Ezekiel 4 (BOYCB)
1 “Nísinsin yìí, ìwọ ọmọ ènìyàn, mú amọ̀ ṣíṣù kan, gbé e sí iwájú rẹ, kí o sì ya àwòrán ìlú Jerusalẹmu sí orí rẹ̀. 2 Kí o sì dó tì í, kí o sì mọ ilé ìṣọ́ tì í, kí o sì mọ odi tì í, kí o sì gbé ogun sí i, kí o sì to òòlù yí i ká. 3 Kí o sì fi àwo irin kan ṣe ògiri láàrín rẹ̀ àti ìlú yìí, kí o sì kọjú sí i, a ó sì dó tì í, ìwọ yóò sì dó tì í. Èyí yóò jẹ́ àmì fún ilé Israẹli. 4 “Lẹ́yìn èyí, lọ fi ẹ̀gbẹ́ òsì dùbúlẹ̀, kí o sì gbé ẹ̀ṣẹ̀ ilé Israẹli lé orí ara rẹ. Iye ọjọ́ tí ìwọ bá fi sùn náà ni ìwọ yóò fi ru ẹ̀ṣẹ̀ wọn. 5 Nítorí mo fi iye ọdún tí wọ́n fi ṣẹ̀ fún ọ gẹ́gẹ́ bí iye ọjọ́ tí ìwọ yóò lò. Nítorí náà, ìwọ yóò ru ẹ̀ṣẹ̀ ilé Israẹli fún irinwó ọjọ́ ó dín mẹ́wàá (390). 6 “Tí o bá parí èyí, tún fi ẹ̀gbẹ́ ọ̀tún dùbúlẹ̀ kí o sì ru ẹ̀ṣẹ̀ ilé Juda fún ogójì ọjọ́, nítorí pé ọjọ́ kan ló dúró fún ọdún kan. 7 Ìwọ dojúkọ ìgbógunti Jerusalẹmu, na ọwọ́ rẹ sí i, kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ìlú náà. 8 Èmi yóò dè ọ́ ní okùn dé bi pé ìwọ kò ní í le yírapadà láti ìhà ọ̀tún sí ìhà òsì títí tí ọjọ́ ìgbóguntì rẹ yóò fi pé. 9 “Mú alikama, ọkà bàbà àti barle, erèé àti lẹntili, jéró àti ẹwẹ; fi àwọn nǹkan wọ̀nyí ṣe àkàrà tí ìwọ yóò máa jẹ nígbà tí ìwọ bá dùbúlẹ̀ fún irinwó ọjọ́ ó dín mẹ́wàá (390). 10 Wọn òsùwọ̀n ogún ṣékélì oúnjẹ tí ìwọ yóò máa jẹ lójoojúmọ́ kí o sì máa jẹ ẹ́ ní àkókò tí a ti yà sọ́tọ̀. 11 Bákan náà, wọn ìdámẹ́fà omi, kí ìwọ ó sì máa mú ní àkókò tí a yà sọ́tọ̀. 12 Ìwọ yóò sì jẹ ẹ́ bí àkàrà barle; dín in ní ojú àwọn ènìyàn, ìgbẹ́ ènìyàn ni kí o fi dáná rẹ.” 13 OLÚWA sọ pé, “Báyìí ni àwọn ọmọ Israẹli yóò jẹ oúnjẹ àìmọ́ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè tí èmi yóò lé wọn lọ.” 14 Nígbà náà ni mo wí pé, “Háà! Kò rí bẹ́ẹ̀ OLÚWA Olódùmarè! Láti ìgbà èwe mi di ìsinsin yìí èmi kò tí ì sọ ara mi di aláìmọ́ rí. Èmi kò tí ì jẹ ohun tó kú fúnra rẹ̀ tàbí èyí tí ẹranko búburú fàya pẹ́rẹpẹ̀rẹ. Bẹ́ẹ̀ ni ẹran àìmọ́ kan kò tí ì wọ ẹnu mi rí.” 15 Nígbà náà ló wí fún mi pé, “Wò ó, Èmi ó fún ọ ní ìgbẹ́ màlúù dípò ìgbẹ́ ènìyàn. Èmi yóò mú ki ó dín àkàrà rẹ lórí ìgbẹ́ màlúù dípò ìgbẹ́ ènìyàn.” 16 Ó sì tún sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, èmi yóò dáwọ́ ìpèsè oúnjẹ dúró ní Jerusalẹmu. Ní pípín ni àwọn ènìyàn yóò máa pín oúnjẹ jẹ pẹ̀lú ìfọkànsọ́nà bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni wọn yóò máa mu omi pẹ̀lú ìdààmú, 17 nítorí pé oúnjẹ àti omi yóò wọ́n. Wọn yóò máa wo ara wọn pẹ̀lú ìyanu, èmi yóò sì jẹ́ kí wọ́n ṣọ̀fọ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.
