Ezra 1 (BOYCB)

1 Ní ọdún kìn-ín-ní Kirusi, ọba Persia, kí a lè mú ọ̀rọ̀ OLÚWA tí Jeremiah sọ ṣẹ, OLÚWA ru ọkàn Kirusi ọba Persia sókè láti ṣe ìkéde jákèjádò gbogbo agbègbè ìjọba rẹ̀, kí ó sì ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ pé, 2 “Èyí ni ohun tí Kirusi ọba Persia wí pé:“ ‘OLÚWA, Ọlọ́run ọ̀run, ti fún mi ní gbogbo ìjọba ayé. Ó sì ti yàn mí láti kọ́ tẹmpili OLÚWA fún un ní Jerusalẹmu tí ó wà ní Juda. 3 Ẹnikẹ́ni nínú àwọn ènìyàn rẹ̀ láàrín yín—kí Ọlọ́run rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀, kí ó sì gòkè lọ sí Jerusalẹmu tí ó wà ní Juda, láti kọ́ tẹmpili OLÚWA Ọlọ́run Israẹli, Ọlọ́run tí ó wà ní Jerusalẹmu. 4 Kí àwọn ènìyàn ní ibikíbi tí ẹni náà bá ń gbé kí ó fi fàdákà àti wúrà pẹ̀lú ohun tí ó dára àti ẹran ọ̀sìn, pẹ̀lú ọrẹ àtinúwá ràn án lọ́wọ́ fún tẹmpili Ọlọ́run ní Jerusalẹmu.’ ” 5 Nígbà náà àwọn olórí ìdílé Juda àti Benjamini àti àwọn àlùfáà àti àwọn ará Lefi—olúkúlùkù ẹni tí Ọlọ́run ti fọwọ́ tọ́ ọkàn rẹ̀—múra láti gòkè lọ láti kọ ilé OLÚWA ní Jerusalẹmu. 6 Gbogbo àwọn aládùúgbò wọn ràn wọ́n lọ́wọ́ pẹ̀lú ohun èlò ti fàdákà àti wúrà, pẹ̀lú onírúurú ohun ìní àti ẹran ọ̀sìn àti pẹ̀lú àwọn ẹ̀bùn iyebíye, ní àfikún si gbogbo àwọn ọrẹ àtinúwá. 7 Ní àfikún, ọba Kirusi mú àwọn ohun èlò tí ó jẹ́ ti ilé OLÚWA jáde wá, tí Nebukadnessari ti kó lọ láti Jerusalẹmu tí ó sì ti kó sí ilé òrìṣà rẹ̀. 8 Kirusi ọba Persia pàṣẹ fún Mitredati olùṣọ́ ilé ìṣúra láti kó wọn jáde, ó sì kà wọ́n fún Ṣeṣbassari ìjòyè Juda. 9 Èyí ni iye wọn. 10 Ọgbọ̀n àdému wúrà 30 11 Gbogbo ohun èlò wúrà àti ti fàdákà ní àpapọ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùn-ún ó lé irinwó (5,400). Ṣeṣbassari kó gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí wá pẹ̀lú àwọn ìgbèkùn tí ó gòkè wá láti Babeli sí Jerusalẹmu.

