń jẹ èrè lórí oko. 10 Ẹni tí ó bá ní ìfẹ́ owó kì í ní owó ànító,ẹni tí ó bá ní ìfẹ́ sí ọrọ̀ kì í ní ìtẹ́lọ́rùnpẹ̀lú èrè tí ó ń wọlé fún un. 11 Bí ẹrù bá ti ń pọ̀ sí i,náà ni àwọn tí ó ń jẹ ẹ́ yóò máa pọ̀ sí iÈrè e kí ni wọ́n sì jẹ́ sí ẹni tí ó ni nǹkan bí kò ṣe pé,kí ó máa mú inú ara rẹ dùn nípa rí rí wọn? 12 Oorun alágbàṣe a máa dùn,yálà ó jẹun kékeré ni tàbí ó jẹun púpọ̀,ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀kì í jẹ́ kí ó sùn rárá. 13 Mo ti rí ohun tí ó burú gidigidi lábẹ́ oòrùnọrọ̀ tí a kó pamọ́ fún ìparun ẹni tó ni nǹkan. 14 Tàbí ọrọ̀ tí ó sọnù nípa àìrí ojúrere,nítorí wí pé bí ó bá ní ọmọkùnrinkò sí ohun tí yóò fi sílẹ̀ fún un. 15 Ìhòhò ni ènìyàn wá láti inú ìyá rẹ̀,bí ó sì ṣe wá, bẹ́ẹ̀ ni yóò kúròkò sí ohunkóhun nínú iṣẹ́ rẹ̀tí ó le mú ní ọwọ́ rẹ̀. 16 Ohun búburú gbá à ni eléyìí pàápàá.Bí ènìyàn ṣe wá, ni yóò lọkí wá ni èrè tí ó jẹnígbà tí ó ṣe wàhálà fún afẹ́fẹ́? 17 Ó ń jẹ nínú òkùnkùn ní gbogbo ọjọ́ ọ rẹ̀,pẹ̀lú iyè ríra tí ó ga, ìnira àti ìbínú. 18 Nígbà náà ni mo wá rí i dájú pé, ó dára, ó sì tọ̀nà fún ènìyàn láti jẹ, kí ó mu, kí ó sì ní ìtẹ́lọ́rùn nínú iṣẹ́ wàhálà rẹ̀ lábẹ́ oòrùn, ní àkókò ọjọ́ ayé díẹ̀ tí Ọlọ́run ti fi fún un, nítorí ìpín rẹ̀ ni èyí. 19 Síwájú sí, nígbà tí Ọlọ́run fún ẹnikẹ́ni ní ọrọ̀ àti ohun ìní, tí ó sì fún un lágbára láti gbádùn wọn, láti gba ìpín rẹ̀ kí inú rẹ̀ sì dùn sí iṣẹ́ rẹ—ẹ̀bùn Ọlọ́run ni èyí. 20 Ó máa ń ronú lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan nípa ọjọ́ ayé rẹ lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan nítorí pé Ọlọ́run ń pa á mọ́ pẹ̀lú inú dídùn ní ọkàn rẹ̀.