In Other Versions
Ezekiel 4 in the ANGEFD
Ezekiel 4 in the ANTPNG2D
Ezekiel 4 in the AS21
Ezekiel 4 in the BAGH
Ezekiel 4 in the BBPNG
Ezekiel 4 in the BBT1E
Ezekiel 4 in the BDS
Ezekiel 4 in the BEV
Ezekiel 4 in the BHAD
Ezekiel 4 in the BIB
Ezekiel 4 in the BLPT
Ezekiel 4 in the BNT
Ezekiel 4 in the BNTABOOT
Ezekiel 4 in the BNTLV
Ezekiel 4 in the BOATCB
Ezekiel 4 in the BOATCB2
Ezekiel 4 in the BOBCV
Ezekiel 4 in the BOCNT
Ezekiel 4 in the BOECS
Ezekiel 4 in the BOGWICC
Ezekiel 4 in the BOHCB
Ezekiel 4 in the BOHCV
Ezekiel 4 in the BOHLNT
Ezekiel 4 in the BOHNTLTAL
Ezekiel 4 in the BOICB
Ezekiel 4 in the BOILNTAP
Ezekiel 4 in the BOITCV
Ezekiel 4 in the BOKCV
Ezekiel 4 in the BOKCV2
Ezekiel 4 in the BOKHWOG
Ezekiel 4 in the BOKSSV
Ezekiel 4 in the BOLCB
Ezekiel 4 in the BOLCB2
Ezekiel 4 in the BOMCV
Ezekiel 4 in the BONAV
Ezekiel 4 in the BONCB
Ezekiel 4 in the BONLT
Ezekiel 4 in the BONUT2
Ezekiel 4 in the BOPLNT
Ezekiel 4 in the BOSCB
Ezekiel 4 in the BOSNC
Ezekiel 4 in the BOTLNT
Ezekiel 4 in the BOVCB
Ezekiel 4 in the BPBB
Ezekiel 4 in the BPH
Ezekiel 4 in the BSB
Ezekiel 4 in the CCB
Ezekiel 4 in the CUV
Ezekiel 4 in the CUVS
Ezekiel 4 in the DBT
Ezekiel 4 in the DGDNT
Ezekiel 4 in the DHNT
Ezekiel 4 in the DNT
Ezekiel 4 in the ELBE
Ezekiel 4 in the EMTV
Ezekiel 4 in the ESV
Ezekiel 4 in the FBV
Ezekiel 4 in the FEB
Ezekiel 4 in the GGMNT
Ezekiel 4 in the GNT
Ezekiel 4 in the HARY
Ezekiel 4 in the HNT
Ezekiel 4 in the IRVA
Ezekiel 4 in the IRVB
Ezekiel 4 in the IRVG
Ezekiel 4 in the IRVH
Ezekiel 4 in the IRVK
Ezekiel 4 in the IRVM
Ezekiel 4 in the IRVM2
Ezekiel 4 in the IRVO
Ezekiel 4 in the IRVP
Ezekiel 4 in the IRVT
Ezekiel 4 in the IRVT2
Ezekiel 4 in the IRVU
Ezekiel 4 in the ISVN
Ezekiel 4 in the JSNT
Ezekiel 4 in the KAPI
Ezekiel 4 in the KBT1ETNIK
Ezekiel 4 in the KBV
Ezekiel 4 in the KJV