In Other Versions

Ezra 1 in the ANGEFD

Ezra 1 in the ANTPNG2D

Ezra 1 in the AS21

Ezra 1 in the BAGH

Ezra 1 in the BBPNG

Ezra 1 in the BBT1E

Ezra 1 in the BDS

Ezra 1 in the BEV

Ezra 1 in the BHAD

Ezra 1 in the BIB

Ezra 1 in the BLPT

Ezra 1 in the BNT

Ezra 1 in the BNTABOOT

Ezra 1 in the BNTLV

Ezra 1 in the BOATCB

Ezra 1 in the BOATCB2

Ezra 1 in the BOBCV

Ezra 1 in the BOCNT

Ezra 1 in the BOECS

Ezra 1 in the BOGWICC

Ezra 1 in the BOHCB

Ezra 1 in the BOHCV

Ezra 1 in the BOHLNT

Ezra 1 in the BOHNTLTAL

Ezra 1 in the BOICB

Ezra 1 in the BOILNTAP

Ezra 1 in the BOITCV

Ezra 1 in the BOKCV

Ezra 1 in the BOKCV2

Ezra 1 in the BOKHWOG

Ezra 1 in the BOKSSV

Ezra 1 in the BOLCB

Ezra 1 in the BOLCB2

Ezra 1 in the BOMCV

Ezra 1 in the BONAV

Ezra 1 in the BONCB

Ezra 1 in the BONLT

Ezra 1 in the BONUT2

Ezra 1 in the BOPLNT

Ezra 1 in the BOSCB

Ezra 1 in the BOSNC

Ezra 1 in the BOTLNT

Ezra 1 in the BOVCB

Ezra 1 in the BPBB

Ezra 1 in the BPH

Ezra 1 in the BSB

Ezra 1 in the CCB

Ezra 1 in the CUV

Ezra 1 in the CUVS

Ezra 1 in the DBT

Ezra 1 in the DGDNT

Ezra 1 in the DHNT

Ezra 1 in the DNT

Ezra 1 in the ELBE

Ezra 1 in the EMTV

Ezra 1 in the ESV

Ezra 1 in the FBV

Ezra 1 in the FEB

Ezra 1 in the GGMNT

Ezra 1 in the GNT

Ezra 1 in the HARY

Ezra 1 in the HNT

Ezra 1 in the IRVA

Ezra 1 in the IRVB

Ezra 1 in the IRVG

Ezra 1 in the IRVH

Ezra 1 in the IRVK

Ezra 1 in the IRVM

Ezra 1 in the IRVM2

Ezra 1 in the IRVO

Ezra 1 in the IRVP

Ezra 1 in the IRVT

Ezra 1 in the IRVT2

Ezra 1 in the IRVU

Ezra 1 in the ISVN

Ezra 1 in the JSNT

Ezra 1 in the KAPI

Ezra 1 in the KBT1ETNIK

Ezra 1 in the KBV

Ezra 1 in the KJV

Ezra 1 in the KNFD

Ezra 1 in the LBA

Ezra 1 in the LBLA

Ezra 1 in the LNT

Ezra 1 in the LSV

Ezra 1 in the MAAL

Ezra 1 in the MBV

Ezra 1 in the MBV2

Ezra 1 in the MHNT

Ezra 1 in the MKNFD

Ezra 1 in the MNG

Ezra 1 in the MNT

Ezra 1 in the MNT2

Ezra 1 in the MRS1T

Ezra 1 in the NAA

Ezra 1 in the NASB

Ezra 1 in the NBLA

Ezra 1 in the NBS

Ezra 1 in the NBVTP

Ezra 1 in the NET2

Ezra 1 in the NIV11

Ezra 1 in the NNT

Ezra 1 in the NNT2

Ezra 1 in the NNT3

Ezra 1 in the PDDPT

Ezra 1 in the PFNT

Ezra 1 in the RMNT

Ezra 1 in the SBIAS

Ezra 1 in the SBIBS

Ezra 1 in the SBIBS2

Ezra 1 in the SBICS

Ezra 1 in the SBIDS

Ezra 1 in the SBIGS

Ezra 1 in the SBIHS

Ezra 1 in the SBIIS

Ezra 1 in the SBIIS2

Ezra 1 in the SBIIS3

Ezra 1 in the SBIKS

Ezra 1 in the SBIKS2

Ezra 1 in the SBIMS

Ezra 1 in the SBIOS

Ezra 1 in the SBIPS

Ezra 1 in the SBISS

Ezra 1 in the SBITS

Ezra 1 in the SBITS2

Ezra 1 in the SBITS3

Ezra 1 in the SBITS4

Ezra 1 in the SBIUS

Ezra 1 in the SBIVS

Ezra 1 in the SBT

Ezra 1 in the SBT1E

Ezra 1 in the SCHL

Ezra 1 in the SNT

Ezra 1 in the SUSU

Ezra 1 in the SUSU2

Ezra 1 in the SYNO

Ezra 1 in the TBIAOTANT

Ezra 1 in the TBT1E

Ezra 1 in the TBT1E2

Ezra 1 in the TFTIP

Ezra 1 in the TFTU

Ezra 1 in the TGNTATF3T

Ezra 1 in the THAI

Ezra 1 in the TNFD

Ezra 1 in the TNT

Ezra 1 in the TNTIK

Ezra 1 in the TNTIL

Ezra 1 in the TNTIN

Ezra 1 in the TNTIP

Ezra 1 in the TNTIZ

Ezra 1 in the TOMA

Ezra 1 in the TTENT

Ezra 1 in the UBG

Ezra 1 in the UGV

Ezra 1 in the UGV2

Ezra 1 in the UGV3

Ezra 1 in the VBL

Ezra 1 in the VDCC

Ezra 1 in the YALU

Ezra 1 in the YAPE

Ezra 1 in the YBVTP

Ezra 1 in the ZBP