In Other Versions

Ecclesiastes 5 in the ANGEFD

Ecclesiastes 5 in the ANTPNG2D

Ecclesiastes 5 in the AS21

Ecclesiastes 5 in the BAGH

Ecclesiastes 5 in the BBPNG

Ecclesiastes 5 in the BBT1E

Ecclesiastes 5 in the BDS

Ecclesiastes 5 in the BEV

Ecclesiastes 5 in the BHAD

Ecclesiastes 5 in the BIB

Ecclesiastes 5 in the BLPT

Ecclesiastes 5 in the BNT

Ecclesiastes 5 in the BNTABOOT

Ecclesiastes 5 in the BNTLV

Ecclesiastes 5 in the BOATCB

Ecclesiastes 5 in the BOATCB2

Ecclesiastes 5 in the BOBCV

Ecclesiastes 5 in the BOCNT

Ecclesiastes 5 in the BOECS

Ecclesiastes 5 in the BOGWICC

Ecclesiastes 5 in the BOHCB

Ecclesiastes 5 in the BOHCV

Ecclesiastes 5 in the BOHLNT

Ecclesiastes 5 in the BOHNTLTAL

Ecclesiastes 5 in the BOICB

Ecclesiastes 5 in the BOILNTAP

Ecclesiastes 5 in the BOITCV

Ecclesiastes 5 in the BOKCV

Ecclesiastes 5 in the BOKCV2

Ecclesiastes 5 in the BOKHWOG

Ecclesiastes 5 in the BOKSSV

Ecclesiastes 5 in the BOLCB

Ecclesiastes 5 in the BOLCB2

Ecclesiastes 5 in the BOMCV

Ecclesiastes 5 in the BONAV

Ecclesiastes 5 in the BONCB

Ecclesiastes 5 in the BONLT

Ecclesiastes 5 in the BONUT2

Ecclesiastes 5 in the BOPLNT

Ecclesiastes 5 in the BOSCB

Ecclesiastes 5 in the BOSNC

Ecclesiastes 5 in the BOTLNT

Ecclesiastes 5 in the BOVCB

Ecclesiastes 5 in the BPBB

Ecclesiastes 5 in the BPH

Ecclesiastes 5 in the BSB

Ecclesiastes 5 in the CCB

Ecclesiastes 5 in the CUV

Ecclesiastes 5 in the CUVS

Ecclesiastes 5 in the DBT

Ecclesiastes 5 in the DGDNT

Ecclesiastes 5 in the DHNT

Ecclesiastes 5 in the DNT

Ecclesiastes 5 in the ELBE

Ecclesiastes 5 in the EMTV

Ecclesiastes 5 in the ESV

Ecclesiastes 5 in the FBV

Ecclesiastes 5 in the FEB

Ecclesiastes 5 in the GGMNT

Ecclesiastes 5 in the GNT

Ecclesiastes 5 in the HARY

Ecclesiastes 5 in the HNT

Ecclesiastes 5 in the IRVA

Ecclesiastes 5 in the IRVB

Ecclesiastes 5 in the IRVG

Ecclesiastes 5 in the IRVH

Ecclesiastes 5 in the IRVK

Ecclesiastes 5 in the IRVM

Ecclesiastes 5 in the IRVM2

Ecclesiastes 5 in the IRVO

Ecclesiastes 5 in the IRVP

Ecclesiastes 5 in the IRVT

Ecclesiastes 5 in the IRVT2

Ecclesiastes 5 in the IRVU

Ecclesiastes 5 in the ISVN

Ecclesiastes 5 in the JSNT

Ecclesiastes 5 in the KAPI

Ecclesiastes 5 in the KBT1ETNIK

Ecclesiastes 5 in the KBV

Ecclesiastes 5 in the KJV

Ecclesiastes 5 in the KNFD

Ecclesiastes 5 in the LBA

Ecclesiastes 5 in the LBLA

Ecclesiastes 5 in the LNT

Ecclesiastes 5 in the LSV

Ecclesiastes 5 in the MAAL

Ecclesiastes 5 in the MBV

Ecclesiastes 5 in the MBV2

Ecclesiastes 5 in the MHNT

Ecclesiastes 5 in the MKNFD

Ecclesiastes 5 in the MNG

Ecclesiastes 5 in the MNT

Ecclesiastes 5 in the MNT2

Ecclesiastes 5 in the MRS1T

Ecclesiastes 5 in the NAA

Ecclesiastes 5 in the NASB

Ecclesiastes 5 in the NBLA

Ecclesiastes 5 in the NBS

Ecclesiastes 5 in the NBVTP

Ecclesiastes 5 in the NET2

Ecclesiastes 5 in the NIV11

Ecclesiastes 5 in the NNT

Ecclesiastes 5 in the NNT2

Ecclesiastes 5 in the NNT3

Ecclesiastes 5 in the PDDPT

Ecclesiastes 5 in the PFNT

Ecclesiastes 5 in the RMNT

Ecclesiastes 5 in the SBIAS

Ecclesiastes 5 in the SBIBS

Ecclesiastes 5 in the SBIBS2

Ecclesiastes 5 in the SBICS

Ecclesiastes 5 in the SBIDS

Ecclesiastes 5 in the SBIGS

Ecclesiastes 5 in the SBIHS

Ecclesiastes 5 in the SBIIS

Ecclesiastes 5 in the SBIIS2

Ecclesiastes 5 in the SBIIS3

Ecclesiastes 5 in the SBIKS

Ecclesiastes 5 in the SBIKS2

Ecclesiastes 5 in the SBIMS

Ecclesiastes 5 in the SBIOS

Ecclesiastes 5 in the SBIPS

Ecclesiastes 5 in the SBISS

Ecclesiastes 5 in the SBITS

Ecclesiastes 5 in the SBITS2

Ecclesiastes 5 in the SBITS3

Ecclesiastes 5 in the SBITS4

Ecclesiastes 5 in the SBIUS

Ecclesiastes 5 in the SBIVS

Ecclesiastes 5 in the SBT

Ecclesiastes 5 in the SBT1E

Ecclesiastes 5 in the SCHL

Ecclesiastes 5 in the SNT

Ecclesiastes 5 in the SUSU

Ecclesiastes 5 in the SUSU2

Ecclesiastes 5 in the SYNO

Ecclesiastes 5 in the TBIAOTANT

Ecclesiastes 5 in the TBT1E

Ecclesiastes 5 in the TBT1E2

Ecclesiastes 5 in the TFTIP

Ecclesiastes 5 in the TFTU

Ecclesiastes 5 in the TGNTATF3T

Ecclesiastes 5 in the THAI

Ecclesiastes 5 in the TNFD

Ecclesiastes 5 in the TNT

Ecclesiastes 5 in the TNTIK

Ecclesiastes 5 in the TNTIL

Ecclesiastes 5 in the TNTIN

Ecclesiastes 5 in the TNTIP

Ecclesiastes 5 in the TNTIZ

Ecclesiastes 5 in the TOMA

Ecclesiastes 5 in the TTENT

Ecclesiastes 5 in the UBG

Ecclesiastes 5 in the UGV

Ecclesiastes 5 in the UGV2

Ecclesiastes 5 in the UGV3

Ecclesiastes 5 in the VBL

Ecclesiastes 5 in the VDCC

Ecclesiastes 5 in the YALU

Ecclesiastes 5 in the YAPE

Ecclesiastes 5 in the YBVTP

Ecclesiastes 5 in the ZBP