Ezekiel 4 in the KNFD
Ezekiel 4 in the LBA
Ezekiel 4 in the LBLA
Ezekiel 4 in the LNT
Ezekiel 4 in the LSV
Ezekiel 4 in the MAAL
Ezekiel 4 in the MBV
Ezekiel 4 in the MBV2
Ezekiel 4 in the MHNT
Ezekiel 4 in the MKNFD
Ezekiel 4 in the MNG
Ezekiel 4 in the MNT
Ezekiel 4 in the MNT2
Ezekiel 4 in the MRS1T
Ezekiel 4 in the NAA
Ezekiel 4 in the NASB
Ezekiel 4 in the NBLA
Ezekiel 4 in the NBS
Ezekiel 4 in the NBVTP
Ezekiel 4 in the NET2
Ezekiel 4 in the NIV11
Ezekiel 4 in the NNT
Ezekiel 4 in the NNT2
Ezekiel 4 in the NNT3
Ezekiel 4 in the PDDPT
Ezekiel 4 in the PFNT
Ezekiel 4 in the RMNT
Ezekiel 4 in the SBIAS
Ezekiel 4 in the SBIBS
Ezekiel 4 in the SBIBS2
Ezekiel 4 in the SBICS
Ezekiel 4 in the SBIDS
Ezekiel 4 in the SBIGS
Ezekiel 4 in the SBIHS
Ezekiel 4 in the SBIIS
Ezekiel 4 in the SBIIS2
Ezekiel 4 in the SBIIS3
Ezekiel 4 in the SBIKS
Ezekiel 4 in the SBIKS2
Ezekiel 4 in the SBIMS
Ezekiel 4 in the SBIOS
Ezekiel 4 in the SBIPS
Ezekiel 4 in the SBISS
Ezekiel 4 in the SBITS
Ezekiel 4 in the SBITS2
Ezekiel 4 in the SBITS3
Ezekiel 4 in the SBITS4
Ezekiel 4 in the SBIUS
Ezekiel 4 in the SBIVS
Ezekiel 4 in the SBT
Ezekiel 4 in the SBT1E
Ezekiel 4 in the SCHL
Ezekiel 4 in the SNT
Ezekiel 4 in the SUSU
Ezekiel 4 in the SUSU2
Ezekiel 4 in the SYNO
Ezekiel 4 in the TBIAOTANT
Ezekiel 4 in the TBT1E
Ezekiel 4 in the TBT1E2
Ezekiel 4 in the TFTIP
Ezekiel 4 in the TFTU
Ezekiel 4 in the TGNTATF3T
Ezekiel 4 in the THAI
Ezekiel 4 in the TNFD
Ezekiel 4 in the TNT
Ezekiel 4 in the TNTIK
Ezekiel 4 in the TNTIL
Ezekiel 4 in the TNTIN
Ezekiel 4 in the TNTIP
Ezekiel 4 in the TNTIZ
Ezekiel 4 in the TOMA
Ezekiel 4 in the TTENT
Ezekiel 4 in the UBG
Ezekiel 4 in the UGV
Ezekiel 4 in the UGV2
Ezekiel 4 in the UGV3
Ezekiel 4 in the VBL
Ezekiel 4 in the VDCC
Ezekiel 4 in the YALU
Ezekiel 4 in the YAPE
Ezekiel 4 in the YBVTP
Ezekiel 4 in the ZBP